Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Proverbs 24 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Má ṣe ṣe ìlara àwọn ènìyàn búburú má ṣe jẹ́ kí àwùjọ wọn wù ọ́;
2 nítorí ọkàn wọn ń gbèrò ohun búburú, ètè wọn sì ń sọ̀rọ̀ nípa dídá rúgúdù sílẹ̀.
3 Nípa ọgbọ́n ni ilé di kíkọ́ nípa òye sì ni ó ti fìdímúlẹ̀;
4 nípa ìmọ̀ ni àwọn yàrá rẹ̀ kún pẹ̀lú àwọn ohun ọ̀ṣọ́ tí ó lẹ́wà tí ó sì ṣọ̀wọ́n.
5 Ọlọ́gbọ́n ènìyàn ní agbára púpọ̀, ènìyàn tí ó ní ìmọ̀ sì ń ní agbára sí i.
6 Láti jagun, ó nílò ìtọ́sọ́nà: nínú ìṣẹ́gun ni ọ̀pọ̀ onígbìmọ̀.
7 Ọgbọ́n ga ju fún aṣiwèrè àti gbọ̀ngàn ìlú níbi ibodè kò ní ohun tí yóò wí.
8 Ẹni tí ń pète ibi ni a ó mọ̀ bí ènìyàn ibi.
9 Ète òmùgọ̀ ènìyàn jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀, àwọn ènìyàn sì kórìíra ẹlẹ́gàn.
10 Bí ìwọ bá dákú lásìkò ìdààmú báwo ni agbára rẹ ha ti kéré tó!
11 Gba àwọn tí a ń wọ́ lọ sí ibi ikú là; fa àwọn tó ń ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lọ sí ibi ìparun padà.
12 Bí ìwọ bá wí pé, “Ṣùgbọ́n a kò mọ nǹkan kan nípa èyí,” ǹjẹ́ ẹni tí ń díwọ̀n ọkàn kò kíyèsi i? Ǹjẹ́ ẹni tí ń ṣọ́ ẹ̀mí rẹ kò mọ̀ ọ́n? Ǹjẹ́ kò ní san án fún ẹnìkọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó ti ṣe?
13 Jẹ oyin, ìwọ ọmọ mi, nítorí tí ó dára, oyin láti inú afárá oyin dùn lẹ́nu.
14 Mọ̀ pẹ̀lú pé ọgbọ́n pẹ̀lú dùn fún ọkàn rẹ bí ìwọ bá rí i ìrètí ọjọ́ iwájú wà fún ọ ìrètí rẹ kì yóò sì já ṣófo.
15 Má ṣe ba ní ibùba bí ènìyàn búburú láti gba ibùjókòó olódodo, má ṣe fi ibi ìsinmi rẹ̀ ṣe ìjẹ;
16 nítorí bí olódodo ènìyàn bá tilẹ̀ ṣubú ní ìgbà méje, yóò tún padà dìde sá á ni, ṣùgbọ́n ìdààmú yóò fa ènìyàn búburú lulẹ̀.
17 Má ṣe yọ̀ nígbà tí ọ̀tá rẹ bá ṣubú; nígbà tí ó bá kọsẹ̀, má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yọ̀.
18 Àìṣe bẹ́ẹ̀ Olúwa yóò rí i yóò sì bínú yóò sì yí ìbínú rẹ̀ padà kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀.
19 Má ṣe fòyà nítorí àwọn ènìyàn ibi tàbí jowú àwọn ènìyàn búburú,
20 nítorí ẹni ibi kò ní ìrètí ọjọ́ iwájú a ó sì pa fìtílà àwọn ènìyàn búburú kú.
21 Bẹ̀rù Olúwa àti ọba, ọmọ mi, má sì ṣe darapọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí kunkun.
22 Nítorí àwọn méjèèjì yóò rán ìparun òjijì sórí wọn, ta ni ó sì mọ irú ìyọnu tí wọ́n lè mú wá?
23 Àwọn wọ̀nyí pẹ̀lú tún jẹ́ ọ̀rọ̀ ọlọ́gbọ́n: láti ṣe ojúsàájú níbi ìdájọ́ kò dára rárá.
24 Ẹnikẹ́ni tí ó wí fún ẹlẹ́bi pé, “Ìwọ lo jàre,” àwọn ènìyàn yóò ṣẹ́ èpè fún un àwọn orílẹ̀-èdè yóò sì kọ̀ ọ́.
25 Ṣùgbọ́n yóò dára fún àwọn tí ń dá ẹlẹ́bi lẹ́bi, ọ̀pọ̀ ìbùkún yóò sì wá sórí wọn.
26 Ìdáhùn òtítọ́ dàbí ìfẹnukoni ní ẹnu.
27 Parí gbogbo iṣẹ́ ajé rẹ sì rí i pé oko rẹ ti ṣe dáradára; lẹ́yìn náà kọ́ ilé rẹ.
28 Má ṣe rojọ́ èké mọ́ aládùúgbò rẹ láìnídìí, tàbí kí o fi ètè rẹ tannijẹ.
29 Má ṣe wí pé, “Èmi yóò ṣe é fún un gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣe fún mi; Èmi yóò san ohun tí ó ṣe fún mi padà fún un.”
30 Mo kọjá níbi oko ọ̀lẹ, mo kọjá níbi ọgbà àjàrà aláìgbọ́n ènìyàn;
31 ẹ̀gún ti hù ní ibi gbogbo, koríko ti gba gbogbo oko náà.
32 Mo fi ọkàn mi sí nǹkan tí mo kíyèsi mo sì kẹ́kọ̀ọ́ lára ohun tí mo rí;
33 oorun díẹ̀, òògbé díẹ̀, ìkáwọ́gbera díẹ̀ láti sinmi,
34 òsì yóò sì dé bá ọ bí adigunjalè àti àìní bí olè.
Chapter information and study resources

Listen to Proverbs 24 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Proverbs 24

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Proverbs 24. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Proverbs 24 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers.

Hebrew interlinear — Proverbs 24:1–34 (269 words)
1
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תְּ֭קַנֵּאtĕqannēʾqana': to be (causatively, make) zealous, i.e. (in a bad sense) jealous or enviousH7065
  3. בְּאַנְשֵׁ֣יbĕʾanšêiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. רָעָ֑הrāʿâra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  5. וְאַלwĕʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  6. תִּ֝תְאָ֗וtitʾāwavah: to wish forH183
  7. לִהְי֥וֹתlihyôthayah: to exist; to be or becomeH1961
  8. אִתָּֽם׃ʾittāmeth: (properly) nearness; (used only as a preposition or an adverb) nearH854
2
  1. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. שֹׁ֭דšōdshod: violence, ravageH7701
  3. יֶהְגֶּ֣הyehgehagah: to murmur (in pleasure or anger); (by implication) to ponderH1897
  4. לִבָּ֑םlibbāmleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  5. וְ֝עָמָ֗לwĕʿāmāl`amal: toil, i.e. wearing effort; (hence) worry, wheth. of body or mindH5999
  6. שִׂפְתֵיהֶ֥םśiptêhemsaphah: the lip (as a natural boundary); (by implication) languageH8193
  7. תְּדַבֵּֽרְנָה׃tĕdabbērĕnâdabar: perhaps properly, to arrange; but used figuratively (of words), to speakH1696
3
  1. בְּ֭חָכְמָהbĕḥokmâchokmah: wisdom (in a good sense)H2451
  2. יִבָּ֣נֶהyibbānebanah: to build (literally and figuratively)H1129
  3. בָּ֑יִתbāyitbayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
  4. וּ֝בִתְבוּנָ֗הûbitbûnâtabuwn: intelligence; (by implication) an argumentH8394
  5. יִתְכּוֹנָֽן׃yitkônānkuwn: (properly) to be erect (i.e. stand perpendicular)H3559
4
  1. וּ֭בְדַעַתûbĕdaʿatda`ath: knowledgeH1847
  2. חֲדָרִ֣יםḥădārîmcheder: an apartment (usually literal)H2315
  3. יִמָּלְא֑וּyimmolʾûmale': to fill or (intransitively) be full of, in a wide application (literally and figuratively)H4390
  4. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  5. ה֖וֹןhônhown: wealth; (by implication) enoughH1952
  6. יָקָ֣רyāqāryaqar: valuableH3368
  7. וְנָעִֽים׃wĕnāʿîmna`iym: delightful (objective or subjective, literal or figurative)H5273
5
  1. גֶּֽבֶרgebergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  2. חָכָ֥םḥākāmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  3. בַּע֑וֹזbaʿôz`oz: strength in various applications (force, security, majesty, praise)H5797
  4. וְאִֽישׁwĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  5. דַּ֝֗עַתdaʿatda`ath: knowledgeH1847
  6. מְאַמֶּץmĕʾammeṣamats: to be alert, physically (on foot) or mentally (in courage)H553
  7. כֹּֽחַ׃kōaḥkoach: vigor, literally (force, in a good or a bad sense) or figuratively (capacity, means, produce)H3581
6
  1. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. בְ֭תַחְבֻּלוֹתbĕtaḥbulôttachbulah: (properly, only in plural) steerage (as the management of steering ropes on a ship)H8458
  3. תַּעֲשֶׂהtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  4. לְּךָ֣lĕkā
  5. מִלְחָמָ֑הmilḥāmâmilchamah: a battle (i.e. the engagement); (generally) war (i.e. warfare)H4421
  6. וּ֝תְשׁוּעָ֗הûtĕšûʿâtshuw`ah: rescue (literal or figurative, pers., national or spir.)H8668
  7. בְּרֹ֣בbĕrōbrob: abundance (in any respect)H7230
  8. יוֹעֵֽץ׃yôʿēṣya`ats: to advise; (reflexively) to deliberate or resolveH3289
7
  1. רָאמ֣וֹתrāʾmôtruwm: to be high actively, to rise or raise (in various applications, literally or figuratively)H7311
  2. לֶֽאֱוִ֣ילleʾĕwîleviyl: (figuratively) sillyH191
  3. חָכְמ֑וֹתḥokmôtchokmowth: wisdomH2454
  4. בַּ֝שַּׁ֗עַרbaššaʿarsha`ar: an opening, i.e. door or gateH8179
  5. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. יִפְתַּחyiptaḥpathach: to open wide (literally or figuratively)H6605
  7. פִּֽיהוּ׃pîhûpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
8
  1. מְחַשֵּׁ֥בmĕḥaššēbchashab: (properly) to plait or interpenetrate, i.e. (literally) to weave or (gen.) to fabricateH2803
  2. לְהָרֵ֑עַlĕhārēaʿra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
  3. ל֝֗וֹlô
  4. בַּֽעַלbaʿalba`al: a masterH1167
  5. מְזִמּ֥וֹתmĕzimmôtmzimmah: a plan, usually evil (machination), sometimes good (sagacity)H4209
  6. יִקְרָֽאוּ׃yiqrāʾûqara': to call out to (i.e. properly, address by name, but used in a wide variety of applications)H7121
9
  1. זִמַּ֣תzimmatzimmah: a plan, especially a bad oneH2154
  2. אִוֶּ֣לֶתʾiwweletivveleth: sillinessH200
  3. חַטָּ֑אתḥaṭṭātchatta'ah: an offence (sometimes habitual sinfulness), and its penalty, occasion, sacrifice, or expiationH2403
  4. וְתוֹעֲבַ֖תwĕtôʿăbattow`ebah: (properly) something disgusting; (morally, as noun) an abhorrenceH8441
  5. לְאָדָ֣םlĕʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  6. לֵֽץ׃lēṣluwts: (properly) to make mouths at, i.e. to scoffH3887
10
  1. הִ֭תְרַפִּיתָhitrappîtāraphah: to slacken (in many applications, literal or figurative)H7503
  2. בְּי֥וֹםbĕyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  3. צָרָ֗הṣārâtsarah: tightness (i.e. figuratively, trouble); transitively, a female rivalH6869
  4. צַ֣רṣartsar: narrow; (as a noun) a tight place (usually figuratively, i.e. trouble)H6862
  5. כֹּחֶֽכָה׃kōḥekâkoach: vigor, literally (force, in a good or a bad sense) or figuratively (capacity, means, produce)H3581
11
  1. הַ֭צֵּלhaṣṣēlnatsal: to snatch away, whether in a good or a bad senseH5337
  2. לְקֻחִ֣יםlĕquḥîmlaqach: to take (in the widest variety of applications)H3947
  3. לַמָּ֑וֶתlammāwetmaveth: death (natural or violent); (concretely) the dead, their place or state (hades)H4194
  4. וּמָטִ֥יםûmāṭîmmowt: to waver; (by implication) , to slip, shake, fallH4131
  5. לַ֝הֶ֗רֶגlahereghereg: slaughterH2027
  6. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  7. תַּחְשֽׂוֹךְ׃taḥśôkchasak: to restrain; (reflexively) refrainH2820
12
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. תֹאמַ֗רtōʾmaramar: to say (used with great latitude)H559
  3. הֵן֮hēnhen: lo!; (as expressing surprise) ifH2005
  4. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. יָדַ֪עְנ֫וּyādaʿnûyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  6. זֶ֥הzezeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  7. הֲֽלֹאhălōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  8. תֹ֘כֵ֤ןtōkēntakan: to balance, i.e. to measure out (by weight or dimension)H8505
  9. לִבּ֨וֹת׀libbôtlibbah: the heartH3826
  10. הֽוּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  11. יָבִ֗יןyābînbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  12. וְנֹצֵ֣רwĕnōṣērnatsar: to guard, in a good sense (to protect, maintain, obey, etc.) or a bad one (to conceal, etc.)H5341
  13. נַ֭פְשְׁךָnapšĕkānephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  14. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  15. יֵדָ֑עyēdāʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  16. וְהֵשִׁ֖יבwĕhēšîbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  17. לְאָדָ֣םlĕʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  18. כְּפָעֳלֽוֹ׃kĕpāʿŏlôpo`al: (concretely) an act or workH6467
13
  1. אֱכָלʾĕkālakal: to eat (literally or figuratively)H398
  2. בְּנִ֣יbĕnîben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  3. דְבַ֣שׁdĕbašdbash: honey (from its stickiness); by analogy, syrupH1706
  4. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  5. ט֑וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  6. וְנֹ֥פֶתwĕnōpetnopheth: a dripping i.e. of honey (from the comb)H5317
  7. מָ֝ת֗וֹקmātôqmathowq: sweetH4966
  8. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  9. חִכֶּֽךָ׃ḥikkekāchek: (properly) the palate or inside of the mouthH2441
14
  1. כֵּ֤ן׀kēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  2. דְּעֶ֥הdĕʿeyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  3. חָכְמָ֗הḥokmâchokmah: wisdom (in a good sense)H2451
  4. לְנַ֫פְשֶׁ֥ךָlĕnapšekānephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  5. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  6. מָ֭צָאתָmāṣāʾtāmatsa': (properly) to come forth to, i.e. appear or existH4672
  7. וְיֵ֣שׁwĕyēšyesh: entity; used adverbially or as a copula for the substantive verb (H1961)H3426
  8. אַחֲרִ֑יתʾaḥărîtachariyth: the last or end; (hence) the futureH319
  9. וְ֝תִקְוָתְךָ֗wĕtiqwotkātiqvah: (literally) a cord (as an attachment); (figuratively) expectancyH8615
  10. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  11. תִכָּרֵֽת׃tikkārētkarath: to cut (off, down or asunder); (by implication) to destroy or consumeH3772
15
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תֶּאֱרֹ֣בteʾĕrōbarab: to lurkH693
  3. רָ֭שָׁעrāšoʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  4. לִנְוֵ֣הlinwēnaveh: (adjectively) at home; (by implication of satisfaction) lovelyH5116
  5. צַדִּ֑יקṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  6. אַֽלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  7. תְּשַׁדֵּ֥דtĕšaddēdshadad: (properly) to be burly; (figuratively) to be powerfulH7703
  8. רִבְצֽוֹ׃ribṣôrebets: a couch or place of reposeH7258
16
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. שֶׁ֨בַע׀šebaʿsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  3. יִפּ֣וֹלyippôlnaphal: to fall, in a great variety of applications (intransitive or causative, literal or figurative)H5307
  4. צַדִּ֣יקṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  5. וָקָ֑םwāqāmquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  6. וּ֝רְשָׁעִ֗יםûrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  7. יִכָּשְׁל֥וּyikkošlûkashal: to totter or waver (through weakness of the legs, especially the ankle)H3782
  8. בְרָעָֽה׃bĕrāʿâra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
17
  1. בִּנְפֹ֣לbinpōlnaphal: to fall, in a great variety of applications (intransitive or causative, literal or figurative)H5307
  2. אֽ֭וֹיִבְיךָʾôyibykāoyeb: hating; an adversaryH341
  3. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  4. תִּשְׂמָ֑חtiśmāḥsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  5. וּ֝בִכָּשְׁל֗וֹûbikkošlôkashal: to totter or waver (through weakness of the legs, especially the ankle)H3782
  6. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  7. יָגֵ֥לyāgēlgiyl: (properly) to spin round (under the influence of any violent emotion), i.e. usually rejoice, or (as cringing) fearH1523
  8. לִבֶּֽךָ׃libbekāleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
18
  1. פֶּןpenpen: (properly) removal; used only (in the construction) adverb as conjunction, lestH6435
  2. יִרְאֶ֣הyirʾera'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  3. יְ֭הוָהyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  4. וְרַ֣עwĕraʿra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
  5. בְּעֵינָ֑יוbĕʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  6. וְהֵשִׁ֖יבwĕhēšîbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  7. מֵעָלָ֣יוmēʿālāyw`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  8. אַפּֽוֹ׃ʾappôaph: (properly) the nose or nostril; (hence) the face, and occasionally a personH639
19
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תִּתְחַ֥רtitḥarcharah: to glow or grow warm; figuratively (usually) to blaze up, of anger, zeal, jealousyH2734
  3. בַּמְּרֵעִ֑יםbammĕrēʿîmra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
  4. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  5. תְּ֝קַנֵּ֗אtĕqannēʾqana': to be (causatively, make) zealous, i.e. (in a bad sense) jealous or enviousH7065
  6. בָּרְשָׁעִֽים׃boršāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
20
  1. כִּ֤י׀kîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. תִהְיֶ֣הtihyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  4. אַחֲרִ֣יתʾaḥărîtachariyth: the last or end; (hence) the futureH319
  5. לָרָ֑עlārāʿra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  6. נֵ֖רnērniyr: H5135) properly, meaning to glisten; a lamp (i.e. the burner) or light (literally or figuratively)H5216
  7. רְשָׁעִ֣יםrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  8. יִדְעָֽךְ׃yidʿākda`ak: to be extinguished; (figuratively) to expire or be dried upH1846
21
  1. יְרָֽאyĕrāʾyare': to fear; morally, to revereH3372
  2. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  3. יְהוָ֣הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  4. בְּנִ֣יbĕnîben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  5. וָמֶ֑לֶךְwāmelekmelek: a kingH4428
  6. עִםʿim`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  7. שׁ֝וֹנִ֗יםšônîmshanah: to fold; (literally or figuratively) to duplicate or doubleH8138
  8. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  9. תִּתְעָרָֽב׃titʿārāb`arab: to braid, i.e. intermix; technically, to traffic (as if by barter)H6148
22
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. פִ֭תְאֹםpitʾōmpith'owm: instantlyH6597
  3. יָק֣וּםyāqûmquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  4. אֵידָ֑םʾêdāmeyd: oppression; (by implication) misfortune, ruinH343
  5. וּפִ֥ידûpîdpiyd: (figuratively) misfortuneH6365
  6. שְׁ֝נֵיהֶ֗םšĕnêhemshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  7. מִ֣יmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  8. יוֹדֵֽעַ׃yôdēaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
23
  1. גַּםgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  2. אֵ֥לֶּהʾēlleel-leh: these or thoseH428
  3. לַֽחֲכָמִ֑יםlaḥăkāmîmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  4. הַֽכֵּרhakkērnakar: (properly) to scrutinize, i.e. look intently atH5234
  5. פָּנִ֖יםpānîmpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  6. בְּמִשְׁפָּ֣טbĕmišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  7. בַּלbalbal: (properly) a failure; (by implication) nothingH1077
  8. טֽוֹב׃ṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
24
  1. אֹ֤מֵ֨ר׀ʾōmēramar: to say (used with great latitude)H559
  2. לְרָשָׁע֮lĕrāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  3. צַדִּ֪יקṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  4. אָ֥תָּהʾāttâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  5. יִקְּבֻ֥הוּyiqqĕbuhûnaqab: to puncture, literally (to perforate, with more or less violence) or figuratively (to specify, designate, libel)H5344
  6. עַמִּ֑יםʿammîm`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  7. יִזְעָמ֥וּהוּyizʿāmûhûza`am: (properly) to foam at the mouth, i.e. to be enragedH2194
  8. לְאֻמִּֽים׃lĕʾummîmlom: a communityH3816
25
  1. וְלַמּוֹכִיחִ֥יםwĕlammôkîḥîmyakach: to be right (i.e. correct); reciprocal, to argueH3198
  2. יִנְעָ֑םyinʿāmna`em: to be agreeable (literally or figuratively)H5276
  3. וַֽ֝עֲלֵיהֶ֗םwaʿălêhem`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. תָּב֥וֹאtābôʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  5. בִרְכַּתbirkatBrakah: benediction; (by implication) prosperityH1293
  6. טֽוֹב׃ṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
26
  1. שְׂפָתַ֥יִםśĕpātayimsaphah: the lip (as a natural boundary); (by implication) languageH8193
  2. יִשָּׁ֑קyiššāqnashaq: to kiss; (literally or figuratively) touchH5401
  3. מֵ֝שִׁ֗יבmēšîbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  4. דְּבָרִ֥יםdĕbārîmdabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  5. נְכֹחִֽים׃nĕkōḥîmnakoach: straightforward, i.e. (figuratively), equitable, correct, or (abstractly), integrityH5228
27
  1. הָ֘כֵ֤ןhākēnkuwn: (properly) to be erect (i.e. stand perpendicular)H3559
  2. בַּח֨וּץ׀baḥûṣchuwts: (properly) separate by a wall, i.e. outside, outdoorsH2351
  3. מְלַאכְתֶּ֗ךָmĕlaktekāmla'kah: (properly) deputyship, i.e. ministry; (generally) employment (never servile)H4399
  4. וְעַתְּדָ֣הּwĕʿattĕdāh`athad: to prepareH6257
  5. בַּשָּׂדֶ֣הbaśśādesadeh: a field (as flat)H7704
  6. לָ֑ךְlāk
  7. אַ֝חַ֗רʾaḥarachar: (properly) the hind part; (generally, as adverb or conjunction) after (in various senses)H310
  8. וּבָנִ֥יתָûbānîtābanah: to build (literally and figuratively)H1129
  9. בֵיתֶֽךָ׃bêtekābayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
28
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תְּהִ֣יtĕhîhayah: to exist; to be or becomeH1961
  3. עֵדʿēd`ed: concretely, a witness; abstractly, testimonyH5707
  4. חִנָּ֣םḥinnāmchinnam: gratis, i.e. devoid of cost, reason or advantageH2600
  5. בְּרֵעֶ֑ךָbĕrēʿekārea`: an associate (more or less close)H7453
  6. וַ֝הֲפִתִּ֗יתָwahăpittîtāpathah: to open, i.e. be (causatively, make) roomyH6601
  7. בִּשְׂפָתֶֽיךָ׃biśpātêkāsaphah: the lip (as a natural boundary); (by implication) languageH8193
29
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תֹּאמַ֗רtōʾmaramar: to say (used with great latitude)H559
  3. כַּאֲשֶׁ֣רkaʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  4. עָֽשָׂהʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  5. לִ֭יlî
  6. כֵּ֤ןkēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  7. אֶֽעֱשֶׂהʾeʿĕśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  8. לּ֑וֹlô
  9. אָשִׁ֖יבʾāšîbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  10. לָאִ֣ישׁlāʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  11. כְּפָעֳלֽוֹ׃kĕpāʿŏlôpo`al: (concretely) an act or workH6467
30
  1. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  2. שְׂדֵ֣הśĕdēsadeh: a field (as flat)H7704
  3. אִישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. עָצֵ֣לʿāṣēl`atsel: indolentH6102
  5. עָבַ֑רְתִּיʿābartî`abar: to cross overH5674
  6. וְעַלwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. כֶּ֝֗רֶםkeremkerem: a garden or vineyardH3754
  8. אָדָ֥םʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  9. חֲסַרḥăsarchacer: lacking; (hence) withoutH2638
  10. לֵֽב׃lēbleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
31
  1. וְהִנֵּ֨הwĕhinnēhinneh: lo!H2009
  2. עָ֘לָ֤הʿālâ`alah: to ascend, intransitively (be high) or actively (mount)H5927
  3. כֻלּ֨וֹ׀kullôkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. קִמְּשֹׂנִ֗יםqimmĕśōnîmcharuwl: (properly) pointed, i.e. a bramble or other thorny weedH2738
  5. כָּסּ֣וּkāssûkacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  6. פָנָ֣יוpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. חֲרֻלִּ֑יםḥărullîmqimmashown: a prickly plantH7063
  8. וְגֶ֖דֶרwĕgedergeder: a circumvallationH1444
  9. אֲבָנָ֣יוʾăbānāyweben: a stoneH68
  10. נֶהֱרָֽסָה׃nehĕrāsâharac: to pull down or in pieces, break, &Š destroyH2040
32
  1. וָֽאֶחֱזֶ֣הwāʾeḥĕzechazah: to gaze at; mentally, to perceive, contemplate (with pleasure)H2372
  2. אָ֭נֹכִֽיʾānōkîanokiy: IH595
  3. אָשִׁ֣יתʾāšîtshiyth: to place (in a very wide application)H7896
  4. לִבִּ֑יlibbîleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  5. רָ֝אִ֗יתִיrāʾîtîra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  6. לָקַ֥חְתִּיlāqaḥtîlaqach: to take (in the widest variety of applications)H3947
  7. מוּסָֽר׃mûsārmuwcar: (properly) chastisement; (figuratively) reproof, warning or instructionH4148
33
  1. מְעַ֣טmĕʿaṭm`at: a little or few (often adverbial or compar.)H4592
  2. שֵׁ֭נוֹתšēnôtshehah: sleepH8142
  3. מְעַ֣טmĕʿaṭm`at: a little or few (often adverbial or compar.)H4592
  4. תְּנוּמ֑וֹתtĕnûmôttnuwmah: drowsiness, i.e. sleepH8572
  5. מְעַ֓ט׀mĕʿaṭm`at: a little or few (often adverbial or compar.)H4592
  6. חִבֻּ֖קḥibbuqchibbuq: a clasping of the hands (in idleness)H2264
  7. יָדַ֣יִםyādayimyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  8. לִשְׁכָּֽב׃liškābshakab: to lie down (for rest, sexual connection, decease or any other purpose)H7901
34
  1. וּבָֽאûbāʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  2. מִתְהַלֵּ֥ךְmithallēkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  3. רֵישֶׁ֑ךָrêšekāreysh: povertyH7389
  4. וּ֝מַחְסֹרֶ֗יךָûmaḥsōrêkāmachcowr: deficiency; (hence) impoverishmentH4270
  5. כְּאִ֣ישׁkĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  6. מָגֵֽן׃māgēnmagen: a shield (i.e. the small one or buckler)H4043

View the full Hebrew interlinear for Proverbs 24 →

Strong's words in Proverbs 24 (6)
Strong's H408 — אַל (ʾal)
al (al) adv. 1. (qualified negation) not (used as a deprecative) 2. (as a noun) nothing (used once in Job 24 [a negative particle (akin to H3808)] KJV: nay, neither, + never, no ,nor, not, nothing (worth), rather than. Root(s): H3808. Appears 11 times in Proverbs 24.
Strong's H376 — בְּאַנְשֵׁ֣י (bĕʾanšê)
iysh (eesh) n-m. 1. a man as an individual or a male person 2. often used as an adjunct to a more definite term (and in such cases frequently not expressed in translation) [contracted for H582 (or perhaps rather from an unused root meaning to be extant)] KJV: also, another, any (man), a certain, + champion, consent, each, every (one), fellow, (foot-, husband-)man, (good-, great, mighty) man, he, high (degree), him (that is), husband, man(-kind), + none, one, people, person, + steward, what (man) soever, whoso(-ever), worthy. Root(s): H582 Compare: H802. Appears 5 times in Proverbs 24.
Strong's H7563 — רָ֭שָׁע (rāšoʿ)
rasha` (raw-shaw') adj. 1. morally wrong 2. (concretely) an (actively) bad person [from H7561] KJV: + condemned, guilty, ungodly, wicked (man), that did wrong. Root(s): H7561. Appears 5 times in Proverbs 24.
Strong's H3045 — יָדַ֪עְנ֫וּ (yādaʿnû)
yada` (yaw-dah') v. 1. to know 2. (properly) to ascertain by seeing 3. used in a great variety of senses 4. figuratively, literally, euphemistically and inferentially (including observation, care, recognition 5. and causatively, instruction, designation, punishment, etc.) (as follow) [a primitive root] KJV: acknowledge, acquaintance(-ted with), advise, answer, appoint, assuredly, be aware, (un-)awares, can(-not), certainly, comprehend, consider, X could they, cunning, declare, be diligent, (can, cause to) discern, discover, endued with, familiar friend, famous, feel, can have, be (ig-)norant, instruct, kinsfolk, kinsman, (cause to let, make) know, (come to give, have, take) knowledge, have (knowledge), (be, make, make to be, make self) known, + be learned, + lie by man, mark, perceive, privy to, X prognosticator, regard, have respect, skilful, shew, can (man of) skill, be sure, of a surety, teach, (can) tell, understand, have (understanding), X will be, wist, wit, wot.. Appears 4 times in Proverbs 24.
Strong's H3820 — לִבָּ֑ם (libbām)
leb (labe) n-m. 1. the heart 2. also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellect 3. likewise for the centre of anything [a form of H3824] KJV: + care for, comfortably, consent, X considered, courag(-eous), friend(-ly), ((broken-), (hard-), (merry-), (stiff-), (stout-), double) heart((-ed)), X heed, X I, kindly, midst, mind(-ed), X regard((-ed)), X themselves, X unawares, understanding, X well, willingly, wisdom. Root(s): H3824. Appears 4 times in Proverbs 24.
Strong's H7725 — וְהֵשִׁ֖יב (wĕhēšîb)
shuwb (shoob) v. 1. to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the idea of return to the starting point) 2. (generally) to retreat 3. (often adverbially) again [a primitive root] KJV: ((break, build, circumcise, dig, do anything, do evil, feed, lay down, lie down, lodge, make, rejoice, send, take, weep)) X again, (cause to) answer (+ again), X in any case (wise), X at all, averse, bring (again, back, home again), call (to mind), carry again (back), cease, X certainly, come again (back), X consider, + continually, convert, deliver (again), + deny, draw back, fetch home again, X fro, get (oneself) (back) again, X give (again), go again (back, home), (go) out, hinder, let, (see) more, X needs, be past, X pay, pervert, pull in again, put (again, up again), recall, recompense, recover, refresh, relieve, render (again), requite, rescue, restore, retrieve, (cause to, make to) return, reverse, reward, + say nay, send back, set again, slide back, still, X surely, take back (off), (cause to, make to) turn (again, self again, away, back, back again, backward, from, off), withdraw.. Appears 4 times in Proverbs 24.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress