Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Genesis 29 Language Awori Bible ID YORDOA Label DOA Catalog Awori - Diocese of Awori, Church of Nigeria, Anglican Communion Available audio Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Jakọbu sì tẹ̀síwájú nínú ìrìnàjò rẹ̀, ó sì dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà-oòrùn.
2 Ó sì rí kànga kan ní pápá, agbo àgùntàn mẹ́ta sì dúró láti mu omi ní ibi kànga náà, nítorí pé láti inú kànga náà ni wọ́n ti ń fi omi fún agbo àgùntàn. Òkúta tí a gbé dí ẹnu kànga náà sì tóbi gidigidi.
3 Nígbà tí gbogbo agbo ẹran bá péjọpọ̀ sí ibẹ̀ tán ni àwọn darandaran yóò tó yí òkúta náà kúrò, tí wọn yóò sì fún àwọn ẹran náà ní omi, tí wọ́n bá sì ti ṣe bẹ́ẹ̀ tán, wọn yóò tún yí òkúta náà padà sí ẹnu kànga náà.
4 Jakọbu béèrè lọ́wọ́ àwọn darandaran náà pé, “Ẹ̀yin arákùnrin mi níbo ni ẹ̀yin ti wá?” Àwọn náà sì dáhùn pé, “Láti Harani ni.”
5 Ó sì bi wọ́n pé, “Ǹjẹ́ ẹ mọ Labani ọmọ ọmọ Nahori?” Wọ́n sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àwa mọ̀ ọ́n.”
6 Jakọbu béèrè pé, “Ṣe àlàáfíà ni ó wà?” Wọ́n sì dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, àlàáfíà ni. Wò ó, Rakeli ọmọ rẹ̀ ni ó ń bọ̀ yìí pẹ̀lú agbo àgùntàn.”
7 Ó sì wí pé, “Kíyèsi, ilẹ̀ ò tí ì ṣú, kò tì í tó àkókò fún àwọn ohun ọ̀sìn láti wọ̀. Ẹ fún àwọn ẹran wọ̀nyí ní omi, kí ẹ ba à le tètè dà wọ́n padà láti jẹun.”
8 Wọ́n dá a lóhùn pé, “Àwa kì í yí òkúta kúrò ní ẹnu kànga láti pọn omi fún àwọn ẹran títí gbogbo àwọn darandaran àti àwọn ẹran yóò fi péjọ tán.”
9 Bí wọ́n sì ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́ ni Rakeli dé pẹ̀lú agbo àgùntàn baba rẹ̀, nítorí darandaran ni òun náà.
10 Nígbà tí Jakọbu rí Rakeli ọmọbìnrin Labani tí í ṣe ẹ̀gbọ́n ìyá rẹ̀, pẹ̀lú àgùntàn Labani, Jakọbu súnmọ́ kànga náà, ó sì yí òkúta kúrò lẹ́nu rẹ̀, ó sì fún àwọn ẹran arákùnrin ìyá rẹ̀ Labani ní omi.
11 Jakọbu sì fẹnu ko Rakeli ní ẹnu. Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọkún.
12 Jakọbu sì wí fún Rakeli pé ìbátan baba rẹ̀ ni òun, àti pé, òun jẹ́ ọmọ Rebeka. Rakeli sì sáré lọ sọ fún baba rẹ̀.
13 Ní kété tí Labani gbúròó Jakọbu ọmọ arábìnrin rẹ̀, ó jáde lọ pàdé Jakọbu, ó dì mọ́ ọn, ó fi ẹnu kò ó ní ẹnu, ó sì mú un lọ sí ilé. Nígbà náà ni Jakọbu ròyìn ohun gbogbo fún un.
14 Labani sì wí pé, “Ẹran-ara àti ẹ̀jẹ̀ ara mi ni ìwọ jẹ́.” Lẹ́yìn tí Jakọbu sì wà pẹ̀lú rẹ̀ fún odidi oṣù kan,
15 Labani wí fún Jakọbu pé, “Bí a tilẹ̀ jẹ́ ìbátan, kò yẹ kí o máa ṣiṣẹ́ fún mi lásán láìgba ohun kankan. Sọ ohun tì ìwọ fẹ́ gbà fún iṣẹ́ tí ìwọ ń ṣe fún mi!”
16 Wàyí o, Labani ní ọmọbìnrin méjì, orúkọ èyí ẹ̀gbọ́n ń jẹ́ Lea, orúkọ àbúrò sì ń jẹ́ Rakeli.
17 Lea kò ní ẹwà púpọ̀, ṣùgbọ́n Rakeli ní ẹwà gidigidi. Ojú rẹ̀ sì fanimọ́ra.
18 Jakọbu sì fẹ́ràn Rakeli, ó sì wí fún baba rẹ̀ pé, “Èmi yóò ṣiṣẹ́ sìn ọ fún ọdún méje, bí ìwọ yóò bá fún mi ní Rakeli ọmọ rẹ ní aya.”
19 Labani sì dáhùn wí pé, “Ó kúkú sàn kí ń fi fún ọ, ju kí ń fi fún ẹlòmíràn lọ, nítorí náà wà ní ọ̀dọ̀ mi.”
20 Jakọbu sì ṣiṣẹ́ sin Labani fún ọdún méje láti fẹ́ Rakeli. Àwọn ọdún wọ̀nyí sì dàbí ọjọ́ díẹ̀ lára rẹ̀, nítorí ó fẹ́ràn rẹ̀.
21 Jakọbu sì wí fún Labani pé, “Mo ti parí àsìkò tí a jọ ṣe àdéhùn rẹ̀, nítorí náà fún mi ní aya mi, kí òun lè ṣe aya fún mi.”
22 Labani sì pe gbogbo ènìyàn ibẹ̀ jọ, ó sì ṣe àsè ìyàwó fún wọ́n.
23 Ṣùgbọ́n nígbà tí ó di òru, Labani mú Lea tọ Jakọbu lọ. Jakọbu sì bá a lòpọ̀.
24 Labani sì fi Silipa ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin fún Lea gẹ́gẹ́ bí ìránṣẹ́.
25 Sì kíyèsi, nígbà ti ilẹ̀ mọ́, Jakọbu rí i pé Lea ni! Ó sì wí fún Labani pé, “Èwo ni ìwọ ṣe sí mi yìí? Ṣe bí nítorí Rakeli ni mo ṣe ṣiṣẹ́ sìn ọ, èéṣe tí ìwọ tàn mi?”
26 Labani sì dáhùn pé, “Kò bá àṣà wa mu láti fi àbúrò fún ọkọ ṣáájú ẹ̀gbọ́n rẹ̀.
27 Mú sùúrù parí ọ̀sẹ̀ ìgbéyàwó yìí náà, nígbà náà ni èmi yóò fi àbúrò rẹ̀ fún ọ pẹ̀lú, bí ìwọ ó bá ṣiṣẹ́ sìn mi fún ọdún méje mìíràn.”
28 Jakọbu sì gbà láti sin Labani fún ọdún méje mìíràn. Labani sì fi Rakeli ọmọ rẹ̀ fún un bí aya.
29 Labani sì fi Biliha ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ obìnrin fún Rakeli bí ìránṣẹ́.
30 Jakọbu sì bá Rakeli náà lòpọ̀. Ó sì fẹ́ràn Rakeli ju Lea lọ, ó sì ṣiṣẹ́ sin Labani fún ọdún méje mìíràn.
31 Nígbà tí Olúwa sì ri pé, Jakọbu kò fẹ́ràn Lea, ó ṣí i ni inú ṣùgbọ́n Rakeli yàgàn.
32 Lea sì lóyún, ó sì bí ọmọkùnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Reubeni, nítorí ó wí pé, “Nítorí Olúwa ti mọ ìpọ́njú mi, dájúdájú, ọkọ mi yóò fẹ́ràn mi báyìí.”
33 Ó sì tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan. Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Simeoni, wí pé, “Nítorí tí Olúwa ti gbọ́ pé a kò fẹ́ràn mi, ó sì fi èyí fún mi pẹ̀lú.”
34 Ó sì tún lóyún, ó bí ọmọkùnrin kan, ó sì wí pé, “Nígbà yìí ni ọkọ mi yóò fi ara mọ́ mi, nítorí tí mo ti bí ọmọkùnrin mẹ́ta fún un,” nítorí náà ni ó ṣe pe orúkọ rẹ̀ ní Lefi.
35 Ó sì tún lóyún, ó sì tún jẹ́ pé ọmọkùnrin ni ó bí, ó sì wí pé, “Nígbà yìí ni èmi yóò yin Olúwa.” Ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Juda. Ó sì dáwọ́ ọmọ bíbí dúró.
Chapter information and study resources

Listen to Genesis 29 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Genesis 29

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Genesis 29. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Genesis 29 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references.

Cross-references in Genesis 29 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Genesis 29:1–35 (471 words)
1
  1. וַ/יִּשָּׂ֥אva/i.yi.Sa'and/ he lifted upH5375
  2. יַעֲקֹ֖בya.'a.KoJacobH3290
  3. רַגְלָ֑י/וrag.La/vfeet/ hisH7272
  4. וַ/יֵּ֖לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  5. אַ֥רְצָ/ה'Ar.tza/hH776
  6. בְנֵי\־ve.nei-H1121
  7. קֶֽדֶם\׃Ke.demH6924
2
  1. וַ/יַּ֞רְאva/i.Yar'and/ he sawH7200
  2. וְ/הִנֵּ֧הve./hi.Nehand/ there!H2009
  3. בְאֵ֣רve.'Era wellH875
  4. בַּ/שָּׂדֶ֗הba./sa.DehH7704
  5. וְ/הִנֵּה\־ve./hi.neh-and/ there!H2009
  6. שָׁ֞םshamthereH8033
  7. שְׁלֹשָׁ֤הshe.lo.ShahthreeH7969
  8. עֶדְרֵי\־'ed.rei-flocks ofH5739
  9. צֹאן֙tzoNsheepH6629
  10. רֹבְצִ֣יםroe.TzimH7257
  11. עָלֶ֔י/הָ'a.Lei./haat/ itH5921
  12. כִּ֚יkiforH3588
  13. מִן\־min-fromH4480
  14. הַ/בְּאֵ֣רha./be.'Erthe/ wellH875
  15. הַ/הִ֔ואha./Hiv'<the>/ thatH1931
  16. יַשְׁק֖וּyash.Kupeople wateredH8248
  17. הָ/עֲדָרִ֑יםha./'a.da.Rimthe/ flocksH5739
  18. וְ/הָ/אֶ֥בֶןve./ha./'E.venand/ the/ stoneH68
  19. גְּדֹלָ֖הge.do.LahH1419
  20. עַל\־'al-overH5921
  21. פִּ֥יpiH6310
  22. הַ/בְּאֵֽר\׃ha./be.'Erthe/ wellH875
3
  1. וְ/נֶאֶסְפוּ\־ve./ne.'es.fu-and/ they were gatheredH622
  2. שָׁ֣מָּ/הSha.ma/hthere/ towardsH8033
  3. כָל\־khol-allH3605
  4. הָ/עֲדָרִ֗יםha./'a.da.Rimthe/ flocksH5739
  5. וְ/גָלֲל֤וּve./ga.la.Luand/ they rolledH1556
  6. אֶת\־'et-<obj.>H853
  7. הָ/אֶ֙בֶן֙ha./'E.venthe/ stoneH68
  8. מֵ/עַל֙me./'Alfrom/ overH5921
  9. פִּ֣יpiH6310
  10. הַ/בְּאֵ֔רha./be.'Erthe/ wellH875
  11. וְ/הִשְׁק֖וּve./hish.Kuand/ they wateredH8248
  12. אֶת\־'et-<obj.>H853
  13. הַ/צֹּ֑אןha./Tzonthe/ sheepH6629
  14. וְ/הֵשִׁ֧יבוּve./he.Shi.vuand/ they put backH7725
  15. אֶת\־'et-<obj.>H853
  16. הָ/אֶ֛בֶןha./'E.venthe/ stoneH68
  17. עַל\־'al-overH5921
  18. פִּ֥יpiH6310
  19. הַ/בְּאֵ֖רha./be.'Erthe/ wellH875
  20. לִ/מְקֹמָֽ/הּ\׃li/m.ko.Ma/hto/ place/ itsH4725
4
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָ/הֶם֙la./Hemto <the>/ themH9038
  3. יַעֲקֹ֔בya.'a.KoJacobH3290
  4. אַחַ֖/י'a.Cha/iO brothers/ myH251
  5. מֵ/אַ֣יִןme./'A.yinfrom/ where?H370
  6. אַתֶּ֑ם'a.TemH859
  7. וַ/יֹּ֣אמְר֔וּva/i.Yo.me.Ruand/ they saidH559
  8. מֵ/חָרָ֖ןme./cha.RanH2771
  9. אֲנָֽחְנוּ\׃'a.Na.che.nuweH587
5
  1. וַ/יֹּ֣אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָ/הֶ֔םla./Hemto <the>/ themH9038
  3. הַ/יְדַעְתֶּ֖םha/y.da'.Tem¿/ do you knowH3045
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. לָבָ֣ןla.VanLabanH3837
  6. בֶּן\־ben-H1121
  7. נָח֑וֹרna.ChorNahorH5152
  8. וַ/יֹּאמְר֖וּva/i.yo.me.Ruand/ they saidH559
  9. יָדָֽעְנוּ\׃ya.Da.'e.nuwe know [him]H3045
6
  1. וַ/יֹּ֥אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָ/הֶ֖םla./Hemto <the>/ themH9038
  3. הֲ/שָׁל֣וֹםha./sha.Lom¿/ [does] healthH7965
  4. ל֑/וֹl/oH9033
  5. וַ/יֹּאמְר֣וּva/i.yo.me.Ruand/ they saidH559
  6. שָׁל֔וֹםsha.LomhealthH7965
  7. וְ/הִנֵּה֙ve./hi.Nehand/ there!H2009
  8. רָחֵ֣לra.ChelRachelH7354
  9. בִּתּ֔/וֹbi.T/odaughter/ hisH1323
  10. בָּאָ֖הba.'AhH935
  11. עִם\־'im-withH5973
  12. הַ/צֹּֽאן\׃ha./Tzonthe/ sheepH6629
7
  1. וַ/יֹּ֗אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. הֵ֥ןhenhere!H2005
  3. עוֹד֙'OdstillH5750
  4. הַ/יּ֣וֹםhai./Yomthe/ dayH3117
  5. גָּד֔וֹלga.DolH1419
  6. לֹא\־lo'-notH3808
  7. עֵ֖ת'etH6256
  8. הֵאָסֵ֣ףhe.'a.SefH622
  9. הַ/מִּקְנֶ֑הha./mik.Nehthe/ livestockH4735
  10. הַשְׁק֥וּhash.KuwaterH8248
  11. הַ/צֹּ֖אןha./Tzonthe/ sheepH6629
  12. וּ/לְכ֥וּu./le.Khuand/ goH1980
  13. רְעֽוּ\׃re.'Upasture [them]H7462
8
  1. וַ/יֹּאמְרוּ֮va/i.yo.me.Ruand/ they saidH559
  2. לֹ֣אlo'notH3808
  3. נוּכַל֒nu.Khalwe are ableH3201
  4. עַ֣ד'aduntilH5704
  5. אֲשֶׁ֤ר'a.SherthatH834
  6. יֵאָֽסְפוּ֙ye.'a.se.Futhey will be gatheredH622
  7. כָּל\־kol-allH3605
  8. הָ֣/עֲדָרִ֔יםha./'a.da.Rimthe/ flocksH5739
  9. וְ/גָֽלֲלוּ֙ve./ga.la.Luand/ people will rollH1556
  10. אֶת\־'et-<obj.>H853
  11. הָ/אֶ֔בֶןha./'E.venthe/ stoneH68
  12. מֵ/עַ֖לme./'Alfrom/ overH5921
  13. פִּ֣יpiH6310
  14. הַ/בְּאֵ֑רha./be.'Erthe/ wellH875
  15. וְ/הִשְׁקִ֖ינוּve./hish.Ki.nuand/ we will waterH8248
  16. הַ/צֹּֽאן\׃ha./Tzonthe/ sheepH6629
9
  1. עוֹדֶ֖/נּוּo.De./nustill [was]/ heH5750
  2. מְדַבֵּ֣רme.da.BerspeakingH1696
  3. עִמָּ֑/ם'i.Ma/mwith/ themH5973
  4. וְ/רָחֵ֣ל\׀ve./ra.Cheland/ RachelH7354
  5. בָּ֗אָהBa.'ahshe cameH935
  6. עִם\־'im-withH5973
  7. הַ/צֹּאן֙ha./tzoNthe/ sheepH6629
  8. אֲשֶׁ֣ר'a.SherwhichH834
  9. לְ/אָבִ֔י/הָle./'a.Vi./haH1
  10. כִּ֥יkiforH3588
  11. רֹעָ֖הro.'AhH7462
  12. הִֽוא\׃hi'sheH1931
10
  1. וַ/יְהִ֡יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. כַּ/אֲשֶׁר֩ka./'a.Sherjust/ asH834
  3. רָאָ֨הra.'Ahhe sawH7200
  4. יַעֲקֹ֜בya.'a.KoJacobH3290
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. רָחֵ֗לra.ChelRachelH7354
  7. בַּת\־bat-H1323
  8. לָבָן֙la.VanLabanH3837
  9. אֲחִ֣י'a.ChiH251
  10. אִמּ֔/וֹ'i.M/omother/ hisH517
  11. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  12. צֹ֥אןtzonH6629
  13. לָבָ֖ןla.VanLabanH3837
  14. אֲחִ֣י'a.ChiH251
  15. אִמּ֑/וֹ'i.M/omother/ hisH517
  16. וַ/יִּגַּ֣שׁva/i.yi.Gashand/ he drew nearH5066
  17. יַעֲקֹ֗בya.'a.KoJacobH3290
  18. וַ/יָּ֤גֶלva/i.Ya.geland/ he rolledH1556
  19. אֶת\־'et-<obj.>H853
  20. הָ/אֶ֙בֶן֙ha./'E.venthe/ stoneH68
  21. מֵ/עַל֙me./'Alfrom/ overH5921
  22. פִּ֣יpiH6310
  23. הַ/בְּאֵ֔רha./be.'Erthe/ wellH875
  24. וַ/יַּ֕שְׁקְva/i.Yashkand/ he wateredH8248
  25. אֶת\־'et-<obj.>H853
  26. צֹ֥אןtzonH6629
  27. לָבָ֖ןla.VanLabanH3837
  28. אֲחִ֥י'a.ChiH251
  29. אִמּֽ/וֹ\׃'i.M/omother/ hisH517
11
  1. וַ/יִּשַּׁ֥קva/i.yi.Shakand/ he kissedH5401
  2. יַעֲקֹ֖בya.'a.KoJacobH3290
  3. לְ/רָחֵ֑לle./ra.Chel<to>/ RachelH7354
  4. וַ/יִּשָּׂ֥אva/i.yi.Sa'and/ he lifted upH5375
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. קֹל֖/וֹko.L/ovoice/ hisH6963
  7. וַ/יֵּֽבְךְּ\׃va/i.Ye.vekand/ he weptH1058
12
  1. וַ/יַּגֵּ֨דva/i.ya.Gedand/ he toldH5046
  2. יַעֲקֹ֜בya.'a.KoJacobH3290
  3. לְ/רָחֵ֗לle./ra.Chelto/ RachelH7354
  4. כִּ֣יkithatH3588
  5. אֲחִ֤י'a.ChiH251
  6. אָבִ֙י/הָ֙'a.Vi./hafather/ herH1
  7. ה֔וּאHu'heH1931
  8. וְ/כִ֥יve./Khiand/ thatH3588
  9. בֶן\־ven-H1121
  10. רִבְקָ֖הriv.KahRebekahH7259
  11. ה֑וּאHu'heH1931
  12. וַ/תָּ֖רָץva./Ta.rotzand/ she ranH7323
  13. וַ/תַּגֵּ֥דva./ta.Gedand/ she toldH5046
  14. לְ/אָבִֽי/הָ\׃le./'a.Vi./hato/ father/ herH1
13
  1. וַ/יְהִי֩va/y.Hiand/ it wasH1961
  2. כִ/שְׁמֹ֨עַkhi/sh.Mo.a'when/ heardH8085
  3. לָבָ֜ןla.VanLabanH3837
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. שֵׁ֣מַע\׀She.ma'H8088
  6. יַעֲקֹ֣בya.'a.KoJacobH3290
  7. בֶּן\־ben-H1121
  8. אֲחֹת֗/וֹ'a.cho.T/osister/ hisH269
  9. וַ/יָּ֤רָץva/i.Ya.rotzand/ he ranH7323
  10. לִ/קְרָאת/וֹ֙li/k.ra.T/oto/ meet/ himH7122
  11. וַ/יְחַבֶּק\־va/y.cha.bek-and/ he embracedH2263
  12. ל/וֹ֙l/o<to> <the>/ himH9033
  13. וַ/יְנַשֶּׁק\־va/y.na.shek-and/ he kissedH5401
  14. ל֔/וֹl/o<to> <the>/ himH9033
  15. וַ/יְבִיאֵ֖/הוּva/y.vi.'E./huand/ he brought/ himH935
  16. אֶל\־'el-toH413
  17. בֵּית֑/וֹbei.T/ohouse/ hisH1004
  18. וַ/יְסַפֵּ֣רva/y.sa.Perand/ he recountedH5608
  19. לְ/לָבָ֔ןle./la.Vanto/ LabanH3837
  20. אֵ֥ת'et<obj.>H853
  21. כָּל\־kol-allH3605
  22. הַ/דְּבָרִ֖יםha./de.va.Rimthe/ thingsH1697
  23. הָ/אֵֽלֶּה\׃ha./'E.leh<the>/ theseH428
14
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. ל/וֹ֙l/oto <the>/ himH9033
  3. לָבָ֔ןla.VanLabanH3837
  4. אַ֛ךְ'akhsurelyH389
  5. עַצְמִ֥/י'atz.M/iH6106
  6. וּ/בְשָׂרִ֖/יu./ve.sa.R/iand/ flesh/ myH1320
  7. אָ֑תָּה'A.tahyouH859
  8. וַ/יֵּ֥שֶׁבva/i.Ye.shevand/ he remainedH3427
  9. עִמּ֖/וֹi.M/owith/ himH5973
  10. חֹ֥דֶשׁCho.desha month ofH2320
  11. יָמִֽים\׃ya.MimdaysH3117
15
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָבָן֙la.VanLabanH3837
  3. לְ/יַעֲקֹ֔בle./ya.'a.Koto/ JacobH3290
  4. הֲ/כִי\־ha./khi-¿/ forH3588
  5. אָחִ֣/י'a.Ch/irelative/ myH251
  6. אַ֔תָּה'A.tahH859
  7. וַ/עֲבַדְתַּ֖/נִיva./'a.vad.Ta./niand/ you will serve/ meH5647
  8. חִנָּ֑םchi.Namfor nothingH2600
  9. הַגִּ֥ידָ/הha.Gi.da/htell/ !H5046
  10. לִּ֖/יl/ito <the>/ meH9030
  11. מַה\־mah-what?H4100
  12. מַּשְׂכֻּרְתֶּֽ/ךָ\׃mas.kur.Te./khaH4909
16
  1. וּ/לְ/לָבָ֖ןu./le./la.Vanand/ [belonged] to/ LabanH3837
  2. שְׁתֵּ֣יshe.TeitwoH8147
  3. בָנ֑וֹתva.NotdaughtersH1323
  4. שֵׁ֤םshemH8034
  5. הַ/גְּדֹלָה֙ha./ge.do.Lahthe/ old [one]H1419
  6. לֵאָ֔הle.'AhH3812
  7. וְ/שֵׁ֥םve./Shemand/ [the] name ofH8034
  8. הַ/קְּטַנָּ֖הha./ke.ta.Nahthe/ young [one]H6996
  9. רָחֵֽל\׃ra.ChelH7354
17
  1. וְ/עֵינֵ֥יve./'ei.Neiand/ [the] eyes ofH5869
  2. לֵאָ֖הle.'AhLeahH3812
  3. רַכּ֑וֹתra.KotH7390
  4. וְ/רָחֵל֙ve./ra.Cheland/ RachelH7354
  5. הָֽיְתָ֔הha.ye.Tahshe wasH1961
  6. יְפַת\־ye.fat-beautiful ofH3303
  7. תֹּ֖אַרTo.'arformH8389
  8. וִ/יפַ֥תvi./Fatand/ beautiful ofH3303
  9. מַרְאֶֽה\׃mar.'EhappearanceH4758
18
  1. וַ/יֶּאֱהַ֥בva/i.ye.'e.Havand/ he lovedH157
  2. יַעֲקֹ֖בya.'a.KoJacobH3290
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. רָחֵ֑לra.ChelRachelH7354
  5. וַ/יֹּ֗אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  6. אֶֽעֱבָדְ/ךָ֙'e.'e.va.de./KhaI will serve/ youH5647
  7. שֶׁ֣בַעShe.va'sevenH7651
  8. שָׁנִ֔יםsha.NimyearsH8141
  9. בְּ/רָחֵ֥לbe./ra.Chelfor/ RachelH7354
  10. בִּתְּ/ךָ֖bi.te./Khadaughter/ yourH1323
  11. הַ/קְּטַנָּֽה\׃ha./ke.ta.Nah<the>/ youngH6996
19
  1. וַ/יֹּ֣אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָבָ֗ןla.VanLabanH3837
  3. ט֤וֹבTovH2896
  4. תִּתִּ֣/יti.T/ito give/ IH5414
  5. אֹתָ֣/הּ'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  6. לָ֔/ךְLa/khto <the>/ youH9032
  7. מִ/תִּתִּ֥/יmi./ti.T/imore than/ to give/ IH5414
  8. אֹתָ֖/הּ'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  9. לְ/אִ֣ישׁle./'Ishto/ a manH376
  10. אַחֵ֑ר'a.CheranotherH312
  11. שְׁבָ֖/הshe.Va/hremain/ !H3427
  12. עִמָּדִֽ/י\׃'i.ma.D/iwith/ meH5978
20
  1. וַ/יַּעֲבֹ֧דva/i.ya.'a.Vodand/ he servedH5647
  2. יַעֲקֹ֛בya.'a.KoJacobH3290
  3. בְּ/רָחֵ֖לbe./ra.Chelfor/ RachelH7354
  4. שֶׁ֣בַעShe.va'sevenH7651
  5. שָׁנִ֑יםsha.NimyearsH8141
  6. וַ/יִּהְי֤וּva/i.yih.Yuand/ they wereH1961
  7. בְ/עֵינָי/ו֙ve./'ei.Na/vin/ view/ hisH5869
  8. כְּ/יָמִ֣יםke./ya.Mimlike/ daysH3117
  9. אֲחָדִ֔ים'a.cha.Dimone<s>H259
  10. בְּ/אַהֲבָת֖/וֹbe./'a.ha.va.T/oin/ love/ hisH160
  11. אֹתָֽ/הּ\׃'o.Ta/h<obj.>/ herH853
21
  1. וַ/יֹּ֨אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. יַעֲקֹ֤בya.'a.KoJacobH3290
  3. אֶל\־'el-toH413
  4. לָבָן֙la.VanLabanH3837
  5. הָבָ֣/הha.Va/hgive/ !H3051
  6. אֶת\־'et-<obj.>H853
  7. אִשְׁתִּ֔/י'ish.T/iwife/ myH802
  8. כִּ֥יkiforH3588
  9. מָלְא֖וּmal.'Uthey have been completedH4390
  10. יָמָ֑/יya.Ma/idays/ myH3117
  11. וְ/אָב֖וֹאָהve./'a.Vo.'ahso/ I may goH935
  12. אֵלֶֽי/הָ\׃'e.Lei./hainto/ herH413
22
  1. וַ/יֶּאֱסֹ֥ףva/i.ye.'e.Sofand/ he gatheredH622
  2. לָבָ֛ןla.VanLabanH3837
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. כָּל\־kol-allH3605
  5. אַנְשֵׁ֥י'an.SheiH582
  6. הַ/מָּק֖וֹםha./ma.Komthe/ placeH4725
  7. וַ/יַּ֥עַשׂva/i.Ya.'asand/ he preparedH6213
  8. מִשְׁתֶּֽה\׃mish.Teha feastH4960
23
  1. וַ/יְהִ֣יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. בָ/עֶ֔רֶבva./'E.revin the/ eveningH6153
  3. וַ/יִּקַּח֙va/i.yi.Kachand/ he tookH3947
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. לֵאָ֣הle.'AhLeahH3812
  6. בִתּ֔/וֹvi.T/odaughter/ hisH1323
  7. וַ/יָּבֵ֥אva/i.ya.Ve'and/ he broughtH935
  8. אֹתָ֖/הּ'o.Ta/h<obj.>/ herH853
  9. אֵלָ֑י/ו'e.La/vto/ himH413
  10. וַ/יָּבֹ֖אva/i.ya.Vo'and/ he wentH935
  11. אֵלֶֽי/הָ\׃'e.Lei./hainto/ herH413
24
  1. וַ/יִּתֵּ֤ןva/i.yi.Tenand/ he had givenH5414
  2. לָבָן֙la.VanLabanH3837
  3. לָ֔/הּLa/hto <the>/ herH9034
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. זִלְפָּ֖הzil.PahZilpahH2153
  6. שִׁפְחָת֑/וֹshif.cha.T/omaidservant/ hisH8198
  7. לְ/לֵאָ֥הle./le.'Ahto/ LeahH3812
  8. בִתּ֖/וֹvi.T/odaughter/ hisH1323
  9. שִׁפְחָֽה\׃shif.Chaha maidservantH8198
25
  1. וַ/יְהִ֣יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. בַ/בֹּ֔קֶרva./Bo.kerin the/ morningH1242
  3. וְ/הִנֵּה\־ve./hi.neh-and/ there!H2009
  4. הִ֖ואhi'sheH1931
  5. לֵאָ֑הle.'AhH3812
  6. וַ/יֹּ֣אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  7. אֶל\־'el-toH413
  8. לָבָ֗ןla.VanLabanH3837
  9. מַה\־mah-what?H4100
  10. זֹּאת֙zoTthisH2063
  11. עָשִׂ֣יתָ'a.Si.tahave you doneH6213
  12. לִּ֔/יL/ito <the>/ meH9030
  13. הֲ/לֹ֤אha./Lo'¿/ notH3808
  14. בְ/רָחֵל֙ve./ra.Chelfor/ RachelH7354
  15. עָבַ֣דְתִּי'a.Vad.tihave I servedH5647
  16. עִמָּ֔/ךְ'i.Ma/khwith/ youH5973
  17. וְ/לָ֖/מָּהve./La./mahand/ <to>/ why?H4100
  18. רִמִּיתָֽ/נִי\׃ri.mi.Ta./nihave you deceived/ meH7411
26
  1. וַ/יֹּ֣אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. לָבָ֔ןla.VanLabanH3837
  3. לֹא\־lo'-notH3808
  4. יֵעָשֶׂ֥הye.'a.Sehit is doneH6213
  5. כֵ֖ןkhenthusH3651
  6. בִּ/מְקוֹמֵ֑/נוּbi/m.ko.Me./nuin/ place/ ourH4725
  7. לָ/תֵ֥תla./Tetto/ giveH5414
  8. הַ/צְּעִירָ֖הha./tze.'i.Rahthe/ youngH6810
  9. לִ/פְנֵ֥יli/f.Nei<to>/ beforeH6440
  10. הַ/בְּכִירָֽה\׃ha./be.khi.Rahthe/ firstbornH1067
27
  1. מַלֵּ֖אma.Le'completeH4390
  2. שְׁבֻ֣עַshe.Vu.a'H7620
  3. זֹ֑אתZotthis [one]H2063
  4. וְ/נִתְּנָ֨הve./ni.te.Nahso/ let us giveH5414
  5. לְ/ךָ֜le./Khato <the>/ youH9031
  6. גַּם\־gam-alsoH1571
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. זֹ֗אתZotthis [one]H2063
  9. בַּ/עֲבֹדָה֙ba./'a.vo.Dahfor/ [the] serviceH5656
  10. אֲשֶׁ֣ר'a.SherwhichH834
  11. תַּעֲבֹ֣דta.'a.Vodyou will serveH5647
  12. עִמָּדִ֔/י'i.ma.D/iwith/ meH5978
  13. ע֖וֹדodagainH5750
  14. שֶֽׁבַע\־she.va'-sevenH7651
  15. שָׁנִ֥יםsha.NimyearsH8141
  16. אֲחֵרֽוֹת\׃'a.che.RotanotherH312
28
  1. וַ/יַּ֤עַשׂva/i.Ya.'asand/ he didH6213
  2. יַעֲקֹב֙ya.'a.KoJacobH3290
  3. כֵּ֔ןKenthusH3651
  4. וַ/יְמַלֵּ֖אva/y.ma.Le'and/ he completedH4390
  5. שְׁבֻ֣עַshe.Vu.a'H7620
  6. זֹ֑אתZotthis [one]H2063
  7. וַ/יִּתֶּן\־va/i.yi.ten-and/ he gaveH5414
  8. ל֛/וֹl/oto <the>/ himH9033
  9. אֶת\־'et-<obj.>H853
  10. רָחֵ֥לra.ChelRachelH7354
  11. בִּתּ֖/וֹbi.T/odaughter/ hisH1323
  12. ל֥/וֹl/oof/ himH9033
  13. לְ/אִשָּֽׁה\׃le./'i.Shahto/ a wifeH802
29
  1. וַ/יִּתֵּ֤ןva/i.yi.Tenand/ he had givenH5414
  2. לָבָן֙la.VanLabanH3837
  3. לְ/רָחֵ֣לle./ra.Chelto/ RachelH7354
  4. בִּתּ֔/וֹbi.T/odaughter/ hisH1323
  5. אֶת\־'et-<obj.>H853
  6. בִּלְהָ֖הbil.HahBilhahH1090
  7. שִׁפְחָת֑/וֹshif.cha.T/omaidservant/ hisH8198
  8. לָ֖/הּla/hto/ herH9034
  9. לְ/שִׁפְחָֽה\׃le./shif.Chahto/ [be] a maidservantH8198
30
  1. וַ/יָּבֹא֙va/i.ya.Vo'and/ he wentH935
  2. גַּ֣םgamalsoH1571
  3. אֶל\־'el-intoH413
  4. רָחֵ֔לra.ChelRachelH7354
  5. וַ/יֶּאֱהַ֥בva/i.ye.'e.Havand/ he lovedH157
  6. גַּֽם\־gam-alsoH1571
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. רָחֵ֖לra.ChelRachelH7354
  9. מִ/לֵּאָ֑הmi./le.'Ahmore than/ LeahH3812
  10. וַ/יַּעֲבֹ֣דva/i.ya.'a.Vodand/ he servedH5647
  11. עִמּ֔/וֹi.M/owith/ himH5973
  12. ע֖וֹדodagainH5750
  13. שֶֽׁבַע\־she.va'-sevenH7651
  14. שָׁנִ֥יםsha.NimyearsH8141
  15. אֲחֵרֽוֹת\׃'a.che.RotanotherH312
31
  1. וַ/יַּ֤רְאva/i.Yar'and/ he sawH7200
  2. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  3. כִּֽי\־ki-thatH3588
  4. שְׂנוּאָ֣הse.nu.'AhH8130
  5. לֵאָ֔הle.'AhLeahH3812
  6. וַ/יִּפְתַּ֖חva/i.yif.Tachand/ he openedH6605
  7. אֶת\־'et-<obj.>H853
  8. רַחְמָ֑/הּrach.Ma/hwomb/ herH7358
  9. וְ/רָחֵ֖לve./ra.Cheland/ RachelH7354
  10. עֲקָרָֽה\׃'a.ka.RahH6135
32
  1. וַ/תַּ֤הַרva./Ta.harand/ she conceivedH2029
  2. לֵאָה֙le.'AhLeahH3812
  3. וַ/תֵּ֣לֶדva./Te.ledand/ she boreH3205
  4. בֵּ֔ןBena sonH1121
  5. וַ/תִּקְרָ֥אva./tik.Ra'and/ she calledH7121
  6. שְׁמ֖/וֹshe.M/oname/ hisH8034
  7. רְאוּבֵ֑ןre.'u.VenReubenH7205
  8. כִּ֣יkiforH3588
  9. אָֽמְרָ֗ה'a.me.Rahshe saidH559
  10. כִּֽי\־ki-thatH3588
  11. רָאָ֤הra.'Ahhe has lookedH7200
  12. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  13. בְּ/עָנְיִ֔/יbe./'on.y/ion/ affliction/ myH6040
  14. כִּ֥יkiforH3588
  15. עַתָּ֖ה'a.TahnowH6258
  16. יֶאֱהָבַ֥/נִיye.'e.ha.Va./nihe will love/ meH157
  17. אִישִֽׁ/י\׃'i.Sh/ihusband/ myH376
33
  1. וַ/תַּ֣הַרva./Ta.harand/ she conceivedH2029
  2. עוֹד֮'OdagainH5750
  3. וַ/תֵּ֣לֶדva./Te.ledand/ she boreH3205
  4. בֵּן֒bena sonH1121
  5. וַ/תֹּ֗אמֶרva./To.merand/ she saidH559
  6. כִּֽי\־ki-thatH3588
  7. שָׁמַ֤עsha.Ma'he has heardH8085
  8. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  9. כִּֽי\־ki-thatH3588
  10. שְׂנוּאָ֣הse.nu.'AhH8130
  11. אָנֹ֔כִי'a.No.khiIH595
  12. וַ/יִּתֶּן\־va/i.yi.ten-and/ he has givenH5414
  13. לִ֖/יl/ito <the>/ meH9030
  14. גַּם\־gam-alsoH1571
  15. אֶת\־'et-<obj.>H853
  16. זֶ֑הZehthis [one]H2088
  17. וַ/תִּקְרָ֥אva./tik.Ra'and/ she calledH7121
  18. שְׁמ֖/וֹshe.M/oname/ hisH8034
  19. שִׁמְעֽוֹן\׃shim.'onSimeonH8095
34
  1. וַ/תַּ֣הַרva./Ta.harand/ she conceivedH2029
  2. עוֹד֮'OdagainH5750
  3. וַ/תֵּ֣לֶדva./Te.ledand/ she boreH3205
  4. בֵּן֒bena sonH1121
  5. וַ/תֹּ֗אמֶרva./To.merand/ she saidH559
  6. עַתָּ֤ה'a.TahnowH6258
  7. הַ/פַּ֙עַם֙ha./Pa.'amthis/ timeH6471
  8. יִלָּוֶ֤הyi.la.Vehhe will join himselfH3867
  9. אִישִׁ/י֙'i.Sh/ihusband/ myH376
  10. אֵלַ֔/י'e.La/ito/ meH413
  11. כִּֽי\־ki-forH3588
  12. יָלַ֥דְתִּיya.Lad.tiI have borneH3205
  13. ל֖/וֹl/oto <the>/ himH9033
  14. שְׁלֹשָׁ֣הshe.lo.ShahthreeH7969
  15. בָנִ֑יםva.NimsonsH1121
  16. עַל\־'al-there-H5921
  17. כֵּ֥ןken-foreH3651
  18. קָרָֽא\־ka.ra'-he calledH7121
  19. שְׁמ֖/וֹshe.M/oname/ hisH8034
  20. לֵוִֽי\׃le.ViLeviH3878
35
  1. וַ/תַּ֨הַרva./Ta.harand/ she conceivedH2029
  2. ע֜וֹדodagainH5750
  3. וַ/תֵּ֣לֶדva./Te.ledand/ she boreH3205
  4. בֵּ֗ןBena sonH1121
  5. וַ/תֹּ֙אמֶר֙va./To.merand/ she saidH559
  6. הַ/פַּ֙עַם֙ha./Pa.'amthis/ timeH6471
  7. אוֹדֶ֣ה'o.DehI will praiseH3034
  8. אֶת\־'et-<obj.>H853
  9. יְהוָ֔הYah.wehYahwehH3068
  10. עַל\־'al-there-H5921
  11. כֵּ֛ןken-foreH3651
  12. קָרְאָ֥הka.re.'Ahshe calledH7121
  13. שְׁמ֖/וֹshe.M/oname/ hisH8034
  14. יְהוּדָ֑הye.hu.DahJudahH3063
  15. וַֽ/תַּעֲמֹ֖דva./ta.'a.Modand/ she stoppedH5975
  16. מִ/לֶּֽדֶת\׃mi./Le.detfrom/ bearing childrenH3205

View the full Hebrew interlinear for Genesis 29 →

Strong's words in Genesis 29 (6)
Strong's H559 — וַ/יֹּ֤אמֶר (va/i.Yo.mer)
and/ he said. Appears 19 times in Genesis 29.
Strong's H3837 — לָבָ֣ן (la.Van)
Laban. Appears 16 times in Genesis 29.
Strong's H7354 — רָחֵ֣ל (ra.Chel)
Rachel. Appears 16 times in Genesis 29.
Strong's H3290 — יַעֲקֹ֖ב (ya.'a.Ko)
Jacob. Appears 12 times in Genesis 29.
Strong's H1121 — בְנֵי\־ (ve.nei-)
[the] people of. Appears 9 times in Genesis 29.
Strong's H1323 — בִּתּ֔/וֹ (bi.T/o)
daughter/ his. Appears 8 times in Genesis 29.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress