Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Psalms 44 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 À ti fi etí wa gbọ́, Ọlọ́run; àwọn baba wa tí sọ fún wa ohun tí ìwọ ṣe ní ọjọ́ wọn, ní ọjọ́ pípẹ́ sẹ́yìn.
2 Ìwọ fi ọwọ́ rẹ lé orílẹ̀-èdè jáde, Ìwọ sì gbin àwọn baba wa; ìwọ run àwọn ènìyàn náà Ìwọ sì mú àwọn baba wa gbilẹ̀.
3 Kì í ṣe nípa idà wọn ni wọ́n gba ilẹ̀ náà, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe apá wọn ní ó gbà wọ́n bí kò ṣe; ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti, apá rẹ; àti ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ̀, nítorí ìwọ fẹ́ wọn.
4 Ìwọ ni ọba àti Ọlọ́run mi, ẹni tí ó pàṣẹ ìṣẹ́gun fún Jakọbu.
5 Nípasẹ̀ rẹ ni àwa ó bi àwọn ọ̀tá wa ṣubú; nípasẹ̀ orúkọ rẹ ni àwa ó tẹ àwọn ọ̀tá tí ó dìde sí wa mọ́lẹ̀,
6 èmi kì yóò gbẹ́kẹ̀lé ọrun mi, idà mi kì yóò mú ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wá,
7 ṣùgbọ́n ìwọ fún wa ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ọ̀tá wa, ìwọ sì ti dójúti àwọn tí ó kórìíra wa.
8 Nínú Ọlọ́run àwa ń ṣògo ní gbogbo ọjọ́, àwa ó sì yin orúkọ rẹ títí láé. Sela.
9 Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, ìwọ ti kọ̀ wá, ìwọ sì ti dójútì wá, Ìwọ kò sì bá àwọn ọmọ-ogun wa jáde mọ́.
10 Ìwọ ti bá wa jà, ìwọ sì ti ṣẹ́gun wa níwájú àwọn ọ̀tá wa, àwọn ọ̀tá wa ti gba ilẹ̀ wa, wọ́n sì fi ipá gba oko wa.
11 Ìwọ fi wá fún jíjẹ bí ẹran àgùntàn, Ìwọ sì ti tú wa ká sí àárín àwọn kèfèrí.
12 Ìwọ ta àwọn ènìyàn rẹ fún owó kékeré, Ìwọ kò sì jẹ èrè kankan lórí iye tí ìwọ tà wọ́n.
13 Ìwọ sọ wá di ẹni ẹ̀sín ní ọ̀dọ̀ àwọn aládùúgbò wa, ẹlẹ́yà àti ẹni àbùkù sí àwọn tí ó yí wa ká.
14 Ìwọ ti sọ wá di ẹni ìfisọ̀rọ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè; àwọn ènìyàn ń mi orí wọn sí wa.
15 Ìdójútì mi ń bẹ pẹ̀lú mi ní gbogbo ọjọ́, ìtìjú sì bojú mi mọ́lẹ̀,
16 nítorí ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn àti ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn ní ojú àwọn ọ̀tá àti olùgbẹ̀san.
17 Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ń ṣẹlẹ̀ sí wa, síbẹ̀ àwa kò gbàgbé rẹ bẹ́ẹ̀ ni a kò ṣèké sí májẹ̀mú rẹ̀.
18 Ọkàn wa kò padà sẹ́yìn; bẹ́ẹ̀ ni ẹsẹ̀ wa kò yẹ̀ kúrò ní ọ̀nà rẹ̀.
19 Ṣùgbọ́n wọ́n kọlù wá, ìwọ sì sọ wá di ẹran ọdẹ fún àwọn ẹranko búburú, tí wọn sì fi òkùnkùn biribiri bò wá mọ́lẹ̀.
20 Bí àwa bá ti gbàgbé orúkọ Ọlọ́run wa tàbí tí a na ọwọ́ wa sí ọlọ́run àjèjì.
21 Ǹjẹ́ Ọlọ́run kì yóò rí ìdí rẹ̀, níwọ̀n ìgbà tí ó mọ ohun ìkọ̀kọ̀ inú ọkàn?
22 Síbẹ̀, nítorí rẹ̀ àwa da àyà kọ ikú, ní ojoojúmọ́ a ń kà wá sí bí àgùntàn fún pípa.
23 Jí, Olúwa! Èéṣe tí ìwọ ń sùn? Dìde fúnra rẹ̀! Má ṣe kọ̀ wá sílẹ̀ láéláé.
24 Èéṣe tí ìwọ ń pa ojú rẹ mọ́ tí ìwọ sì gbàgbé ìpọ́njú àti ìnira wa?
25 Nítorí a tẹrí ọkàn wa ba sínú eruku; ara wa sì dì mọ́ erùpẹ̀ ilẹ̀.
26 Dìde kí o sì ràn wá lọ́wọ́; rà wá padà nítorí ìfẹ́ rẹ tí ó dúró ṣinṣin.
Chapter information and study resources

Listen to Psalms 44 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Psalm 44

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Psalm 44. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Psalm 44 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 12 cross-references, 1 Early-Church citation.

Cross-references in Psalm 44 (12)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Psalm 44:1–26 (192 words)
1
  1. אֱלֹהִ֤ים׀ʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  2. בְּאָזְנֵ֬ינוּbĕʾoznênûozen: broadness; (concretely) the ear (from its form in man)H241
  3. שָׁמַ֗עְנוּšāmaʿnûshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  4. אֲבוֹתֵ֥ינוּʾăbôtênûab: fatherH1
  5. סִפְּרוּsippĕrûcaphar: (properly) to score with a mark as a tally or recordH5608
  6. לָ֑נוּlānû
  7. פֹּ֥עַלpōʿalpo`al: (concretely) an act or workH6467
  8. פָּעַ֥לְתָּpāʿaltāpa`al: to do or make (systematically and habitually), especially to practiseH6466
  9. בִֽ֝ימֵיהֶ֗םbîmêhemyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  10. בִּ֣ימֵיbîmêyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  11. קֶֽדֶם׃qedemqedem: the front, of place (absolutely, the fore part, relatively the East) or time (antiquity)H6924
2
  1. אַתָּ֤ה׀ʾattâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  2. יָדְךָ֡yodkāyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  3. גּוֹיִ֣םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  4. ה֭וֹרַשְׁתָּhôraštāyarash: to occupy (by driving out previous tenants, and possessing in their place)H3423
  5. וַתִּטָּעֵ֑םwattiṭṭāʿēmnata`: (properly) to strike in, i.e. fix; specifically, to plant (literally or figuratively)H5193
  6. תָּרַ֥עtāraʿra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
  7. לְ֝אֻמִּ֗יםlĕʾummîmlom: a communityH3816
  8. וַֽתְּשַׁלְּחֵֽם׃wattĕšallĕḥēmshalach: to send away, for, or out (in a great variety of applications)H7971
3
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. לֹ֪אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. בְחַרְבָּ֡םbĕḥarbāmchereb: drought; also a cutting instrument (from its destructive effect), as a knife, sword, or other sharp implementH2719
  4. יָ֥רְשׁוּyārĕšûyarash: to occupy (by driving out previous tenants, and possessing in their place)H3423
  5. אָ֗רֶץʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  6. וּזְרוֹעָם֮ûzĕrôʿāmzrowa`: the arm (as stretched out), or (of animals) the forelegH2220
  7. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  8. הוֹשִׁ֪יעָ֫הhôšîʿâyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  9. לָּ֥מוֹlāmô
  10. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  11. יְמִֽינְךָ֣yĕmînĕkāyamiyn: the right hand or side (leg, eye) of a person or other object (as the stronger and more dexterous)H3225
  12. וּ֭זְרוֹעֲךָûzĕrôʿăkāzrowa`: the arm (as stretched out), or (of animals) the forelegH2220
  13. וְא֥וֹרwĕʾôrowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  14. פָּנֶ֗יךָpānêkāpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  15. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  16. רְצִיתָֽם׃rĕṣîtāmratsah: to be pleased with; specifically, to satisfy a debtH7521
4
  1. אַתָּהʾattâattah: thou and thee, or (plural) ye and youH859
  2. ה֣וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  3. מַלְכִּ֣יmalkîmelek: a kingH4428
  4. אֱלֹהִ֑יםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  5. צַ֝וֵּ֗הṣawwētsavah: (intensively) to constitute, enjoinH6680
  6. יְשׁוּע֥וֹתyĕšûʿôtyshuw`ah: something saved, i.e. (abstractly) deliveranceH3444
  7. יַעֲקֹֽב׃yaʿăqōbYa`aqob: heel-catcher (i.e. supplanter); Jaakob, the Israelitish patriarchH3290
5
  1. בְּ֭ךָbĕkā
  2. צָרֵ֣ינוּṣārênûtsar: narrow; (as a noun) a tight place (usually figuratively, i.e. trouble)H6862
  3. נְנַגֵּ֑חַnĕnaggēaḥnagach: to but with the horns; (figuratively) to war againstH5055
  4. בְּ֝שִׁמְךָ֗bĕšimkāshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  5. נָב֥וּסnābûsbuwc: to trample (literally or figuratively)H947
  6. קָמֵֽינוּ׃qāmênûquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
6
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  3. בְקַשְׁתִּ֣יbĕqaštîqesheth: X arch(-er), + arrow, bow((-man, -shot))H7198
  4. אֶבְטָ֑חʾebṭāḥbatach: (properly) to hie for refuge (but not so precipitately as H2620)H982
  5. וְ֝חַרְבִּ֗יwĕḥarbîchereb: drought; also a cutting instrument (from its destructive effect), as a knife, sword, or other sharp implementH2719
  6. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. תוֹשִׁיעֵֽנִי׃tôšîʿēnîyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
7
  1. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. ה֭וֹשַׁעְתָּנוּhôšaʿtānûyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  3. מִצָּרֵ֑ינוּmiṣṣārênûtsar: narrow; (as a noun) a tight place (usually figuratively, i.e. trouble)H6862
  4. וּמְשַׂנְאֵ֥ינוּûmĕśanʾênûsane': to hate (personally)H8130
  5. הֱבִישֽׁוֹתָ׃hĕbîšôtābuwsh: (properly) to pale; (by implication) to be ashamedH954
8
  1. בֵּֽ֭אלֹהִיםbēʾlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  2. הִלַּלְ֣נוּhillalnûhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  3. כָלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. הַיּ֑וֹםhayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  5. וְשִׁמְךָ֓׀wĕšimkāshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  6. לְעוֹלָ֖םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  7. נוֹדֶ֣הnôdeyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  8. סֶֽלָה׃selâcelah: suspension (of music), i.e. pauseH5542
9
  1. אַףʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  2. זָ֭נַחְתָּzānaḥtāzanach: cast away (off), remove far away (off)H2186
  3. וַתַּכְלִימֵ֑נוּwattaklîmēnûkalam: (properly) to wound; (figuratively) to taunt or insultH3637
  4. וְלֹאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. תֵ֝צֵ֗אtēṣēʾyatsa': to go out; (causatively) to bring outH3318
  6. בְּצִבְאוֹתֵֽינוּ׃bĕṣibʾôtênûtsaba': a mass of persons; (figuratively) a mass of thingsH6635
10
  1. תְּשִׁיבֵ֣נוּtĕšîbēnûshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  2. אָ֭חוֹרʾāḥôrachowr: the hinder part; (hence, adverbly) behind, backwardH268
  3. מִנִּיminnîmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  4. צָ֑רṣārtsar: narrow; (as a noun) a tight place (usually figuratively, i.e. trouble)H6862
  5. וּ֝מְשַׂנְאֵ֗ינוּûmĕśanʾênûsane': to hate (personally)H8130
  6. שָׁ֣סוּšāsûshacah: to plunderH8154
11
  1. תִּ֭תְּנֵנוּtittĕnēnûnathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  2. כְּצֹ֣אןkĕṣōntso'n: a collective name for a flock (of sheep or goats)H6629
  3. מַאֲכָ֑לmaʾăkālma'akal: an eatable (includ. provender, flesh and fruit)H3978
  4. וּ֝בַגּוֹיִ֗םûbaggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  5. זֵרִיתָֽנוּ׃zērîtānûzarah: to toss about; (by implication) to diffuse, winnowH2219
12
  1. תִּמְכֹּֽרtimkōrmakar: to sell, literally (as merchandise, a daughter in marriage, into slavery), or figuratively (to surrender)H4376
  2. עַמְּךָ֥ʿammĕkā`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  3. בְלֹאbĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  4. ה֑וֹןhônhown: wealth; (by implication) enoughH1952
  5. וְלֹ֥אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. רִ֝בִּ֗יתָribbîtārabah: to increase (in whatever respect)H7235
  7. בִּמְחִירֵיהֶֽם׃bimḥîrêhemmchiyr: price, payment, wagesH4242
13
  1. תְּשִׂימֵ֣נוּtĕśîmēnûsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  2. חֶ֭רְפָּהḥerpâcherpah: contumely, disgrace, the pudendaH2781
  3. לִשְׁכֵנֵ֑ינוּliškēnênûshaken: a resident; by extension, a fellow-citizenH7934
  4. לַ֥עַגlaʿagla`ag: derision, scoffingH3933
  5. וָ֝קֶ֗לֶסwāqelesqelec: a laughing-stockH7047
  6. לִסְבִיבוֹתֵֽינוּ׃lisbîbôtênûcabiyb: (as noun) a circle, neighbour, or environsH5439
14
  1. תְּשִׂימֵ֣נוּtĕśîmēnûsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  2. מָ֭שָׁלmāšolmashal: (properly) a pithy maxim, usually of metaphorical natureH4912
  3. בַּגּוֹיִ֑םbaggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  4. מְנֽוֹדmĕnôdmanowd: shakingH4493
  5. רֹ֝֗אשׁrōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  6. בַּלְאֻמִּֽים׃balʾummîmlom: a communityH3816
15
  1. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. הַ֭יּוֹםhayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  3. כְּלִמָּתִ֣יkĕlimmātîklimmah: disgraceH3639
  4. נֶגְדִּ֑יnegdîneged: a front, i.e. part opposite; specifically a counterpart, or mateH5048
  5. וּבֹ֖שֶׁתûbōšetbosheth: shame (the feeling and the condition, as well as its cause)H1322
  6. פָּנַ֣יpānaypaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. כִּסָּֽתְנִי׃kissātĕnîkacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
16
  1. מִ֭קּוֹלmiqqôlqowl: a voice or soundH6963
  2. מְחָרֵ֣ףmĕḥārēpcharaph.: to pull off; (by implication) to expose (as by stripping)H2778
  3. וּמְגַדֵּ֑ףûmĕgaddēpgadaph: to hack (with words); to revileH1442
  4. מִפְּנֵ֥יmippĕnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  5. א֝וֹיֵ֗בʾôyēboyeb: hating; an adversaryH341
  6. וּמִתְנַקֵּֽם׃ûmitnaqqēmnaqam: to grudge, i.e. avenge or punishH5358
17
  1. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. זֹ֣אתzōtzo'th: this (often used adverb)H2063
  3. בָּ֭אַתְנוּbāʾatnûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  4. וְלֹ֣אwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  5. שְׁכַחֲנ֑וּךָšĕkaḥănûkāshakach: to mislay, i.e. to be oblivious of, from want of memory or attentionH7911
  6. וְלֹֽאwĕlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. שִׁ֝קַּ֗רְנוּšiqqarnûshaqar: to cheat, i.e. be untrue (usually in words)H8266
  8. בִּבְרִיתֶֽךָ׃bibrîtekābriyth: a compact (because made by passing between pieces of flesh)H1285
18
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. נָס֣וֹגnāsôgcuwg: (properly) to flinch; (by implication) to go back, literally (to retreat) or figuratively (to apostatize)H5472
  3. אָח֣וֹרʾāḥôrachowr: the hinder part; (hence, adverbly) behind, backwardH268
  4. לִבֵּ֑נוּlibbēnûleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  5. וַתֵּ֥טwattēṭnatah: to stretch or spread out; (by implication) to bend away (including moral deflection)H5186
  6. אֲשֻׁרֵ֗ינוּʾăšurênûashur: a stepH838
  7. מִנִּ֥יminnîmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  8. אָרְחֶֽךָ׃ʾorḥekāorach: (literally or figuratively) a well-trodden roadH734
19
  1. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. דִ֭כִּיתָנוּdikkîtānûdakah: to collapse (phys. or mentally)H1794
  3. בִּמְק֣וֹםbimqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  4. תַּנִּ֑יםtannîmtanniyn: a marine or land monster, i.e. sea-serpent or jackalH8577
  5. וַתְּכַ֖סwattĕkaskacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  6. עָלֵ֣ינוּʿālênû`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. בְצַלְמָֽוֶת׃bĕṣalmāwettsalmaveth: shade of death, i.e. the grave (figuratively, calamity)H6757
20
  1. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  2. שָׁ֭כַחְנוּšākaḥnûshakach: to mislay, i.e. to be oblivious of, from want of memory or attentionH7911
  3. שֵׁ֣םšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  4. אֱלֹהֵ֑ינוּʾĕlōhênûelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  5. וַנִּפְרֹ֥שׂwanniprōśparas: to break apart, disperse, etcH6566
  6. כַּ֝פֵּ֗ינוּkappênûkaph: the hollow hand or palm (so of the paw of an animal, of the sole, and even of the bowl of a dish or sling, the...H3709
  7. לְאֵ֣לlĕʾēlel: strength; (as adjective) mightyH410
  8. זָֽר׃zārzuwr: to turn aside (especially for lodging); hence to be a foreigner, strange, profaneH2114
21
  1. הֲלֹ֣אhălōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. אֱ֭לֹהִיםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  3. יַֽחֲקָרyaḥăqorchaqar: (properly) to penetrate; (hence) to examine intimatelyH2713
  4. זֹ֑אתzōtzo'th: this (often used adverb)H2063
  5. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  6. ה֥וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  7. יֹ֝דֵ֗עַyōdēaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  8. תַּעֲלֻמ֥וֹתtaʿălumôtta`alummah: a secretH8587
  9. לֵֽב׃lēbleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
22
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. עָ֭לֶיךָʿālêkā`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  3. הֹרַ֣גְנוּhōragnûharag: to smite with deadly intentH2026
  4. כָלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  5. הַיּ֑וֹםhayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  6. נֶ֝חְשַׁ֗בְנוּneḥšabnûchashab: (properly) to plait or interpenetrate, i.e. (literally) to weave or (gen.) to fabricateH2803
  7. כְּצֹ֣אןkĕṣōntso'n: a collective name for a flock (of sheep or goats)H6629
  8. טִבְחָֽה׃ṭibḥâtibehah: flesh, slaughterH2878
23
  1. ע֤וּרָה׀ʿûrâ`uwr: to wake (literally or figuratively)H5782
  2. לָ֖מָּהlāmmâmah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  3. תִישַׁ֥ן׀tîšanyashen: (properly) to be slack or languid; (by implication) to sleepH3462
  4. אֲדֹנָ֑יʾădōnāyAdonay: the Lord (used as a proper name of God only)H136
  5. הָ֝קִ֗יצָהhāqîṣâquwts: to awake (literally or figuratively)H6974
  6. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  7. תִּזְנַ֥חtiznaḥzanach: cast away (off), remove far away (off)H2186
  8. לָנֶֽצַח׃lāneṣaḥnetsach: (properly) a goal, i.e. the bright object at a distance travelled towardsH5331
24
  1. לָֽמָּהlāmmâmah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. פָנֶ֥יךָpānêkāpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  3. תַסְתִּ֑ירtastîrcathar: to hide (by covering), literally or figurativelyH5641
  4. תִּשְׁכַּ֖חtiškaḥshakach: to mislay, i.e. to be oblivious of, from want of memory or attentionH7911
  5. עָנְיֵ֣נוּʿonyēnû`oniy: depression, i.e. miseryH6040
  6. וְֽלַחֲצֵֽנוּ׃wĕlaḥăṣēnûlachats: distressH3906
25
  1. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. שָׁ֣חָהšāḥâshuwach: to sink, literally or figurativelyH7743
  3. לֶעָפָ֣רleʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
  4. נַפְשֵׁ֑נוּnapšēnûnephesh: (properly) a breathing creature, i.e. animal of (abstractly) vitalityH5315
  5. דָּבְקָ֖הdobqâdabaq: (properly) to impinge, i.e. cling or adhereH1692
  6. לָאָ֣רֶץlāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  7. בִּטְנֵֽנוּ׃biṭnēnûbeten: the belly, especially the womb; also the bosom or body of anythingH990
26
  1. ק֭וּמָֽהqûmâquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  2. עֶזְרָ֣תָהʿezrātâ`ezrah: aidH5833
  3. לָּ֑נוּlānû
  4. וּ֝פְדֵ֗נוּûpĕdēnûpadah: to sever, i.e. ransom; gener. to release, preserveH6299
  5. לְמַ֣עַןlĕmaʿanma`an: (properly) heed, i.e. purposeH4616
  6. חַסְדֶּֽךָ׃ḥasdekācheced: kindness; (by implication, towards God) pietyH2617

View the full Hebrew interlinear for Psalm 44 →

Strong's words in Psalm 44 (6)
Strong's H3117 — בִֽ֝ימֵיהֶ֗ם (bîmêhem)
yowm (yome) n-m. 1. a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or figurative (a space of time defined by an associated term), (often used adverb) [from an unused root meaning to be hot] KJV: age, + always, + chronicals, continually(-ance), daily, ((birth-), each, to) day, (now a, two) days (agone), + elder, X end, + evening, + (for) ever(-lasting, -more), X full, life, as (so) long as (... live), (even) now, + old, + outlived, + perpetually, presently, + remaineth, X required, season, X since, space, then, (process of) time, + as at other times, + in trouble, weather, (as) when, (a, the, within a) while (that), X whole (+ age), (full) year(-ly), + younger.. Appears 5 times in Psalm 44.
Strong's H430 — אֱלֹהִ֤ים׀ (ʾĕlōhîm)
elohiym (el-o-heem') n-m. 1. gods in the ordinary sense 2. but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the supreme God 3. occasionally applied by way of deference to magistrates 4. and sometimes as a superlative [plural of H433] KJV: angels, X exceeding, God (gods)(-dess, -ly), X (very) great, judges, X mighty. Root(s): H433. Appears 5 times in Psalm 44.
Strong's H3605 — כָל (kāl)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 4 times in Psalm 44.
Strong's H6440 — פָּנֶ֗יךָ (pānêkā)
paniym (paw-neem') (plural (but always as singular) of an unused noun (paneh {paw-neh'}) n-m. 1. the face (as the part that turns) 2. (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc. {used in a great variety of applications, literally and figuratively} [from H6437] KJV: + accept, a-(be- )fore(-time), against, anger, X as (long as), at, + battle, + because (of), + beseech, countenance, edge, + employ, endure, + enquire, face, favour, fear of, for, forefront(-part), form(-er time, -ward), from, front, heaviness, X him(-self), + honourable, + impudent, + in, it, look(-eth) (- s), X me, + meet, X more than, mouth, of, off, (of) old (time), X on, open, + out of, over against, the partial, person, + please, presence, propect, was purposed, by reason of, + regard, right forth, + serve, X shewbread, sight, state, straight, + street, X thee, X them(-selves), through (+ - out), till, time(-s) past, (un-)to(-ward), + upon, upside (+ down), with(- in, + -stand), X ye, X you. Root(s): H6437. Appears 4 times in Psalm 44.
Strong's H1471 — גּוֹיִ֣ם (gôyim)
gowy (go'-ee) (rarely (shortened) goy {go'-ee}) n-m. 1. a foreign nation 2. (hence) a Gentile 3. (figuratively) a troop of animals, or a flight of locusts [apparently from the same root as H1465 (in the sense of massing)] KJV: Gentile, heathen, nation, people. See also: H1465. Appears 3 times in Psalm 44.
Strong's H3467 — הוֹשִׁ֪יעָ֫ה (hôšîʿâ)
yasha` (yaw-shah') v. 1. (properly) to be open, wide or free 2. (by implication) to be safe 3. causatively, to free or succor [a primitive root] KJV: X at all, avenging, defend, deliver(-er), help, preserve, rescue, be safe, bring (having) salvation, save(-iour), get victory.. Appears 3 times in Psalm 44.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress