Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Job 15 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé,
2 “Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán kí ó sì máa fi afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn kún ara rẹ̀ nínú?
3 Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè, tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere?
4 Ṣùgbọ́n ìwọ ṣá ìbẹ̀rù tì, ìwọ sì dí iṣẹ́ ìsìn lọ́nà níwájú Ọlọ́run.
5 Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, ìwọ sì yàn ahọ́n alárékérekè ni ààyò.
6 Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi; àní ètè ara rẹ̀ ni ó jẹ́rìí gbè ọ́.
7 “Ìwọ ha í ṣe ọkùnrin tí a kọ́ bí? Tàbí a ha dá ọ ṣáájú àwọn òkè?
8 Ìwọ gbúròó àṣírí Ọlọ́run rí? Tàbí ìwọ ha dá ọgbọ́n dúró sọ́dọ̀ ara rẹ?
9 Kí ni ìwọ mọ̀ tí àwa kò mọ̀? Òye kí ní ó yé ọ tí kò sí nínú wa?
10 Àwọn arúgbó àti ògbólógbòó ènìyàn wà pẹ̀lú wa, tí wọ́n dàgbà ju baba rẹ lọ.
11 Ìtùnú Ọlọ́run ha kéré lọ́dọ̀ rẹ? Ọ̀rọ̀ kan sì ṣe jẹ́jẹ́ jù lọ́dọ̀ rẹ?
12 Èéṣe ti ọkàn rẹ fi ń ti ọ kiri, kí ni ìwọ tẹjúmọ́ tóbẹ́ẹ̀.
13 Tí ìwọ fi yí ẹ̀mí rẹ padà lòdì sí Ọlọ́run, tí ó fi ń jẹ́ ki ọ̀rọ̀kọ́rọ̀ kí ó máa bọ́ ní ẹnu rẹ̀ bẹ́ẹ̀?
14 “Kí ni ènìyàn tí ó fi jẹ mímọ́, àti ẹni tí a tinú obìnrin bí tí yóò fi ṣe olódodo?
15 Kíyèsi i, bi Ọlọ́run ko ba gbẹ́kẹ̀lé àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀, àní àwọn ọ̀run kò mọ́ ní ojú rẹ̀,
16 mélòó mélòó ni ènìyàn, ẹni ìríra àti eléèérí, tí ń mu ẹ̀ṣẹ̀ bi ẹní mu omi.
17 “Èmi ó fihàn ọ́, gbọ́ ti èmi; èyí tí èmi sì rí, òun ni èmi ó sì sọ,
18 ohun tí àwọn ọlọ́gbọ́n ti pa ní ìtàn láti ọ̀dọ̀ àwọn baba wọn wá, ti wọ́n kò sì fi pamọ́.
19 Àwọn tí a fi ilẹ̀ ayé fún nìkan, ti àlejò kan kò sì là wọ́n kọjá.
20 Ènìyàn búburú ń ṣe làálàá, pẹ̀lú ìrora, ní ọjọ́ rẹ̀ gbogbo, àti iye ọdún ní a dá sílẹ̀ fún aninilára.
21 Ìró ìbẹ̀rù ń bẹ ní etí rẹ̀; nínú ìrora ni apanirun yóò dìde sí i.
22 Kò gbàgbọ́ pé òun ó jáde kúrò nínú òkùnkùn; a sì ṣà á sápá kan fún idà.
23 Ó ń wò káàkiri fún oúnjẹ wí pé, níbo ní ó wà? Ó mọ̀ pé ọjọ́ òkùnkùn súnmọ́ tòsí.
24 Ìpọ́njú pẹ̀lú ìrora ọkàn yóò mú un bẹ̀rù, wọ́n ó sì ṣẹ́gun rẹ̀ bi ọba ti ìmúra ogun.
25 Nítorí pé ó ti nawọ́ rẹ̀ jáde lòdì sí Ọlọ́run, ó sì múra rẹ̀ le lòdì sí Olódùmarè,
26 ó súre, ó sì fi ẹ̀yìn gíga, àní fi ike-kókó àpáta rẹ̀ tí ó nípọn kọlù ú.
27 “Nítorí tí òun fi ọ̀rá rẹ̀ bo ara rẹ̀ lójú, o sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀.
28 Òun sì gbé inú ahoro ìlú, àti nínú ilẹ̀ tí ènìyàn kò gbé mọ́, tí ó múra tán láti di àlàpà.
29 Òun kò lé di ọlọ́rọ̀, bẹ́ẹ̀ ohun ìní rẹ̀ kò lè dúró pẹ́; bẹ́ẹ̀ kò lè mú pípé rẹ̀ dúró pẹ́ lórí ilẹ̀.
30 Òun kì yóò jáde kúrò nínú òkùnkùn; ọ̀wọ́-iná ni yóò jó ẹ̀ka rẹ̀, àti nípasẹ̀ ẹ̀mí ẹnu Ọlọ́run ní a ó gba kúrò.
31 Kí òun kí ó má ṣe gbẹ́kẹ̀lé asán, kí ó má sì ṣe tan ara rẹ̀ jẹ. Nítorí pé asán ní yóò jásí èrè rẹ̀.
32 A ó mú un ṣẹ ṣáájú pípé ọjọ́ rẹ̀, ẹ̀ka rẹ̀ kì yóò sì tutù.
33 Yóò dàbí àjàrà tí a gbọn èso àìpọ́n rẹ̀ dànù, yóò sì rẹ̀ ìtànná rẹ̀ dànù bí i ti igi Olifi.
34 Nítorí pé ayọ̀ àwọn àgàbàgebè yóò túká, iná ní yóò sì jó àgọ́ àwọn tí ó fẹ́ràn àbẹ̀tẹ́lẹ̀.
35 Wọ́n lóyún ìwà ìkà, wọ́n sì bí ẹ̀ṣẹ̀, ikùn wọn sì pèsè ẹ̀tàn.”
Chapter information and study resources

Listen to Job 15 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Job 15

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Job 15. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Job 15 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 23 cross-references.

Cross-references in Job 15 (23)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Job 15:1–35 (259 words)
1
  1. וַ֭יַּעַןwayyaʿan`anah: (properly) to eye; (generally) to heed, i.e. pay attentionH6030
  2. אֱלִיפַ֥זʾĕlîpazEliyphaz: God of gold; Eliphaz, the name of one of Job's friends, and of a son of EsauH464
  3. הַֽתֵּימָנִ֗יhattêmānîTeymaniy: a Temanite or descendant of TemanH8489
  4. וַיֹּאמַֽר׃wayyōʾmaramar: to say (used with great latitude)H559
2
  1. הֶֽחָכָ֗םheḥākāmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  2. יַעֲנֶ֥הyaʿăne`anah: (properly) to eye; (generally) to heed, i.e. pay attentionH6030
  3. דַֽעַתdaʿatda`ath: knowledgeH1847
  4. ר֑וּחַrûaḥruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  5. וִֽימַלֵּ֖אwîmallēʾmale': to fill or (intransitively) be full of, in a wide application (literally and figuratively)H4390
  6. קָדִ֣יםqādîmqadiym: the fore or front part; hence (by orientation) the East (often adverbially, eastward, for brevity the east wind)H6921
  7. בִּטְנֽוֹ׃biṭnôbeten: the belly, especially the womb; also the bosom or body of anythingH990
3
  1. הוֹכֵ֣חַhôkēaḥyakach: to be right (i.e. correct); reciprocal, to argueH3198
  2. בְּ֭דָבָרbĕdābordabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  3. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יִסְכּ֑וֹןyiskôncakan: to be familiar with; (by implication) to minister to, be serviceable to, be customaryH5532
  5. וּ֝מִלִּ֗יםûmillîmmillah: a word; collectively, a discourseH4405
  6. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. יוֹעִ֥ילyôʿîlya`al: (properly) to ascend; (figuratively) to be valuable (objectivelyH3276
4
  1. אַףʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  2. אַ֭תָּהʾattâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  3. תָּפֵ֣רtāpērparar: to break up (usually figuratively, i.e. to violate, frustrateH6565
  4. יִרְאָ֑הyirʾâyir'ah: fear (also used as infinitive); morally, reverenceH3374
  5. וְתִגְרַ֥עwĕtigraʿgara`: to scrape off; (by implication) to shave, remove, lessen, withholdH1639
  6. שִׂ֝יחָ֗הśîḥâsiychah: reflection; be extension, devotionH7881
  7. לִפְנֵיlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  8. אֵֽל׃ʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
5
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. יְאַלֵּ֣ףyĕʾallēpalph: hence, to learn (and causatively to teach)H502
  3. עֲוֺנְךָ֣ʿăwōnĕkā`avon: perversity, i.e. (moral) evilH5771
  4. פִ֑יךָpîkāpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
  5. וְ֝תִבְחַ֗רwĕtibḥarbachar: (properly) to try; (by implication) selectH977
  6. לְשׁ֣וֹןlĕšônlashown: the tongue (of man or animals), used literally (as the instrument of licking, eating, or speech), and...H3956
  7. עֲרוּמִֽים׃ʿărûmîm`aruwm: cunning (usually in a bad sense)H6175
6
  1. יַרְשִֽׁיעֲךָ֣yaršîʿăkārasha`: to be wrong; (causatively) to do or declare wrongH7561
  2. פִ֣יךָpîkāpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
  3. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. אָ֑נִיʾānîaniy: IH589
  5. וּ֝שְׂפָתֶ֗יךָûśĕpātêkāsaphah: the lip (as a natural boundary); (by implication) languageH8193
  6. יַעֲנוּyaʿănû`anah: (properly) to eye; (generally) to heed, i.e. pay attentionH6030
7
  1. הֲרִאישׁ֣וֹןhăriyšônri'shown: first, in place, time or rank (as adjective or noun)H7223
  2. אָ֭דָםʾādomadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  3. תִּוָּלֵ֑דtiwwālēdyalad: to bear young; (causatively) to begetH3205
  4. וְלִפְנֵ֖יwĕlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  5. גְבָע֣וֹתgĕbāʿôtgib`ah: a hillockH1389
  6. חוֹלָֽלְתָּ׃ḥôlālĕttāchuwl: (properly) to twist or whirl (in a circular or spiral manner), i.e. (specifically) to dance, to writhe in pain...H2342
8
  1. הַבְס֣וֹדhabsôdcowd: a session, i.e. company of persons (in close deliberation)H5475
  2. אֱל֣וֹהַʾĕlôahelowahh: a deity or the DeityH433
  3. תִּשְׁמָ֑עtišmāʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  4. וְתִגְרַ֖עwĕtigraʿgara`: to scrape off; (by implication) to shave, remove, lessen, withholdH1639
  5. אֵלֶ֣יךָʾēlêkāel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  6. חָכְמָֽה׃ḥokmâchokmah: wisdom (in a good sense)H2451
9
  1. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. יָּ֭דַעְתָּyādaʿtāyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  3. וְלֹ֣אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. נֵדָ֑עnēdāʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  5. תָּ֝בִ֗יןtābînbiyn: to separate mentally (or distinguish); (generally) understandH995
  6. וְֽלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. עִמָּ֥נוּʿimmānû`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  8. הֽוּא׃hûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
10
  1. גַּםgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  2. שָׂ֣בśābsiyb: (properly) to become aged; (by implication) to grow grayH7867
  3. גַּםgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  4. יָשִׁ֣ישׁyāšîšyashiysh: an old manH3453
  5. בָּ֑נוּbānû
  6. כַּבִּ֖ירkabbîrkabbiyr: vast, whether in extent (figuratively, of power, mightyH3524
  7. מֵאָבִ֣יךָmēʾābîkāab: fatherH1
  8. יָמִֽים׃yāmîmyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
11
  1. הַמְעַ֣טhamʿaṭm`at: a little or few (often adverbial or compar.)H4592
  2. מִ֭מְּךָmimmĕkāmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  3. תַּנְחוּמ֣וֹתtanḥûmôttanchuwm: compassion, solaceH8575
  4. אֵ֑לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  5. וְ֝דָבָ֗רwĕdābārdabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  6. לָאַ֥טlāʾaṭat: (as a noun) a necromancer (from their soft incantations), (as an adverb) gentlyH328
  7. עִמָּֽךְ׃ʿimmāk`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
12
  1. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. יִּקָּחֲךָ֥yiqqāḥăkālaqach: to take (in the widest variety of applications)H3947
  3. לִבֶּ֑ךָlibbekāleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  4. וּֽמַהûmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  5. יִּרְזְמ֥וּןyirzĕmûnrazam: to twinkle the eye (in mockery)H7335
  6. עֵינֶֽיךָ׃ʿênêkā`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
13
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. תָשִׁ֣יבtāšîbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  3. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. אֵ֣לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  5. רוּחֶ֑ךָrûḥekāruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  6. וְהֹצֵ֖אתָwĕhōṣēʾtāyatsa': to go out; (causatively) to bring outH3318
  7. מִפִּ֣יךָmippîkāpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
  8. מִלִּֽין׃millînmillah: a word; collectively, a discourseH4405
14
  1. מָֽהmâmah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. אֱנ֥וֹשׁʾĕnôšenowsh: (properly) a mortal (and thus differing from the more dignified H0120)H582
  3. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  4. יִזְכֶּ֑הyizkezakah: to be translucent; (figuratively) to be innocentH2135
  5. וְכִֽיwĕkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  6. יִ֝צְדַּ֗קyiṣdaqtsadaq: to be (causatively, make) right (in a moral or forensic sense)H6663
  7. יְל֣וּדyĕlûdyalad: to bear young; (causatively) to begetH3205
  8. אִשָּֽׁה׃ʾiššâishshah: irregular plural, nashiym {naw-sheem'}; a woman (used in the same wide sense as H0582)H802
15
  1. הֵ֣ןhēnhen: lo!; (as expressing surprise) ifH2005
  2. בִּ֭קְדֹשָׁוbiqdōšowqadowsh: sacred (ceremonially or morally); (as noun) GodH6918
  3. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יַאֲמִ֑יןyaʾămînaman: (properly) to build up or support; to foster as a parent or nurseH539
  5. וְ֝שָׁמַ֗יִםwĕšāmayimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
  6. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. זַכּ֥וּzakkûzakak: to be transparent or clean (phys. or morally)H2141
  8. בְעֵינָֽיו׃bĕʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
16
  1. אַ֭ףʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  2. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  3. נִתְעָ֥בnitʿābta`ab: to loathe, i.e. (morally) detestH8581
  4. וְֽנֶאֱלָ֑חwĕneʾĕlāḥalach: to muddle; (figuratively and intransitive) to turnH444
  5. אִישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  6. שֹׁתֶ֖הšōteshathah: to imbibe (literally or figuratively)H8354
  7. כַמַּ֣יִםkammayimmayim: water; (figuratively) juiceH4325
  8. עַוְלָֽה׃ʿawlâ`evel: (moral) evilH5766
17
  1. אֲחַוְךָ֥ʾăḥawkāchavah: (properly) to live; (by implication) (intensively) to declare or showH2331
  2. שְֽׁמַֽעšĕmaʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  3. לִ֑יlî
  4. וְזֶֽהwĕzezeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  5. חָ֝זִ֗יתִיḥāzîtîchazah: to gaze at; mentally, to perceive, contemplate (with pleasure)H2372
  6. וַאֲסַפֵּֽרָה׃waʾăsappērâcaphar: (properly) to score with a mark as a tally or recordH5608
18
  1. אֲשֶׁרʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  2. חֲכָמִ֥יםḥăkāmîmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  3. יַגִּ֑ידוּyaggîdûnagad: (properly) to front, i.e. stand boldly out oppositeH5046
  4. וְלֹ֥אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. כִֽ֝חֲד֗וּkiḥădûkachad: to secrete, by act or word; hence (intensively) to destroyH3582
  6. מֵאֲבוֹתָֽם׃mēʾăbôtāmab: fatherH1
19
  1. לָהֶ֣םlāhem
  2. לְ֭בַדָּםlĕbaddombad: (properly) separation; (by implication) a part of the body, branch of a tree, bar for carryingH905
  3. נִתְּנָ֣הnittĕnânathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  4. הָאָ֑רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. עָ֖בַרʿābar`abar: to cross overH5674
  7. זָ֣רzārzuwr: to turn aside (especially for lodging); hence to be a foreigner, strange, profaneH2114
  8. בְּתוֹכָֽם׃bĕtôkāmtavek: a bisection; (by implication) the centreH8432
20
  1. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. יְמֵ֣יyĕmêyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  3. רָ֭שָׁעrāšoʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  4. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  5. מִתְחוֹלֵ֑לmitḥôlēlchuwl: (properly) to twist or whirl (in a circular or spiral manner), i.e. (specifically) to dance, to writhe in pain...H2342
  6. וּמִסְפַּ֥רûmisparmicpar: a number; (definite) arithmetical numberH4557
  7. שָׁ֝נִ֗יםšānîmshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
  8. נִצְפְּנ֥וּniṣpĕnûtsaphan: to hide (by covering over); (by implication) to hoard or reserveH6845
  9. לֶעָרִֽיץ׃leʿārîṣ`ariyts: fearful, i.e. powerful or tyrannicalH6184
21
  1. קוֹלqôlqowl: a voice or soundH6963
  2. פְּחָדִ֥יםpĕḥādîmpachad: a (sudden) alarm; (properly) the object fearedH6343
  3. בְּאָזְנָ֑יוbĕʾoznāywozen: broadness; (concretely) the ear (from its form in man)H241
  4. בַּ֝שָּׁל֗וֹםbaššālômshalowm: safe; (figuratively) well, happy, friendlyH7965
  5. שׁוֹדֵ֥דšôdēdshadad: (properly) to be burly; (figuratively) to be powerfulH7703
  6. יְבוֹאֶֽנּוּ׃yĕbôʾennûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
22
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יַאֲמִ֣יןyaʾămînaman: (properly) to build up or support; to foster as a parent or nurseH539
  3. שׁ֭וּבšûbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  4. מִנִּיminnîmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  5. חֹ֑שֶׁךְḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
  6. וְצָפ֖וּwĕṣāpûtsaphah: (properly) to lean forward, i.e. to peer into the distanceH6822
  7. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. אֱלֵיʾĕlêel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  9. חָֽרֶב׃ḥārebchereb: drought; also a cutting instrument (from its destructive effect), as a knife, sword, or other sharp implementH2719
23
  1. נֹ֘דֵ֤דnōdēdnadad: (properly) to wave to and fro (rarely to flap up and down)H5074
  2. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  3. לַלֶּ֣חֶםlalleḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  4. אַיֵּ֑הʾayyēayeh: where?H346
  5. יָדַ֓ע׀yādaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  6. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  7. נָכ֖וֹןnākônkuwn: (properly) to be erect (i.e. stand perpendicular)H3559
  8. בְּיָד֣וֹbĕyādôyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  9. יֽוֹםyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  10. חֹֽשֶׁךְ׃ḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
24
  1. יְֽ֭בַעֲתֻהוּyĕbaʿătuhûba`ath: to fearH1204
  2. צַ֣רṣartsar: narrow; (as a noun) a tight place (usually figuratively, i.e. trouble)H6862
  3. וּמְצוּקָ֑הûmĕṣûqâmtsuwqah: narrowness, i.e. (figuratively) troubleH4691
  4. תִּ֝תְקְפֵ֗הוּtitqĕpēhûtaqaph: to overpowerH8630
  5. כְּמֶ֤לֶךְ׀kĕmelekmelek: a kingH4428
  6. עָתִ֬ידʿātîd`athiyd: prepared; (by implication) skilfulH6264
  7. לַכִּידֽוֹר׃lakkîdôrkiydowr: perhaps tumultH3593
25
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. נָטָ֣הnāṭânatah: to stretch or spread out; (by implication) to bend away (including moral deflection)H5186
  3. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. אֵ֣לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  5. יָד֑וֹyādôyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  6. וְאֶלwĕʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  7. שַׁ֝דַּ֗יšaddayShadday: the AlmightyH7706
  8. יִתְגַּבָּֽר׃yitgabbārgabar: to be strong; (by implication) to prevail, act insolentlyH1396
26
  1. יָר֣וּץyārûṣruwts: to run (for whatever reason, especially to rush)H7323
  2. אֵלָ֣יוʾēlāywel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  3. בְּצַוָּ֑ארbĕṣawwārtsavva'r: the back of the neck (as that on which burdens are bound)H6677
  4. בַּ֝עֲבִ֗יbaʿăbî`abiy: density, i.e. depth or widthH5672
  5. גַּבֵּ֥יgabbêgab: the back (as rounded); by analogy, the top or rim, a boss, a vault, arch of eye, bulwarks, etcH1354
  6. מָֽגִנָּֽיו׃māginnāywmagen: a shield (i.e. the small one or buckler)H4043
27
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. כִסָּ֣הkissâkacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  3. פָנָ֣יוpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  4. בְּחֶלְבּ֑וֹbĕḥelbôcheleb: fat, whether literally or figuratively; (hence) the richest or choice partH2459
  5. וַיַּ֖עַשׂwayyaʿaś`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  6. פִּימָ֣הpîmâpiymah: obesityH6371
  7. עֲלֵיʿălê`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  8. כָֽסֶל׃kāselkecel: (properly) fatness; (by implication, literally) the loin (as the seat of the leaf fat)H3689
28
  1. וַיִּשְׁכּ֤וֹן׀wayyiškônshakan: to reside or permanently stay (literally or figuratively)H7931
  2. עָ֘רִ֤יםʿārîm`iyr: a city (a place guarded by waking or a watch) in the widest sense (even of a mere encampment or post)H5892
  3. נִכְחָד֗וֹתnikḥādôtkachad: to secrete, by act or word; hence (intensively) to destroyH3582
  4. בָּ֭תִּיםbāttîmbayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
  5. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. יֵ֣שְׁבוּyēšĕbûyashab: (properly) to sit down (specifically as judge. in ambush, in quiet)H3427
  7. לָ֑מוֹlāmô
  8. אֲשֶׁ֖רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  9. הִתְעַתְּד֣וּhitʿattĕdû`athad: to prepareH6257
  10. לְגַלִּֽים׃lĕgallîmgal: something rolled, i.e. a heap of stone or dung (plural ruins), by analogy, a spring of water (plural waves)H1530
29
  1. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יֶ֭עְשַׁרyeʿšar`ashar: (properly) to accumulate; chiefly (specifically) to grow (causatively, make) richH6238
  3. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יָק֣וּםyāqûmquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  5. חֵיל֑וֹḥêlôchayil: probably a force, whether of men, means or other resourcesH2428
  6. וְלֹֽאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. יִטֶּ֖הyiṭṭenatah: to stretch or spread out; (by implication) to bend away (including moral deflection)H5186
  8. לָאָ֣רֶץlāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  9. מִנְלָֽם׃minlāmminleh: completion, i.e. (in produce) wealthH4512
30
  1. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יָס֨וּר׀yāsûrcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  3. מִנִּיminnîmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  4. חֹ֗שֶׁךְḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
  5. יֹֽ֭נַקְתּוֹyōnaqtôyowneqeth: a sproutH3127
  6. תְּיַבֵּ֣שׁtĕyabbēšyabesh: to be ashamed, confused or disappointed; (as failing) to dry up (as water) or wither (as herbage)H3001
  7. שַׁלְהָ֑בֶתšalhābetshalhebeth: a flare of fireH7957
  8. וְ֝יָס֗וּרwĕyāsûrcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  9. בְּר֣וּחַbĕrûaḥruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  10. פִּֽיו׃pîwpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
31
  1. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. יַאֲמֵ֣ןyaʾămēnaman: (properly) to build up or support; to foster as a parent or nurseH539
  3. בַּשָּׁ֣וbaššāwshav': evil (as destructive), literally (ruin) or morally (especially guile)H7723
  4. נִתְעָ֑הnitʿâta`ah: to vacillate, i.e. reel or stray (literally or figuratively)H8582
  5. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  6. שָׁ֝֗וְאšāwĕʾshav': evil (as destructive), literally (ruin) or morally (especially guile)H7723
  7. תִּהְיֶ֥הtihyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  8. תְמוּרָתֽוֹ׃tĕmûrātôtmuwrah: barter, compensationH8545
32
  1. בְּֽלֹאbĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. י֭וֹמוֹyômôyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  3. תִּמָּלֵ֑אtimmālēʾmale': to fill or (intransitively) be full of, in a wide application (literally and figuratively)H4390
  4. וְ֝כִפָּת֗וֹwĕkippātôkippah: a leaf of a palm-treeH3712
  5. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. רַעֲנָֽנָה׃raʿănānâra`anan: green; (figuratively) prosperousH7488
33
  1. יַחְמֹ֣סyaḥmōschamac: to be violent; (by implication) to maltreatH2554
  2. כַּגֶּ֣פֶןkaggepengephen: a vine (as twining), especially the grapeH1612
  3. בִּסְר֑וֹbisrôbecer: an immature grapeH1154
  4. וְיַשְׁלֵ֥ךְwĕyašlēkshalak: to throw out, down or away (literally or figuratively)H7993
  5. כַּ֝זַּ֗יִתkazzayitzayith: an olive (as yielding illuminating oil), the tree, the branch or the berryH2132
  6. נִצָּתֽוֹ׃niṣṣātônitstsah: a blossomH5328
34
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. עֲדַ֣תʿădat`edah: a stated assemblage; (specifically) a concourseH5712
  3. חָנֵ֣ףḥānēpchaneph: soiled (i.e. with sin), impiousH2611
  4. גַּלְמ֑וּדgalmûdgalmuwd: sterile (as wrapped up too hard); (figuratively) desolateH1565
  5. וְ֝אֵ֗שׁwĕʾēšesh: fire (literally or figuratively)H784
  6. אָכְלָ֥הʾoklâakal: to eat (literally or figuratively)H398
  7. אָֽהֳלֵיʾāhŏlêohel: a tent (as clearly conspicuous from a distance)H168
  8. שֹֽׁחַד׃šōḥadshachad: a donation (venal or redemptive)H7810
35
  1. הָרֹ֣הhārōharah: to be (or become) pregnant, conceive (literally or figuratively)H2029
  2. עָ֭מָלʿāmol`amal: toil, i.e. wearing effort; (hence) worry, wheth. of body or mindH5999
  3. וְיָ֣לֹדwĕyālōdyalad: to bear young; (causatively) to begetH3205
  4. אָ֑וֶןʾāwenaven: (strictly) nothingness; (also) trouble, vanity, wickednessH205
  5. וּ֝בִטְנָ֗םûbiṭnāmbeten: the belly, especially the womb; also the bosom or body of anythingH990
  6. תָּכִ֥יןtākînkuwn: (properly) to be erect (i.e. stand perpendicular)H3559
  7. מִרְמָֽה׃mirmâmirmah: fraudH4820

View the full Hebrew interlinear for Job 15 →

Strong's words in Job 15 (6)
Strong's H3117 — יָמִֽים׃ (yāmîm)
yowm (yome) n-m. 1. a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or figurative (a space of time defined by an associated term), (often used adverb) [from an unused root meaning to be hot] KJV: age, + always, + chronicals, continually(-ance), daily, ((birth-), each, to) day, (now a, two) days (agone), + elder, X end, + evening, + (for) ever(-lasting, -more), X full, life, as (so) long as (... live), (even) now, + old, + outlived, + perpetually, presently, + remaineth, X required, season, X since, space, then, (process of) time, + as at other times, + in trouble, weather, (as) when, (a, the, within a) while (that), X whole (+ age), (full) year(-ly), + younger.. Appears 4 times in Job 15.
Strong's H410 — אֵֽל׃ (ʾēl)
el (ale) n-m. 1. strength 2. (as adjective) mighty 3. (especially) the Almighty (but used also of any deity) [shortened from H352] KJV: God (god), X goodly, X great, idol, might(-y one), power, strong. Root(s): H352 Compare: names, in, "-el.". Appears 4 times in Job 15.
Strong's H4100 — מַה (ma)
mah (maw) (or mah {mah} or ma {maw}; or ma {mah}; also meh {meh};) p/i. 1. (properly, interrogative) what? (including how? why? when?) 2. (also, exclamation) what! (including how!) 3. (indefinitely) what (including whatever, and even relatively, that which) 4. often used with prefixes in various adverbial or conjunctive senses [a primitive particle] KJV: how (long, oft, (- soever)), (no-)thing, what (end, good, purpose, thing), whereby(-fore, -in, -to, -with), (for) why.. Appears 4 times in Job 15.
Strong's H6310 — פִ֑יךָ (pîkā)
peh (peh) n-m. 1. the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech) 2. specifically edge, portion or side 3. adverbially (with preposition) according to [from H6284] KJV: accord(-ing as, -ing to), after, appointment, assent, collar, command(-ment), X eat, edge, end, entry, + file, hole, X in, mind, mouth, part, portion, X (should) say(-ing), sentence, skirt, sound, speech, X spoken, talk, tenor, X to, + two-edged, wish, word. Root(s): H6284. Appears 4 times in Job 15.
Strong's H2822 — חֹ֑שֶׁךְ (ḥōšek)
choshek (kho-shek') n-m. 1. the dark 2. hence (literally) darkness 3. (figuratively) misery, destruction, death, ignorance, sorrow, wickedness [from H2821] KJV: dark(-ness), night, obscurity. Root(s): H2821. Appears 3 times in Job 15.
Strong's H3045 — יָּ֭דַעְתָּ (yādaʿtā)
yada` (yaw-dah') v. 1. to know 2. (properly) to ascertain by seeing 3. used in a great variety of senses 4. figuratively, literally, euphemistically and inferentially (including observation, care, recognition 5. and causatively, instruction, designation, punishment, etc.) (as follow) [a primitive root] KJV: acknowledge, acquaintance(-ted with), advise, answer, appoint, assuredly, be aware, (un-)awares, can(-not), certainly, comprehend, consider, X could they, cunning, declare, be diligent, (can, cause to) discern, discover, endued with, familiar friend, famous, feel, can have, be (ig-)norant, instruct, kinsfolk, kinsman, (cause to let, make) know, (come to give, have, take) knowledge, have (knowledge), (be, make, make to be, make self) known, + be learned, + lie by man, mark, perceive, privy to, X prognosticator, regard, have respect, skilful, shew, can (man of) skill, be sure, of a surety, teach, (can) tell, understand, have (understanding), X will be, wist, wit, wot.. Appears 3 times in Job 15.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress