Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Proverbs 28 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Ènìyàn búburú ń sá bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹnìkan kò lé e ṣùgbọ́n olódodo láyà bí i kìnnìún.
2 Nígbà tí orílẹ̀-èdè bá ní orí kunkun, àwọn ọba rẹ̀ a máa pọ̀, ṣùgbọ́n olóye àti onímọ̀ a máa pa òfin mọ́.
3 Ọba tí ó ni àwọn tálákà lára dàbí àgbàrá òjò tí ó ń gbá gbogbo ọ̀gbìn lọ.
4 Àwọn tí ó kọ òfin sílẹ̀ a máa gbóríyìn fún ènìyàn búburú ṣùgbọ́n àwọn tí ó pa òfin mọ́ kọjú ìjà sí ènìyàn búburú.
5 Òye ìdájọ́ òdodo kò yé àwọn ẹni ibi ṣùgbọ́n ó yé àwọn tí ń wá Olúwa dáradára.
6 Ó sàn láti jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ jẹ́ aláìlábùkù ju ọlọ́rọ̀ tí ọ̀nà rẹ̀ rí pálapàla.
7 Ẹni tí ó pa òfin mọ́ jẹ́ olóye ọmọ ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ẹ́ jẹgúdújẹrá kẹ́gbẹ́ dójútì baba rẹ̀.
8 Ẹni tí ó mú ọrọ̀ rẹ̀ di púpọ̀ nípa èrè àjẹjù ń kó jọ fún ẹlòmíràn, tí yóò ní àánú àwọn tálákà.
9 Bí ẹnikẹ́ni bá kọ etí ikún sí òfin, kódà àdúrà rẹ̀ jẹ́ ìríra.
10 Ẹni tí ó mú olódodo rìn ọ̀nà búburú yóò bọ́ sínú pàkúté ara rẹ̀ ṣùgbọ́n aláìlẹ́gàn yóò gba ogún rere.
11 Ọlọ́rọ̀ ènìyàn le è gbọ́n lójú ara rẹ̀ ṣùgbọ́n tálákà tí ó ní òye rí ìdí, rẹ̀.
12 Nígbà tí olódodo ń lékè ariwo ayọ̀ ta; ṣùgbọ́n nígbà tí ènìyàn búburú gorí òye, àwọn ènìyàn a na pápá bora.
13 Ẹni tí ó bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kì yóò ṣe rere, ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá jẹ́wọ́ tí ó sì kọ̀ wọ́n sílẹ̀ máa ń rí àánú gbà.
14 Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run nígbà gbogbo ṣùgbọ́n ẹni tí ó sé ọkàn rẹ̀ le bọ́ sínú wàhálà.
15 Bí kìnnìún tí ń ké tàbí Beari tí ń halẹ̀ ni ènìyàn búburú tí ń jẹ ọba lórí àwọn aláìlágbára.
16 Ọmọ-aládé tí ó ṣe aláìmòye púpọ̀ ní ń ṣe ìwà ìkà púpọ̀ pẹ̀lú, ṣùgbọ́n èyí tí ó kórìíra ojúkòkòrò yóò mú ọjọ́ rẹ̀ pẹ́.
17 Ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò balẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ìpànìyàn yóò máa joró rẹ̀ títí ikú má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni ràn án lọ́wọ́.
18 Ẹni tí ń rìn déédéé ní yóò là, ṣùgbọ́n ẹni tí ọ̀nà rẹ̀ jẹ́ àyídáyidà ni yóò ṣubú lójijì.
19 Ẹni tí ó bá ro ilẹ̀ rẹ̀ yóò ní oúnjẹ lọ́pọ̀lọ́pọ̀ ṣùgbọ́n ẹni tí ń lé ohun asán yóò kún fún òsì.
20 Olóòtítọ́ ènìyàn yóò rí ìbùkún gbà gan an ṣùgbọ́n ẹni tí ojú ń kán láti di ọlọ́rọ̀ kì yóò lọ láìjìyà.
21 Ojúsàájú ṣíṣe kò dára, síbẹ̀ ènìyàn kan ń ṣẹ̀ nítorí òkèlè oúnjẹ kan.
22 Ahun ń sáré àti là kò sì funra pé òsì dúró de òun.
23 Ẹni tí ó bá ènìyàn kan wí yóò rí ojúrere ni nígbẹ̀yìn ju ẹni tí ó ní ètè ẹ̀tàn lọ.
24 Ẹni tí ó ja baba tàbí ìyá rẹ̀ lólè tí ó sì wí pé, “Kì í ṣe ẹ̀ṣẹ̀,” irú kan ni òun àti ẹni tí ń pa ni run.
25 Ọ̀kánjúwà ènìyàn a máa dá ìjà sílẹ̀, ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò gbilẹ̀.
26 Ẹni tí ó gbẹ́kẹ̀lé ara rẹ̀ jẹ́ aláìgbọ́n ṣùgbọ́n ẹni tí ń rìn nínú ọgbọ́n wà láìléwu.
27 Ẹni tí ó ń fi fún tálákà kì yóò ṣe aláìní ohunkóhun, ṣùgbọ́n ẹni tí ó di ojú rẹ̀ sí wọn gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ègún.
28 Nígbà tí ènìyàn búburú bá dórí ìjọba, àwọn ènìyàn a na pápá bora; ṣùgbọ́n nígbà tí ènìyàn búburú bá ṣègbé, àwọn olódodo ń gbilẹ̀ sí i.
Chapter information and study resources

Listen to Proverbs 28 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Proverbs 28

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Proverbs 28. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Proverbs 28 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 30 cross-references.

Cross-references in Proverbs 28 (30)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Proverbs 28:1–28 (227 words)
1
  1. נָ֣סוּnāsûnuwc: to flit, i.e. vanish away (subside, escapeH5127
  2. וְאֵיןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  3. רֹדֵ֣ףrōdēpradaph: to run after (usually with hostile intentH7291
  4. רָשָׁ֑עrāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  5. וְ֝צַדִּיקִ֗יםwĕṣaddîqîmtsaddiyq: justH6662
  6. כִּכְפִ֥ירkikpîrkphiyr: a village (as covered in by walls); also a young lion (perhaps as covered with a mane)H3715
  7. יִבְטָֽח׃yibṭāḥbatach: (properly) to hie for refuge (but not so precipitately as H2620)H982
2
  1. בְּפֶ֣שַֽׁעbĕpešaʿpesha`: a revolt (national, moral or religious)H6588
  2. אֶ֭רֶץʾereṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  3. רַבִּ֣יםrabbîmrab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  4. שָׂרֶ֑יהָśārêhāsar: a head person (of any rank or class)H8269
  5. וּבְאָדָ֥םûbĕʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  6. מֵבִ֥יןmēbînbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  7. יֹ֝דֵ֗עַyōdēaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  8. כֵּ֣ןkēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  9. יַאֲרִֽיךְ׃yaʾărîkarak: to be (causative, make) long (literally or figuratively)H748
3
  1. גֶּ֣בֶרgebergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  2. רָ֭שׁrāšruwsh: to be destituteH7326
  3. וְעֹשֵׁ֣קwĕʿōšēq`ashaq: to press upon, i.e. oppress, defraud, violate, overflowH6231
  4. דַּלִּ֑יםdallîmdal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  5. מָטָ֥רmāṭārmatar: rainH4306
  6. סֹ֝חֵ֗ףsōḥēpcachaph: to scrape offH5502
  7. וְאֵ֣יןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  8. לָֽחֶם׃lāḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
4
  1. עֹזְבֵ֣יʿōzĕbê`azab: to loosen, i.e. relinquish, permit, etcH5800
  2. ת֭וֹרָהtôrâtowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  3. יְהַֽלְל֣וּyĕhallûhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  4. רָשָׁ֑עrāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  5. וְשֹׁמְרֵ֥יwĕšōmĕrêshamar: (properly) to hedge about (as with thorns), i.e. guardH8104
  6. ת֝וֹרָ֗הtôrâtowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  7. יִתְגָּ֥רוּyitgārûgarah: (properly) to grate, i.e. (figuratively) to angerH1624
5
  1. אַנְשֵׁיʾanšêenowsh: (properly) a mortal (and thus differing from the more dignified H0120)H582
  2. רָ֭עrāʿra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  3. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יָבִ֣ינוּyābînûbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  5. מִשְׁפָּ֑טmišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  6. וּמְבַקְשֵׁ֥יûmĕbaqšêbaqash: to search out (by any method, specifically in worship or prayer)H1245
  7. יְ֝הוָ֗הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  8. יָבִ֥ינוּyābînûbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  9. כֹֽל׃kōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
6
  1. טֽוֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  2. רָ֭שׁrāšruwsh: to be destituteH7326
  3. הוֹלֵ֣ךְhôlēkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  4. בְּתֻמּ֑וֹbĕtummôtom: completeness; (figuratively) prosperityH8537
  5. מֵעִקֵּ֥שׁmēʿiqqēš`iqqesh: distorted; (hence) falseH6141
  6. דְּ֝רָכַ֗יִםdĕrākayimderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  7. וְה֣וּאwĕhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. עָשִֽׁיר׃ʿāšîr`ashiyr: rich, whether literal or figurative (noble)H6223
7
  1. נוֹצֵ֣רnôṣērnatsar: to guard, in a good sense (to protect, maintain, obey, etc.) or a bad one (to conceal, etc.)H5341
  2. תּ֭וֹרָהtôrâtowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  3. בֵּ֣ןbēnben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  4. מֵבִ֑יןmēbînbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  5. וְרֹעֶהwĕrōʿera`ah: to tend a flock i.e. pasture it; (intransitively, literally or figuratively) to grazeH7462
  6. זֽ֝וֹלְלִ֗יםzôlĕlîmzalal: to shake (as in the wind), i.e. to quakeH2151
  7. יַכְלִ֥יםyaklîmkalam: (properly) to wound; (figuratively) to taunt or insultH3637
  8. אָבִֽיו׃ʾābîwab: fatherH1
8
  1. מַרְבֶּ֣הmarberabah: to increase (in whatever respect)H7235
  2. ה֭וֹנוֹhônôhown: wealth; (by implication) enoughH1952
  3. בְּנֶ֣שֶׁךְbĕnešekneshek: interest on a debtH5392
  4. וְבתַרְבִּ֑יתwĕbtarbîttarbiyth: multiplication, i.e. percentage or bonus in addition to principalH8636
  5. לְחוֹנֵ֖ןlĕḥônēnchanan: (properly) to bend or stoop in kindness to an inferiorH2603
  6. דַּלִּ֣יםdallîmdal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  7. יִקְבְּצֶֽנּוּ׃yiqbĕṣennûqabats: to grasp, i.e. collectH6908
9
  1. מֵסִ֣ירmēsîrcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  2. אָ֭זְנוֹʾāzĕnôozen: broadness; (concretely) the ear (from its form in man)H241
  3. מִשְּׁמֹ֣עַmiššĕmōaʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  4. תּוֹרָ֑הtôrâtowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  5. גַּ֥םgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  6. תְּ֝פִלָּת֗וֹtĕpillātôtphillah: intercession, supplication; (by implication) a hymnH8605
  7. תּוֹעֵבָֽה׃tôʿēbâtow`ebah: (properly) something disgusting; (morally, as noun) an abhorrenceH8441
10
  1. מַשְׁגֶּ֤הmašgeshagah: to stray (causatively, mislead), usually (figuratively) to mistake, especially (morally) to transgressH7686
  2. יְשָׁרִ֨ים׀yĕšārîmyashar: straightH3477
  3. בְּדֶ֥רֶךְbĕderekderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  4. רָ֗עrāʿra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  5. בִּשְׁחוּת֥וֹbišḥûtôshchuwth: pitH7816
  6. הֽוּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  7. יִפּ֑וֹלyippôlnaphal: to fall, in a great variety of applications (intransitive or causative, literal or figurative)H5307
  8. וּ֝תְמִימִ֗יםûtĕmîmîmtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  9. יִנְחֲלוּyinḥălûnachal: to inherit (as a (figurative) mode of descent)H5157
  10. טֽוֹב׃ṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
11
  1. חָכָ֣םḥākāmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  2. בְּ֭עֵינָיוbĕʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  3. אִ֣ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. עָשִׁ֑ירʿāšîr`ashiyr: rich, whether literal or figurative (noble)H6223
  5. וְדַ֖לwĕdaldal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  6. מֵבִ֣יןmēbînbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  7. יַחְקְרֶֽנּוּ׃yaḥqĕrennûchaqar: (properly) to penetrate; (hence) to examine intimatelyH2713
12
  1. בַּעֲלֹ֣ץbaʿălōṣ`alats: to jump for joy, i.e. exultH5970
  2. צַ֭דִּיקִיםṣaddîqîmtsaddiyq: justH6662
  3. רַבָּ֣הrabbârab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  4. תִפְאָ֑רֶתtipʾārettiph'arah: ornamentH8597
  5. וּבְק֥וּםûbĕqûmquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  6. רְ֝שָׁעִ֗יםrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  7. יְחֻפַּ֥שׂyĕḥuppaśchaphas: to seek; causatively, to conceal oneself (i.e. let be sought), or maskH2664
  8. אָדָֽם׃ʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
13
  1. מְכַסֶּ֣הmĕkassekacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  2. פְ֭שָׁעָיוpĕšāʿāywpesha`: a revolt (national, moral or religious)H6588
  3. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יַצְלִ֑יחַyaṣlîaḥtsalach: to push forward, in various senses (literal or figurative, transitive or intransitive)H6743
  5. וּמוֹדֶ֖הûmôdeyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  6. וְעֹזֵ֣בwĕʿōzēb`azab: to loosen, i.e. relinquish, permit, etcH5800
  7. יְרֻחָֽם׃yĕruḥāmracham: to fondle; (by implication) to loveH7355
14
  1. אַשְׁרֵ֣יʾašrêesher: happiness; only in masculine plural construction as interjection, how happy!H835
  2. אָ֭דָםʾādomadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  3. מְפַחֵ֣דmĕpaḥēdpachad: to be startled (by a sudden alarm); (hence) to fear in generalH6342
  4. תָּמִ֑ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  5. וּמַקְשֶׁ֥הûmaqšeqashah: (properly) to be dense, i.e. tough or severe (in various applications)H7185
  6. לִ֝בּ֗וֹlibbôleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  7. יִפּ֥וֹלyippôlnaphal: to fall, in a great variety of applications (intransitive or causative, literal or figurative)H5307
  8. בְּרָעָֽה׃bĕrāʿâra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
15
  1. אֲרִיʾărîariy: a lionH738
  2. נֹ֭הֵםnōhēmnaham: to growlH5098
  3. וְדֹ֣בwĕdōbdob: the bear (as slow)H1677
  4. שׁוֹקֵ֑קšôqēqshaqaq: to course (like a beast of prey); (by implication) to seek greedilyH8264
  5. מוֹשֵׁ֥לmôšēlmashal: to ruleH4910
  6. רָ֝שָׁ֗עrāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  7. עַ֣לʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  8. עַםʿam`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  9. דָּֽל׃dāldal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
16
  1. נָגִ֗ידnāgîdnagiyd: a commander (as occupying the front), either civil, military or religiousH5057
  2. חֲסַ֣רḥăsarchacer: lacking; (hence) withoutH2638
  3. תְּ֭בוּנוֹתtĕbûnôttabuwn: intelligence; (by implication) an argumentH8394
  4. וְרַ֥בwĕrabrab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  5. מַעֲשַׁקּ֑וֹתmaʿăšaqqôtma`ashaqqah: oppressionH4642
  6. שֹׂ֥נֵאיśōnēysane': to hate (personally)H8130
  7. בֶ֝֗צַעbeṣaʿbetsa`: plunder; by extension, gain (usually unjust)H1215
  8. יַאֲרִ֥יךְyaʾărîkarak: to be (causative, make) long (literally or figuratively)H748
  9. יָמִֽים׃yāmîmyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
17
  1. אָ֭דָםʾādomadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  2. עָשֻׁ֣קʿāšuq`ashaq: to press upon, i.e. oppress, defraud, violate, overflowH6231
  3. בְּדַםbĕdamdam: blood (as that which when shed causes death) of man or an animalH1818
  4. נָ֑פֶשׁnāpešnephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  5. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  6. בּ֥וֹרbôrbowr: a pit hole (especially one used as a cistern or a prison)H953
  7. יָ֝נ֗וּסyānûsnuwc: to flit, i.e. vanish away (subside, escapeH5127
  8. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  9. יִתְמְכוּyitmĕkûtamak: to sustain; (by implication) to obtain, keep fastH8551
18
  1. הוֹלֵ֣ךְhôlēkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  2. תָּ֭מִיםtāmîmtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  3. יִוָּשֵׁ֑עַyiwwāšēaʿyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  4. וְנֶעְקַ֥שׁwĕneʿqaš`aqash: to knot or distort; (figuratively) to pervert (act or declare perverse)H6140
  5. דְּ֝רָכַ֗יִםdĕrākayimderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  6. יִפּ֥וֹלyippôlnaphal: to fall, in a great variety of applications (intransitive or causative, literal or figurative)H5307
  7. בְּאֶחָֽת׃bĕʾeḥātechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
19
  1. עֹבֵ֣דʿōbēd`abad: to work (in any sense); (by implication) to serve, tillH5647
  2. אַ֭דְמָתוֹʾadmātôadamah: soil (from its general redness)H127
  3. יִֽשְׂבַּֽעyiśĕbbaʿsaba`: to sate, i.e. fill to satisfaction (literally or figuratively)H7646
  4. לָ֑חֶםlāḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  5. וּמְרַדֵּ֥ףûmĕraddēpradaph: to run after (usually with hostile intentH7291
  6. רֵ֝יקִ֗יםrêqîmreyq: empty; (figuratively) worthlessH7386
  7. יִֽשְׂבַּֽעyiśĕbbaʿsaba`: to sate, i.e. fill to satisfaction (literally or figuratively)H7646
  8. רִֽישׁ׃rîšreysh: povertyH7389
20
  1. אִ֣ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  2. אֱ֭מוּנוֹתʾĕmûnôtemuwnah: literally firmness; figuratively securityH530
  3. רַבrabrab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  4. בְּרָכ֑וֹתbĕrākôtBrakah: benediction; (by implication) prosperityH1293
  5. וְאָ֥ץwĕʾāṣuwts: to press; (by implication) to be close, hurry, withdrawH213
  6. לְ֝הַעֲשִׁ֗ירlĕhaʿăšîr`ashar: (properly) to accumulate; chiefly (specifically) to grow (causatively, make) richH6238
  7. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  8. יִנָּקֶֽה׃yinnāqenaqah: to be (or make) clean (literally or figuratively)H5352
21
  1. הַֽכֵּרhakkērnakar: (properly) to scrutinize, i.e. look intently atH5234
  2. פָּנִ֥יםpānîmpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  3. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. ט֑וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  5. וְעַלwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  6. פַּתpatpath: a bitH6595
  7. לֶ֝֗חֶםleḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  8. יִפְשַׁעyipšaʿpasha`: to break away (from just authority), i.e. trespass, apostatize, quarrelH6586
  9. גָּֽבֶר׃gābergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
22
  1. נִֽבֳהָ֥לnibŏhālbahal: to tremble inwardly (or palpitate); (figuratively) to be (suddenly) alarmed or agitatedH926
  2. לַה֗וֹןlahônhown: wealth; (by implication) enoughH1952
  3. אִ֭ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. רַ֣עraʿra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  5. עָ֑יִןʿāyin`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  6. וְלֹֽאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. יֵ֝דַעyēdaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  8. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  9. חֶ֥סֶרḥeserchecer: lack; (hence) destitutionH2639
  10. יְבֹאֶֽנּוּ׃yĕbōʾennûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
23
  1. מ֘וֹכִ֤יחַmôkîaḥyakach: to be right (i.e. correct); reciprocal, to argueH3198
  2. אָדָ֣םʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  3. אַ֭חֲרַיʾaḥărayachar: (properly) the hind part; (generally, as adverb or conjunction) after (in various senses)H310
  4. חֵ֣ןḥēnchen: graciousness, i.e. subjective (kindness, favor) or objective (beauty)H2580
  5. יִמְצָ֑אyimṣāʾmatsa': (properly) to come forth to, i.e. appear or existH4672
  6. מִֽמַּחֲלִ֥יקmimmaḥălîqchalaq: to be smooth (figuratively); (by implication) (as smooth stones were used for lots) to apportion or separateH2505
  7. לָשֽׁוֹן׃lāšônlashown: the tongue (of man or animals), used literally (as the instrument of licking, eating, or speech), and...H3956
24
  1. גּוֹזֵ֤ל׀gôzēlgazal: to pluck off; specifically to flay, strip or robH1497
  2. אָ֘בִ֤יוʾābîwab: fatherH1
  3. וְאִמּ֗וֹwĕʾimmôem: a mother (as the bond of the family); in a wide sense (both literally and figuratively (like H0001H517
  4. וְאֹמֵ֥רwĕʾōmēramar: to say (used with great latitude)H559
  5. אֵֽיןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  6. פָּ֑שַׁעpāšaʿpesha`: a revolt (national, moral or religious)H6588
  7. חָבֵ֥רḥābērchaber: an associateH2270
  8. ה֝֗וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  9. לְאִ֣ישׁlĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  10. מַשְׁחִֽית׃mašḥîtshachath: to decay, i.e. (causatively) ruin (literally or figuratively)H7843
25
  1. רְחַבrĕḥabrachab: roomy, in any (or every) direction, literally or figurativelyH7342
  2. נֶ֭פֶשׁnepešnephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  3. יְגָרֶ֣הyĕgāregarah: (properly) to grate, i.e. (figuratively) to angerH1624
  4. מָד֑וֹןmādônmadown: a contest or quarrelH4066
  5. וּבֹטֵ֖חַûbōṭēaḥbatach: (properly) to hie for refuge (but not so precipitately as H2620)H982
  6. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. יְהוָ֣הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  8. יְדֻשָּֽׁן׃yĕduššāndashen: to be fat; transitively, to fatten (or regard as fat)H1878
26
  1. בּוֹטֵ֣חַbôṭēaḥbatach: (properly) to hie for refuge (but not so precipitately as H2620)H982
  2. בְּ֭לִבּוֹbĕlibbôleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  3. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  4. כְסִ֑ילkĕsîlkciyl: (properly) fat, i.e. (figuratively) stupid or sillyH3684
  5. וְהוֹלֵ֥ךְwĕhôlēkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  6. בְּ֝חָכְמָ֗הbĕḥokmâchokmah: wisdom (in a good sense)H2451
  7. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. יִמָּלֵֽט׃yimmālēṭmalat: (properly) to be smooth; (by implication) to escape (as if by slipperiness)H4422
27
  1. נוֹתֵ֣ןnôtēnnathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  2. לָ֭רָשׁlārošruwsh: to be destituteH7326
  3. אֵ֣יןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  4. מַחְס֑וֹרmaḥsôrmachcowr: deficiency; (hence) impoverishmentH4270
  5. וּמַעְלִ֥יםûmaʿlîm`alam: to veil from sight, i.e. conceal (literally or figuratively)H5956
  6. עֵ֝ינָ֗יוʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  7. רַבrabrab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  8. מְאֵרֽוֹת׃mĕʾērôtmerah: an execrationH3994
28
  1. בְּק֣וּםbĕqûmquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  2. רְ֭שָׁעִיםrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  3. יִסָּתֵ֣רyissātērcathar: to hide (by covering), literally or figurativelyH5641
  4. אָדָ֑םʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  5. וּ֝בְאָבְדָ֗םûbĕʾobdāmabad: (properly) to wander away, i.e. lose oneselfH6
  6. יִרְבּ֥וּyirbûrabah: to increase (in whatever respect)H7235
  7. צַדִּיקִֽים׃ṣaddîqîmtsaddiyq: justH6662

View the full Hebrew interlinear for Proverbs 28 →

Strong's words in Proverbs 28 (6)
Strong's H120 — וּבְאָדָ֥ם (ûbĕʾādām)
adam (aw-dawm') n-m. 1. ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.) [from H119] KJV: X another, + hypocrite, + common sort, X low, man (mean, of low degree), person. Root(s): H119. Appears 6 times in Proverbs 28.
Strong's H7227 — רַבִּ֣ים (rabbîm)
rab (rab) adj. 1. abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality) [by contracted from H7231] KJV: (in) abound(-undance, -ant, -antly), captain, elder, enough, exceedingly, full, great(-ly, man, one), increase, long (enough, (time)), (do, have) many(-ifold, things, a time), ((ship-))master, mighty, more, (too, very) much, multiply(-tude), officer, often(-times), plenteous, populous, prince, process (of time), suffice(-lent). Root(s): H7231. Appears 5 times in Proverbs 28.
Strong's H7563 — רָשָׁ֑ע (rāšāʿ)
rasha` (raw-shaw') adj. 1. morally wrong 2. (concretely) an (actively) bad person [from H7561] KJV: + condemned, guilty, ungodly, wicked (man), that did wrong. Root(s): H7561. Appears 5 times in Proverbs 28.
Strong's H995 — מֵבִ֥ין (mēbîn)
biyn (bene) v. 1. to separate mentally (or distinguish) 2. (generally) understand [a primitive root] KJV: attend, consider, be cunning, diligently, direct, discern, eloquent, feel, inform, instruct, have intelligence, know, look well to, mark, perceive, be prudent, regard, (can) skill(-full), teach, think, (cause, make to, get, give, have) understand(-ing), view, (deal) wise(-ly, man).. Appears 5 times in Proverbs 28.
Strong's H1800 — דַּלִּ֑ים (dallîm)
dal (dal) adj. 1. (properly) dangling 2. (by implication) weak or thin [from H1809] KJV: lean, needy, poor (man), weaker. Root(s): H1809. Appears 4 times in Proverbs 28.
Strong's H369 — וְאֵין (wĕʾên)
ayin (ah'-yin) prt-n. 1. a non-entity 2. (generally) used as a negative particle [as if from a primitive root meaning to be nothing or not exist] KJV: else, except, fail, (father-)less, be gone, in(-curable), neither, never, no (where), none, nor, (any, thing), not, nothing, to nought, past, un(-searchable), well-nigh, without. Compare: H370. Appears 4 times in Proverbs 28.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress