Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Genesis 50 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Josẹfu sì ṣubú lé baba rẹ̀, ó sọkún, ó sì fẹnukò ó ní ẹnu.
2 Nígbà náà ni Josẹfu pàṣẹ fún àwọn oníṣègùn tí ó wà ní ìkáwọ́ rẹ̀ pé kí wọn kí ó ṣe òkú Israẹli baba rẹ̀ lọ́jọ̀, àwọn oníṣègùn náà sì ṣe bẹ́ẹ̀.
3 Fún ogójì ọjọ́ ni wọ́n fi ṣe èyí, nítorí èyí ni àsìkò tí a máa ń fi ṣe ẹ̀ǹbáàmù òkú. Àwọn ará Ejibiti sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀ fún àádọ́rin ọjọ́.
4 Nígbà tí ọjọ́ ìṣọ̀fọ̀ náà kọjá. Josẹfu wí fún àwọn ará ilé Farao pé, “Bí mo bá bá ojúrere yín pàdé, ẹ bá mi sọ fún Farao.
5 ‘Baba mi mú mi búra ó sì wí fún mi pé, “Mo ti fẹ́rẹ kú: sinmi sínú ibojì tí mo gbẹ́ fún ara mi ní ilẹ̀ Kenaani.” Nísinsin yìí, jẹ́ kí n lọ kí n sì sìnkú baba mi, lẹ́yìn náà èmi yóò padà wa.’ ”
6 Farao wí pé, “Gòkè lọ, kí o sì sin baba rẹ, bí ó tí mú ọ búra.”
7 Báyìí ni Josẹfu gòkè lọ láti sìnkú baba rẹ̀. Gbogbo àwọn ìjòyè Farao ni ó sìn ín lọ—àwọn àgbàgbà ilé rẹ̀, àti gbogbo àwọn àgbàgbà ilẹ̀ Ejibiti.
8 Yàtọ̀ fún gbogbo àwọn ará ilé Josẹfu àti ti àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn tí ó jẹ́ ilé baba rẹ̀, àwọn ọmọ wọn nìkan àti agbo ẹran pẹ̀lú agbo màlúù ni ó sẹ́ kù ní Goṣeni.
9 Kẹ̀kẹ́-ẹṣin àti àwọn ẹlẹ́ṣin pẹ̀lú gòkè lọ. Àìmoye ènìyàn ni ó lọ.
10 Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ ìpakà Atadi, ní ẹ̀bá Jordani, wọn pohùnréré ẹkún, níbẹ̀ ni Josẹfu sì tún dúró ṣọ̀fọ̀ baba rẹ̀ fún ọjọ́ méje.
11 Nígbà tí àwọn ará Kenaani tí ń gbé níbẹ̀ rí i bí wọ́n ti ń ṣọ̀fọ̀ náà ni ilẹ̀ ìpakà Atadi, wọ́n wí pé, “Ọ̀fọ̀ ńlá ni àwọn ará Ejibiti ń ṣe yìí.” Ìdí èyí ni a fi ń pe ibẹ̀ ní Abeli-Misraimu. Kò sì jìnnà sí Jordani.
12 Báyìí ni àwọn ọmọ Jakọbu ṣe ohun tí baba wọn pàṣẹ fún wọn.
13 Wọ́n gbé e lọ sí ilẹ̀ Kenaani, wọ́n sì sin ín sínú ihò àpáta tí ó wà ní oko Makpela, ní tòsí i Mamre tí Abrahamu rà gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ ìsìnkú lọ́wọ́ Efroni ará Hiti, pẹ̀lú ilẹ̀ náà.
14 Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti sìnkú baba rẹ̀ tan, Josẹfu padà sí Ejibiti pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀ àti àwọn mìíràn tí ó tẹ̀lé e lọ láti sin baba rẹ̀.
15 Nígbà tí àwọn arákùnrin Josẹfu rí i pé baba wọn kú, wọ́n wí fún ara wọn pé, “Ǹjẹ́ bí ó bá ṣe pé Josẹfu ṣì fi wá sínú ń kọ́, tí ó sì fẹ́ gbẹ̀san gbogbo aburú tí a ti ṣe sí i?”
16 Nítorí náà wọ́n ránṣẹ́ sí Josẹfu wí pé, “Baba rẹ fi àṣẹ yìí sílẹ̀ kí ó tó lọ wí pé,
17 ‘Èyí ni kí ẹ̀yin kí ó sọ fún Josẹfu, mo bẹ̀ ọ́ kí o dáríjì àwọn arákùnrin rẹ, gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ àti aburú tí wọ́n ṣe sí ọ, èyí tí ó mú ibi bá ọ’. Nísinsin yìí, jọ̀wọ́ dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run baba rẹ jì wọ́n.” Nígbà tí iṣẹ́ ti wọ́n rán dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, Josẹfu sọkún.
18 Àwọn arákùnrin rẹ̀ wá, wọ́n sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀, wọ́n wí pé, “Ẹrú rẹ ni a jẹ́.”
19 Ṣùgbọ́n Josẹfu wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe bẹ̀rù, èmi ha wà ní ipò Ọlọ́run bí?
20 Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ gbèrò láti ṣe mi ní ibi, ṣùgbọ́n Ọlọ́run gbèrò láti fi ṣe rere tí ń ṣe lọ́wọ́ yìí; ni gbígba ẹ̀mí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn là.
21 Nítorí náà, ẹ má ṣe bẹ̀rù. Èmi yóò pèsè fún ẹ̀yin àti àwọn ọmọ yín.” Ó tún fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀, ó sì sọ ọ̀rọ̀ rere fun wọn.
22 Josẹfu sì ń gbé ní Ejibiti pẹ̀lú gbogbo ìdílé baba rẹ̀. Ó sì wà láààyè fún àádọ́fà ọdún.
23 Ó sì rí ìran kẹta ọmọ Efraimu-Àwọn ọmọ Makiri, ọmọkùnrin Manase ni a sì gbé le eékún Josẹfu nígbà tí ó bí wọn.
24 Nígbà náà ni Josẹfu wí fún àwọn arákùnrin rẹ̀ pé, “Mo ti fẹ́rẹ kú, ṣùgbọ́n dájúdájú Ọlọ́run yóò wá sí ìrànlọ́wọ́ yín, yóò sì mú un yín jáde kúrò ní ilẹ̀ yìí lọ sí ilẹ̀ tí ó ti ṣèlérí ní ìbúra fún Abrahamu, Isaaki àti Jakọbu.”
25 Josẹfu sì mú kí àwọn ọmọ Israẹli búra májẹ̀mú kan wí pé, “Dájúdájú Ọlọ́run yóò wá sí ìrànlọ́wọ́ yín, nígbà náà ni ẹ gbọdọ̀ kó egungun mi lọ́wọ́ kúrò ní ìhín.”
26 Báyìí ni Josẹfu kú nígbà tí ó pé àádọ́fà ọdún. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n ṣe òkú rẹ̀ lọ́jọ̀ tan, a gbé e sí inú pósí ní Ejibiti.
Chapter information and study resources

Listen to Genesis 50 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Genesis 50

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Genesis 50. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Genesis 50 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references.

Cross-references in Genesis 50 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Genesis 50:1–26 (375 words)
1
  1. וַ/יִּפֹּ֥לva/i.yi.Poland/ he fellH5307
  2. יוֹסֵ֖ףyo.SefJosephH3130
  3. עַל\־'al-onH5921
  4. פְּנֵ֣יpe.NeiH6440
  5. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  6. וַ/יֵּ֥בְךְּva/i.Ye.vekand/ he weptH1058
  7. עָלָ֖י/ו'a.La/vover/ himH5921
  8. וַ/יִּשַּׁק\־va/i.yi.shak-and/ he kissedH5401
  9. לֽ/וֹ\׃l/o<to>/ himH9033
2
  1. וַ/יְצַ֨וva/y.Tzavand/ he commandedH6680
  2. יוֹסֵ֤ףyo.SefJosephH3130
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. עֲבָדָי/ו֙'a.va.Da/vservants/ hisH5650
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. הָ/רֹ֣פְאִ֔יםha./Ro.fe.'Imthe/ physiciansH7495
  7. לַ/חֲנֹ֖טla./cha.Notto/ embalmH2590
  8. אֶת\־'et-<obj.>H853
  9. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  10. וַ/יַּחַנְט֥וּva/i.ya.chan.Tuand/ they embalmedH2590
  11. הָ/רֹפְאִ֖יםha./ro.fe.'Imthe/ physiciansH7495
  12. אֶת\־'et-<obj.>H853
  13. יִשְׂרָאֵֽל\׃Yis.ra.'ElIsraelH3478
3
  1. וַ/יִּמְלְאוּ\־va/i.yim.le.'u-and/ they were completedH4390
  2. ל/וֹ֙l/ofor/ himH9033
  3. אַרְבָּעִ֣ים'ar.ba.'ImfortyH705
  4. י֔וֹםYomday[s]H3117
  5. כִּ֛יkiforH3588
  6. כֵּ֥ןkenthusH3651
  7. יִמְלְא֖וּyim.le.'Uthey were completedH4390
  8. יְמֵ֣יye.MeiH3117
  9. הַ/חֲנֻטִ֑יםha./cha.nu.Timthe/ embalming<s>H2590
  10. וַ/יִּבְכּ֥וּva/i.yiv.Kuand/ they wept forH1058
  11. אֹת֛/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  12. מִצְרַ֖יִםmitz.Ra.yimEgyptH4713
  13. שִׁבְעִ֥יםshiv.'ImseventyH7657
  14. יֽוֹם\׃Yomday[s]H3117
4
  1. וַ/יַּֽעַבְרוּ֙va/i.ya.'av.Ruand/ they passedH5674
  2. יְמֵ֣יye.MeiH3117
  3. בְכִית֔/וֹve.khi.T/oweeping/ hisH1068
  4. וַ/יְדַבֵּ֣רva/y.da.Berand/ he spokeH1696
  5. יוֹסֵ֔ףyo.SefJosephH3130
  6. אֶל\־'el-toH413
  7. בֵּ֥יתbeitH1004
  8. פַּרְעֹ֖הpar.'OhPharaohH6547
  9. לֵ/אמֹ֑רle./Mor<to>/ sayingH559
  10. אִם\־'im-ifH518
  11. נָ֨אna'pleaseH4994
  12. מָצָ֤אתִיma.Tza.tiI have foundH4672
  13. חֵן֙chenfavorH2580
  14. בְּ/עֵ֣ינֵי/כֶ֔םbe./'Ei.nei./Khemin/ view/ yourH5869
  15. דַּבְּרוּ\־da.be.ru-speakH1696
  16. נָ֕אna'pleaseH4994
  17. בְּ/אָזְנֵ֥יbe./'a.ze.Neiin/ [the] ears ofH241
  18. פַרְעֹ֖הfar.'OhPharaohH6547
  19. לֵ/אמֹֽר\׃le./Mor<to>/ sayingH559
5
  1. אָבִ֞/י'a.V/ifather/ myH1
  2. הִשְׁבִּיעַ֣/נִיhish.bi.'A./nihe made swear an oath/ meH7650
  3. לֵ/אמֹ֗רle./Mor<to>/ sayingH559
  4. הִנֵּ֣הhi.Nehhere!H2009
  5. אָנֹכִי֮'a.no.KhiIH595
  6. מֵת֒metH4191
  7. בְּ/קִבְרִ֗/יbe./kiv.R/iin/ grave/ myH6913
  8. אֲשֶׁ֨ר'a.SherwhichH834
  9. כָּרִ֤יתִיka.Ri.tiI dugH3738
  10. לִ/י֙l/ifor/ myselfH9030
  11. בְּ/אֶ֣רֶץbe./'E.retzin/ [the] land ofH776
  12. כְּנַ֔עַןke.Na.'anCanaanH3667
  13. שָׁ֖מָּ/הSha.ma/hthere/ <towards>H8033
  14. תִּקְבְּרֵ֑/נִיtik.be.Re./niyou will bury/ meH6912
  15. וְ/עַתָּ֗הve./'a.Tahand/ thereforeH6258
  16. אֶֽעֱלֶה\־'e.'e.leh-let me go upH5927
  17. נָּ֛אna'pleaseH4994
  18. וְ/אֶקְבְּרָ֥הve./'ek.be.Rahso/ I may buryH6912
  19. אֶת\־'et-<obj.>H853
  20. אָבִ֖/י'a.V/ifather/ myH1
  21. וְ/אָשֽׁוּבָה\׃ve./'a.Shu.vahand/ I will returnH7725
6
  1. וַ/יֹּ֖אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. פַּרְעֹ֑הpar.'OhPharaohH6547
  3. עֲלֵ֛ה'a.Lehgo upH5927
  4. וּ/קְבֹ֥רu./ke.Vorand/ buryH6912
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. אָבִ֖י/ךָ'a.Vi./khafather/ yourH1
  7. כַּ/אֲשֶׁ֥רka./'a.Sherjust/ asH834
  8. הִשְׁבִּיעֶֽ/ךָ\׃hish.bi.'E./khahe made swear/ youH7650
7
  1. וַ/יַּ֥עַלva/i.Ya.'aland/ he went upH5927
  2. יוֹסֵ֖ףyo.SefJosephH3130
  3. לִ/קְבֹּ֣רli/k.Borto/ buryH6912
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  6. וַ/יַּֽעֲל֨וּva/i.ya.'a.Luand/ they went upH5927
  7. אִתּ֜/וֹ'i.T/owith/ himH854
  8. כָּל\־kol-allH3605
  9. עַבְדֵ֤י'av.DeiH5650
  10. פַרְעֹה֙far.'OhPharaohH6547
  11. זִקְנֵ֣יzik.NeiH2205
  12. בֵית֔/וֹvei.T/ohousehold/ hisH1004
  13. וְ/כֹ֖לve./Kholand/ allH3605
  14. זִקְנֵ֥יzik.NeiH2205
  15. אֶֽרֶץ\־'e.retz-H776
  16. מִצְרָֽיִם\׃mitz.Ra.yimEgyptH4714
8
  1. וְ/כֹל֙ve./Kholand/ allH3605
  2. בֵּ֣יתbeitH1004
  3. יוֹסֵ֔ףyo.SefJosephH3130
  4. וְ/אֶחָ֖י/וve./'e.Cha/vand/ brothers/ hisH251
  5. וּ/בֵ֣יתu./Veitand/ [the] household ofH1004
  6. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  7. רַ֗קRakonlyH7535
  8. טַפָּ/ם֙ta.Pa/mlittle one[s]/ theirH2945
  9. וְ/צֹאנָ֣/םve./tzo.Na/mand/ sheep/ theirH6629
  10. וּ/בְקָרָ֔/םu./ve.ka.Ra/mand/ cattle/ theirH1241
  11. עָזְב֖וּ'a.ze.Vuthey leftH5800
  12. בְּ/אֶ֥רֶץbe./'E.retzin/ [the] land ofH776
  13. גֹּֽשֶׁן\׃Go.shenGoshenH1657
9
  1. וַ/יַּ֣עַלva/i.Ya.'aland/ it went upH5927
  2. עִמּ֔/וֹi.M/owith/ himH5973
  3. גַּם\־gam-bothH1571
  4. רֶ֖כֶבRe.khevchariotryH7393
  5. גַּם\־gam-as well asH1571
  6. פָּרָשִׁ֑יםpa.ra.ShimhorsemenH6571
  7. וַ/יְהִ֥יva/y.Hiand/ it wasH1961
  8. הַֽ/מַּחֲנֶ֖הha./ma.cha.Nehthe/ companyH4264
  9. כָּבֵ֥דka.VednumerousH3515
  10. מְאֹֽד\׃me.'OdveryH3966
10
  1. וַ/יָּבֹ֜אוּva/i.ya.Vo.'uand/ they cameH935
  2. עַד\־'ad-toH5704
  3. גֹּ֣רֶןGo.renH1637
  4. הָ/אָטָ֗דha./'a.Tad<the>/ AtadH329
  5. אֲשֶׁר֙'a.SherwhichH834
  6. בְּ/עֵ֣בֶרbe./'E.verH5676
  7. הַ/יַּרְדֵּ֔ןhai./yar.Denthe/ JordanH3383
  8. וַ/יִּ֨סְפְּדוּ\־va/i.Yis.pe.du-and/ they lamentedH5594
  9. שָׁ֔םShamthereH8033
  10. מִסְפֵּ֛דmis.Peda lamentH4553
  11. גָּד֥וֹלga.DolgreatH1419
  12. וְ/כָבֵ֖דve./kha.Vedand/ heavyH3515
  13. מְאֹ֑דme.'OdveryH3966
  14. וַ/יַּ֧עַשׂva/i.Ya.'asand/ he madeH6213
  15. לְ/אָבִ֛י/וle./'a.Vi/vfor/ father/ hisH1
  16. אֵ֖בֶל'E.velmourningH60
  17. שִׁבְעַ֥תshiv.'AtsevenH7651
  18. יָמִֽים\׃ya.MimdaysH3117
11
  1. וַ/יַּ֡רְאva/i.Yar'and/ he sawH7200
  2. יוֹשֵׁב֩yo.ShevH3427
  3. הָ/אָ֨רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  4. הַֽ/כְּנַעֲנִ֜יha./ke.na.'a.Nithe/ Canaanite[s]H3669
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. הָ/אֵ֗בֶלha./'E.velthe/ mourningH60
  7. בְּ/גֹ֙רֶן֙be./Go.renat/ [the] threshing floor ofH1637
  8. הָֽ/אָטָ֔דha./'a.Tad<the>/ AtadH329
  9. וַ/יֹּ֣אמְר֔וּva/i.Yo.me.Ruand/ they saidH559
  10. אֵֽבֶל\־'e.vel-H60
  11. כָּבֵ֥דka.VedheavyH3515
  12. זֶ֖הzehthisH2088
  13. לְ/מִצְרָ֑יִםle./mitz.Ra.yimfor/ EgyptH4714
  14. עַל\־'al-there-H5921
  15. כֵּ֞ןken-foreH3651
  16. קָרָ֤אka.Ra'someone calledH7121
  17. שְׁמָ/הּ֙she.Ma/hname/ itsH8034
  18. אָבֵ֣ל'a.VelAbelH67
  19. מִצְרַ֔יִםmitz.Ra.yimMizraimH67
  20. אֲשֶׁ֖ר'a.SherwhichH834
  21. בְּ/עֵ֥בֶרbe./'E.verH5676
  22. הַ/יַּרְדֵּֽן\׃hai./yar.Denthe/ JordanH3383
12
  1. וַ/יַּעֲשׂ֥וּva/i.ya.'a.Suand/ they didH6213
  2. בָנָ֖י/וva.Na/vsons/ hisH1121
  3. ל֑/וֹl/ofor/ himH9033
  4. כֵּ֖ןkenthusH3651
  5. כַּ/אֲשֶׁ֥רka./'a.Sherjust/ asH834
  6. צִוָּֽ/ם\׃tzi.Va/mhe had commanded/ themH6680
13
  1. וַ/יִּשְׂא֨וּva/i.yis.'Uand/ they carriedH5375
  2. אֹת֤/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  3. בָנָי/ו֙va.Na/vsons/ hisH1121
  4. אַ֣רְצָ/ה'Ar.tza/hH776
  5. כְּנַ֔עַןke.Na.'anCanaanH3667
  6. וַ/יִּקְבְּר֣וּva/i.yik.be.Ruand/ they buriedH6912
  7. אֹת֔/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  8. בִּ/מְעָרַ֖תbi/m.'a.Ratin/ [the] cave ofH4631
  9. שְׂדֵ֣הse.DehH7704
  10. הַ/מַּכְפֵּלָ֑הha./makh.pe.Lah<the>/ MachpelahH4375
  11. אֲשֶׁ֣ר'a.SherwhichH834
  12. קָנָה֩ka.Nahhe had boughtH7069
  13. אַבְרָהָ֨ם'av.ra.HamAbrahamH85
  14. אֶת\־'et-<obj.>H853
  15. הַ/שָּׂדֶ֜הha./sa.Dehthe/ fieldH7704
  16. לַ/אֲחֻזַּת\־la./'a.chu.zat-to/ a possession ofH272
  17. קֶ֗בֶרKe.vera burial siteH6913
  18. מֵ/אֵ֛תme./'Etfrom/ withH854
  19. עֶפְרֹ֥ן'ef.RonEphronH6085
  20. הַ/חִתִּ֖יha./chi.Tithe/ HittiteH2850
  21. עַל\־'al-onH5921
  22. פְּנֵ֥יpe.NeiH6440
  23. מַמְרֵֽא\׃mam.Re'MamreH4471
14
  1. וַ/יָּ֨שָׁבva/i.Ya.shovand/ he went backH7725
  2. יוֹסֵ֤ףyo.SefJosephH3130
  3. מִצְרַ֙יְמָ/ה֙mitz.Ray.ma/hEgypt/ towardsH4714
  4. ה֣וּאhu'heH1931
  5. וְ/אֶחָ֔י/וve./'e.Cha/vand/ brothers/ hisH251
  6. וְ/כָל\־ve./kholand/ allH3605
  7. הָ/עֹלִ֥יםha./'o.Limthose/ [who] had gone upH5927
  8. אִתּ֖/וֹ'i.T/owith/ himH854
  9. לִ/קְבֹּ֣רli/k.Borto/ buryH6912
  10. אֶת\־'et-<obj.>H853
  11. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  12. אַחֲרֵ֖י'a.cha.ReiafterH310
  13. קָבְר֥/וֹka.ve.R/ohad buried/ heH6912
  14. אֶת\־'et-<obj.>H853
  15. אָבִֽי/ו\׃'a.Vi/vfather/ hisH1
15
  1. וַ/יִּרְא֤וּva/i.yir.'Uand/ they sawH7200
  2. אֲחֵֽי\־'a.chei-H251
  3. יוֹסֵף֙yo.SefJosephH3130
  4. כִּי\־ki-thatH3588
  5. מֵ֣תmethe had diedH4191
  6. אֲבִי/הֶ֔ם'a.vi./Hemfather/ theirH1
  7. וַ/יֹּ֣אמְר֔וּva/i.Yo.me.Ruand/ they saidH559
  8. ל֥וּluifH3863
  9. יִשְׂטְמֵ֖/נוּyis.te.Me./nuhe will bear a grudge/ usH7852
  10. יוֹסֵ֑ףyo.SefJosephH3130
  11. וְ/הָשֵׁ֤בve./ha.Shevand/ certainly <to repay>H7725
  12. יָשִׁיב֙ya.Shivhe will repayH7725
  13. לָ֔/נוּLa./nuto/ usH9035
  14. אֵ֚ת'et<obj.>H853
  15. כָּל\־kol-allH3605
  16. הָ֣/רָעָ֔הha./ra.'Ahthe/ harmH7451
  17. אֲשֶׁ֥ר'a.SherwhichH834
  18. גָּמַ֖לְנוּga.Mal.nuwe dealt out toH1580
  19. אֹתֽ/וֹ\׃'o.T/o<obj.>/ himH853
16
  1. וַ/יְצַוּ֕וּva/y.tza.Vuand/ they commandedH6680
  2. אֶל\־'el-toH413
  3. יוֹסֵ֖ףyo.SefJosephH3130
  4. לֵ/אמֹ֑רle./Mor<to>/ sayingH559
  5. אָבִ֣י/ךָ'a.Vi./khafather/ yourH1
  6. צִוָּ֔הtzi.Vahhe commandedH6680
  7. לִ/פְנֵ֥יli/f.Nei<to>/ beforeH6440
  8. מוֹת֖/וֹmo.T/odeath/ hisH4194
  9. לֵ/אמֹֽר\׃le./Mor<to>/ sayingH559
17
  1. כֹּֽה\־koh-thusH3541
  2. תֹאמְר֣וּto.me.Ruyou will sayH559
  3. לְ/יוֹסֵ֗ףle./yo.Sefto/ JosephH3130
  4. אָ֣נָּ֡א'a.Na'we beg youH577
  5. שָׂ֣אsa'forgiveH5375
  6. נָ֠אna'pleaseH4994
  7. פֶּ֣שַׁעPe.sha'H6588
  8. אַחֶ֤י/ךָ'a.Chei./khabrothers/ yourH251
  9. וְ/חַטָּאתָ/ם֙ve./cha.ta.Ta/mand/ sin/ theirH2403
  10. כִּי\־ki-forH3588
  11. רָעָ֣הra.'AhevilH7451
  12. גְמָל֔וּ/ךָge.ma.Lu./khathey dealt out to/ youH1580
  13. וְ/עַתָּה֙ve./'a.Tahand/ nowH6258
  14. שָׂ֣אsa'forgiveH5375
  15. נָ֔אNa'pleaseH4994
  16. לְ/פֶ֥שַׁעle./Fe.sha'to/ [the] transgression ofH6588
  17. עַבְדֵ֖י'av.DeiH5650
  18. אֱלֹהֵ֣י'e.lo.HeiH430
  19. אָבִ֑י/ךָ'a.Vi./khafather/ yourH1
  20. וַ/יֵּ֥בְךְּva/i.Ye.vekand/ he weptH1058
  21. יוֹסֵ֖ףyo.SefJosephH3130
  22. בְּ/דַבְּרָ֥/םbe./da.be.Ra/mwhen/ spoke/ theyH1696
  23. אֵלָֽי/ו\׃'e.La/vto/ himH413
18
  1. וַ/יֵּלְכוּ֙va/i.ye.le.Khuand/ they wentH1980
  2. גַּם\־gam-alsoH1571
  3. אֶחָ֔י/ו'e.Cha/vbrothers/ hisH251
  4. וַֽ/יִּפְּל֖וּva/i.yi.pe.Luand/ they fellH5307
  5. לְ/פָנָ֑י/וle./fa.Na/v<to>/ before/ himH6440
  6. וַ/יֹּ֣אמְר֔וּva/i.Yo.me.Ruand/ they saidH559
  7. הִנֶּ֥/נּֽוּhi.Ne./nuhere/ weH2009
  8. לְ/ךָ֖le./KhaH9031
  9. לַ/עֲבָדִֽים\׃la./'a.va.Dimto/ slavesH5650
19
  1. וַ/יֹּ֧אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. אֲלֵ/הֶ֛ם'a.le./Hemto/ themH413
  3. יוֹסֵ֖ףyo.SefJosephH3130
  4. אַל\־'al-may notH408
  5. תִּירָ֑אוּti.Ra.'uyou fearH3372
  6. כִּ֛יkithatH3588
  7. הֲ/תַ֥חַתha./Ta.chat¿/ in place ofH8478
  8. אֱלֹהִ֖ים'E.lo.HimGodH430
  9. אָֽנִי\׃'A.niH589
20
  1. וְ/אַתֶּ֕םve./'a.Temand/ youH859
  2. חֲשַׁבְתֶּ֥םcha.shav.Temyou plannedH2803
  3. עָלַ֖/י'a.La/ion/ meH5921
  4. רָעָ֑הra.'AhharmH7451
  5. אֱלֹהִים֙'E.lo.HimGodH430
  6. חֲשָׁבָ֣/הּcha.sha.Va/hhe planned/ itH2803
  7. לְ/טֹבָ֔הle./to.Vahfor/ goodH2896
  8. לְמַ֗עַןle.Ma.'anso asH4616
  9. עֲשֹׂ֛ה'a.Sohto actH6213
  10. כַּ/יּ֥וֹםka/i.Yomas the/ dayH3117
  11. הַ/זֶּ֖הha./Zeh<the>/ thisH2088
  12. לְ/הַחֲיֹ֥תle./ha.cha.Yotto/ preserve aliveH2421
  13. עַם\־'am-a peopleH5971
  14. רָֽב\׃RavnumerousH7227
21
  1. וְ/עַתָּה֙ve./'a.Tahand/ thereforeH6258
  2. אַל\־'al-may notH408
  3. תִּירָ֔אוּti.Ra.'uyou fearH3372
  4. אָנֹכִ֛י'a.no.KhiIH595
  5. אֲכַלְכֵּ֥ל'a.khal.KelI will provide forH3557
  6. אֶתְ/כֶ֖ם'et./Khem<obj.>/ youH853
  7. וְ/אֶֽת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  8. טַפְּ/כֶ֑םta.pe./Khemlittle one[s]/ yourH2945
  9. וַ/יְנַחֵ֣םva/y.na.Chemand/ he comfortedH5162
  10. אוֹתָ֔/ם'o.Ta/m<obj.>/ themH853
  11. וַ/יְדַבֵּ֖רva/y.da.Berand/ he spokeH1696
  12. עַל\־'al-toH5921
  13. לִבָּֽ/ם\׃li.Ba/mheart/ theirH3820
22
  1. וַ/יֵּ֤שֶׁבva/i.Ye.shevand/ he remainedH3427
  2. יוֹסֵף֙yo.SefJosephH3130
  3. בְּ/מִצְרַ֔יִםbe./mitz.Ra.yimin/ EgyptH4714
  4. ה֖וּאhu'heH1931
  5. וּ/בֵ֣יתu./Veitand/ [the] household ofH1004
  6. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  7. וַ/יְחִ֣יva/y.Chiand/ he livedH2421
  8. יוֹסֵ֔ףyo.SefJosephH3130
  9. מֵאָ֥הme.'Ahone hundredH3967
  10. וָ/עֶ֖שֶׂרva./'E.serand/ tenH6235
  11. שָׁנִֽים\׃sha.NimyearsH8141
23
  1. וַ/יַּ֤רְאva/i.Yar'and/ he sawH7200
  2. יוֹסֵף֙yo.SefJosephH3130
  3. לְ/אֶפְרַ֔יִםle./'ef.Ra.yimof/ EphraimH669
  4. בְּנֵ֖יbe.Neisons ofH1121
  5. שִׁלֵּשִׁ֑יםshi.le.Shima third generationH8029
  6. גַּ֗םGamalsoH1571
  7. בְּנֵ֤יbe.NeiH1121
  8. מָכִיר֙ma.KhirMakirH4353
  9. בֶּן\־ben-H1121
  10. מְנַשֶּׁ֔הme.na.ShehManassehH4519
  11. יֻלְּד֖וּyu.le.Duthey were bornH3205
  12. עַל\־'al-onH5921
  13. בִּרְכֵּ֥יbir.KeiH1290
  14. יוֹסֵֽף\׃yo.SefJosephH3130
24
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. יוֹסֵף֙yo.SefJosephH3130
  3. אֶל\־'el-toH413
  4. אֶחָ֔י/ו'e.Cha/vbrothers/ hisH251
  5. אָנֹכִ֖י'a.no.KhiIH595
  6. מֵ֑תMetH4191
  7. וֵֽ/אלֹהִ֞יםve./lo.Himand/ GodH430
  8. פָּקֹ֧דpa.Kodcertainly <to visit>H6485
  9. יִפְקֹ֣דyif.Kodhe will visitH6485
  10. אֶתְ/כֶ֗ם'et./Khem<obj.>/ youH853
  11. וְ/הֶעֱלָ֤הve./he.'e.Lahand/ he will bring upH5927
  12. אֶתְ/כֶם֙'et./Khem<obj.>/ youH853
  13. מִן\־min-fromH4480
  14. הָ/אָ֣רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  15. הַ/זֹּ֔אתha./Zot<the>/ thisH2063
  16. אֶל\־'el-toH413
  17. הָ/אָ֕רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  18. אֲשֶׁ֥ר'a.SherwhichH834
  19. נִשְׁבַּ֛עnish.Ba'he sworeH7650
  20. לְ/אַבְרָהָ֥םle./'av.ra.Hamto/ AbrahamH85
  21. לְ/יִצְחָ֖קle./yitz.Chakto/ IsaacH3327
  22. וּֽ/לְ/יַעֲקֹֽב\׃u./le./ya.'a.koand/ to/ JacobH3290
25
  1. וַ/יַּשְׁבַּ֣עva/i.yash.Ba'and/ he made to swear an oathH7650
  2. יוֹסֵ֔ףyo.SefJosephH3130
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. בְּנֵ֥יbe.NeiH1121
  5. יִשְׂרָאֵ֖לYis.ra.'ElIsraelH3478
  6. לֵ/אמֹ֑רle./Mor<to>/ sayingH559
  7. פָּקֹ֨דpa.Kodcertainly <to visit>H6485
  8. יִפְקֹ֤דyif.Kodhe will visitH6485
  9. אֱלֹהִים֙'E.lo.HimGodH430
  10. אֶתְ/כֶ֔ם'et./Khem<obj.>/ youH853
  11. וְ/הַעֲלִתֶ֥םve./ha.'a.li.Temand/ you will bring upH5927
  12. אֶת\־'et-<obj.>H853
  13. עַצְמֹתַ֖/י'atz.mo.Ta/ibones/ myH6106
  14. מִ/זֶּֽה\׃mi./Zehfrom/ hereH2088
26
  1. וַ/יָּ֣מָתva/i.Ya.motand/ he diedH4191
  2. יוֹסֵ֔ףyo.SefJosephH3130
  3. בֶּן\־ben-a son ofH1121
  4. מֵאָ֥הme.'Ahone hundredH3967
  5. וָ/עֶ֖שֶׂרva./'E.serand/ tenH6235
  6. שָׁנִ֑יםsha.NimyearsH8141
  7. וַ/יַּחַנְט֣וּva/i.ya.chan.Tuand/ people embalmedH2590
  8. אֹת֔/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  9. וַ/יִּ֥ישֶׂםva/i.Yi.semand/ he was putH3455
  10. בָּ/אָר֖וֹןba./'a.Ronin the/ coffinH727
  11. בְּ/מִצְרָֽיִם\׃be./mitz.Ra.yimin/ EgyptH4714

View the full Hebrew interlinear for Genesis 50 →

Strong's words in Genesis 50 (6)
Strong's H3130 — יוֹסֵ֖ף (yo.Sef)
Joseph. Appears 19 times in Genesis 50.
Strong's H1 — אָבִ֑י/ו ('a.Vi/v)
father/ his. Appears 14 times in Genesis 50.
Strong's H559 — לֵ/אמֹ֑ר (le./Mor)
<to>/ saying. Appears 13 times in Genesis 50.
Strong's H5927 — אֶֽעֱלֶה\־ ('e.'e.leh-)
let me go up. Appears 8 times in Genesis 50.
Strong's H1121 — בָנָ֖י/ו (va.Na/v)
sons/ his. Appears 7 times in Genesis 50.
Strong's H6912 — תִּקְבְּרֵ֑/נִי (tik.be.Re./ni)
you will bury/ me. Appears 7 times in Genesis 50.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress