Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Genesis 12 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Olúwa sì wí fún Abramu, “Jáde kúrò ní orílẹ̀-èdè rẹ àti kúrò lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ, lọ sí ilẹ̀ kan tí èmi yóò fihàn ọ́.
2 “Èmi yóò sọ ọ́ di orílẹ̀-èdè ńlá, èmi yóò sì bùkún fún ọ; èmi yóò sọ orúkọ rẹ di ńlá, ìbùkún ni ìwọ yóò sì jásí.
3 Èmi yóò bùkún fún àwọn tí ó súre fún ọ, ẹni tí ó fi ọ́ ré ni Èmi yóò fi ré; nínú rẹ ni a ó bùkún gbogbo ìdílé ayé.”
4 Bẹ́ẹ̀ ni Abramu lọ bí Olúwa ti sọ fún un. Lọti náà sì bá a lọ. Abramu jẹ́ ẹni àrùndínlọ́gọ́rin ọdún nígbà tí ó jáde kúrò ní Harani.
5 Abramu sì mú Sarai aya rẹ̀, àti Lọti ọmọ arákùnrin rẹ̀: gbogbo ohun ìní tí wọ́n ti kójọ àti àwọn ènìyàn tí wọ́n ní ní Harani. Wọ́n sì jáde lọ sí ilẹ̀ Kenaani. Wọ́n sì gúnlẹ̀ síbẹ̀.
6 Abramu sì rìn la ilẹ̀ náà já títí dé ibi igi ńlá kan tí à ń pè ni More ní Ṣekemu. Àwọn ará Kenaani sì wà ní ilẹ̀ náà.
7 Olúwa sì farahan Abramu, ó sì wí fún un pé, “Irú-ọmọ rẹ ni Èmi yóò fi ilẹ̀ yìí fún.” Abramu tẹ́ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Olúwa tí ó fi ara hàn án.
8 Ó sì kúrò níbẹ̀ lọ sí agbègbè àwọn òkè kan ní ìhà ìlà-oòrùn Beteli, ó sì pàgọ́ rẹ̀ síbẹ̀. Beteli wà ní ìwọ̀-oòrùn, Ai wà ní ìlà-oòrùn. Ó tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀ fún Olúwa, ó sì ké pe orúkọ Olúwa.
9 Nígbà náà ni Abramu tẹ̀síwájú sí ìhà gúúsù.
10 Ìyàn kan sì mú ní ilẹ̀ náà, Abramu sì sọ̀kalẹ̀ lọ sí Ejibiti láti ṣe àtìpó níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀, nítorí ìyàn náà mú gidigidi.
11 Bí ó ti ku díẹ̀ kí ó wọ Ejibiti, ó wí fún Sarai, aya rẹ̀ pé, “Mo mọ̀ pé arẹwà obìnrin ni ìwọ,
12 nígbà tí àwọn ará Ejibiti bá rí ọ, wọn yóò wí pé, ‘Aya rẹ̀ nìyí.’ Wọn yóò si pa mí, ṣùgbọ́n wọn yóò dá ọ sí.
13 Nítorí náà, sọ pé, arábìnrin mi ni ìwọ, wọn yóò sì ṣe mí dáradára, a ó sì dá ẹ̀mí mi sí nítorí tìrẹ.”
14 Nígbà tí Abramu dé Ejibiti, àwọn ará Ejibiti ri i pé aya rẹ̀ rẹwà gidigidi.
15 Nígbà tí àwọn ìjòyè Farao sì rí i, wọ́n ròyìn rẹ̀ níwájú Farao, wọ́n sì mú un lọ sí ààfin.
16 Ó sì kẹ́ Abramu dáradára nítorí Sarai, Abramu sì ní àgùntàn àti màlúù, akọ àti abo kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, pẹ̀lú ìbákasẹ.
17 Olúwa sì rán àjàkálẹ̀-ààrùn búburú sí Farao àti ilé rẹ̀, nítorí Sarai aya Abramu.
18 Nítorí náà Farao ránṣẹ́ pe Abramu, ó sì wí fun pé, “Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí? Kí ló dé tí ìwọ kò sọ fún mi pé aya rẹ ní í ṣe?
19 Èéṣe tí o fi wí pé, ‘Arábìnrin mi ni,’ tí èmi sì fi fẹ́ ẹ gẹ́gẹ́ bí aya? Nítorí náà nísinsin yìí, aya rẹ náà nìyí, mú un kí o sì máa lọ.”
20 Nígbà náà ni Farao pàṣẹ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ nípa Abramu, wọ́n sì lé e jáde ti òun ti aya rẹ̀ àti ohun gbogbo tí ó ní.
Chapter information and study resources

Listen to Genesis 12 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Genesis 12

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Genesis 12. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Genesis 12 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references, 1 Early-Church citation.

Cross-references in Genesis 12 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Genesis 12:1–20 (268 words)
1
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  3. אֶל\־'el-toH413
  4. אַבְרָ֔ם'av.RamAbramH87
  5. לֶךְ\־lekh-goH1980
  6. לְ/ךָ֛le./Khafor <the>/ yourselfH9031
  7. מֵ/אַרְצְ/ךָ֥me./'ar.tze./Khafrom/ land/ yourH776
  8. וּ/מִ/מּֽוֹלַדְתְּ/ךָ֖u./mi./mo.lad.te./Khaand/ from/ kindred/ yourH4138
  9. וּ/מִ/בֵּ֣יתu./mi./Beitand/ from/ [the] household ofH1004
  10. אָבִ֑י/ךָ'a.Vi./khafather/ yourH1
  11. אֶל\־'el-toH413
  12. הָ/אָ֖רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  13. אֲשֶׁ֥ר'a.SherwhichH834
  14. אַרְאֶֽ/ךָּ\׃'ar.'E./kaI will show/ youH7200
2
  1. וְ/אֶֽעֶשְׂ/ךָ֙ve./'e.'es./Khaso/ I may make/ youH6213
  2. לְ/ג֣וֹיle./Goyinto/ a nationH1471
  3. גָּד֔וֹלga.DolgreatH1419
  4. וַ/אֲבָ֣רֶכְ/ךָ֔va./'a.Va.rekh./khaand/ I will bless/ youH1288
  5. וַ/אֲגַדְּלָ֖הva./'a.ga.de.Lahand/ I will make greatH1431
  6. שְׁמֶ֑/ךָshe.Me./khaname/ yourH8034
  7. וֶ/הְיֵ֖הve/h.Yehand/ you beH1961
  8. בְּרָכָֽה\׃be.ra.Khaha blessingH1293
3
  1. וַ/אֲבָֽרֲכָה֙va./'a.va.ra.Khahso/ let me blessH1288
  2. מְבָ֣רְכֶ֔י/ךָme.Va.re.Khei./khaH1288
  3. וּ/מְקַלֶּלְ/ךָ֖u./me.ka.lel./Chaand/ [one who] disdains/ youH7043
  4. אָאֹ֑ר'a.'OrI will curseH779
  5. וְ/נִבְרְכ֣וּve./niv.re.Khuand/ they will be blessedH1288
  6. בְ/ךָ֔ve./Khaby <the>/ youH9031
  7. כֹּ֖לkolallH3605
  8. מִשְׁפְּחֹ֥תmish.pe.ChotH4940
  9. הָ/אֲדָמָֽה\׃ha./'a.da.Mahthe/ earthH127
4
  1. וַ/יֵּ֣לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  2. אַבְרָ֗ם'av.RamAbramH87
  3. כַּ/אֲשֶׁ֨רka./'a.Sherjust/ asH834
  4. דִּבֶּ֤רdi.Berhe had saidH1696
  5. אֵלָי/ו֙'e.La/vto/ himH413
  6. יְהוָ֔הYah.wehYahwehH3068
  7. וַ/יֵּ֥לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  8. אִתּ֖/וֹ'i.T/owith/ himH854
  9. ל֑וֹטLotLotH3876
  10. וְ/אַבְרָ֗םve./'av.Ramand/ AbramH87
  11. בֶּן\־ben-H1121
  12. חָמֵ֤שׁcha.MeshfiveH2568
  13. שָׁנִים֙sha.NimyearsH8141
  14. וְ/שִׁבְעִ֣יםve./shiv.'Imand/ seventyH7657
  15. שָׁנָ֔הsha.Nahyear[s]H8141
  16. בְּ/צֵאת֖/וֹbe./tze.T/owhen/ came out/ heH3318
  17. מֵ/חָרָֽן\׃me./cha.Ranfrom/ HaranH2771
5
  1. וַ/יִּקַּ֣חva/i.yi.Kachand/ he tookH3947
  2. אַבְרָם֩'av.RamAbramH87
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. שָׂרַ֨יsa.RaiSaraiH8297
  5. אִשְׁתּ֜/וֹ'ish.T/owife/ hisH802
  6. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  7. ל֣וֹטLotLotH3876
  8. בֶּן\־ben-H1121
  9. אָחִ֗י/ו'a.Chi/vbrother/ hisH251
  10. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  11. כָּל\־kol-allH3605
  12. רְכוּשָׁ/ם֙re.khu.Sha/mpossession[s]/ theirH7399
  13. אֲשֶׁ֣ר'a.SherwhichH834
  14. רָכָ֔שׁוּra.Kha.shuthey had accumulatedH7408
  15. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  16. הַ/נֶּ֖פֶשׁha./Ne.feshthe/ person[s]H5315
  17. אֲשֶׁר\־'a.Sher-whomH834
  18. עָשׂ֣וּ'a.Suthey had acquiredH6213
  19. בְ/חָרָ֑ןve./cha.Ranin/ HaranH2771
  20. וַ/יֵּצְא֗וּva/i.ye.tze.'Uand/ they went outH3318
  21. לָ/לֶ֙כֶת֙la./Le.khetto/ goH1980
  22. אַ֣רְצָ/ה'Ar.tza/hH776
  23. כְּנַ֔עַןke.Na.'anCanaanH3667
  24. וַ/יָּבֹ֖אוּva/i.ya.Vo.'uand/ they cameH935
  25. אַ֥רְצָ/ה'Ar.tza/hH776
  26. כְּנָֽעַן\׃ke.Na.'anCanaanH3667
6
  1. וַ/יַּעֲבֹ֤רva/i.ya.'a.Vorand/ he passedH5674
  2. אַבְרָם֙'av.RamAbramH87
  3. בָּ/אָ֔רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  4. עַ֚ד'adtoH5704
  5. מְק֣וֹםme.KomH4725
  6. שְׁכֶ֔םshe.KhemShechemH7927
  7. עַ֖ד'adtoH5704
  8. אֵל֣וֹן'e.LonH436
  9. מוֹרֶ֑הmo.RehMorehH4176
  10. וְ/הַֽ/כְּנַעֲנִ֖יve./ha./ke.na.'a.Niand/ the/ Canaanite[s]H3669
  11. אָ֥ז'azthenH227
  12. בָּ/אָֽרֶץ\׃ba./'A.retzH776
7
  1. וַ/יֵּרָ֤אva/i.ye.Ra'and/ he appearedH7200
  2. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  3. אֶל\־'el-toH413
  4. אַבְרָ֔ם'av.RamAbramH87
  5. וַ/יֹּ֕אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  6. לְ/זַ֨רְעֲ/ךָ֔le./Zar.'a./khato/ offspring/ yourH2233
  7. אֶתֵּ֖ן'e.TenI will giveH5414
  8. אֶת\־'et-<obj.>H853
  9. הָ/אָ֣רֶץha./'A.retzthe/ landH776
  10. הַ/זֹּ֑אתha./Zot<the>/ thisH2063
  11. וַ/יִּ֤בֶןva/i.Yi.venand/ he builtH1129
  12. שָׁם֙shamthereH8033
  13. מִזְבֵּ֔חַmiz.Be.achan altarH4196
  14. לַ/יהוָ֖הla./Yah.wehto/ YahwehH3068
  15. הַ/נִּרְאֶ֥הha./nir.'Ehwho/ had appearedH7200
  16. אֵלָֽי/ו\׃'e.La/vto/ himH413
8
  1. וַ/יַּעְתֵּ֨קva/i.ya'.Tekand/ he moved onH6275
  2. מִ/שָּׁ֜םmi./Shamfrom/ thereH8033
  3. הָ/הָ֗רָ/הha./Ha.ra/hthe/ hill country/ towardsH2022
  4. מִ/קֶּ֛דֶםmi./Ke.demfrom/ [the] eastH6924
  5. לְ/בֵֽית\־le./veit-of/ Beth-H1008
  6. אֵ֖ל'el-elH1008
  7. וַ/יֵּ֣טva/i.Yetand/ he pitchedH5186
  8. אָהְָל֑/וֹ'o.ho.L/otent/ hisH168
  9. בֵּֽית\־beit-Beth-H1008
  10. אֵ֤ל'el-elH1008
  11. מִ/יָּם֙mi./YamH3220
  12. וְ/הָ/עַ֣יve./ha./'Aiand/ <the>/ AiH5857
  13. מִ/קֶּ֔דֶםmi./Ke.demH6924
  14. וַ/יִּֽבֶן\־va/i.yi.ven-and/ he builtH1129
  15. שָׁ֤םshamthereH8033
  16. מִזְבֵּ֙חַ֙miz.Be.achan altarH4196
  17. לַֽ/יהוָ֔הla./Yah.wehto/ YahwehH3068
  18. וַ/יִּקְרָ֖אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  19. בְּ/שֵׁ֥םbe./Shemon/ [the] name ofH8034
  20. יְהוָֽה\׃Yah.wehYahwehH3068
9
  1. וַ/יִּסַּ֣עva/i.yi.Sa'and/ he journeyedH5265
  2. אַבְרָ֔ם'av.RamAbramH87
  3. הָל֥וֹךְha.LokhgoingH1980
  4. וְ/נָס֖וֹעַve./na.So.a'and/ journeyingH5265
  5. הַ/נֶּֽגְבָּ/ה\׃\ \פha./Neg.ba/hthe/ south/ towardsH5045
10
  1. וַ/יְהִ֥יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. רָעָ֖בra.'Ava famineH7458
  3. בָּ/אָ֑רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  4. וַ/יֵּ֨רֶדva/i.Ye.redand/ he went downH3381
  5. אַבְרָ֤ם'av.RamAbramH87
  6. מִצְרַ֙יְמָ/ה֙mitz.Ray.ma/hEgypt/ towardsH4714
  7. לָ/ג֣וּרla./Gurto/ sojournH1481
  8. שָׁ֔םShamthereH8033
  9. כִּֽי\־ki-forH3588
  10. כָבֵ֥דkha.VedH3515
  11. הָ/רָעָ֖בha./ra.'Avthe/ famineH7458
  12. בָּ/אָֽרֶץ\׃ba./'A.retzin the/ landH776
11
  1. וַ/יְהִ֕יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. כַּ/אֲשֶׁ֥רka./'a.Sherjust/ asH834
  3. הִקְרִ֖יבhik.Rivhe drew nearH7126
  4. לָ/ב֣וֹאla./Vo'to/ enterH935
  5. מִצְרָ֑יְמָ/הmitz.Ra.ye.ma/hEgypt/ <towards>H4714
  6. וַ/יֹּ֙אמֶר֙va/i.Yo.merand/ he saidH559
  7. אֶל\־'el-toH413
  8. שָׂרַ֣יsa.RaiSaraiH8297
  9. אִשְׁתּ֔/וֹ'ish.T/owife/ hisH802
  10. הִנֵּה\־hi.neh-here!H2009
  11. נָ֣אna'pleaseH4994
  12. יָדַ֔עְתִּיya.Da'.tiI knowH3045
  13. כִּ֛יkithatH3588
  14. אִשָּׁ֥ה'i.ShahH802
  15. יְפַת\־ye.fat-beautiful ofH3303
  16. מַרְאֶ֖הmar.'EhappearanceH4758
  17. אָֽתְּ\׃'AtyouH859
12
  1. וְ/הָיָ֗הve./ha.Yahand/ it will beH1961
  2. כִּֽי\־ki-thatH3588
  3. יִרְא֤וּyir.'Uthey will seeH7200
  4. אֹתָ/ךְ֙'o.to/Kh<obj.>/ youH853
  5. הַ/מִּצְרִ֔יםha./mitz.Rimthe/ EgyptiansH4713
  6. וְ/אָמְר֖וּve./'a.me.Ruand/ they will sayH559
  7. אִשְׁתּ֣/וֹ'ish.T/oH802
  8. זֹ֑אתZotthisH2063
  9. וְ/הָרְג֥וּve./ha.re.Guand/ they will killH2026
  10. אֹתִ֖/י'o.T/i<obj.>/ meH853
  11. וְ/אֹתָ֥/ךְve./'o.Ta/khand/ <obj.>/ youH853
  12. יְחַיּֽוּ\׃ye.chai.Yuthey will let liveH2421
13
  1. אִמְרִי\־'im.ri-sayH559
  2. נָ֖אna'pleaseH4994
  3. אֲחֹ֣תִ/י'a.Cho.t/iH269
  4. אָ֑תְּ'AtyouH859
  5. לְמַ֙עַן֙le.Ma.'anso thatH4616
  6. יִֽיטַב\־yi.tav-it may go wellH3190
  7. לִ֣/יl/ifor <the>/ meH9030
  8. בַ/עֲבוּרֵ֔/ךְva./'a.vu.Re/khfor/ sake of/ youH5668
  9. וְ/חָיְתָ֥הve./cha.ye.Tahand/ it will liveH2421
  10. נַפְשִׁ֖/יnaf.Sh/ilife/ myH5315
  11. בִּ/גְלָלֵֽ/ךְ\׃bi/g.la.Le/khon/ account of/ youH1558
14
  1. וַ/יְהִ֕יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. כְּ/ב֥וֹאke./Vo'when/ enteredH935
  3. אַבְרָ֖ם'av.RamAbramH87
  4. מִצְרָ֑יְמָ/הmitz.Ra.ye.ma/hEgypt/ <towards>H4714
  5. וַ/יִּרְא֤וּva/i.yir.'Uand/ they sawH7200
  6. הַ/מִּצְרִים֙ha./mitz.Rimthe/ EgyptiansH4713
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. הָ֣/אִשָּׁ֔הha./'i.Shahthe/ womanH802
  9. כִּֽי\־ki-thatH3588
  10. יָפָ֥הya.FahH3303
  11. הִ֖ואhi'sheH1931
  12. מְאֹֽד\׃me.'OdveryH3966
15
  1. וַ/יִּרְא֤וּva/i.yir.'Uand/ they sawH7200
  2. אֹתָ/הּ֙'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  3. שָׂרֵ֣יsa.ReiH8269
  4. פַרְעֹ֔הfar.'OhPharaohH6547
  5. וַ/יְהַֽלְל֥וּva/y.ha.Luand/ they praisedH1984
  6. אֹתָ֖/הּ'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  7. אֶל\־'el-toH413
  8. פַּרְעֹ֑הpar.'OhPharaohH6547
  9. וַ/תֻּקַּ֥חva./tu.Kachand/ she was takenH3947
  10. הָ/אִשָּׁ֖הha./'i.Shahthe/ womanH802
  11. בֵּ֥יתbeitH1004
  12. פַּרְעֹֽה\׃par.'OhPharaohH6547
16
  1. וּ/לְ/אַבְרָ֥םu/l./'av.Ramand/ to/ AbramH87
  2. הֵיטִ֖יבhei.Tivhe did goodH3190
  3. בַּ/עֲבוּרָ֑/הּba./'a.vu.Ra/hfor/ sake of/ herH5668
  4. וַֽ/יְהִי\־va/y.hi-and/ it be[longed]H1961
  5. ל֤/וֹl/oto <the>/ himH9033
  6. צֹאן\־tzon-sheepH6629
  7. וּ/בָקָר֙u./va.Karand/ cattleH1241
  8. וַ/חֲמֹרִ֔יםva./cha.mo.Rimand/ [male] donkeysH2543
  9. וַ/עֲבָדִים֙va./'a.va.Dimand/ [male] servantsH5650
  10. וּ/שְׁפָחֹ֔תu./she.fa.Chotand/ female servantsH8198
  11. וַ/אֲתֹנֹ֖תva./'a.to.Notand/ female donkeysH860
  12. וּ/גְמַלִּֽים\׃u./ge.ma.Limand/ camelsH1581
17
  1. וַ/יְנַגַּ֨עva/y.na.Ga'and/ he struckH5060
  2. יְהוָ֧ה\׀Yah.wehYahwehH3068
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. פַּרְעֹ֛הpar.'OhPharaohH6547
  5. נְגָעִ֥יםne.ga.'ImplaguesH5061
  6. גְּדֹלִ֖יםge.do.LimgreatH1419
  7. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  8. בֵּית֑/וֹbei.T/ohouse/ hisH1004
  9. עַל\־'al-onH5921
  10. דְּבַ֥רde.VarH1697
  11. שָׂרַ֖יsa.RaiSaraiH8297
  12. אֵ֥שֶׁת'E.shetH802
  13. אַבְרָֽם\׃'av.RamAbramH87
18
  1. וַ/יִּקְרָ֤אva/i.yik.Ra'and/ he summonedH7121
  2. פַרְעֹה֙far.'OhPharaohH6547
  3. לְ/אַבְרָ֔םle./'av.Ram<to>/ AbramH87
  4. וַ/יֹּ֕אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  5. מַה\־mah-what?H4100
  6. זֹּ֖אתzotthisH2063
  7. עָשִׂ֣יתָ'a.Si.tahave you doneH6213
  8. לִּ֑/יL/ito <the>/ meH9030
  9. לָ֚/מָּהLa./mah<to>/ why?H4100
  10. לֹא\־lo'-notH3808
  11. הִגַּ֣דְתָּhi.Gad.tadid you tellH5046
  12. לִּ֔/יL/ito <the>/ meH9030
  13. כִּ֥יkithatH3588
  14. אִשְׁתְּ/ךָ֖'ish.te./KhaH802
  15. הִֽוא\׃hi'sheH1931
19
  1. לָ/מָ֤הla./Mah<to>/ why?H4100
  2. אָמַ֙רְתָּ֙'a.Mar.tadid you sayH559
  3. אֲחֹ֣תִ/י'a.Cho.t/iH269
  4. הִ֔ואhi'sheH1931
  5. וָ/אֶקַּ֥חva./'e.Kachand/ I tookH3947
  6. אֹתָ֛/הּ'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  7. לִ֖/יl/ifor <the>/ myselfH9030
  8. לְ/אִשָּׁ֑הle./'i.Shahto/ a wifeH802
  9. וְ/עַתָּ֕הve./'a.Tahand/ nowH6258
  10. הִנֵּ֥הhi.Nehhere!H2009
  11. אִשְׁתְּ/ךָ֖'ish.te./Khawife/ yourH802
  12. קַ֥חkachtake [her]H3947
  13. וָ/לֵֽךְ\׃va./Lekhand/ goH1980
20
  1. וַ/יְצַ֥וva/y.Tzavand/ he commandedH6680
  2. עָלָ֛י/ו'a.La/von/ himH5921
  3. פַּרְעֹ֖הpar.'OhPharaohH6547
  4. אֲנָשִׁ֑ים'a.na.ShimmenH582
  5. וַֽ/יְשַׁלְּח֥וּva/y.sha.le.Chuand/ they sent awayH7971
  6. אֹת֛/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  7. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  8. אִשְׁתּ֖/וֹ'ish.T/owife/ hisH802
  9. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  10. כָּל\־kol-allH3605
  11. אֲשֶׁר\־'a.Sher-thatH834
  12. לֽ/וֹ\׃l/oH9033

View the full Hebrew interlinear for Genesis 12 →

Strong's words in Genesis 12 (6)
Strong's H87 — אַבְרָ֔ם ('av.Ram)
Abram. Appears 12 times in Genesis 12.
Strong's H802 — אִשְׁתּ֜/וֹ ('ish.T/o)
wife/ his. Appears 11 times in Genesis 12.
Strong's H776 — מֵ/אַרְצְ/ךָ֥ (me./'ar.tze./Kha)
from/ land/ your. Appears 9 times in Genesis 12.
Strong's H3068 — יְהוָה֙ (Yah.weh)
Yahweh. Appears 7 times in Genesis 12.
Strong's H559 — וַ/יֹּ֤אמֶר (va/i.Yo.mer)
and/ he said. Appears 7 times in Genesis 12.
Strong's H1961 — וֶ/הְיֵ֖ה (ve/h.Yeh)
and/ you be. Appears 6 times in Genesis 12.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress