Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Job 34 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Nígbà náà ni Elihu dáhùn, ó sì wí pé,
2 “Ẹ̀yin ọlọ́gbọ́n ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, kí ẹ sì fi etí sílẹ̀ sí mi ẹ̀yin tí ẹ ní ìmòye.
3 Nítorí pé etí a máa dán ọ̀rọ̀ wò, bí adùn ẹnu ti ń tọ́ oúnjẹ wò.
4 Ẹ jẹ́ kí a mọ òye ohun tí o tọ́ fún ara wa; ẹ jẹ́ kí a mọ ohun tí ó dára láàrín wa.
5 “Nítorí pé Jobu wí pé, ‘Aláìlẹ́ṣẹ̀ ni èmi; Ọlọ́run sì ti gba ìdájọ́ mi lọ.
6 Èmi ha purọ́ sí ẹ̀tọ́ mi bí, bí mo tilẹ̀ jẹ́ aláìjẹ̀bi, ọfà rẹ̀ kò ní àwòtán ọgbẹ́.’
7 Ọkùnrin wo ni ó dàbí Jobu, tí ń mu ẹ̀gàn bí ẹní mú omi?
8 Tí ń bá àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ kẹ́gbẹ́ tí ó sì ń bá àwọn ènìyàn búburú rìn.
9 Nítorí ó sá ti wí pé, ‘Èrè kan kò sí fún ènìyàn, tí yóò fi máa ṣe inú dídùn sí Ọlọ́run.’
10 “Ǹjẹ́ nítorí náà, ẹ fetísílẹ̀ sí mi, ẹ fi etí sí mi ẹ̀yin ènìyàn amòye: Ó di èèwọ̀ fún Ọlọ́run ti ìbá fi hùwà búburú, àti fún Olódùmarè, tí yóò fi ṣe àìṣedéédéé!
11 Nítorí pé ó ń sán fún ènìyàn fún gẹ́gẹ́ bi ohun tí a bá ṣe, yóò sì mú olúkúlùkù kí ó rí gẹ́gẹ́ bí ipa ọ̀nà rẹ̀.
12 Nítòótọ́ Ọlọ́run kì yóò hùwàkiwà; bẹ́ẹ̀ ni Olódùmarè kì yóò yí ìdájọ́ po.
13 Ta ni ó fi ìtọ́jú ayé lé e lọ́wọ́, tàbí ta ni ó fi gbogbo ayé lé e lọ́wọ́?
14 Bí ó bá gbé ayé rẹ̀ lé kìkì ara rẹ̀ tí ó sì gba ọkàn rẹ̀ àti ẹ̀mí rẹ̀ sọ́dọ̀ ara rẹ̀,
15 gbogbo ènìyàn ni yóò parun pọ̀, ènìyàn a sì tún padà di erùpẹ̀.
16 “Ǹjẹ́ nísinsin yìí, bí ìwọ bá ní òye, gbọ́ èyí; fetísí ohùn ẹnu mi.
17 Ẹni tí ó kórìíra òtítọ́ ha le ṣe olórí bí? Ìwọ ó ha sì dá olóòótọ́ àti ẹni ńlá lẹ́bi?
18 O ha tọ́ láti wí fún ọba pé, ‘Ènìyàn búburú ní ìwọ,’ tàbí fún àwọn ọmọ-aládé pé, ‘Ìkà ni ẹ̀yin,’
19 mélòó mélòó fún ẹni tí kì í ṣe ojúsàájú àwọn ọmọ-aládé tàbí tí kò kà ọlọ́rọ̀ sí ju tálákà lọ, nítorí pé iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ ni gbogbo wọn í ṣe?
20 Ní ìṣẹ́jú kan ni wọn ó kú, àwọn ènìyàn á sì di yíyọ́ lẹ́nu láàrín ọ̀gànjọ́, wọn a sì kọjá lọ; a sì mú àwọn alágbára kúrò láìsí ọwọ́ ènìyàn níbẹ̀.
21 “Nítorí pé ojú rẹ̀ ń bẹ ní ipa ọ̀nà ènìyàn, òun sì rí ìrìn rẹ̀ gbogbo.
22 Kò sí ibi òkùnkùn, tàbí òjìji ikú, níbi tí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ yóò gbé sá pamọ́ sí.
23 Nítorí pé òun kò pẹ́ àti kíyèsi ẹnìkan, kí òun kí ó sì mú lọ sínú ìdájọ́ níwájú Ọlọ́run.
24 Òun ó sì fọ́ àwọn alágbára túútúú láìní ìwádìí, a sì fi ẹlòmíràn dípò wọn,
25 nítorí pé ó mọ iṣẹ́ wọn, ó sì yí wọn po ní òru, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n di ìtẹ̀mọ́lẹ̀.
26 Ó kọlù wọ́n nítorí ìwà búburú wọn níbi tí àwọn ẹlòmíràn ti lè rí i,
27 nítorí pé wọ́n padà pẹ̀yìndà sí i, wọn kò sì fiyèsí ipa ọ̀nà rẹ̀ gbogbo,
28 kí wọn kí ó sì mú igbe ẹkún àwọn tálákà lọ dé ọ̀dọ̀ rẹ̀, òun sì gbọ́ igbe ẹkún aláìní.
29 Ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dákẹ́ síbẹ̀, ta ni yóò dá lẹ́bi? Nígbà tí ó bá pa ojú rẹ̀ mọ́, ta ni yóò lè rí i? Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe si orílẹ̀-èdè tàbí sí ènìyàn kan ṣoṣo;
30 kí aláìwà bi Ọlọ́run kí ó má bá à jẹ ọba kí wọn kí ó má di ìdẹwò fún ènìyàn.
31 “Nítorí pé ẹnìkan ha lè wí fún Ọlọ́run pé, èmi jẹ̀bi, èmi kò sì ní ṣẹ̀ mọ́?
32 Èyí tí èmi kò rí ìwọ fi kọ́ mi bi mo bá sì dẹ́ṣẹ̀ èmi kì yóò ṣe bẹ́ẹ̀ mọ́.
33 Ǹjẹ́ bí ti inú rẹ̀ ni ki òun ó san ẹ̀ṣẹ̀ padà? Ǹjẹ́ òun yóò san án padà bí ìwọ bá kọ̀ ọ́ láti jẹ́wọ́, ìwọ gbọdọ̀ yan, kì í ṣe èmi. Nítorí náà sọ ohun tí o mọ̀, pẹ̀lúpẹ̀lú ohun tí ìwọ mọ̀, sọ ọ́!
34 “Àwọn ènìyàn amòye yóò wí fún mi, àti pẹ̀lúpẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí í ṣe ọlọ́gbọ́n tí ó sì gbọ́ mi pé,
35 ‘Jobu ti fi àìmọ̀ sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ rẹ̀ sì ṣe aláìgbọ́n.’
36 Ìfẹ́ mi ni kí a dán Jobu wò dé òpin, nítorí ìdáhùn rẹ̀ dàbí i ti ènìyàn búburú.
37 Nítorí pe ó fi ìṣọ̀tẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀; ó pàtẹ́wọ́ ní àárín wa, ó sì sọ ọ̀rọ̀ odi púpọ̀ sí Ọlọ́run.”
Chapter information and study resources

Listen to Job 34 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Job 34

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Job 34. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Job 34 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 13 cross-references, 1 Early-Church citation.

Cross-references in Job 34 (13)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Job 34:1–37 (295 words)
1
  1. וַיַּ֥עַןwayyaʿan`anah: (properly) to eye; (generally) to heed, i.e. pay attentionH6030
  2. אֱלִיה֗וּאʾĕlîhûʾEliyhuw: God of him; Elihu, the name of one of Job's friends, and of three IsraelitesH453
  3. וַיֹּאמַֽר׃wayyōʾmaramar: to say (used with great latitude)H559
2
  1. שִׁמְע֣וּšimʿûshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  2. חֲכָמִ֣יםḥăkāmîmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  3. מִלָּ֑יmillāymillah: a word; collectively, a discourseH4405
  4. וְ֝יֹדְעִ֗יםwĕyōdĕʿîmyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  5. הַאֲזִ֥ינוּhaʾăzînûazan: to broaden out the ear (with the hand); (by implication) to listenH238
3
  1. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. אֹ֭זֶןʾōzenozen: broadness; (concretely) the ear (from its form in man)H241
  3. מִלִּ֣יןmillînmillah: a word; collectively, a discourseH4405
  4. תִּבְחָ֑ןtibḥānbachan: to test (especially metals); (generally and figuratively) to investigateH974
  5. וְ֝חֵ֗ךְwĕḥēkchek: (properly) the palate or inside of the mouthH2441
  6. יִטְעַ֥םyiṭʿamta`am: to taste; (figuratively) to perceiveH2938
  7. לֶאֱכֹֽל׃leʾĕkōlakal: to eat (literally or figuratively)H398
4
  1. מִשְׁפָּ֥טmišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  2. נִבְחֲרָהnibḥărâbachar: (properly) to try; (by implication) selectH977
  3. לָּ֑נוּlānû
  4. נֵדְעָ֖הnēdĕʿâyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  5. בֵינֵ֣ינוּbênênûbeyn: a distinction; (but used only as a prep) between (repeated before each noun, often with other particles)H996
  6. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  7. טּֽוֹב׃ṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
5
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. אָ֭מַרʾāmaramar: to say (used with great latitude)H559
  3. אִיּ֣וֹבʾiyyôbIyowb: hated (i.e. persecuted); Ijob, the patriarch famous for his patienceH347
  4. צָדַ֑קְתִּיṣādaqtîtsadaq: to be (causatively, make) right (in a moral or forensic sense)H6663
  5. וְ֝אֵ֗לwĕʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  6. הֵסִ֥ירhēsîrcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  7. מִשְׁפָּטִֽי׃mišpāṭîmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
6
  1. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  2. מִשְׁפָּטִ֥יmišpāṭîmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  3. אֲכַזֵּ֑בʾăkazzēbkazab: to lie (i.e. deceive), literally or figurativelyH3576
  4. אָנ֖וּשׁʾānûšanash: to be frail, feeble, or (figuratively) melancholyH605
  5. חִצִּ֣יḥiṣṣîchets: (properly) a piercer, i.e. an arrow; (by implication) a woundH2671
  6. בְלִיbĕlîbliy: (properly) failure; nothing or destructionH1097
  7. פָֽשַׁע׃pāšaʿpesha`: a revolt (national, moral or religious)H6588
7
  1. מִיmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  2. גֶ֥בֶרgebergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  3. כְּאִיּ֑וֹבkĕʾiyyôbIyowb: hated (i.e. persecuted); Ijob, the patriarch famous for his patienceH347
  4. יִֽשְׁתֶּהyišĕtteshathah: to imbibe (literally or figuratively)H8354
  5. לַּ֥עַגlaʿagla`ag: derision, scoffingH3933
  6. כַּמָּֽיִם׃kammāyimmayim: water; (figuratively) juiceH4325
8
  1. וְאָרַ֣חwĕʾāraḥarach: to travelH732
  2. לְ֭חֶבְרָהlĕḥebrâchebrah: associationH2274
  3. עִםʿim`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  4. פֹּ֣עֲלֵיpōʿălêpa`al: to do or make (systematically and habitually), especially to practiseH6466
  5. אָ֑וֶןʾāwenaven: (strictly) nothingness; (also) trouble, vanity, wickednessH205
  6. וְ֝לָלֶ֗כֶתwĕlālekethalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  7. עִםʿim`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  8. אַנְשֵׁיʾanšêiysh: a man as an individual or a male personH376
  9. רֶֽשַׁע׃rešaʿresha`: a wrong (especially moral)H7562
9
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. אָ֭מַרʾāmaramar: to say (used with great latitude)H559
  3. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. יִסְכָּןyiskāncakan: to be familiar with; (by implication) to minister to, be serviceable to, be customaryH5532
  5. גָּ֑בֶרgābergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  6. בִּ֝רְצֹת֗וֹbirṣōtôratsah: to be pleased with; specifically, to satisfy a debtH7521
  7. עִםʿim`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  8. אֱלֹהִֽים׃ʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
10
  1. לָכֵ֤ן׀lākēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  2. אַ֥נֲשֵׁ֥יʾanăšêiysh: a man as an individual or a male personH376
  3. לֵבָ֗בlēbāblebab: the heart (as the most interior organ); used also like H3820H3824
  4. שִׁמְע֫וּšimʿûshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  5. לִ֥יlî
  6. חָלִ֖לָהḥālilâchaliylah: literal for a profaned thing; used (interj.) far be it!H2486
  7. לָאֵ֥לlāʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  8. מֵרֶ֗שַׁעmērešaʿresha`: a wrong (especially moral)H7562
  9. וְשַׁדַּ֥יwĕšaddayShadday: the AlmightyH7706
  10. מֵעָֽוֶל׃mēʿāwel`evel: (moral) evilH5766
11
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. פֹ֣עַלpōʿalpo`al: (concretely) an act or workH6467
  3. אָ֭דָםʾādomadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  4. יְשַׁלֶּםyĕšallemshalam: to be safe (in mind, body or estate); (figuratively) to be completedH7999
  5. ל֑וֹlô
  6. וּֽכְאֹ֥רַחûkĕʾōraḥorach: (literally or figuratively) a well-trodden roadH734
  7. אִ֝֗ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  8. יַמְצִאֶֽנּוּ׃yamṣiʾennûmatsa': (properly) to come forth to, i.e. appear or existH4672
12
  1. אַףʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  2. אָמְנָ֗םʾomnāmomnam: verilyH551
  3. אֵ֥לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  4. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. יַרְשִׁ֑יעַyaršîaʿrasha`: to be wrong; (causatively) to do or declare wrongH7561
  6. וְ֝שַׁדַּ֗יwĕšaddayShadday: the AlmightyH7706
  7. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  8. יְעַוֵּ֥תyĕʿawwēt`avath: to wrestH5791
  9. מִשְׁפָּֽט׃mišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
13
  1. מִֽיmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  2. פָקַ֣דpāqadpaqad: to visit (with friendly or hostile intent)H6485
  3. עָלָ֣יוʿālāyw`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. אָ֑רְצָהʾārĕṣâerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. וּמִ֥יûmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  6. שָׂ֝֗םśāmsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  7. תֵּבֵ֥לtēbēltebel: the earth (as moist and therefore inhabited)H8398
  8. כֻּלָּֽהּ׃kullāhkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
14
  1. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  2. יָשִׂ֣יםyāśîmsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  3. אֵלָ֣יוʾēlāywel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. לִבּ֑וֹlibbôleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  5. רוּח֥וֹrûḥôruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  6. וְ֝נִשְׁמָת֗וֹwĕnišmātônshamah: a puff, i.e. wind, angry or vital breath, divine inspiration, intellect. or (concretely) an animalH5397
  7. אֵלָ֥יוʾēlāywel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  8. יֶאֱסֹֽף׃yeʾĕsōpacaph: to gather for any purpose; (hence) to receive, take awayH622
15
  1. יִגְוַ֣עyigwaʿgava`: to breathe out; (by implication) expireH1478
  2. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. בָּשָׂ֣רbāśārbasar: flesh (from its freshness); by extension, body, personH1320
  4. יָ֑חַדyāḥadyachad: (properly) a unit, i.e. (adverb) unitedlyH3162
  5. וְ֝אָדָ֗םwĕʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  6. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. עָפָ֥רʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
  8. יָשֽׁוּב׃yāšûbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
16
  1. וְאִםwĕʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  2. בִּ֥ינָהbînâbiynah: understandingH998
  3. שִׁמְעָהšimʿâshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  4. זֹּ֑אתzōtzo'th: this (often used adverb)H2063
  5. הַ֝אֲזִ֗ינָהhaʾăzînâazan: to broaden out the ear (with the hand); (by implication) to listenH238
  6. לְק֣וֹלlĕqôlqowl: a voice or soundH6963
  7. מִלָּֽי׃millāymillah: a word; collectively, a discourseH4405
17
  1. הַאַ֬ףhaʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  2. שׂוֹנֵ֣אśônēʾsane': to hate (personally)H8130
  3. מִשְׁפָּ֣טmišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  4. יַחֲב֑וֹשׁyaḥăbôšchabash: to wrap firmly (especially a turban, compress, or saddle)H2280
  5. וְאִםwĕʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  6. צַדִּ֖יקṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  7. כַּבִּ֣ירkabbîrkabbiyr: vast, whether in extent (figuratively, of power, mightyH3524
  8. תַּרְשִֽׁיעַ׃taršîaʿrasha`: to be wrong; (causatively) to do or declare wrongH7561
18
  1. הַאֲמֹ֣רhaʾămōramar: to say (used with great latitude)H559
  2. לְמֶ֣לֶךְlĕmelekmelek: a kingH4428
  3. בְּלִיָּ֑עַלbĕliyyāʿalbliya`al: without profit, worthlessnessH1100
  4. רָ֝שָׁ֗עrāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  5. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  6. נְדִיבִֽים׃nĕdîbîmnadiyb: (properly) voluntary, i.e. generous; (hence) magnanimousH5081
19
  1. אֲשֶׁ֤רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  2. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. נָשָׂ֨א׀nāśāʾnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  4. פְּנֵ֥יpĕnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  5. שָׂרִ֗יםśārîmsar: a head person (of any rank or class)H8269
  6. וְלֹ֣אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. נִכַּרnikkarnakar: (properly) to scrutinize, i.e. look intently atH5234
  8. שׁ֭וֹעַšôaʿshowa`: a noble, i.e. liberal, opulent; (as noun in the derived sense) a hallo, a call outH7771
  9. לִפְנֵיlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  10. דָ֑לdāldal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  11. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  12. מַעֲשֵׂ֖הmaʿăśēma`aseh: an action (good or bad); (generally) a transactionH4639
  13. יָדָ֣יוyādāywyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  14. כֻּלָּֽם׃kullāmkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
20
  1. רֶ֤גַע׀regaʿrega`: instant, moment, space, suddenlyH7281
  2. יָמֻתוּ֮yāmutûmuwth: (literally or figuratively) to die; (causatively) to killH4191
  3. וַחֲצ֪וֹתwaḥăṣôtchatsowth: the middle (of the night)H2676
  4. לָ֥יְלָהlāyĕlâlayil: (properly) a twist (away of the light), i.e. nightH3915
  5. יְגֹעֲשׁ֣וּyĕgōʿăšûga`ash: move, shake, toss, troubleH1607
  6. עָ֣םʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  7. וְיַעֲבֹ֑רוּwĕyaʿăbōrû`abar: to cross overH5674
  8. וְיָסִ֥ירוּwĕyāsîrûcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  9. אַ֝בִּ֗ירʾabbîrabbiyr: mighty (spoken of created beingsH47
  10. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  11. בְיָֽד׃bĕyādyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
21
  1. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. עֵ֭ינָיוʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  3. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. דַּרְכֵיdarkêderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  5. אִ֑ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  6. וְֽכָלwĕkolkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  7. צְעָדָ֥יוṣĕʿādāywtsa`ad: a pace or regular stepH6806
  8. יִרְאֶֽה׃yirʾera'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
22
  1. אֵֽיןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  2. חֹ֭שֶׁךְḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
  3. וְאֵ֣יןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  4. צַלְמָ֑וֶתṣalmāwettsalmaveth: shade of death, i.e. the grave (figuratively, calamity)H6757
  5. לְהִסָּ֥תֶרlĕhissātercathar: to hide (by covering), literally or figurativelyH5641
  6. שָׁ֝֗םšāmsham: there (transferring to time) then; often thither, or thenceH8033
  7. פֹּ֣עֲלֵיpōʿălêpa`al: to do or make (systematically and habitually), especially to practiseH6466
  8. אָֽוֶן׃ʾāwenaven: (strictly) nothingness; (also) trouble, vanity, wickednessH205
23
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. אִ֭ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  5. יָשִׂ֣יםyāśîmsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  6. ע֑וֹדʿôd`owd: (properly) iteration or continuance; used only adverbially (with or without preposition), again, repeatedly...H5750
  7. לַהֲלֹ֥ךְlahălōkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  8. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  9. אֵ֝֗לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  10. בַּמִּשְׁפָּֽט׃bammišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
24
  1. יָרֹ֣עַyārōaʿra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
  2. כַּבִּירִ֣יםkabbîrîmkabbiyr: vast, whether in extent (figuratively, of power, mightyH3524
  3. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. חֵ֑קֶרḥēqercheqer: examination, enumeration, deliberationH2714
  5. וַיַּעֲמֵ֖דwayyaʿămēd`amad: to stand, in various relations (literal and figurative, intransitive and transitive)H5975
  6. אֲחֵרִ֣יםʾăḥērîmacher: (properly) hinder; (generally) next, other, etcH312
  7. תַּחְתָּֽם׃taḥtāmtachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
25
  1. לָכֵ֗ןlākēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  2. יַ֭כִּירyakkîrnakar: (properly) to scrutinize, i.e. look intently atH5234
  3. מַעְבָּֽדֵיהֶ֑םmaʿbādêhemma`bad: an actH4566
  4. וְהָ֥פַךְwĕhāpakhaphak: to turn about or over; (by implication) to change, overturn, return, pervertH2015
  5. לַ֝֗יְלָהlaylâlayil: (properly) a twist (away of the light), i.e. nightH3915
  6. וְיִדַּכָּֽאוּ׃wĕyiddakkāʾûdaka': to crumble; transitively, to bruise (literally or figuratively)H1792
26
  1. תַּֽחַתtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  2. רְשָׁעִ֥יםrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  3. סְפָקָ֗םsĕpāqāmcaphaq: to clap the hands (in token of compact, derision, grief, indignation, or punishment)H5606
  4. בִּמְק֥וֹםbimqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  5. רֹאִֽים׃rōʾîmra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
27
  1. אֲשֶׁ֣רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  2. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  3. כֵּ֭ןkēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  4. סָ֣רוּsārûcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  5. מֵֽאַחֲרָ֑יוmēʾaḥărāywachar: (properly) the hind part; (generally, as adverb or conjunction) after (in various senses)H310
  6. וְכָלwĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  7. דְּ֝רָכָ֗יוdĕrākāywderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  8. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  9. הִשְׂכִּֽילוּ׃hiśkîlûsakal: to be (causatively, make or act) circumspect and hence, intelligentH7919
28
  1. לְהָבִ֣יאlĕhābîʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  2. עָ֭לָיוʿālāyw`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  3. צַֽעֲקַתṣaʿăqattsa`aqah: a shriekH6818
  4. דָּ֑לdāldal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  5. וְצַעֲקַ֖תwĕṣaʿăqattsa`aqah: a shriekH6818
  6. עֲנִיִּ֣יםʿăniyyîm`aniy: depressed, in mind or circumstances (practically the same as H6035, although the margin constantly disputes...H6041
  7. יִשְׁמָֽע׃yišmāʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
29
  1. וְה֤וּאwĕhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  2. יַשְׁקִ֨ט׀yašqiṭshaqat: to repose (usually figurative)H8252
  3. וּמִ֥יûmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  4. יַרְשִׁ֗עַyaršiaʿrasha`: to be wrong; (causatively) to do or declare wrongH7561
  5. וְיַסְתֵּ֣רwĕyastērcathar: to hide (by covering), literally or figurativelyH5641
  6. פָּ֭נִיםpānîmpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. וּמִ֣יûmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  8. יְשׁוּרֶ֑נּוּyĕšûrennûshuwr: to spy out; (generally) to surveyH7789
  9. וְעַלwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  10. גּ֖וֹיgôygowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  11. וְעַלwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  12. אָדָ֣םʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  13. יָֽחַד׃yāḥadyachad: (properly) a unit, i.e. (adverb) unitedlyH3162
30
  1. מִ֭מְּלֹךְmimmĕlōkmalak: to reign; (inceptively) to ascend the throneH4427
  2. אָדָ֥םʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  3. חָנֵ֗ףḥānēpchaneph: soiled (i.e. with sin), impiousH2611
  4. מִמֹּ֥קְשֵׁיmimmōqĕšêmowqesh: (literally or figuratively) a noose (for catching animals)H4170
  5. עָֽם׃ʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
31
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  3. אֵ֭לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  4. הֶאָמַ֥רheʾāmaramar: to say (used with great latitude)H559
  5. נָשָׂ֗אתִיnāśāʾtînasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  6. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. אֶחְבֹּֽל׃ʾeḥbōlchabal: to wind tightly (as a rope), i.e. to bindH2254
32
  1. בִּלְעֲדֵ֣יbilʿădêbil`adey: not till; (as preposition or adverb) except, without, besidesH1107
  2. אֶ֭חֱזֶהʾeḥĕzechazah: to gaze at; mentally, to perceive, contemplate (with pleasure)H2372
  3. אַתָּ֣הʾattâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  4. הֹרֵ֑נִיhōrēnîyarah: (properly) to flow as water; (hence) to rainH3384
  5. אִֽםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  6. עָ֥וֶלʿāwel`evel: (moral) evilH5766
  7. פָּ֝עַ֗לְתִּיpāʿaltîpa`al: to do or make (systematically and habitually), especially to practiseH6466
  8. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  9. אֹסִֽיף׃ʾōsîpyacaph: to add or augment (often adverbial, to continue to do a thing)H3254
33
  1. הֲֽמֵעִמְּךָ֬hămēʿimmĕkā`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  2. יְשַׁלְמֶ֨נָּה׀yĕšalmennâshalam: to be safe (in mind, body or estate); (figuratively) to be completedH7999
  3. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  4. מָאַ֗סְתָּmāʾastāma'ac: to spurn; (intransitively) to disappearH3988
  5. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  6. אַתָּ֣הʾattâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  7. תִבְחַ֣רtibḥarbachar: (properly) to try; (by implication) selectH977
  8. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  9. אָ֑נִיʾānîaniy: IH589
  10. וּֽמַהûmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  11. יָדַ֥עְתָּyādaʿtāyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  12. דַבֵּֽר׃dabbērdabar: perhaps properly, to arrange; but used figuratively (of words), to speakH1696
34
  1. אַנְשֵׁ֣יʾanšêenowsh: (properly) a mortal (and thus differing from the more dignified H0120)H582
  2. לֵ֭בָבlēboblebab: the heart (as the most interior organ); used also like H3820H3824
  3. יֹ֣אמְרוּyōʾmĕrûamar: to say (used with great latitude)H559
  4. לִ֑יlî
  5. וְגֶ֥בֶרwĕgebergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  6. חָ֝כָ֗םḥākāmchakam: wise, (i.e. intelligent, skilful or artful)H2450
  7. שֹׁמֵ֥עַֽšōmēʿashama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
35
  1. אִ֭יּוֹבʾiyyôbIyowb: hated (i.e. persecuted); Ijob, the patriarch famous for his patienceH347
  2. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. בְדַ֣עַתbĕdaʿatda`ath: knowledgeH1847
  4. יְדַבֵּ֑רyĕdabbērdabar: perhaps properly, to arrange; but used figuratively (of words), to speakH1696
  5. וּ֝דְבָרָ֗יוûdĕbārāywdabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  6. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. בְהַשְׂכֵּֽיל׃bĕhaśkêlsakal: to be (causatively, make or act) circumspect and hence, intelligentH7919
36
  1. אָבִ֗יʾābîabeh: longingH15
  2. יִבָּחֵ֣ןyibbāḥēnbachan: to test (especially metals); (generally and figuratively) to investigateH974
  3. אִיּ֣וֹבʾiyyôbIyowb: hated (i.e. persecuted); Ijob, the patriarch famous for his patienceH347
  4. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  5. נֶ֑צַחneṣaḥnetsach: (properly) a goal, i.e. the bright object at a distance travelled towardsH5331
  6. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. תְּ֝שֻׁבֹ֗תtĕšubōttshuwbah: a recurrence (of time or place); a reply (as returned)H8666
  8. בְּאַנְשֵׁיbĕʾanšêiysh: a man as an individual or a male personH376
  9. אָֽוֶן׃ʾāwenaven: (strictly) nothingness; (also) trouble, vanity, wickednessH205
37
  1. כִּ֥יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. יֹ֘סִ֤יףyōsîpyacaph: to add or augment (often adverbial, to continue to do a thing)H3254
  3. עַֽלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. חַטָּאת֣וֹḥaṭṭāʾtôchatta'ah: an offence (sometimes habitual sinfulness), and its penalty, occasion, sacrifice, or expiationH2403
  5. פֶ֭שַׁעpešaʿpesha`: a revolt (national, moral or religious)H6588
  6. בֵּינֵ֣ינוּbênênûbeyn: a distinction; (but used only as a prep) between (repeated before each noun, often with other particles)H996
  7. יִסְפּ֑וֹקyispôqcaphaq: to clap the hands (in token of compact, derision, grief, indignation, or punishment)H5606
  8. וְיֶ֖רֶבwĕyerebrabah: to increase (in whatever respect)H7235
  9. אֲמָרָ֣יוʾămārāywemer: something saidH561
  10. לָאֵֽל׃lāʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410

View the full Hebrew interlinear for Job 34 →

Strong's words in Job 34 (6)
Strong's H376 — אַנְשֵׁי (ʾanšê)
iysh (eesh) n-m. 1. a man as an individual or a male person 2. often used as an adjunct to a more definite term (and in such cases frequently not expressed in translation) [contracted for H582 (or perhaps rather from an unused root meaning to be extant)] KJV: also, another, any (man), a certain, + champion, consent, each, every (one), fellow, (foot-, husband-)man, (good-, great, mighty) man, he, high (degree), him (that is), husband, man(-kind), + none, one, people, person, + steward, what (man) soever, whoso(-ever), worthy. Root(s): H582 Compare: H802. Appears 6 times in Job 34.
Strong's H410 — וְ֝אֵ֗ל (wĕʾēl)
el (ale) n-m. 1. strength 2. (as adjective) mighty 3. (especially) the Almighty (but used also of any deity) [shortened from H352] KJV: God (god), X goodly, X great, idol, might(-y one), power, strong. Root(s): H352 Compare: names, in, "-el.". Appears 6 times in Job 34.
Strong's H4941 — מִשְׁפָּ֥ט (mišpāṭ)
mishpat (mish-pawt') n-m. 1. (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree (human or (participant's) divine law, individual or collective), including the act, the place, the suit, the crime, and the penalty 2. abstractly, justice, including a participant's right or privilege (statutory or customary), or even a style [from H8199] KJV: + adversary, ceremony, charge, X crime, custom, desert, determination, discretion, disposing, due, fashion, form, to be judged, judgment, just(-ice, -ly), (manner of) law(-ful), manner, measure, (due) order, ordinance, right, sentence, usest, X worthy, + wrong. Root(s): H8199. Appears 6 times in Job 34.
Strong's H559 — וַיֹּאמַֽר׃ (wayyōʾmar)
amar (aw-mar') v. 1. to say (used with great latitude) [a primitive root] KJV: answer, appoint, avouch, bid, boast self, call, certify, challenge, charge, + (at the, give) command(-ment), commune, consider, declare, demand, X desire, determine, X expressly, X indeed, X intend, name, X plainly, promise, publish, report, require, say, speak (against, of), X still, X suppose, talk, tell, term, X that is, X think, use (speech), utter, X verily, X yet.. Appears 6 times in Job 34.
Strong's H3605 — כֻּלָּֽהּ׃ (kullāh)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 5 times in Job 34.
Strong's H4310 — מִי (mî)
miy (me) p/i. 1. who? 2. (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which? 3. (indefinitely) whoever {often used in oblique construction with prefix or suffix} [an interrogative pronoun of persons, as H4100 is of things] KJV: any (man), X he, X him, + O that! what, which, who(-m, -se, -soever), + would to God. Root(s): H4100. Appears 5 times in Job 34.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress