Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Psalms 72 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Fi ìdájọ́ fún àwọn ọba, Ọlọ́run, ọmọ-aládé ni ìwọ fi òdodo rẹ fún.
2 Yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ pẹ̀lú òdodo, yóò sì máa fi ẹ̀tọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn tálákà rẹ̀.
3 Àwọn òkè ńlá yóò máa mú àlàáfíà fún àwọn ènìyàn àti òkè kéékèèké nípa òdodo.
4 Yóò dáàbò bo àwọn tí a pọ́n lójú láàrín àwọn ènìyàn yóò gba àwọn ọmọ aláìní; yóò sì fa àwọn aninilára ya.
5 Àwọn òtòṣì àti aláìní yóò máa fi ọ̀wọ̀ ńlá fún ọ nígbà gbogbo, níwọ̀n ìgbà tí oòrùn àti òṣùpá bá ń ràn, yóò ti pẹ́ tó, láti ìrandíran.
6 Yóò dàbí òjò tí ó ń rọ̀ sórí pápá ìrẹ́mọ́lẹ̀, bí ọwọ́ òjò tó ń rin ilẹ̀.
7 Àwọn olódodo yóò gbilẹ̀ ni ọjọ́ rẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà yóò sì wà; títí tí òṣùpá kò fi ní sí mọ́.
8 Yóò máa jẹ ọba láti òkun dé òkun àti láti odò Eufurate títí dé òpin ayé.
9 Àwọn tí ó wà ní aginjù yóò tẹríba fún un àwọn ọ̀tá rẹ̀ yóò máa lá erùpẹ̀ ilẹ̀.
10 Àwọn ọba Tarṣiṣi àti ti erékùṣù wọn yóò mú ọrẹ wá fún un; àwọn ọba Ṣeba àti Seba wọn ó mú ẹ̀bùn wá fún un.
11 Gbogbo ọba yóò tẹríba fún un àti gbogbo orílẹ̀-èdè yóò sìn ín.
12 Nítorí yóò gba àwọn aláìní nígbà tí ó bá ń ké, tálákà àti ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́.
13 Yóò káàánú àwọn aláìlera àti aláìní yóò pa aláìní mọ́ kúrò nínú ikú.
14 Yóò ra ọkàn wọn padà lọ́wọ́ ẹ̀tàn àti ipá nítorí ẹ̀jẹ̀ wọn ṣọ̀wọ́n níwájú rẹ̀.
15 Yóò sì pẹ́ ní ayé! A ó sì fún un ní wúrà Ṣeba. Àwọn ènìyàn yóò sì máa gbàdúrà fún un nígbà gbogbo kí a sì bùkún fún un lójoojúmọ́.
16 Kí ìkúnwọ́ ọkà wà lórí ilẹ̀; ní orí òkè ni kí ó máa dàgbà kí èso rẹ̀ kí o gbilẹ̀ bí ti Lebanoni yóò máa gbá yìn bí i koríko ilẹ̀.
17 Kí orúkọ rẹ̀ kí ó wà títí láé; orúkọ rẹ̀ yóò máa gbilẹ̀ níwọ̀n bí oòrùn yóò ti pẹ́ tó. Wọn ó sì máa bùkún fún ara wọn nípasẹ̀ rẹ. Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ní yóò máa pè mí ní alábùkún fún.
18 Olùbùkún ni Olúwa Ọlọ́run, Ọlọ́run Israẹli, ẹnìkan ṣoṣo tí ó ń ṣe ohun ìyanu.
19 Olùbùkún ni orúkọ rẹ̀ tí ó lógo títí láé; kí gbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀. Àmín àti Àmín.
20 Èyí ni ìparí àdúrà Dafidi ọmọ Jese.
Chapter information and study resources

Listen to Psalms 72 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Psalm 72

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Psalm 72. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Psalm 72 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 23 cross-references, 1 Early-Church citation.

Cross-references in Psalm 72 (23)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Psalm 72:1–20 (160 words)
1
  1. אֱֽלֹהִ֗יםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  2. מִ֭שְׁפָּטֶיךָmišpāṭêkāmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  3. לְמֶ֣לֶךְlĕmelekmelek: a kingH4428
  4. תֵּ֑ןtēnnathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  5. וְצִדְקָתְךָ֥wĕṣidqotkātsdaqah: rightness (abstractly), subjectively (rectitude), objectively (justice), morally (virtue) or figuratively...H6666
  6. לְבֶןlĕbenben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  7. מֶֽלֶךְ׃melekmelek: a kingH4428
2
  1. יָדִ֣יןyādîndiyn: a straight course, i.e. sail directH1777
  2. עַמְּךָ֣ʿammĕkā`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  3. בְצֶ֑דֶקbĕṣedeqtsedeq: the right (natural, moral or legal); (abstractly) equityH6664
  4. וַעֲנִיֶּ֥יךָwaʿăniyyêkā`aniy: depressed, in mind or circumstances (practically the same as H6035, although the margin constantly disputes...H6041
  5. בְמִשְׁפָּֽט׃bĕmišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
3
  1. יִשְׂא֤וּyiśʾûnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  2. הָרִ֓יםhārîmhar: a mountain or range of hills (sometimes used figuratively)H2022
  3. שָׁ֘ל֥וֹםšālômshalowm: safe; (figuratively) well, happy, friendlyH7965
  4. לָעָ֑םlāʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  5. וּ֝גְבָע֗וֹתûgĕbāʿôtgib`ah: a hillockH1389
  6. בִּצְדָקָֽה׃biṣdāqâtsdaqah: rightness (abstractly), subjectively (rectitude), objectively (justice), morally (virtue) or figuratively...H6666
4
  1. יִשְׁפֹּ֤ט׀yišpōṭshaphat: to judge, i.e. pronounce sentence (for or against)H8199
  2. עֲֽנִיֵּיʿăniyyê`aniy: depressed, in mind or circumstances (practically the same as H6035, although the margin constantly disputes...H6041
  3. עָ֗םʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  4. י֭וֹשִׁיעַyôšîaʿyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  5. לִבְנֵ֣יlibnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  6. אֶבְי֑וֹןʾebyônebyown: destituteH34
  7. וִֽידַכֵּ֣אwîdakkēʾdaka': to crumble; transitively, to bruise (literally or figuratively)H1792
  8. עוֹשֵֽׁק׃ʿôšēq`ashaq: to press upon, i.e. oppress, defraud, violate, overflowH6231
5
  1. יִֽירָא֥וּךָyîrāʾûkāyare': to fear; morally, to revereH3372
  2. עִםʿim`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  3. שָׁ֑מֶשׁšāmešshemesh: the sun; (by implication) the eastH8121
  4. וְלִפְנֵ֥יwĕlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  5. יָ֝רֵ֗חַyārēaḥyareach: the moonH3394
  6. דּ֣וֹרdôrdowr: (properly) a revolution of time, i.e. an age or generationH1755
  7. דּוֹרִֽים׃dôrîmdowr: (properly) a revolution of time, i.e. an age or generationH1755
6
  1. יֵ֭רֵדyērēdyarad: to descend; (literally) to go downwardsH3381
  2. כְּמָטָ֣רkĕmāṭārmatar: rainH4306
  3. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  4. גֵּ֑זgēzgez: a fleece (as shorn); also mown grassH1488
  5. כִּ֝רְבִיבִ֗יםkirbîbîmrabiyb: a rain (as an accumulation of drops)H7241
  6. זַרְזִ֥יףzarzîpzarziyph: a pouring rainH2222
  7. אָֽרֶץ׃ʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
7
  1. יִֽפְרַחyipĕraḥparach: to break forth as a bud, i.e. bloom; (generally) to spreadH6524
  2. בְּיָמָ֥יוbĕyāmāywyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  3. צַדִּ֑יקṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  4. וְרֹ֥בwĕrōbrob: abundance (in any respect)H7230
  5. שָׁ֝ל֗וֹםšālômshalowm: safe; (figuratively) well, happy, friendlyH7965
  6. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  7. בְּלִ֥יbĕlîbliy: (properly) failure; nothing or destructionH1097
  8. יָרֵֽחַ׃yārēaḥyareach: the moonH3394
8
  1. וְ֭יֵרְדְּwĕyērĕdradah: to tread down, i.e. subjugate; specifically, to crumble offH7287
  2. מִיָּ֣םmiyyāmyam: a sea (as breaking in noisy surf) or large body of waterH3220
  3. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  4. יָ֑םyāmyam: a sea (as breaking in noisy surf) or large body of waterH3220
  5. וּ֝מִנָּהָ֗רûminnāhārnahar: a stream (including the sea; expec. the Nile, Euphrates, etc.)H5104
  6. עַדʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  7. אַפְסֵיʾapsêephec: cessation; an end (especially of the earth)H657
  8. אָֽרֶץ׃ʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
9
  1. לְ֭פָנָיוlĕpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  2. יִכְרְע֣וּyikrĕʿûkara`: to bend the knee; (by implication) to sink, to prostrateH3766
  3. צִיִּ֑יםṣiyyîmtsiyiy: a desert-dweller, i.e. nomad or wild beastH6728
  4. וְ֝אֹיְבָ֗יוwĕʾôybāywoyeb: hating; an adversaryH341
  5. עָפָ֥רʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
  6. יְלַחֵֽכוּ׃yĕlaḥēkûlachak: to lickH3897
10
  1. מַלְכֵ֬יmalkêmelek: a kingH4428
  2. תַרְשִׁ֣ישׁtaršîšTarshiysh: Tarshish, a place on the Mediterranean; (hence) the ephithet of a merchant vessel (as if for or from that...H8659
  3. וְ֭אִיִּיםwĕʾiyyîmiy: (properly) a habitable spot (as desirable)H339
  4. מִנְחָ֣הminḥâminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. יָשִׁ֑יבוּyāšîbûshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  6. מַלְכֵ֥יmalkêmelek: a kingH4428
  7. שְׁבָ֥אšĕbāʾShba': Sheba, the name of three early progenitors of tribes and of an Ethiopian districtH7614
  8. וּ֝סְבָ֗אûsĕbāʾCba': Seba, a son of Cush, and the country settled by himH5434
  9. אֶשְׁכָּ֥רʾeškāreshkar: a gratuityH814
  10. יַקְרִֽיבוּ׃yaqrîbûqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
11
  1. וְיִשְׁתַּחֲווּwĕyištaḥăwûshachah: to depress, i.e. prostrate (especially reflexive, in homage to royalty or God)H7812
  2. ל֥וֹlô
  3. כָלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. מְלָכִ֑יםmĕlākîmmelek: a kingH4428
  5. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  6. גּוֹיִ֥םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  7. יַֽעַבְדֽוּהוּ׃yaʿabdûhû`abad: to work (in any sense); (by implication) to serve, tillH5647
12
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. יַ֭צִּילyaṣṣîlnatsal: to snatch away, whether in a good or a bad senseH5337
  3. אֶבְי֣וֹןʾebyônebyown: destituteH34
  4. מְשַׁוֵּ֑עַmĕšawwēaʿshava`: (properly) to be free; but used only causatively and reflexively, to halloo (for help, i.e. freedom from some...H7768
  5. וְ֝עָנִ֗יwĕʿānî`aniy: depressed, in mind or circumstances (practically the same as H6035, although the margin constantly disputes...H6041
  6. וְֽאֵיןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  7. עֹזֵ֥רʿōzēr`azar: to surround, i.e. protect or aidH5826
13
  1. יָ֭חֹסyāḥōschuwc: (properly) to cover, i.e. (figuratively) to compassionateH2347
  2. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  3. דַּ֣לdaldal: (properly) dangling; (by implication) weak or thinH1800
  4. וְאֶבְי֑וֹןwĕʾebyônebyown: destituteH34
  5. וְנַפְשׁ֖וֹתwĕnapšôtnephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  6. אֶבְיוֹנִ֣יםʾebyônîmebyown: destituteH34
  7. יוֹשִֽׁיעַ׃yôšîaʿyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
14
  1. מִתּ֣וֹךְmittôktok: oppressionH8496
  2. וּ֭מֵחָמָסûmēḥāmoschamac: violence; (by implication) wrongH2555
  3. יִגְאַ֣לyigʾalga'al: to redeem (according to the Oriental law of kinship)H1350
  4. נַפְשָׁ֑םnapšāmnephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  5. וְיֵיקַ֖רwĕyêqaryaqar: (properly) apparently, to be heavy, i.e. (figuratively) valuableH3365
  6. דָּמָ֣םdāmāmdam: blood (as that which when shed causes death) of man or an animalH1818
  7. בְּעֵינָֽיו׃bĕʿênāyw`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
15
  1. וִיחִ֗יwîḥîchayah: to live, whether literally or figurativelyH2421
  2. וְיִתֶּןwĕyittennathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  3. לוֹ֮lô
  4. מִזְּהַ֪בmizzĕhabzahab: gold; (figuratively) golden, something gold-colored (i.e. yellow) such as oil or a clear, sunny skyH2091
  5. שְׁ֫בָ֥אšĕbāʾShba': Sheba, the name of three early progenitors of tribes and of an Ethiopian districtH7614
  6. וְיִתְפַּלֵּ֣לwĕyitpallēlpalal: to judge (officially or mentally); by extension, to intercede, prayH6419
  7. בַּעֲד֣וֹbaʿădôb`ad: in up to or over against; (generally) at, beside, among, behind, for, etcH1157
  8. תָמִ֑ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  9. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  10. הַ֝יּ֗וֹםhayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  11. יְבָרֲכֶֽנְהֽוּ׃yĕbārăkenĕhûbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
16
  1. יְהִ֤יyĕhîhayah: to exist; to be or becomeH1961
  2. פִסַּתpissatpiccah: expansion, i.e. abundanceH6451
  3. בַּ֨ר׀barbar: grain of any kind (even while standing in the field)H1250
  4. בָּאָרֶץ֮bāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. בְּרֹ֪אשׁbĕrōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  6. הָ֫רִ֥יםhārîmhar: a mountain or range of hills (sometimes used figuratively)H2022
  7. יִרְעַ֣שׁyirʿašra`ash: to undulate (as the earth, the sky, etc; also a field of grain), partic. through fearH7493
  8. כַּלְּבָנ֣וֹןkallĕbānônLbanown: (the) white mountain (from its snow); Lebanon, a mountain range in IsraelH3844
  9. פִּרְי֑וֹpiryôpriy: fruit (literally or figuratively)H6529
  10. וְיָצִ֥יצוּwĕyāṣîṣûtsuwts: to twinkle, i.e. glance; by analogy, to blossom (figuratively, flourish)H6692
  11. מֵ֝עִ֗ירmēʿîr`iyr: a city (a place guarded by waking or a watch) in the widest sense (even of a mere encampment or post)H5892
  12. כְּעֵ֣שֶׂבkĕʿēśeb`eseb: grass (or any tender shoot)H6212
  13. הָאָֽרֶץ׃hāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
17
  1. יְהִ֤יyĕhîhayah: to exist; to be or becomeH1961
  2. שְׁמ֨וֹšĕmôshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  3. לְֽעוֹלָ֗םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  4. לִפְנֵיlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  5. שֶׁמֶשׁ֮šemešshemesh: the sun; (by implication) the eastH8121
  6. יִנּ֪יֹןyinnyōnnuwn: to resprout, i.e. propagate by shoots; (figuratively) to be perpetualH5125
  7. שְׁ֫מ֥וֹšĕmôshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  8. וְיִתְבָּ֥רְכוּwĕyitbārĕkûbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  9. ב֑וֹbô
  10. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  11. גּוֹיִ֥םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  12. יְאַשְּׁרֽוּהוּ׃yĕʾaššĕrûhûashar: to be straight (used in the widest sense, especially to be level, right, happy)H833
18
  1. בָּר֤וּךְ׀bārûkbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  2. יְהוָ֣הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. אֱ֭לֹהִיםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  4. אֱלֹהֵ֣יʾĕlōhêelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  5. יִשְׂרָאֵ֑לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  6. עֹשֵׂ֖הʿōśē`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  7. נִפְלָא֣וֹתniplāʾôtpala': (properly, literally or figuratively) perhaps to separate, i.e. distinguishH6381
  8. לְבַדּֽוֹ׃lĕbaddôbad: (properly) separation; (by implication) a part of the body, branch of a tree, bar for carryingH905
19
  1. וּבָר֤וּךְ׀ûbārûkbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  2. שֵׁ֥םšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  3. כְּבוֹד֗וֹkĕbôdôkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  4. לְע֫וֹלָ֥םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  5. וְיִמָּלֵ֣אwĕyimmālēʾmale': to fill or (intransitively) be full of, in a wide application (literally and figuratively)H4390
  6. כְ֭בוֹדוֹkĕbôdôkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  7. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  8. כֹּ֥לkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  9. הָאָ֗רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  10. אָ֘מֵ֥ן׀ʾāmēnamen: sure; (abstract) faithfulnessH543
  11. וְאָמֵֽן׃wĕʾāmēnamen: sure; (abstract) faithfulnessH543
20
  1. כָּלּ֥וּkāllûkalah: to end, whether intransitive (to cease, be finished, perish) or transitived (to complete, prepare, consume)H3615
  2. תְפִלּ֑וֹתtĕpillôttphillah: intercession, supplication; (by implication) a hymnH8605
  3. דָּ֝וִ֗דdāwidDavid: loving; David, the youngest son of JesseH1732
  4. בֶּןbenben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  5. יִשָֽׁי׃yišāyYishay: extant; Jishai, David's fatherH3448

View the full Hebrew interlinear for Psalm 72 →

Strong's words in Psalm 72 (6)
Strong's H3605 — כָל (kāl)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 5 times in Psalm 72.
Strong's H4428 — לְמֶ֣לֶךְ (lĕmelek)
melek (meh'-lek) n-m. 1. a king [from H4427] KJV: king, royal. Root(s): H4427. Appears 5 times in Psalm 72.
Strong's H776 — אָֽרֶץ׃ (ʾāreṣ)
erets (eh'-rets) n-f. 1. the earth (at large, or partitively a land) [from an unused root probably meaning to be firm] KJV: X common, country, earth, field, ground, land, X natins, way, + wilderness, world.. Appears 5 times in Psalm 72.
Strong's H1288 — יְבָרֲכֶֽנְהֽוּ׃ (yĕbārăkenĕhû)
barak (baw-rak') v. 1. to kneel 2. (implication, man toward God) to bless God as an act of adoration 3. (implication, God toward man) to bless man as a benefit 4. (by euphemism) to curse (God or the king, as treason) [a primitive root] KJV: X abundantly, X altogether, X at all, blaspheme, bless, congratulate, curse, X greatly, X indeed, kneel (down), praise, salute, X still, thank.. Appears 4 times in Psalm 72.
Strong's H34 — אֶבְי֑וֹן (ʾebyôn)
ebyown (eb-yone') adj. 1. destitute [from H14, in the sense of want (especially in feeling)] KJV: beggar, needy, poor (man). Root(s): H14. Appears 4 times in Psalm 72.
Strong's H1121 — לְבֶן (lĕben)
ben (bane) n-m. 1. a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including grandson, subject, nation, quality or condition, etc., (like H0001 H0251, etc.)) [from H1129] KJV: + afflicted, age, (Ahoh-) (Ammon-) (Hachmon-) (Lev-)ite, (anoint-)ed one, appointed to, (+) arrow, (Assyr-) (Babylon-) (Egypt-) (Grec-)ian, one born, bough, branch, breed, + (young) bullock, + (young) calf, X came up in, child, colt, X common, X corn, daughter, X of first, + firstborn, foal, + very fruitful, + postage, X in, + kid, + lamb, (+) man, meet, + mighty, + nephew, old, (+) people, + rebel, + robber, X servant born, X soldier, son, + spark, + steward, + stranger, X surely, them of, + tumultuous one, + valiant(-est), whelp, worthy, young (one), youth. Root(s): H1129 See also: H1, H251. Appears 3 times in Psalm 72.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress