Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Genesis 26 Language Awori Bible ID YORDOA Label DOA Catalog Awori - Diocese of Awori, Church of Nigeria, Anglican Communion Available audio Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Ìyàn kan sì mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ fún èyí tí ó mú ní ìgbà ayé Abrahamu, Isaaki sì lọ sọ́dọ̀ Abimeleki ọba àwọn Filistini ni Gerari.
2 Olúwa sì fi ara han Isaaki, ó sì wí pé, “Má ṣe sọ̀kalẹ̀ lọ sí Ejibiti, jókòó ní ilẹ̀ tí èmi ó fún ọ.
3 Máa ṣe àtìpó ní ilẹ̀ yìí fún ìgbà díẹ̀, èmi ó sì wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò sì bùkún fún ọ. Nítorí ìwọ àti irú-ọmọ rẹ ni èmi yóò fi gbogbo àwọn ilẹ̀ wọ̀nyí fún, èmi yóò sì fi ìdí ìbúra tí mo ṣe fún Abrahamu baba rẹ múlẹ̀.
4 Èmi yóò sọ ìran rẹ di púpọ̀ bí ìràwọ̀ ojú ọ̀run, èmi yóò sì fi gbogbo ilẹ̀ yìí fún irú àwọn ọmọ rẹ, àti nípasẹ̀ irú-ọmọ rẹ ni a ó bùkún fún gbogbo orílẹ̀-èdè ayé,
5 nítorí tí Abrahamu gba ohùn mi gbọ́, ó sì pa gbogbo ìkìlọ̀, àṣẹ, ìlànà àti òfin mi mọ́.”
6 Nítorí náà Isaaki jókòó ní Gerari.
7 Nígbà tí àwọn ọkùnrin ìlú náà bi í léèrè ní ti aya rẹ̀, ó sì wí pé, “Arábìnrin mi ní í ṣe,” nítorí tí ó bẹ̀rù láti jẹ́wọ́ wí pé, “Aya mi ni.” Ó ń rò wí pé, “Kí àwọn ọkùnrin ibẹ̀ náà má ba à pa mí nítorí Rebeka, nítorí tí òun ní ẹwà púpọ̀.”
8 Nígbà tí Isaaki sì ti wà níbẹ̀ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjọ́, Abimeleki ọba Filistini yọjú lójú fèrèsé, ó sì rí Isaaki ń bá Rebeka aya rẹ̀ tage.
9 Nígbà náà ni Abimeleki ránṣẹ́ pe Isaaki ó sì wí fun pé, “Nítòótọ́, aya rẹ ni obìnrin yìí í ṣe, èéṣe tí ìwọ fi wí fún wa pé arábìnrin mi ni?” Isaaki sì fèsì pé, “Nítorí mo rò pé mo le pàdánù ẹ̀mí mi nítorí rẹ̀.”
10 Nígbà náà ni Abimeleki dáhùn pé, “Èwo ni èyí tí ìwọ ṣe sí wa yìí? Bí ọ̀kan nínú àwọn ènìyàn wọ̀nyí bá ti bá a lòpọ̀ ń kọ́? Ìwọ ìbá wá mú ẹ̀bi wá sórí wa.”
11 Nígbà náà ni Abimeleki pàṣẹ fún gbogbo ènìyàn pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá fọwọ́ kan ọkùnrin yìí tàbí aya rẹ̀ yóò jẹ̀bi ikú.”
12 Ní ọdún náà, Isaaki gbin ohun ọ̀gbìn sí ilẹ̀ náà, ó sì kórè rẹ̀ ní ìlọ́po ọgọ́rùn-ún ọdún ni ọdún kan náà, nítorí Olúwa bùkún un.
13 Ọkùnrin náà sì di ọlọ́rọ̀ púpọ̀, ọrọ̀ rẹ̀ sì ń pọ̀ si, títí ó fi di ènìyàn ńlá.
14 Ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran ọ̀sìn àti agbo ẹran àti àwọn ìránṣẹ́ tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn Filistini ń ṣe ìlara rẹ̀.
15 Nítorí náà àwọn ará Filistini ru erùpẹ̀ di gbogbo kànga tí àwọn ìránṣẹ́ Abrahamu baba rẹ̀ ti gbẹ́.
16 Nígbà náà ni Abimeleki wí fún Isaaki pé, “Jáde kúrò ní ilẹ̀ wa, nítorí tí ìwọ ti di alágbára púpọ̀ jù wá lọ.”
17 Isaaki sì ṣí kúrò níbẹ̀, ó sì pàgọ́ sí àfonífojì Gerari ó sì ń gbé ibẹ̀.
18 Isaaki sì ṣe àtúngbẹ́ àwọn kànga tí Abrahamu baba rẹ̀ ti gbẹ́ nígbà ayé rẹ̀, èyí tí àwọn Filistini ti dí lẹ́yìn ikú Abrahamu baba rẹ̀, ó sì fún wọn lórúkọ tí baba rẹ̀ ti sọ wọ́n tẹ́lẹ̀.
19 Àwọn ìránṣẹ́ Isaaki sì gbẹ́ kànga ní àfonífojì náà, wọ́n kan ìsun omi níbẹ̀.
20 Ṣùgbọ́n àwọn darandaran Gerari ń bá àwọn darandaran Isaaki jà sí kànga náà pé àwọn ni àwọn ni í. Nítorí náà ni ó fi pe orúkọ kànga náà ní Eseki, nítorí pé wọ́n bá a jà sí kànga náà.
21 Àwọn ìránṣẹ́ Isaaki tún gbẹ́ kànga mìíràn, wọ́n sì tún jà nítorí rẹ̀ pẹ̀lú, ó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Sitna.
22 Ó sì tún kúrò níbẹ̀, ó sì gbẹ́ kànga mìíràn, wọn kò sì jásí èyí rárá, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Rehoboti, ó wí pé, “Nísinsin yìí, Olúwa ti fi ààyè gbà wá, a ó sì gbilẹ̀ si ní ilẹ̀ náà.”
23 Láti ibẹ̀, ó kúrò lọ sí Beerṣeba.
24 Ní òru ọjọ́ tí ó dé ibẹ̀, Olúwa sì fi ara hàn án, ó sì wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run Abrahamu baba rẹ. Má ṣe bẹ̀rù nítorí èmi wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò sì bùsi fún ọ, èmi yóò sì sọ iye ìran rẹ di púpọ̀, nítorí Abrahamu ìránṣẹ́ mi.”
25 Isaaki sì kọ́ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì pe orúkọ Olúwa. Níbẹ̀ ni ó pàgọ́ rẹ̀ sí, àwọn ìránṣẹ́ rẹ sì gbẹ́ kànga kan níbẹ̀.
26 Nígbà náà ni Abimeleki tọ̀ ọ́ wá láti Gerari, àti Ahussati, olùdámọ̀ràn rẹ̀ àti Fikoli, olórí ogun rẹ̀.
27 Isaaki sì bi wọ́n léèrè pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin tọ̀ mí wá, níwọ̀n ìgbà tí ẹ̀yin kórìíra mi tí ẹ sì lé mi jáde kúrò lọ́dọ̀ yín?”
28 Wọ́n dáhùn pé, “A rí i dájú pé Olúwa wà pẹ̀lú rẹ, nítorí náà ni a fi rò ó wí pé, ó yẹ kí májẹ̀mú kí o wà láàrín àwa àti ìwọ. Jẹ́ kí a ṣe àdéhùn
29 pé ìwọ kì yóò ṣe wá ní ibi, bí àwa pẹ̀lú kò ti ṣe ọ́ ní aburú, tí a sì ń ṣe ọ́ dáradára, tí a sì rán ọ jáde ní àlàáfíà láìṣe ọ́ ní ibi, kíyèsi Olúwa sì ti bùkún fún ọ.”
30 Isaaki sì ṣe àsè fún wọn, wọn sì jẹ, wọ́n sì mu.
31 Ní òwúrọ̀ ọjọ́ kejì wọn búra fún ara wọn. Isaaki sì rán wọn lọ, wọ́n sì lọ ní àlàáfíà.
32 Ní ọjọ́ náà gan an ni àwọn ìránṣẹ́ Isaaki wá sọ fún un pé àwọn ti kan omi ní kànga kan tí àwọn gbẹ́.
33 Ó sì pe orúkọ kànga náà ní Ṣiba, títí di òní olónìí, orúkọ ìlú náà ni Beerṣeba.
34 Nígbà tí Esau pé ọmọ ogójì ọdún ó fẹ́ ọmọbìnrin kan tí a ń pè ní Juditi, ọmọ Beeri, ará Hiti, ó sì tún fẹ́ Basemati, ọmọ Eloni ará Hiti.
35 Fífẹ́ tí a fẹ́ àwọn obìnrin wọ̀nyí jẹ́ ìbànújẹ́ fún Isaaki àti Rebeka.
Chapter information and study resources

Listen to Genesis 26 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Genesis 26

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Genesis 26. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Genesis 26 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references.

Cross-references in Genesis 26 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Genesis 26:1–35 (466 words)
1
  1. וַ/יְהִ֤יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. רָעָב֙ra.'Ava famineH7458
  3. בָּ/אָ֔רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  4. מִ/לְּ/בַד֙mi./le./Vad<from>/ <to>/ besidesH905
  5. הָ/רָעָ֣בha./ra.'Avthe/ famineH7458
  6. הָ/רִאשׁ֔וֹןha./ri.Shon<the>/ formerH7223
  7. אֲשֶׁ֥ר'a.SherwhichH834
  8. הָיָ֖הha.Yahit wasH1961
  9. בִּ/ימֵ֣יbi./Meiin/ [the] days ofH3117
  10. אַבְרָהָ֑ם'av.ra.HamAbrahamH85
  11. וַ/יֵּ֧לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  12. יִצְחָ֛קyitz.ChakIsaacH3327
  13. אֶל\־'el-toH413
  14. אֲבִימֶּ֥לֶךְ'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  15. מֶֽלֶךְ\־Me.lekh-H4428
  16. פְּלִשְׁתִּ֖יםpe.lish.TimH6430
  17. גְּרָֽרָ/ה\׃ge.Ra.ra/hGerar/ towardsH1642
2
  1. וַ/יֵּרָ֤אva/i.ye.Ra'and/ he appearedH7200
  2. אֵלָי/ו֙'e.La/vto/ himH413
  3. יְהוָ֔הYah.wehYahwehH3068
  4. וַ/יֹּ֖אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  5. אַל\־'al-may notH408
  6. תֵּרֵ֣דte.Redyou go downH3381
  7. מִצְרָ֑יְמָ/הmitz.Ra.ye.ma/hEgypt/ towardsH4714
  8. שְׁכֹ֣ןshe.KhondwellH7931
  9. בָּ/אָ֔רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  10. אֲשֶׁ֖ר'a.SherwhichH834
  11. אֹמַ֥ר'o.MarI will sayH559
  12. אֵלֶֽי/ךָ\׃'e.Lei./khato/ youH413
3
  1. גּ֚וּרgursojournH1481
  2. בָּ/אָ֣רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  3. הַ/זֹּ֔אתha./Zot<the>/ thisH2063
  4. וְ/אֶֽהְיֶ֥הve./'eh.Yehso/ I may beH1961
  5. עִמְּ/ךָ֖'i.me./Khawith/ youH5973
  6. וַ/אֲבָרְכֶ֑/ךָּva./'a.va.re.Khe./kaand/ I will bless/ youH1288
  7. כִּֽי\־ki-forH3588
  8. לְ/ךָ֣le./Khato/ youH9031
  9. וּֽ/לְ/זַרְעֲ/ךָ֗u./le./zar.'a./Khaand/ to/ offspring/ yourH2233
  10. אֶתֵּן֙'e.TenI will giveH5414
  11. אֶת\־'et-<obj.>H853
  12. כָּל\־kol-allH3605
  13. הָֽ/אֲרָצֹ֣תha./'a.ra.Tzotthe/ landsH776
  14. הָ/אֵ֔לha./'El<the>/ theseH411
  15. וַ/הֲקִֽמֹתִי֙va./ha.ki.mo.Tiand/ I will establishH6965
  16. אֶת\־'et-<obj.>H853
  17. הַ/שְּׁבֻעָ֔הha./she.vu.'Ahthe/ oathH7621
  18. אֲשֶׁ֥ר'a.SherwhichH834
  19. נִשְׁבַּ֖עְתִּיnish.Ba'.tiI sworeH7650
  20. לְ/אַבְרָהָ֥םle./'av.ra.Hamto/ AbrahamH85
  21. אָבִֽי/ךָ\׃'a.Vi./khafather/ yourH1
4
  1. וְ/הִרְבֵּיתִ֤יve./hir.bei.Tiand/ I will multiplyH7235
  2. אֶֽת\־'et-<obj.>H853
  3. זַרְעֲ/ךָ֙zar.'a./Khaoffspring/ yourH2233
  4. כְּ/כוֹכְבֵ֣יke./chokh.Veilike/ [the] stars ofH3556
  5. הַ/שָּׁמַ֔יִםha./sha.Ma.yimthe/ heavensH8064
  6. וְ/נָתַתִּ֣יve./na.ta.Tiand/ I will giveH5414
  7. לְ/זַרְעֲ/ךָ֔le./zar.'a./Khato/ offspring/ yourH2233
  8. אֵ֥ת'et<obj.>H853
  9. כָּל\־kol-allH3605
  10. הָ/אֲרָצֹ֖תha./'a.ra.Tzotthe/ landsH776
  11. הָ/אֵ֑לha./'El<the>/ theseH411
  12. וְ/הִתְבָּרֲכ֣וּve./hit.ba.ra.Khuand/ they will bless themselvesH1288
  13. בְ/זַרְעֲ/ךָ֔ve./zar.'a./Khaby/ offspring/ yourH2233
  14. כֹּ֖לkolallH3605
  15. גּוֹיֵ֥יgo.YeiH1471
  16. הָ/אָֽרֶץ\׃ha./'A.retzthe/ earthH776
5
  1. עֵ֕קֶב'E.kevconsequenceH6118
  2. אֲשֶׁר\־'a.Sher-thatH834
  3. שָׁמַ֥עsha.Ma'he listenedH8085
  4. אַבְרָהָ֖ם'av.ra.HamAbrahamH85
  5. בְּ/קֹלִ֑/יbe./ko.L/ito/ voice/ myH6963
  6. וַ/יִּשְׁמֹר֙va/i.yish.Morand/ he keptH8104
  7. מִשְׁמַרְתִּ֔/יmish.mar.T/iduty/ myH4931
  8. מִצְוֹתַ֖/יmitz.vo.Ta/icommandments/ myH4687
  9. חֻקּוֹתַ֥/יchu.ko.Ta/istatutes/ myH2708
  10. וְ/תוֹרֹתָֽ/י\׃ve./to.ro.Ta/iand/ laws/ myH8451
6
  1. וַ/יֵּ֥שֶׁבva/i.Ye.shevand/ he dweltH3427
  2. יִצְחָ֖קyitz.ChakIsaacH3327
  3. בִּ/גְרָֽר\׃bi/g.Rarin/ GerarH1642
7
  1. וַֽ/יִּשְׁאֲל֞וּva/i.yish.'a.Luand/ they askedH7592
  2. אַנְשֵׁ֤י'an.SheiH582
  3. הַ/מָּקוֹם֙ha./ma.kOmthe/ placeH4725
  4. לְ/אִשְׁתּ֔/וֹle./'ish.T/oof/ wife/ hisH802
  5. וַ/יֹּ֖אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  6. אֲחֹ֣תִ/י'a.Cho.t/iH269
  7. הִ֑ואhi'sheH1931
  8. כִּ֤יkiforH3588
  9. יָרֵא֙ya.Re'he was afraidH3372
  10. לֵ/אמֹ֣רle./Morto/ sayH559
  11. אִשְׁתִּ֔/י'ish.T/iwife/ myH802
  12. פֶּן\־pen-lestH6435
  13. יַֽהַרְגֻ֜/נִיya.har.Gu./nithey should kill/ meH2026
  14. אַנְשֵׁ֤י'an.SheiH582
  15. הַ/מָּקוֹם֙ha./ma.kOmthe/ placeH4725
  16. עַל\־'al-onH5921
  17. רִבְקָ֔הriv.KahRebekahH7259
  18. כִּֽי\־ki-forH3588
  19. טוֹבַ֥תto.VatH2896
  20. מַרְאֶ֖הmar.'EhappearanceH4758
  21. הִֽיא\׃Hi'sheH1931
8
  1. וַ/יְהִ֗יva/y.Hiand/ it wasH1961
  2. כִּ֣יkithatH3588
  3. אָֽרְכוּ\־'a.re.khu-they had become longH748
  4. ל֥/וֹl/oto <the>/ himH9033
  5. שָׁם֙shamthereH8033
  6. הַ/יָּמִ֔יםhai./ya.Mimthe/ daysH3117
  7. וַ/יַּשְׁקֵ֗ףva/i.yash.Kefand/ he looked downH8259
  8. אֲבִימֶ֙לֶךְ֙'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  9. מֶ֣לֶךְMe.lekhH4428
  10. פְּלִשְׁתִּ֔יםpe.lish.TimH6430
  11. בְּעַ֖דbe.'AdthroughH1157
  12. הַֽ/חַלּ֑וֹןha./cha.Lonthe/ windowH2474
  13. וַ/יַּ֗רְאva/i.Yar'and/ he sawH7200
  14. וְ/הִנֵּ֤הve./hi.Nehand/ there!H2009
  15. יִצְחָק֙yitz.ChakIsaacH3327
  16. מְצַחֵ֔קme.tza.ChekH6711
  17. אֵ֖ת'etwithH854
  18. רִבְקָ֥הriv.KahRebekahH7259
  19. אִשְׁתּֽ/וֹ\׃'ish.T/owife/ hisH802
9
  1. וַ/יִּקְרָ֨אva/i.yik.Ra'and/ he summonedH7121
  2. אֲבִימֶ֜לֶךְ'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  3. לְ/יִצְחָ֗קle./yitz.Chak<to>/ IsaacH3327
  4. וַ/יֹּ֙אמֶר֙va/i.Yo.merand/ he saidH559
  5. אַ֣ךְ'akhsurelyH389
  6. הִנֵּ֤הhi.Nehhere!H2009
  7. אִשְׁתְּ/ךָ֙'ish.te./KhaH802
  8. הִ֔ואhi'sheH1931
  9. וְ/אֵ֥יךְve./'Eikhand/ how?H349
  10. אָמַ֖רְתָּ'a.Mar.tadid you sayH559
  11. אֲחֹ֣תִ/י'a.Cho.t/iH269
  12. הִ֑ואhi'sheH1931
  13. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  14. אֵלָי/ו֙'e.La/vto/ himH413
  15. יִצְחָ֔קyitz.ChakIsaacH3327
  16. כִּ֣יkiforH3588
  17. אָמַ֔רְתִּי'a.Mar.tiI thoughtH559
  18. פֶּן\־pen-lestH6435
  19. אָמ֖וּת'a.MutI should dieH4191
  20. עָלֶֽי/הָ\׃'a.Lei./haon/ herH5921
10
  1. וַ/יֹּ֣אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. אֲבִימֶ֔לֶךְ'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  3. מַה\־mah-what?H4100
  4. זֹּ֖אתzotthisH2063
  5. עָשִׂ֣יתָ'a.Si.tahave you doneH6213
  6. לָּ֑/נוּLa./nuto <the>/ usH9035
  7. כִּ֠/מְעַטKi/m.'atlike/ a littleH4592
  8. שָׁכַ֞בsha.Khavhe lay withH7901
  9. אַחַ֤ד'a.Chadone ofH259
  10. הָ/עָם֙ha./'Amthe/ peopleH5971
  11. אֶת\־'et-<obj.>H853
  12. אִשְׁתֶּ֔/ךָ'ish.Te./khawife/ yourH802
  13. וְ/הֵבֵאתָ֥ve./he.ve.Taand/ you will bringH935
  14. עָלֵ֖י/נוּ'a.Lei./nuon/ usH5921
  15. אָשָֽׁם\׃'a.ShamguiltH817
11
  1. וַ/יְצַ֣וva/y.Tzavand/ he commandedH6680
  2. אֲבִימֶ֔לֶךְ'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  3. אֶת\־'et-<obj.>H853
  4. כָּל\־kol-allH3605
  5. הָ/עָ֖םha./'Amthe/ peopleH5971
  6. לֵ/אמֹ֑רle./Mor<to>/ sayingH559
  7. הַ/נֹּגֵ֜עַha./no.Ge.a'who/ [-ever] touchesH5060
  8. בָּ/אִ֥ישׁba./'Ish<in> the/ manH376
  9. הַ/זֶּ֛הha./Zeh<the>/ thisH2088
  10. וּ/בְ/אִשְׁתּ֖/וֹu./ve./'ish.T/oand/ <in>/ wife/ hisH802
  11. מ֥וֹתMotcertainly <to die>H4191
  12. יוּמָֽת\׃yu.Mathe will be put to deathH4191
12
  1. וַ/יִּזְרַ֤עva/i.yiz.Ra'and/ he sowedH2232
  2. יִצְחָק֙yitz.ChakIsaacH3327
  3. בָּ/אָ֣רֶץba./'A.retzin the/ landH776
  4. הַ/הִ֔ואha./Hiv'<the>/ thatH1931
  5. וַ/יִּמְצָ֛אva/i.yim.Tza'and/ he foundH4672
  6. בַּ/שָּׁנָ֥הba./sha.Nahin the/ yearH8141
  7. הַ/הִ֖ואha./Hiv'<the>/ thatH1931
  8. מֵאָ֣הme.'Ahone hundredH3967
  9. שְׁעָרִ֑יםshe.'a.RimmeasuresH8180
  10. וַֽ/יְבָרֲכֵ֖/הוּva/y.va.ra.Khe./huand/ he blessed/ himH1288
  11. יְהוָֽה\׃Yah.wehYahwehH3068
13
  1. וַ/יִּגְדַּ֖לva/i.yig.Daland/ he became greatH1431
  2. הָ/אִ֑ישׁha./'Ishthe/ manH376
  3. וַ/יֵּ֤לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  4. הָלוֹךְ֙ha.loKhcontinuously <to go>H1980
  5. וְ/גָדֵ֔לve./ga.Deland/ becoming greatH1432
  6. עַ֥ד'aduntilH5704
  7. כִּֽי\־ki-forH3588
  8. גָדַ֖לga.Dalhe became greatH1431
  9. מְאֹֽד\׃me.'OdexceedinglyH3966
14
  1. וַֽ/יְהִי\־va/y.hi-and/ it be[longed]H1961
  2. ל֤/וֹl/oto <the>/ himH9033
  3. מִקְנֵה\־mik.neh-livestock ofH4735
  4. צֹאן֙tzoNflockH6629
  5. וּ/מִקְנֵ֣הu./mik.Nehand/ livestock ofH4735
  6. בָקָ֔רva.KarherdH1241
  7. וַ/עֲבֻדָּ֖הva./'a.vu.Dahand/ serviceH5657
  8. רַבָּ֑הra.BahmuchH7227
  9. וַ/יְקַנְא֥וּva/y.kan.'Uand/ they enviedH7065
  10. אֹת֖/וֹ'o.T/o<obj.>/ himH853
  11. פְּלִשְׁתִּֽים\׃pe.lish.TimH6430
15
  1. וְ/כָל\־ve./kholand/ allH3605
  2. הַ/בְּאֵרֹ֗תha./be.'e.Rotthe/ wellsH875
  3. אֲשֶׁ֤ר'a.SherwhichH834
  4. חָֽפְרוּ֙cha.fe.Ruthey had dugH2658
  5. עַבְדֵ֣י'av.DeiH5650
  6. אָבִ֔י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  7. בִּ/ימֵ֖יbi./Meiin/ [the] days ofH3117
  8. אַבְרָהָ֣ם'av.ra.HamAbrahamH85
  9. אָבִ֑י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  10. סִתְּמ֣וּ/םsi.te.Mu/mthey stopped up/ themH5640
  11. פְּלִשְׁתִּ֔יםpe.lish.TimH6430
  12. וַ/יְמַלְא֖וּ/םva/y.mal.'U/mand/ they filled/ themH4390
  13. עָפָֽר\׃'a.FarearthH6083
16
  1. וַ/יֹּ֥אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. אֲבִימֶ֖לֶךְ'a.vi.Me.lekhAbimelechH40
  3. אֶל\־'el-toH413
  4. יִצְחָ֑קyitz.ChakIsaacH3327
  5. לֵ֚ךְlekhgoH1980
  6. מֵֽ/עִמָּ֔/נוּme./'i.Ma./nufrom/ with <the>/ usH5973
  7. כִּֽי\־ki-forH3588
  8. עָצַֽמְתָּ\־'a.tzam.ta-you have become [too] powerfulH6105
  9. מִמֶּ֖/נּוּmi.Me./nufor/ usH4480
  10. מְאֹֽד\׃me.'OdmuchH3966
17
  1. וַ/יֵּ֥לֶךְva/i.Ye.lekhand/ he wentH1980
  2. מִ/שָּׁ֖םmi./Shamfrom/ thereH8033
  3. יִצְחָ֑קyitz.ChakIsaacH3327
  4. וַ/יִּ֥חַןva/i.Yi.chanand/ he encampedH2583
  5. בְּ/נַֽחַל\־be./na.chal-in/ [the] wadi ofH5158
  6. גְּרָ֖רge.RarGerarH1642
  7. וַ/יֵּ֥שֶׁבva/i.Ye.shevand/ he dweltH3427
  8. שָֽׁם\׃ShamthereH8033
18
  1. וַ/יָּ֨שָׁבva/i.Ya.shovand/ he returnedH7725
  2. יִצְחָ֜קyitz.ChakIsaacH3327
  3. וַ/יַּחְפֹּ֣ר\׀va/i.yach.Porand/ he dugH2658
  4. אֶת\־'et-<obj.>H853
  5. בְּאֵרֹ֣תbe.'e.RotH875
  6. הַ/מַּ֗יִםha./Ma.yim<the>/ waterH4325
  7. אֲשֶׁ֤ר'a.SherwhichH834
  8. חָֽפְרוּ֙cha.fe.Rupeople had dugH2658
  9. בִּ/ימֵי֙bi./Meiin/ [the] days ofH3117
  10. אַבְרָהָ֣ם'av.ra.HamAbrahamH85
  11. אָבִ֔י/ו'a.Vi/vfather/ hisH1
  12. וַ/יְסַתְּמ֣וּ/םva/y.sa.te.Mu/mand/ they had stopped up/ themH5640
  13. פְּלִשְׁתִּ֔יםpe.lish.TimH6430
  14. אַחֲרֵ֖י'a.cha.ReiafterH310
  15. מ֣וֹתMotH4194
  16. אַבְרָהָ֑ם'av.ra.HamAbrahamH85
  17. וַ/יִּקְרָ֤אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  18. לָ/הֶן֙la./Hen<to> <the>/ themH9039
  19. שֵׁמ֔וֹתshe.MotnamesH8034
  20. כַּ/שֵּׁמֹ֕תka./she.Motlike the/ namesH8034
  21. אֲשֶׁר\־'a.Sher-whichH834
  22. קָרָ֥אka.Ra'he had calledH7121
  23. לָ/הֶ֖ןla./Hen<to> <the>/ themH9039
  24. אָבִֽי/ו\׃'a.Vi/vfather/ hisH1
19
  1. וַ/יַּחְפְּר֥וּva/i.yach.pe.Ruand/ they dugH2658
  2. עַבְדֵֽי\־'av.dei-H5650
  3. יִצְחָ֖קyitz.ChakIsaacH3327
  4. בַּ/נָּ֑חַלba./Na.chalin the/ wadiH5158
  5. וַ/יִּ֨מְצְאוּ\־va/i.Yim.tze.'u-and/ they foundH4672
  6. שָׁ֔םShamthereH8033
  7. בְּאֵ֖רbe.'Era well ofH875
  8. מַ֥יִםMa.yimwaterH4325
  9. חַיִּֽים\׃chai.YimlivingH2416
20
  1. וַ/יָּרִ֜יבוּva/i.ya.Ri.vuand/ they disputedH7378
  2. רֹעֵ֣יro.'EiH7462
  3. גְרָ֗רge.RarGerarH1642
  4. עִם\־'im-withH5973
  5. רֹעֵ֥יro.'EiH7462
  6. יִצְחָ֛קyitz.ChakIsaacH3327
  7. לֵ/אמֹ֖רle./Mor<to>/ sayingH559
  8. לָ֣/נוּLa./nuH9035
  9. הַ/מָּ֑יִםha./Ma.yimthe/ waterH4325
  10. וַ/יִּקְרָ֤אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  11. שֵֽׁם\־shem-H8034
  12. הַ/בְּאֵר֙ha./be.'Erthe/ wellH875
  13. עֵ֔שֶׂק'E.sekEsekH6230
  14. כִּ֥יkiforH3588
  15. הִֽתְעַשְּׂק֖וּhit.'a.se.Kuthey quarreledH6229
  16. עִמּֽ/וֹ\׃i.M/owith/ himH5973
21
  1. וַֽ/יַּחְפְּרוּ֙va/i.yach.pe.Ruand/ they dugH2658
  2. בְּאֵ֣רbe.'Era wellH875
  3. אַחֶ֔רֶת'a.Che.retanotherH312
  4. וַ/יָּרִ֖יבוּva/i.ya.Ri.vuand/ they disputedH7378
  5. גַּם\־gam-alsoH1571
  6. עָלֶ֑י/הָ'a.Lei./haon/ itH5921
  7. וַ/יִּקְרָ֥אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  8. שְׁמָ֖/הּshe.Ma/hname/ itsH8034
  9. שִׂטְנָֽה\׃sit.NahSitnahH7856
22
  1. וַ/יַּעְתֵּ֣קva/i.ya'.Tekand/ he moved onH6275
  2. מִ/שָּׁ֗םmi./Shamfrom/ thereH8033
  3. וַ/יַּחְפֹּר֙va/i.yach.Porand/ he dugH2658
  4. בְּאֵ֣רbe.'Era wellH875
  5. אַחֶ֔רֶת'a.Che.retanotherH312
  6. וְ/לֹ֥אve./Lo'and/ notH3808
  7. רָב֖וּra.Vuthey disputedH7378
  8. עָלֶ֑י/הָ'a.Lei./haon/ itH5921
  9. וַ/יִּקְרָ֤אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  10. שְׁמָ/הּ֙she.Ma/hname/ itsH8034
  11. רְחֹב֔וֹתre.cho.VotRehobothH7344
  12. וַ/יֹּ֗אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  13. כִּֽי\־ki-thatH3588
  14. עַתָּ֞ה'a.TahnowH6258
  15. הִרְחִ֧יבhir.Chivhe has made spaceH7337
  16. יְהוָ֛הYah.wehYahwehH3068
  17. לָ֖/נוּLa./nufor <the>/ usH9035
  18. וּ/פָרִ֥ינוּu./fa.Ri.nuand/ we will be fruitfulH6509
  19. בָ/אָֽרֶץ\׃va./'A.retzin the/ landH776
23
  1. וַ/יַּ֥עַלva/i.Ya.'aland/ he went upH5927
  2. מִ/שָּׁ֖םmi./Shamfrom/ thereH8033
  3. בְּאֵ֥רbe.'ErBeerH884
  4. שָֽׁבַע\׃Sha.va'ShebaH884
24
  1. וַ/יֵּרָ֨אva/i.ye.Ra'and/ he appearedH7200
  2. אֵלָ֤י/ו'e.La/vto/ himH413
  3. יְהוָה֙Yah.wehYahwehH3068
  4. בַּ/לַּ֣יְלָהba./Lay.lahin the/ nightH3915
  5. הַ/ה֔וּאha./Hu'<the>/ thatH1931
  6. וַ/יֹּ֕אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  7. אָנֹכִ֕י'a.no.KhiIH595
  8. אֱלֹהֵ֖י'e.lo.HeiH430
  9. אַבְרָהָ֣ם'av.ra.HamAbrahamH85
  10. אָבִ֑י/ךָ'a.Vi./khafather/ yourH1
  11. אַל\־'al-may notH408
  12. תִּירָא֙ti.Ra'you be afraidH3372
  13. כִּֽי\־ki-forH3588
  14. אִתְּ/ךָ֣'i.te./KhaH854
  15. אָנֹ֔כִי'a.No.khiIH595
  16. וּ/בֵֽרַכְתִּ֙י/ךָ֙u./ve.rakh.Ti./khaand/ I will bless/ youH1288
  17. וְ/הִרְבֵּיתִ֣יve./hir.bei.Tiand/ I will multiplyH7235
  18. אֶֽת\־'et-<obj.>H853
  19. זַרְעֲ/ךָ֔zar.'a./Khaoffspring/ yourH2233
  20. בַּ/עֲב֖וּרba./'a.Vurfor/sake ofH5668
  21. אַבְרָהָ֥ם'av.ra.HamAbrahamH85
  22. עַבְדִּֽ/י\׃'av.D/iservant/ myH5650
25
  1. וַ/יִּ֧בֶןva/i.Yi.venand/ he builtH1129
  2. שָׁ֣םshamthereH8033
  3. מִזְבֵּ֗חַmiz.Be.achan altarH4196
  4. וַ/יִּקְרָא֙va/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  5. בְּ/שֵׁ֣םbe./Shemon/ [the] name ofH8034
  6. יְהוָ֔הYah.wehYahwehH3068
  7. וַ/יֶּט\־va/i.yet-and/ he pitchedH5186
  8. שָׁ֖םshamthereH8033
  9. אָהֳל֑/וֹ'o.ho.L/otent/ hisH168
  10. וַ/יִּכְרוּ\־va/i.yikh.ru-and/ they dugH3738
  11. שָׁ֥םshamthereH8033
  12. עַבְדֵי\־'av.dei-H5650
  13. יִצְחָ֖קyitz.ChakIsaacH3327
  14. בְּאֵֽר\׃be.'Era wellH875
26
  1. וַ/אֲבִימֶ֕לֶךְva./'a.vi.Me.lekhand/ AbimelechH40
  2. הָלַ֥ךְha.Lakhhe cameH1980
  3. אֵלָ֖י/ו'e.La/vto/ himH413
  4. מִ/גְּרָ֑רmi./ge.Rarfrom/ GerarH1642
  5. וַ/אֲחֻזַּת֙va./'a.chu.Zatand/ AhuzzahH276
  6. מֵֽרֵעֵ֔/הוּme.re.'E./huclose friend/ hisH4828
  7. וּ/פִיכֹ֖לu./fi.Kholand/ PhicolH6369
  8. שַׂר\־sar-H8269
  9. צְבָאֽ/וֹ\׃tze.va.'/Oarmy/ hisH6635
27
  1. וַ/יֹּ֤אמֶרva/i.Yo.merand/ he saidH559
  2. אֲלֵ/הֶם֙'a.le./Hemto/ themH413
  3. יִצְחָ֔קyitz.ChakIsaacH3327
  4. מַדּ֖וּעַma.Du.a'why?H4069
  5. בָּאתֶ֣םba.Temhave you comeH935
  6. אֵלָ֑/י'e.La/ito/ meH413
  7. וְ/אַתֶּם֙ve./'a.Temand/ youH859
  8. שְׂנֵאתֶ֣םse.ne.Temyou hateH8130
  9. אֹתִ֔/י'o.T/i<obj.>/ meH853
  10. וַ/תְּשַׁלְּח֖וּ/נִיva./te.sha.le.Chu./niand/ you sent away/ meH7971
  11. מֵ/אִתְּ/כֶֽם\׃me./'i.te./Khemfrom/ with <the>/ youH854
28
  1. וַ/יֹּאמְר֗וּva/i.yo.me.Ruand/ they saidH559
  2. רָא֣וֹra.'Ocertainly <to see>H7200
  3. רָאִינוּ֮ra.'i.Nuwe have seenH7200
  4. כִּֽי\־ki-thatH3588
  5. הָיָ֣הha.Yahhe has beenH1961
  6. יְהוָ֣ה\׀Yah.wehYahwehH3068
  7. עִמָּ/ךְ֒'i.mo/Khwith/ youH5973
  8. וַ/נֹּ֗אמֶרva./No.merand/ we saidH559
  9. תְּהִ֨יte.Hilet it beH1961
  10. נָ֥אna'pleaseH4994
  11. אָלָ֛ה'a.Lahan oathH423
  12. בֵּינוֹתֵ֖י/נוּbei.no.Tei./nubetween/ usH996
  13. בֵּינֵ֣י/נוּbei.Nei./nubetween/ usH996
  14. וּ/בֵינֶ֑/ךָu./vei.Ne./khaand/ between/ youH996
  15. וְ/נִכְרְתָ֥הve./nikh.re.Tahand/ let us makeH3772
  16. בְרִ֖יתve.Rita covenantH1285
  17. עִמָּֽ/ךְ\׃'i.Ma/khwith/ youH5973
29
  1. אִם\־'im-ifH518
  2. תַּעֲשֵׂ֨הta.'a.Sehyou will doH6213
  3. עִמָּ֜/נוּ'i.Ma./nuwith/ usH5973
  4. רָעָ֗הra.'AhharmH7451
  5. כַּ/אֲשֶׁר֙ka./'a.Sherjust/ asH834
  6. לֹ֣אlo'notH3808
  7. נְגַֽעֲנ֔וּ/ךָne.ga.'a.Nu./khawe have touched/ youH5060
  8. וְ/כַ/אֲשֶׁ֨רve./kha./'a.Sherand/ just/ asH834
  9. עָשִׂ֤ינוּ'a.Si.nuwe have doneH6213
  10. עִמְּ/ךָ֙'i.me./Khawith/ youH5973
  11. רַק\־rak-onlyH7535
  12. ט֔וֹבTovgoodH2896
  13. וַ/נְּשַׁלֵּֽחֲ/ךָ֖va./ne.sha.le.cha./Khaand/ we sent away/ youH7971
  14. בְּ/שָׁל֑וֹםbe./sha.Lomin/ peaceH7965
  15. אַתָּ֥ה'a.TahyouH859
  16. עַתָּ֖ה'a.TahnowH6258
  17. בְּר֥וּךְbe.RukhH1288
  18. יְהוָֽה\׃Yah.wehYahwehH3068
30
  1. וַ/יַּ֤עַשׂva/i.Ya.'asand/ he preparedH6213
  2. לָ/הֶם֙la./Hemfor <the>/ themH9038
  3. מִשְׁתֶּ֔הmish.Teha feastH4960
  4. וַ/יֹּאכְל֖וּva/i.yo.khe.Luand/ they ateH398
  5. וַ/יִּשְׁתּֽוּ\׃va/i.yish.Tuand/ they drankH8354
31
  1. וַ/יַּשְׁכִּ֣ימוּva/i.yash.Ki.muand/ they rose earlyH7925
  2. בַ/בֹּ֔קֶרva./Bo.kerin the/ morningH1242
  3. וַ/יִּשָּׁבְע֖וּva/i.yi.sha.ve.'Uand/ they swore an oathH7650
  4. אִ֣ישׁ'isheachH376
  5. לְ/אָחִ֑י/וle./'a.Chi/vto/ brother/ hisH251
  6. וַ/יְשַׁלְּחֵ֣/םva/y.sha.le.Che/mand/ he sent off/ themH7971
  7. יִצְחָ֔קyitz.ChakIsaacH3327
  8. וַ/יֵּלְכ֥וּva/i.ye.le.Khuand/ they wentH1980
  9. מֵ/אִתּ֖/וֹme./'i.T/ofrom/ with <the>/ himH854
  10. בְּ/שָׁלֽוֹם\׃be./sha.Lomin/ peaceH7965
32
  1. וַ/יְהִ֣י\׀va/y.Hiand/ it wasH1961
  2. בַּ/יּ֣וֹםba/i.Yomon the/ dayH3117
  3. הַ/ה֗וּאha./Hu'<the>/ thatH1931
  4. וַ/יָּבֹ֙אוּ֙va/i.ya.Vo.'uand/ they cameH935
  5. עַבְדֵ֣י'av.DeiH5650
  6. יִצְחָ֔קyitz.ChakIsaacH3327
  7. וַ/יַּגִּ֣דוּva/i.ya.Gi.duand/ they toldH5046
  8. ל֔/וֹl/oto <the>/ himH9033
  9. עַל\־'al-onH5921
  10. אֹד֥וֹת'o.DotH182
  11. הַ/בְּאֵ֖רha./be.'Erthe/ wellH875
  12. אֲשֶׁ֣ר'a.SherwhichH834
  13. חָפָ֑רוּcha.Fa.ruthey had dugH2658
  14. וַ/יֹּ֥אמְרוּva/i.Yo.me.ruand/ they saidH559
  15. ל֖/וֹl/oto <the>/ himH9033
  16. מָצָ֥אנוּma.Tza.nuwe have foundH4672
  17. מָֽיִם\׃Ma.yimwaterH4325
33
  1. וַ/יִּקְרָ֥אva/i.yik.Ra'and/ he calledH7121
  2. אֹתָ֖/הּ'o.Ta/h<obj.>/ itH853
  3. שִׁבְעָ֑הshiv.'AhShibahH7656
  4. עַל\־'al-there-H5921
  5. כֵּ֤ןken-foreH3651
  6. שֵׁם\־shem-H8034
  7. הָ/עִיר֙ha./'Irthe/ cityH5892
  8. בְּאֵ֣רbe.'ErH884
  9. שֶׁ֔בַעShe.va'ShebaH884
  10. עַ֖ד'aduntilH5704
  11. הַ/יּ֥וֹםhai./Yomthe/ dayH3117
  12. הַ/זֶּֽה\׃\ \סha./Zeh<the>/ thisH2088
34
  1. וַ/יְהִ֤יva/y.Hiand/ he wasH1961
  2. עֵשָׂו֙'e.SavEsauH6215
  3. בֶּן\־ben-a son ofH1121
  4. אַרְבָּעִ֣ים'ar.ba.'ImfortyH705
  5. שָׁנָ֔הsha.Nahyear[s]H8141
  6. וַ/יִּקַּ֤חva/i.yi.Kachand/ he tookH3947
  7. אִשָּׁה֙'i.Shaha wifeH802
  8. אֶת\־'et-<obj.>H853
  9. יְהוּדִ֔יתye.hu.DitJudithH3067
  10. בַּת\־bat-H1323
  11. בְּאֵרִ֖יbe.'e.RiBeeriH882
  12. הַֽ/חִתִּ֑יha./chi.Tithe/ HittiteH2850
  13. וְ/אֶת\־ve./'Etand/ <obj.>H853
  14. בָּ֣שְׂמַ֔תba.se.MatBasemathH1315
  15. בַּת\־bat-H1323
  16. אֵילֹ֖ן'ei.LonElonH356
  17. הַֽ/חִתִּֽי\׃Ha./chi.Tithe/ HittiteH2850
35
  1. וַ/תִּהְיֶ֖יןָva./tih.Yei.naand/ they wereH1961
  2. מֹ֣רַתMo.ratbitterness ofH4786
  3. ר֑וּחַRu.achspiritH7307
  4. לְ/יִצְחָ֖קle./yitz.Chakto/ IsaacH3327
  5. וּ/לְ/רִבְקָֽה\׃\ \סu./le./riv.Kahand/ to/ RebekahH7259

View the full Hebrew interlinear for Genesis 26 →

Strong's words in Genesis 26 (6)
Strong's H559 — וַ/יֹּ֖אמֶר (va/i.Yo.mer)
and/ he said. Appears 18 times in Genesis 26.
Strong's H3327 — יִצְחָ֛ק (yitz.Chak)
Isaac. Appears 16 times in Genesis 26.
Strong's H1961 — וַ/יְהִ֤י (va/y.Hi)
and/ it was. Appears 10 times in Genesis 26.
Strong's H8033 — שָׁם֙ (sham)
there. Appears 9 times in Genesis 26.
Strong's H5973 — עִמְּ/ךָ֖ ('i.me./Kha)
with/ you. Appears 8 times in Genesis 26.
Strong's H7121 — וַ/יִּקְרָ֨א (va/i.yik.Ra')
and/ he summoned. Appears 8 times in Genesis 26.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress