Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Job 22 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Ìgbà náà ni Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé,
2 “Ènìyàn lè è ṣe rere fún Ọlọ́run? Bí ọlọ́gbọ́n ti í ṣe rere fún ara rẹ̀?
3 Ohun ayọ̀ ha ni fún Olódùmarè pé olódodo ni ìwọ? Tàbí èrè kí ni fún un ti ìwọ mú ọ̀nà rẹ̀ pé?
4 “Yóò ha bá ọ wí bí, nítorí ìbẹ̀rù Ọlọ́run rẹ? Yóò ha bá ọ lọ sínú ìdájọ́ bí?
5 Ìwà búburú rẹ kò ha tóbi, àti ẹ̀ṣẹ̀ rẹ láìníye?
6 Nítòótọ́ ìwọ béèrè fún ààbò ni ọwọ́ arákùnrin rẹ láìnídìí, ìwọ sì tú oníhòhò ní aṣọ wọn.
7 Ìwọ kò fi omi fún aláàárẹ̀ mu, ìwọ sì háwọ́ oúnjẹ fún ẹni tí ebi ń pa.
8 Bí ó ṣe ti alágbára nì, òun ni ó ní ilẹ̀, ọlọ́lá sì tẹ̀dó sínú rẹ̀.
9 Ìwọ ti rán àwọn opó padà lọ ní ọwọ́ òfo, apá àwọn ọmọ aláìní baba ti di ṣiṣẹ́.
10 Nítorí náà ni ìdẹ̀kùn ṣe yí ọ káàkiri, àti ìbẹ̀rù òjijì ń yọ ọ́ lẹ́nu.
11 Èéṣe tí òkùnkùn fi pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ìwọ kò fi lè ríran. Èéṣe tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ omi sì bò ọ́ mọ́lẹ̀.
12 “Ọlọ́run kò ha jẹ́ ẹni gíga ọ̀run? Sá wo orí àwọn ìràwọ̀ bí wọ́n ti ga tó!
13 Ìwọ sì wí pé, Ọlọ́run ti ṣe mọ̀? Òun ha lè ṣe ìdájọ́ láti inú òkùnkùn wá bí?
14 Ǹjẹ́ àwọsánmọ̀ tí ó nípọn jẹ ìbora fún un, tí kò fi lè ríran; ó sì ń rìn nínú àyíká ọ̀run.
15 Ǹjẹ́ ìwọ fẹ́ rin ipa ọ̀nà ìgbàanì tí àwọn ènìyàn búburú tí rìn?
16 A ké wọn lulẹ̀ kúrò nínú ayé láìpé ọjọ́ wọn, ìpìlẹ̀ wọn ti da bí odò ṣíṣàn.
17 Àwọn ẹni tí ó wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa! Kí ni Olódùmarè yóò ṣe fún wọn?’
18 Síbẹ̀ ó fi ohun rere kún ilé wọn! Ṣùgbọ́n ìmọ̀ ènìyàn búburú jìnnà sí mi!
19 Àwọn olódodo rí ìparun wọn, wọ́n sì yọ̀, àwọn aláìlẹ́ṣẹ̀ sì fi wọ́n rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà pé,
20 ‘Lóòtítọ́ àwọn ọ̀tá wa ni a ké kúrò, iná yóò sì jó oró wọn run.’
21 “Fa ara rẹ súnmọ́ Ọlọ́run, ìwọ ó sì rí àlàáfíà; nípa èyí ni rere yóò wá bá ọ.
22 Èmi bẹ̀ ọ́, gba òfin láti ẹnu rẹ̀ wá, kí o sì to ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí àyà rẹ.
23 Bí ìwọ bá yípadà sọ́dọ̀ Olódùmarè, a sì gbé ọ ró. Bí ìwọ bá sì mú ẹ̀ṣẹ̀ jìnnà réré kúrò nínú àgọ́ rẹ,
24 tí ìwọ bá tẹ́ wúrà dáradára sílẹ̀, lórí erùpẹ̀ àti wúrà Ofiri lábẹ́ òkúta odò,
25 nígbà náà ní Olódùmarè yóò jẹ́ wúrà rẹ, àní yóò sì jẹ́ fàdákà fún ọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀.
26 Lóòtítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmarè, ìwọ ó sì gbé ojú rẹ sókè sọ́dọ̀ Ọlọ́run.
27 Bí ìwọ bá gbàdúrà rẹ sọ́dọ̀ rẹ̀, yóò sì gbọ́ tìrẹ, ìwọ ó sì san ẹ̀jẹ́ rẹ.
28 Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ; ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ.
29 Nígbà tí ipa ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀, nígbà náà ni ìwọ o wí pé, ‘Ìgbésókè ń bẹ!’ Ọlọ́run yóò sì gba onírẹ̀lẹ̀ là!
30 Yóò gba ẹni tí kì í ṣe aláìjẹ̀bi là, a ó sì gbà á nípa mímọ́ ọwọ́ rẹ̀.”
Chapter information and study resources

Listen to Job 22 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Job 22

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Job 22. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Job 22 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 13 cross-references, 2 Early-Church citations.

Cross-references in Job 22 (13)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Job 22:1–30 (206 words)
1
  1. וַ֭יַּעַןwayyaʿan`anah: (properly) to eye; (generally) to heed, i.e. pay attentionH6030
  2. אֱלִיפַ֥זʾĕlîpazEliyphaz: God of gold; Eliphaz, the name of one of Job's friends, and of a son of EsauH464
  3. הַֽתֵּמָנִ֗יhattēmānîTeymaniy: a Temanite or descendant of TemanH8489
  4. וַיֹּאמַֽר׃wayyōʾmaramar: to say (used with great latitude)H559
2
  1. הַלְאֵ֥לhalʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  2. יִסְכָּןyiskāncakan: to be familiar with; (by implication) to minister to, be serviceable to, be customaryH5532
  3. גָּ֑בֶרgābergeber: (properly) a valiant man or warrior; (generally) a person simplyH1397
  4. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  5. יִסְכֹּ֖ןyiskōncakan: to be familiar with; (by implication) to minister to, be serviceable to, be customaryH5532
  6. עָלֵ֣ימוֹʿālêmô`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. מַשְׂכִּֽיל׃maśkîlsakal: to be (causatively, make or act) circumspect and hence, intelligentH7919
3
  1. הַחֵ֣פֶץhaḥēpeṣchephets: pleasure; (hence, abstractly) desireH2656
  2. לְ֭שַׁדַּיlĕšaddayShadday: the AlmightyH7706
  3. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  4. תִצְדָּ֑קtiṣdāqtsadaq: to be (causatively, make) right (in a moral or forensic sense)H6663
  5. וְאִםwĕʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  6. בֶּ֝֗צַעbeṣaʿbetsa`: plunder; by extension, gain (usually unjust)H1215
  7. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  8. תַתֵּ֥םtattēmtamam: to complete, in a good or a bad sense, literal, or figurative, transitive or intransitive (as follows)H8552
  9. דְּרָכֶֽיךָ׃dĕrākêkāderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
4
  1. הֲֽ֭מִיִּרְאָ֣תְךָhămiyyirʾātĕkāyir'ah: fear (also used as infinitive); morally, reverenceH3374
  2. יֹכִיחֶ֑ךָyōkîḥekāyakach: to be right (i.e. correct); reciprocal, to argueH3198
  3. יָב֥וֹאyābôʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  4. עִ֝מְּךָ֗ʿimmĕkā`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  5. בַּמִּשְׁפָּֽט׃bammišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
5
  1. הֲלֹ֣אhălōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. רָעָֽתְךָ֣rāʿātĕkāra`: bad or (as noun) evil (natural or moral)H7451
  3. רַבָּ֑הrabbârab: abundant (in quantity, size, age, number, rank, quality)H7227
  4. וְאֵֽיןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  5. קֵ֝֗ץqēṣqets: an extremity; adverbially (with prepositional prefix) afterH7093
  6. לַעֲוֺנֹתֶֽיךָ׃laʿăwōnōtêkā`avon: perversity, i.e. (moral) evilH5771
6
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. תַחְבֹּ֣לtaḥbōlchabal: to wind tightly (as a rope), i.e. to bindH2254
  3. אַחֶ֣יךָʾaḥêkāach: a brother (used in the widest sense of literal relationship and metaphorical affinity or resemblance (like H0001))H251
  4. חִנָּ֑םḥinnāmchinnam: gratis, i.e. devoid of cost, reason or advantageH2600
  5. וּבִגְדֵ֖יûbigdêbeged: a covering; clothingH899
  6. עֲרוּמִּ֣יםʿărûmmîm`arowm: nude, either partially or totallyH6174
  7. תַּפְשִֽׁיט׃tapšîṭpashat: to spread out (i.e. deploy in hostile array)H6584
7
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. מַ֭יִםmayimmayim: water; (figuratively) juiceH4325
  3. עָיֵ֣ףʿāyēp`ayeph: languidH5889
  4. תַּשְׁקֶ֑הtašqeshaqah: to quaff, i.e. (causatively) to irrigate or furnish a potion toH8248
  5. וּ֝מֵרָעֵ֗בûmērāʿēbra`eb: hungry (more or less intensely)H7457
  6. תִּֽמְנַֽעtimĕnaʿmana`: to debar (negatively or positively) from benefit or injuryH4513
  7. לָֽחֶם׃lāḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
8
  1. וְאִ֣ישׁwĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  2. זְ֭רוֹעַzĕrôaʿzrowa`: the arm (as stretched out), or (of animals) the forelegH2220
  3. ל֣וֹlô
  4. הָאָ֑רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. וּנְשׂ֥וּאûnĕśûʾnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  6. פָ֝נִ֗יםpānîmpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. יֵ֣שֶׁבyēšebyashab: (properly) to sit down (specifically as judge. in ambush, in quiet)H3427
9
  1. אַ֭לְמָנוֹתʾalmānôtalmanah: a widow; (also) a desolate placeH490
  2. שִׁלַּ֣חְתָּšillaḥtāshalach: to send away, for, or out (in a great variety of applications)H7971
  3. רֵיקָ֑םrêqāmreyqam: emptily; figuratively (objective) ineffectually, (subjective) undeservedlyH7387
  4. וּזְרֹע֖וֹתûzĕrōʿôtzrowa`: the arm (as stretched out), or (of animals) the forelegH2220
  5. יְתֹמִ֣יםyĕtōmîmyathowm: a bereaved personH3490
  6. יְדֻכָּֽא׃yĕdukkāʾdaka': to crumble; transitively, to bruise (literally or figuratively)H1792
10
  1. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  2. כֵּ֭ןkēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  3. סְבִיבוֹתֶ֣יךָsĕbîbôtêkācabiyb: (as noun) a circle, neighbour, or environsH5439
  4. פַחִ֑יםpaḥîmpach: a (metallic) sheet (as pounded thin); also a spring net (as spread out like a lamina)H6341
  5. וִֽ֝יבַהֶלְךָwîbahelkābahal: to tremble inwardly (or palpitate); (figuratively) to be (suddenly) alarmed or agitatedH926
  6. פַּ֣חַדpaḥadpachad: a (sudden) alarm; (properly) the object fearedH6343
  7. פִּתְאֹֽם׃pitʾōmpith'owm: instantlyH6597
11
  1. אוֹʾôow: desire (and so probably in Prov. 31; hence (by way of alternative) or, also ifH176
  2. חֹ֥שֶׁךְḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
  3. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. תִרְאֶ֑הtirʾera'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  5. וְֽשִׁפְעַתwĕšipʿatshiph`ah: copiousnessH8229
  6. מַ֥יִםmayimmayim: water; (figuratively) juiceH4325
  7. תְּכַסֶּֽךָּ׃tĕkassekkākacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
12
  1. הֲֽלֹאhălōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. אֱ֭לוֹהַּʾĕlôahelowahh: a deity or the DeityH433
  3. גֹּ֣בַהּgōbahgobahh: elation, grandeur, arroganceH1363
  4. שָׁמָ֑יִםšāmāyimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
  5. וּרְאֵ֤הûrĕʾēra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  6. רֹ֖אשׁrōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  7. כּוֹכָבִ֣יםkôkābîmkowkab: a star (as round or as shining); (figuratively) a princeH3556
  8. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  9. רָֽמּוּ׃rāmmûruwm: to be high actively, to rise or raise (in various applications, literally or figuratively)H7311
13
  1. וְֽ֭אָמַרְתָּwĕʾāmartāamar: to say (used with great latitude)H559
  2. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  3. יָּ֣דַֽעyādaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  4. אֵ֑לʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  5. הַבְעַ֖דhabʿadb`ad: in up to or over against; (generally) at, beside, among, behind, for, etcH1157
  6. עֲרָפֶ֣לʿărāpel`araphel: gloom (as of a lowering sky)H6205
  7. יִשְׁפּֽוֹט׃yišpôṭshaphat: to judge, i.e. pronounce sentence (for or against)H8199
14
  1. עָבִ֣יםʿābîm`ab: (properly) an envelope, i.e. darkness (or density, 2 Chron. 4H5645
  2. סֵֽתֶרsētercether: a cover (in a good or a bad, a literal or a figurative sense)H5643
  3. ל֭וֹlô
  4. וְלֹ֣אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. יִרְאֶ֑הyirʾera'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  6. וְח֥וּגwĕḥûgchuwg: a circleH2329
  7. שָׁ֝מַ֗יִםšāmayimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
  8. יִתְהַלָּֽךְ׃yithallākhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
15
  1. הַאֹ֣רַחhaʾōraḥorach: (literally or figuratively) a well-trodden roadH734
  2. עוֹלָ֣םʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  3. תִּשְׁמ֑וֹרtišmôrshamar: (properly) to hedge about (as with thorns), i.e. guardH8104
  4. אֲשֶׁ֖רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. דָּרְכ֣וּdorkûdarak: to tread; (by implication) to walkH1869
  6. מְתֵיmĕtêmath: (properly) an adult (as of full length); (by implication) a man (only in the plural)H4962
  7. אָֽוֶן׃ʾāwenaven: (strictly) nothingness; (also) trouble, vanity, wickednessH205
16
  1. אֲשֶֽׁרʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  2. קֻמְּט֥וּqummĕṭûqamat: to pluck, i.e. destroyH7059
  3. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. עֵ֑תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  5. נָ֝הָ֗רnāhārnahar: a stream (including the sea; expec. the Nile, Euphrates, etc.)H5104
  6. יוּצַ֥קyûṣaqyatsaq: (properly) to pour out (transitive or intransitive)H3332
  7. יְסוֹדָֽם׃yĕsôdāmycowd: a foundation (literally or figuratively)H3247
17
  1. הָאֹמְרִ֣יםhāʾōmĕrîmamar: to say (used with great latitude)H559
  2. לָ֭אֵלlāʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  3. ס֣וּרsûrcuwr: to turn off (literal or figurative)H5493
  4. מִמֶּ֑נּוּmimmennûmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  5. וּמַהûmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  6. יִּפְעַ֖לyipʿalpa`al: to do or make (systematically and habitually), especially to practiseH6466
  7. שַׁדַּ֣יšaddayShadday: the AlmightyH7706
18
  1. וְה֤וּאwĕhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  2. מִלֵּ֣אmillēʾmale': to fill or (intransitively) be full of, in a wide application (literally and figuratively)H4390
  3. בָתֵּיהֶ֣םbottêhembayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
  4. ט֑וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  5. וַעֲצַ֥תwaʿăṣat`etsah: advice; (by implication) planH6098
  6. רְ֝שָׁעִ֗יםrĕšāʿîmrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  7. רָ֣חֲקָהrāḥăqârachaq: to widen (in any direction), i.e. (intransitively) recede or (transitively) remove (literally or figuratively...H7368
  8. מֶֽנִּי׃mennîmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
19
  1. יִרְא֣וּyirʾûra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  2. צַדִּיקִ֣יםṣaddîqîmtsaddiyq: justH6662
  3. וְיִשְׂמָ֑חוּwĕyiśmāḥûsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  4. וְ֝נָקִ֗יwĕnāqînaqiy: innocentH5355
  5. יִלְעַגyilʿagla`ag: to deride; (by implication) (as if imitating a foreigner) to speak unintelligiblyH3932
20
  1. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  2. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. נִכְחַ֣דnikḥadkachad: to secrete, by act or word; hence (intensively) to destroyH3582
  4. קִימָ֑נוּqîmānûqiym: an opponent (as rising against one), i.e. (collectively) enemiesH7009
  5. וְ֝יִתְרָ֗םwĕyitrāmyether: (properly) an overhanging; (by implication) an excess, superiority, remainderH3499
  6. אָ֣כְלָהʾākĕlâakal: to eat (literally or figuratively)H398
  7. אֵֽשׁ׃ʾēšesh: fire (literally or figuratively)H784
21
  1. הַסְכֶּןhaskencakan: to be familiar with; (by implication) to minister to, be serviceable to, be customaryH5532
  2. נָ֣אnāʾna': added mostly to verbs (in the Imperative or Future), or to interjections, occasionally to an adverb or conjunctionH4994
  3. עִמּ֑וֹʿimmô`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  4. וּשְׁלםûšĕlmshalam: to be safe (in mind, body or estate); (figuratively) to be completedH7999
  5. בָּ֝הֶ֗םbāhem
  6. תְּֽבוֹאַתְךָ֥tĕbôʾatkābow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  7. טוֹבָֽה׃ṭôbâtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
22
  1. קַחqaḥlaqach: to take (in the widest variety of applications)H3947
  2. נָ֣אnāʾna': added mostly to verbs (in the Imperative or Future), or to interjections, occasionally to an adverb or conjunctionH4994
  3. מִפִּ֣יוmippîwpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
  4. תּוֹרָ֑הtôrâtowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  5. וְשִׂ֥יםwĕśîmsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  6. אֲ֝מָרָ֗יוʾămārāywemer: something saidH561
  7. בִּלְבָבֶֽךָ׃bilbābekālebab: the heart (as the most interior organ); used also like H3820H3824
23
  1. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  2. תָּשׁ֣וּבtāšûbshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  3. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  4. שַׁ֭דַּיšaddayShadday: the AlmightyH7706
  5. תִּבָּנֶ֑הtibbānebanah: to build (literally and figuratively)H1129
  6. תַּרְחִ֥יקtarḥîqrachaq: to widen (in any direction), i.e. (intransitively) recede or (transitively) remove (literally or figuratively...H7368
  7. עַ֝וְלָ֗הʿawlâ`evel: (moral) evilH5766
  8. מֵאָהֳלֶֽךָ׃mēʾāhŏlekāohel: a tent (as clearly conspicuous from a distance)H168
24
  1. וְשִׁיתwĕšîtshiyth: to place (in a very wide application)H7896
  2. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  3. עָפָ֥רʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
  4. בָּ֑צֶרbāṣerbetser: (strictly) a clipping; gold (as dug out)H1220
  5. וּבְצ֖וּרûbĕṣûrtsuwr: (properly) a cliff (or sharp rock, as compressed)H6697
  6. נְחָלִ֣יםnĕḥālîmnachal: a stream, especially a winter torrent; (by implication) a (narrow) valley (in which a brook runs)H5158
  7. אוֹפִֽיר׃ʾôpîrOwphiyr: Ophir, the name of a son of Joktan, and of a gold region in the EastH211
25
  1. וְהָיָ֣הwĕhāyâhayah: to exist; to be or becomeH1961
  2. שַׁדַּ֣יšaddayShadday: the AlmightyH7706
  3. בְּצָרֶ֑יךָbĕṣārêkābetser: (strictly) a clipping; gold (as dug out)H1220
  4. וְכֶ֖סֶףwĕkesepkeceph: silver (from its pale color); (by implication) moneyH3701
  5. תּוֹעָפ֣וֹתtôʿāpôttow`aphah: (only in plural collective) weariness; (by implication) toil (treasure so obtained) or speedH8443
26
  1. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. אָ֭זʾāzaz: at that time or place; (as a conjunction) thereforeH227
  3. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. שַׁדַּ֣יšaddayShadday: the AlmightyH7706
  5. תִּתְעַנָּ֑גtitʿannāg`anag: to be soft or pliable, i.e. (figuratively) effeminate or luxuriousH6026
  6. וְתִשָּׂ֖אwĕtiśśāʾnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  7. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  8. אֱל֣וֹהַּʾĕlôahelowahh: a deity or the DeityH433
  9. פָּנֶֽיךָ׃pānêkāpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
27
  1. תַּעְתִּ֣ירtaʿtîr`athar: to burn incense in worship, i.e. intercede (reciprocally, listen to prayer)H6279
  2. אֵ֭לָיוʾēlāywel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  3. וְיִשְׁמָעֶ֑ךָּwĕyišmāʿekkāshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  4. וּנְדָרֶ֥יךָûnĕdārêkāneder: a promise (to God); (concretely) a thing promisedH5088
  5. תְשַׁלֵּֽם׃tĕšallēmshalam: to be safe (in mind, body or estate); (figuratively) to be completedH7999
28
  1. וְֽתִגְזַרwĕtigzargazar: to cut down or off; (figuratively) to destroy, divide, exclude, or decideH1504
  2. אֹ֭מֶרʾōmeromer: promise, speech, thing, wordH562
  3. וְיָ֣קָםwĕyāqomquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  4. לָ֑ךְlāk
  5. וְעַלwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  6. דְּ֝רָכֶ֗יךָdĕrākêkāderek: a road (as trodden); (figuratively) a course of life or mode of action, often adverbH1870
  7. נָ֣גַֽהּnāgahnagahh: to glitter; causatively, to illuminateH5050
  8. אֽוֹר׃ʾôrowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
29
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. הִ֭שְׁפִּילוּhišpîlûshaphel: to depress or sink (expec. figuratively, to humiliate, intransitive or transitive)H8213
  3. וַתֹּ֣אמֶרwattōʾmeramar: to say (used with great latitude)H559
  4. גֵּוָ֑הgēwâgevah: exaltation; (figuratively) arroganceH1466
  5. וְשַׁ֖חwĕšaḥshach: sunk, i.e. downcastH7807
  6. עֵינַ֣יִםʿênayim`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  7. יוֹשִֽׁעַ׃yôšiaʿyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
30
  1. יְֽמַלֵּ֥טyĕmallēṭmalat: (properly) to be smooth; (by implication) to escape (as if by slipperiness)H4422
  2. אִֽיʾîiy: notH336
  3. נָקִ֑יnāqînaqiy: innocentH5355
  4. וְ֝נִמְלַ֗טwĕnimlaṭmalat: (properly) to be smooth; (by implication) to escape (as if by slipperiness)H4422
  5. בְּבֹ֣רbĕbōrbor: purifyH1252
  6. כַּפֶּֽיךָ׃kappêkākaph: the hollow hand or palm (so of the paw of an animal, of the sole, and even of the bowl of a dish or sling, the...H3709

View the full Hebrew interlinear for Job 22 →

Strong's words in Job 22 (6)
Strong's H7706 — לְ֭שַׁדַּי (lĕšadday)
Shadday (shad-dah'-ee) n-m. 1. the Almighty [from H7703] KJV: Almighty. Root(s): H7703. Appears 5 times in Job 22.
Strong's H559 — וַיֹּאמַֽר׃ (wayyōʾmar)
amar (aw-mar') v. 1. to say (used with great latitude) [a primitive root] KJV: answer, appoint, avouch, bid, boast self, call, certify, challenge, charge, + (at the, give) command(-ment), commune, consider, declare, demand, X desire, determine, X expressly, X indeed, X intend, name, X plainly, promise, publish, report, require, say, speak (against, of), X still, X suppose, talk, tell, term, X that is, X think, use (speech), utter, X verily, X yet.. Appears 4 times in Job 22.
Strong's H7200 — תִרְאֶ֑ה (tirʾe)
ra'ah (raw-aw') v. 1. to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and causative) [a primitive root] KJV: advise self, appear, approve, behold, X certainly, consider, discern, (make to) enjoy, have experience, gaze, take heed, X indeed, X joyfully, lo, look (on, one another, one on another, one upon another, out, up, upon), mark, meet, X be near, perceive, present, provide, regard, (have) respect, (fore-, cause to, let) see(-r, -m, one another), shew (self), X sight of others, (e-)spy, stare, X surely, X think, view, visions.. Appears 4 times in Job 22.
Strong's H410 — הַלְאֵ֥ל (halʾēl)
el (ale) n-m. 1. strength 2. (as adjective) mighty 3. (especially) the Almighty (but used also of any deity) [shortened from H352] KJV: God (god), X goodly, X great, idol, might(-y one), power, strong. Root(s): H352 Compare: names, in, "-el.". Appears 3 times in Job 22.
Strong's H518 — וְאִם (wĕʾim)
im (eem) prt. 1. (used very widely as demonstrative) lo! 2. (interrogatively) whether? 3. (conditionally), if, although 4. (also) Oh that!, when 5. (hence, as a negative) not [a primitive particle] KJV: (and, can-, doubtless, if, that) (not), + but, either, + except, + more(-over if, than), neither, nevertheless, nor, oh that, or, + save (only, -ing), seeing, since, sith, + surely (no more, none, not), though, + of a truth, + unless, + verily, when, whereas, whether, while, + yet.. Appears 3 times in Job 22.
Strong's H5532 — יִסְכָּן (yiskān)
cakan (saw-kan') v. 1. to be familiar with 2. (by implication) to minister to, be serviceable to, be customary [a primitive root] KJV: acquaint (self), be advantage, X ever, (be, (un-))profit(-able), treasurer, be wont.. Appears 3 times in Job 22.

Browse the full Strong's concordance →

What the Early Church wrote about Job 22 (1 additional)
  • “This is what he means, in my opinion: "Confess your sins; receive from God's mouth his support after your confession; and take his words into your heart." Certainly Eliphaz said these things, as he believed, by making himself equal to Job.… However, he pronounces a correct dog...”

    — Origen (3rd century) on Job 22:22

Read the full Ante-Nicene Fathers library →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress