Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Genesis 10 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Èyí ni ìran àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti, tí àwọn náà sì bí ọmọ lẹ́yìn ìkún omi.
2 Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai, Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi.
3 Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.
4 Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.
5 (Láti ọ̀dọ̀ àwọn wọ̀nyí ni àwọn tí ń gbé agbègbè tí omi wà ti tàn ká agbègbè wọn, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, ìdílé wọn ní orílẹ̀-èdè wọn, olúkúlùkù pẹ̀lú èdè tirẹ̀).
6 Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti àti Kenaani.
7 Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama ni: Ṣeba àti Dedani.
8 Kuṣi sì bí Nimrodu, ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.
9 Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nimrodu, ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”
10 Ìjọba rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ni Babeli, Ereki, Akkadi, Kalne, gbogbo wọn wà ní ilẹ̀ Ṣinari.
11 Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala,
12 àti Resini, tí ó wà ní àárín Ninefe àti Kala, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí.
13 Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu.
14 Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.
15 Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, àti Heti.
16 Àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,
17 àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini,
18 àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati. Lẹ́yìn èyí ni àwọn ẹ̀yà Kenaani tànkálẹ̀.
19 Ààlà ilẹ̀ àwọn ará Kenaani sì dé Sidoni, lọ sí Gerari títí dé Gasa, lọ sí Sodomu, Gomorra, Adma àti Seboimu, títí dé Laṣa.
20 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Hamu, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà wọn, àti èdè wọn, ní ìpínlẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn.
21 A bí àwọn ọmọ fún Ṣemu tí Jafeti jẹ́ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin: Ṣemu sì ni baba gbogbo àwọn ọmọ Eberi.
22 Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu.
23 Àwọn ọmọ Aramu ni: Usi, Huli, Geteri àti Meṣeki.
24 Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.
25 Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.
26 Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.
27 Hadoramu, Usali, Dikla,
28 Obali, Abimaeli, Ṣeba.
29 Ofiri, Hafila àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.
30 Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Meṣa títí dé Sefari, ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà-oòrùn.
31 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Ṣemu gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn, ní èdè wọn, ní ilẹ̀ wọn àti ní orílẹ̀-èdè wọn.
32 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Noa gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, ní orílẹ̀-èdè wọn. Ní ipasẹ̀ wọn ni àwọn ènìyàn ti tàn ká ilẹ̀ ayé lẹ́yìn ìkún omi.
Chapter information and study resources

Listen to Genesis 10 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Genesis 10

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Genesis 10. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Genesis 10 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references, 2 Early-Church citations.

Cross-references in Genesis 10 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Genesis 10:1–32 (287 words)
1
  1. וְ/אֵ֙לֶּה֙ve./'E.lehand/ theseH428
  2. תּוֹלְדֹ֣תtol.DotH8435
  3. בְּנֵי\־be.nei-H1121
  4. נֹ֔חַNo.achNoahH5146
  5. שֵׁ֖םshemShemH8035
  6. חָ֣םchamHamH2526
  7. וָ/יָ֑פֶתva./Ya.fetand/ JaphethH3315
  8. וַ/יִּוָּלְד֥וּva/i.yi.val.Duand/ they were bornH3205
  9. לָ/הֶ֛םla./Hemto <the>/ themH9038
  10. בָּנִ֖יםba.NimsonsH1121
  11. אַחַ֥ר'a.CharafterH310
  12. הַ/מַּבּֽוּל\׃ha./ma.Bulthe/ floodH3999
2
  1. בְּנֵ֣יbe.NeiH1121
  2. יֶ֔פֶתYe.fetJaphethH3315
  3. גֹּ֣מֶרGo.merH1586
  4. וּ/מָג֔וֹגu./ma.Gogand/ MagogH4031
  5. וּ/מָדַ֖יu./ma.Daiand/ MadaiH4074
  6. וְ/יָוָ֣ןve./ya.Vanand/ JavanH3120
  7. וְ/תֻבָ֑לve./tu.Valand/ TubalH8422
  8. וּ/מֶ֖שֶׁךְu./Me.shekhand/ MeshechH4902
  9. וְ/תִירָֽס\׃ve./ti.Rasand/ TirasH8494
3
  1. וּ/בְנֵ֖יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  2. גֹּ֑מֶרGo.merGomerH1586
  3. אַשְׁכֲּנַ֥ז'ash.ka.NazH813
  4. וְ/רִיפַ֖תve./ri.Fatand/ RiphathH7384
  5. וְ/תֹגַרְמָֽה\׃ve./to.gar.Mahand/ TogarmahH8425
4
  1. וּ/בְנֵ֥יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  2. יָוָ֖ןya.VanJavanH3120
  3. אֱלִישָׁ֣ה'e.li.ShahH473
  4. וְ/תַרְשִׁ֑ישׁve./tar.Shishand/ TarshishH8659
  5. כִּתִּ֖יםki.TimKittimH3794
  6. וְ/דֹדָנִֽים\׃ve./do.da.Nimand/ DodanimH1721
5
  1. מֵ֠/אֵלֶּהMe./'e.lehfrom/ theseH428
  2. נִפְרְד֞וּnif.re.Duthey separatedH6504
  3. אִיֵּ֤י'i.YeiH339
  4. הַ/גּוֹיִם֙ha./go.Yimthe/ nationsH1471
  5. בְּ/אַרְצֹתָ֔/םbe./'ar.tzo.Ta/min/ own lands/ theirH776
  6. אִ֖ישׁ'isheachH376
  7. לִ/לְשֹׁנ֑/וֹli/l.sho.N/oto/ own language/ itsH3956
  8. לְ/מִשְׁפְּחֹתָ֖/םle./mish.pe.cho.Ta/mto/ clans/ theirH4940
  9. בְּ/גוֹיֵ/הֶֽם\׃be./go.ye./Hemin/ nations/ theirH1471
6
  1. וּ/בְנֵ֖יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  2. חָ֑םChamHamH2526
  3. כּ֥וּשׁkushH3568
  4. וּ/מִצְרַ֖יִםu./mitz.Ra.yimand/ MizraimH4714
  5. וּ/פ֥וּטu./Futand/ PutH6316
  6. וּ/כְנָֽעַן\׃u./khe.Na.'anand/ CanaanH3667
7
  1. וּ/בְנֵ֣יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  2. כ֔וּשׁKhushCushH3568
  3. סְבָא֙se.Va'H5434
  4. וַֽ/חֲוִילָ֔הva./cha.vi.Lahand/ HavilahH2341
  5. וְ/סַבְתָּ֥הve./sav.Tahand/ SabtahH5454
  6. וְ/רַעְמָ֖הve./ra'.Mahand/ RaamahH7484
  7. וְ/סַבְתְּכָ֑אve./sav.te.Kha'and/ SabtecaH5455
  8. וּ/בְנֵ֥יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  9. רַעְמָ֖הra'.MahRaamahH7484
  10. שְׁבָ֥אshe.Va'H7614
  11. וּ/דְדָֽן\׃u./de.Danand/ DedanH1719
8
  1. וְ/כ֖וּשׁve./Khushand/ CushH3568
  2. יָלַ֣דya.Ladhe fatheredH3205
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. נִמְרֹ֑דnim.RodNimrodH5248
  5. ה֣וּאhu'heH1931
  6. הֵחֵ֔לhe.Chelhe beganH2490
  7. לִֽ/הְי֥וֹתli/h.Yotto/ beH1961
  8. גִּבֹּ֖רgi.Bora mighty [man]H1368
  9. בָּ/אָֽרֶץ\׃ba./'A.retzon the/ earthH776
9
  1. הֽוּא\־hu'-heH1931
  2. הָיָ֥הha.Yahhe wasH1961
  3. גִבֹּֽר\־gi.bor-a mighty [man] ofH1368
  4. צַ֖יִדTza.yidhuntingH6718
  5. לִ/פְנֵ֣יli/f.Nei<to>/ beforeH6440
  6. יְהוָ֑הYah.wehYahwehH3068
  7. עַל\־'al-there-H5921
  8. כֵּן֙ken-foreH3651
  9. יֵֽאָמַ֔רye.'a.Marit is saidH559
  10. כְּ/נִמְרֹ֛דke./nim.Rodlike/ NimrodH5248
  11. גִּבּ֥וֹרgi.Bora mighty [man] ofH1368
  12. צַ֖יִדTza.yidhuntingH6718
  13. לִ/פְנֵ֥יli/f.Nei<to>/ beforeH6440
  14. יְהוָֽה\׃Yah.wehYahwehH3068
10
  1. וַ/תְּהִ֨יva./te.Hiand/ it wasH1961
  2. רֵאשִׁ֤יתre.ShitH7225
  3. מַמְלַכְתּ/וֹ֙mam.lakh.T/okingdom/ hisH4467
  4. בָּבֶ֔לba.VelBabelH894
  5. וְ/אֶ֖רֶךְve./'E.rekhand/ ErechH751
  6. וְ/אַכַּ֣דve./'a.Kadand/ AkkadH390
  7. וְ/כַלְנֵ֑הve./khal.Nehand/ CalnehH3641
  8. בְּ/אֶ֖רֶץbe./'E.retzin/ [the] land ofH776
  9. שִׁנְעָֽר\׃shin.'ArShinarH8152
11
  1. מִן\־min-fromH4480
  2. הָ/אָ֥רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  3. הַ/הִ֖ואha./Hiv'<the>/ thatH1931
  4. יָצָ֣אya.Tza'he went forthH3318
  5. אַשּׁ֑וּר'a.ShurAssyriaH804
  6. וַ/יִּ֙בֶן֙va/i.Yi.venand/ he builtH1129
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. נִ֣ינְוֵ֔הnin.VehNinevehH5210
  9. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  10. רְחֹבֹ֥תre.cho.VotRehoboth-H7344
  11. עִ֖יר'irIrH5893
  12. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  13. כָּֽלַח\׃Ka.lachCalahH3625
12
  1. וְֽ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. רֶ֔סֶןRe.senResenH7449
  3. בֵּ֥יןbeinbetweenH996
  4. נִֽינְוֵ֖הnin.VehNinevehH5210
  5. וּ/בֵ֣יןu./Veinand/ betweenH996
  6. כָּ֑לַחKa.lachCalahH3625
  7. הִ֖ואhi'thatH1931
  8. הָ/עִ֥ירha./'IrH5892
  9. הַ/גְּדֹלָֽה\׃ha./ge.do.Lah<the>/ greatH1419
13
  1. וּ/מִצְרַ֡יִםu./mitz.Ra.yimand/ MizraimH4714
  2. יָלַ֞דya.Ladhe fatheredH3205
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. לוּדִ֧יםlu.DimH3866
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. עֲנָמִ֛ים'a.na.MimH6047
  7. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  8. לְהָבִ֖יםle.ha.VimH3853
  9. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  10. נַפְתֻּחִֽים\׃naf.tu.ChimH5320
14
  1. וְֽ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. פַּתְרֻסִ֞יםpat.ru.SimH6625
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. כַּסְלֻחִ֗יםkas.lu.ChimH3695
  5. אֲשֶׁ֨ר'a.SherwhereH834
  6. יָצְא֥וּya.tze.'Uthey came outH3318
  7. מִ/שָּׁ֛םmi./Shamfrom/ thereH8033
  8. פְּלִשְׁתִּ֖יםpe.lish.TimH6430
  9. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  10. כַּפְתֹּרִֽים\׃\ \סkaf.to.RimH3732
15
  1. וּ/כְנַ֗עַןu./khe.Na.'anand/ CanaanH3667
  2. יָלַ֛דya.Ladhe fatheredH3205
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. צִידֹ֥ןtzi.DonSidonH6721
  5. בְּכֹר֖/וֹbe.kho.R/ofirstborn/ hisH1060
  6. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  7. חֵֽת\׃ChetHethH2845
16
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. הַ/יְבוּסִי֙ha/y.vu.Sithe/ Jebusite[s]H2983
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. הָ֣/אֱמֹרִ֔יha./'e.mo.Rithe/ Amorite[s]H567
  5. וְ/אֵ֖תve./'Etand/ <obj.>H853
  6. הַ/גִּרְגָּשִֽׁי\׃ha./gir.ga.Shithe/ Girgashite[s]H1622
17
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. הַֽ/חִוִּ֥יha./chi.Vithe/ Hivite[s]H2340
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. הַֽ/עַרְקִ֖יha./'ar.Kithe/ Arkite[s]H6208
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. הַ/סִּינִֽי\׃ha./si.Nithe/ Sinite[s]H5513
18
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. הָֽ/אַרְוָדִ֥יha./'ar.va.Dithe/ Arvadite[s]H721
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. הַ/צְּמָרִ֖יha./tze.ma.Rithe/ Zemarite[s]H6786
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. הַֽ/חֲמָתִ֑יha./cha.ma.Tithe/ Hamathite[s]H2577
  7. וְ/אַחַ֣רve./'a.Charand/ afterH310
  8. נָפֹ֔צוּna.Fo.tzuthey were scatteredH6327
  9. מִשְׁפְּח֖וֹתmish.pe.ChotH4940
  10. הַֽ/כְּנַעֲנִֽי\׃Ha./ke.na.'a.Nithe/ Canaanite[s]H3669
19
  1. וַֽ/יְהִ֞יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. גְּב֤וּלge.VulH1366
  3. הַֽ/כְּנַעֲנִי֙ha./ke.na.'a.Nithe/ Canaanite[s]H3669
  4. מִ/צִּידֹ֔ןmi./tzi.Donfrom/ SidonH6721
  5. בֹּאֲ/כָ֥הbo.'a./Khahgoing/ youH935
  6. גְרָ֖רָ/הge.Ra.ra/hGerar/ towardsH1642
  7. עַד\־'ad-toH5704
  8. עַזָּ֑ה'a.ZahGazaH5804
  9. בֹּאֲ/כָ֞הbo.'a./Khahgoing/ youH935
  10. סְדֹ֧מָ/הse.Do.ma/hSodom/ towardsH5467
  11. וַ/עֲמֹרָ֛הva./'a.mo.Rahand/ GomorrahH6017
  12. וְ/אַדְמָ֥הve./'ad.Mahand/ AdmahH126
  13. וּ/צְבֹיִ֖םu./tze.vo.Yimand/ ZeboiimH6636
  14. עַד\־'ad-toH5704
  15. לָֽשַׁע\׃La.sha'LashaH3962
20
  1. אֵ֣לֶּה'E.lehtheseH428
  2. בְנֵי\־ve.nei-H1121
  3. חָ֔םChamHamH2526
  4. לְ/מִשְׁפְּחֹתָ֖/םle./mish.pe.cho.Ta/mto/ clans/ theirH4940
  5. לִ/לְשֹֽׁנֹתָ֑/םli/l.sho.no.Ta/mto/ languages/ theirH3956
  6. בְּ/אַרְצֹתָ֖/םbe./'ar.tzo.Ta/min/ lands/ theirH776
  7. בְּ/גוֹיֵ/הֶֽם\׃\ \סbe./go.ye./Hemin/ nations/ theirH1471
21
  1. וּ/לְ/שֵׁ֥םu/l./Shemand/ to/ ShemH8035
  2. יֻלַּ֖דyu.Lad<it> was bornH3205
  3. גַּם\־gam-alsoH1571
  4. ה֑וּאHu'heH1931
  5. אֲבִי֙'a.ViH1
  6. כָּל\־kol-allH3605
  7. בְּנֵי\־be.nei-H1121
  8. עֵ֔בֶר'E.verEberH5677
  9. אֲחִ֖י'a.ChiH251
  10. יֶ֥פֶתYe.fetJaphethH3315
  11. הַ/גָּדֽוֹל\׃ha./ga.Dol<the>/ oldH1419
22
  1. בְּנֵ֥יbe.NeiH1121
  2. שֵׁ֖םshemShemH8035
  3. עֵילָ֣ם'ei.LamH5867
  4. וְ/אַשּׁ֑וּרve./'a.Shurand/ AsshurH804
  5. וְ/אַרְפַּכְשַׁ֖דve./'ar.pakh.Shadand/ ArphaxadH775
  6. וְ/ל֥וּדve./Ludand/ LudH3865
  7. וַֽ/אֲרָֽם\׃Va./'a.Ramand/ AramH758
23
  1. וּ/בְנֵ֖יu./ve.Neiand/ [the] sons ofH1121
  2. אֲרָ֑ם'a.RamAramH758
  3. ע֥וּץ'utzH5780
  4. וְ/ח֖וּלve./Chuland/ HulH2343
  5. וְ/גֶ֥תֶרve./Ge.terand/ GetherH1666
  6. וָ/מַֽשׁ\׃va./Mashand/ MashH4851
24
  1. וְ/אַרְפַּכְשַׁ֖דve./'ar.pakh.Shadand/ ArphaxadH775
  2. יָלַ֣דya.Ladhe fatheredH3205
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. שָׁ֑לַחSha.lachShelahH7974
  5. וְ/שֶׁ֖לַחve./She.lachand/ ShelahH7974
  6. יָלַ֥דya.Ladhe fatheredH3205
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. עֵֽבֶר\׃'E.verEberH5677
25
  1. וּ/לְ/עֵ֥בֶרu/l./'E.verand/ to/ EberH5677
  2. יֻלַּ֖דyu.Lad<it> was bornH3205
  3. שְׁנֵ֣יshe.NeitwoH8147
  4. בָנִ֑יםva.NimsonsH1121
  5. שֵׁ֣םshemH8034
  6. הָֽ/אֶחָ֞דha./'e.Chadthe/ oneH259
  7. פֶּ֗לֶגPe.legH6389
  8. כִּ֤יkiforH3588
  9. בְ/יָמָי/ו֙ve./ya.Ma/vin/ days/ hisH3117
  10. נִפְלְגָ֣הnif.le.Gah<it> was dividedH6385
  11. הָ/אָ֔רֶץha./'A.retzthe/ earthH776
  12. וְ/שֵׁ֥םve./Shemand/ [the] name ofH8034
  13. אָחִ֖י/ו'a.Chi/vbrother/ hisH251
  14. יָקְטָֽן\׃ya.ke.TanH3355
26
  1. וְ/יָקְטָ֣ןve./ya.ke.Tanand/ JoktanH3355
  2. יָלַ֔דya.Ladhe fatheredH3205
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. אַלְמוֹדָ֖ד'al.mo.DadAlmodadH486
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. שָׁ֑לֶףSha.lefShelephH8026
  7. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  8. חֲצַרְמָ֖וֶתcha.tzar.Ma.vetHazarmavethH2700
  9. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  10. יָֽרַח\׃Ya.rachJerahH3392
27
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. הֲדוֹרָ֥םha.do.RamHadoramH1913
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. אוּזָ֖ל'u.ZalUzalH187
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. דִּקְלָֽה\׃dik.LahDiklahH1853
28
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. עוֹבָ֥לo.ValObalH5745
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. אֲבִֽימָאֵ֖ל'a.vi.ma.'ElAbimaelH39
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. שְׁבָֽא\׃she.Va'ShebaH7614
29
  1. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  2. אוֹפִ֥ר'o.FirOphirH211
  3. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  4. חֲוִילָ֖הcha.vi.LahHavilahH2341
  5. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  6. יוֹבָ֑בyo.VavJobabH3103
  7. כָּל\־kol-allH3605
  8. אֵ֖לֶּה'E.lehtheseH428
  9. בְּנֵ֥יbe.NeiH1121
  10. יָקְטָֽן\׃ya.ke.TanJoktanH3355
30
  1. וַֽ/יְהִ֥יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. מוֹשָׁבָ֖/םmo.sha.Va/mdwelling place/ theirH4186
  3. מִ/מֵּשָׁ֑אmi./me.Sha'from/ MeshaH4852
  4. בֹּאֲ/כָ֥הbo.'a./Khahgoing/ youH935
  5. סְפָ֖רָ/הse.Fa.ra/hSephar/ towardsH5611
  6. הַ֥רharH2022
  7. הַ/קֶּֽדֶם\׃ha./Ke.demthe/ eastH6924
31
  1. אֵ֣לֶּה'E.lehtheseH428
  2. בְנֵי\־ve.nei-H1121
  3. שֵׁ֔םShemShemH8035
  4. לְ/מִשְׁפְּחֹתָ֖/םle./mish.pe.cho.Ta/mto/ clans/ theirH4940
  5. לִ/לְשֹׁנֹתָ֑/םli/l.sho.no.Ta/mto/ languages/ theirH3956
  6. בְּ/אַרְצֹתָ֖/םbe./'ar.tzo.Ta/min/ lands/ theirH776
  7. לְ/גוֹיֵ/הֶֽם\׃le./go.ye./Hemto/ nations/ theirH1471
32
  1. אֵ֣לֶּה'E.lehtheseH428
  2. מִשְׁפְּחֹ֧תmish.pe.ChotH4940
  3. בְּנֵי\־be.nei-H1121
  4. נֹ֛חַNo.achNoahH5146
  5. לְ/תוֹלְדֹתָ֖/םle./tol.do.Ta/mto/ descendants/ theirH8435
  6. בְּ/גוֹיֵ/הֶ֑םbe./go.ye./Hemin/ nations/ theirH1471
  7. וּ/מֵ/אֵ֜לֶּהu./me./'E.lehand/ from/ theseH428
  8. נִפְרְד֧וּnif.re.Duthey separatedH6504
  9. הַ/גּוֹיִ֛םha./go.Yimthe/ nationsH1471
  10. בָּ/אָ֖רֶץba./'A.retzon the/ earthH776
  11. אַחַ֥ר'a.CharafterH310
  12. הַ/מַּבּֽוּל\׃\ \פha./ma.Bulthe/ floodH3999

View the full Hebrew interlinear for Genesis 10 →

Strong's words in Genesis 10 (6)
Strong's H1121 — בְּנֵי\־ (be.nei-)
[the] sons of. Appears 16 times in Genesis 10.
Strong's H3205 — וַ/יִּוָּלְד֥וּ (va/i.yi.val.Du)
and/ they were born. Appears 9 times in Genesis 10.
Strong's H776 — בְּ/אַרְצֹתָ֔/ם (be./'ar.tzo.Ta/m)
in/ own lands/ their. Appears 8 times in Genesis 10.
Strong's H428 — וְ/אֵ֙לֶּה֙ (ve./'E.leh)
and/ these. Appears 7 times in Genesis 10.
Strong's H1471 — הַ/גּוֹיִם֙ (ha./go.Yim)
the/ nations. Appears 6 times in Genesis 10.
Strong's H1961 — לִֽ/הְי֥וֹת (li/h.Yot)
to/ be. Appears 5 times in Genesis 10.

Browse the full Strong's concordance →

What the Early Church wrote about Genesis 10 (1 additional)
  • “Sala was the son of Arphaxad; and his son was Heber, from whom they originally called the Jews Hebrews. (18) Heber begat Joetan and Phaleg: he was called Phaleg, because he was born at the dispersion of the nations to their several countries; for Phaleg among the Hebrews signi...”

    — Josephus, Jewish historian (1st century) on Genesis 10:21

Read the full Ante-Nicene Fathers library →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress