Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Numbers 28 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Olúwa sọ fún Mose pé,
2 “Fún àwọn ọmọ Israẹli ní òfin yìí kí o sì wí fún wọn pé: ‘Ẹ rí i wí pé ẹ gbé e wá sí iwájú mi ní àkókò tí a ti yàn, oúnjẹ ọrẹ ẹbọ mi tí a fi iná ṣe sí mi, gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn sí mi.’
3 Sọ fún wọn, ‘Èyí ní ọrẹ ẹbọ tí a fi iná sun tí ẹ gbọdọ̀ mú wá fún Olúwa: akọ ọ̀dọ́-àgùntàn méjì ọlọ́dún kan aláìlábàwọ́n gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun ní ojoojúmọ́.
4 Pèsè ọ̀dọ́-àgùntàn kan ní òwúrọ̀ àti òmíràn ní àfẹ̀mọ́júmọ́.
5 Pẹ̀lú ẹbọ ohun jíjẹ tí ó jẹ́ ìdámẹ́wàá efa ìyẹ̀fun dáradára tí a pò mọ́ ìdámẹ́rin hínì òróró tí a yọ lára Olifi.
6 Èyí ni ẹbọ sísun gbogbo ìgbà tí a fi lélẹ̀ ní òkè Sinai gẹ́gẹ́ bí olóòórùn dídùn ẹbọ tí a fi iná sun fún Olúwa pẹ̀lú iná.
7 Àfikún ọrẹ ohun mímu rẹ gbọdọ̀ jẹ́ ìdámẹ́rin ti hínì dídé omi mímu tí ó kan pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀dọ́-àgùntàn. Da ẹbọ mímu náà síta sí Olúwa ní ibi mímọ́.
8 Pèsè ọ̀dọ́-àgùntàn kejì ní àfẹ̀mọ́júmọ́, pẹ̀lú oríṣìí ẹbọ ohun jíjẹ àti ẹbọ ohun mímu èyí tí ó pèsè ní òwúrọ̀, èyí ni ẹbọ tí a fi iná ṣe, olóòórùn dídùn sí Olúwa.
9 “ ‘Ní ọjọ́ ìsinmi, pèsè akọ ọ̀dọ́-àgùntàn méjì ọlọ́dún kan tí kò lábùkù, pẹ̀lú ẹbọ ohun mímu àti ẹbọ ohun jíjẹ tí i ṣe ìdá méjì nínú ìdámẹ́wàá òsùwọ̀n ìyẹ̀fun tí a fi òróró pò.
10 Èyí ni ẹbọ sísun fún gbogbo ọjọ́ ìsinmi kọ̀ọ̀kan, ní àfikún pẹ̀lú ẹbọ sísun àti ẹbọ ohun mímu.
11 “ ‘Àti ní ọjọ́ tí o bẹ̀rẹ̀ oṣù kọ̀ọ̀kan, kí ẹ̀yin kí ó gbé ẹbọ sísun fún Olúwa pẹ̀lú ọ̀dọ́ akọ màlúù méjì, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn méje ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan, kí gbogbo rẹ̀ sì jẹ́ aláìlábùkù.
12 Pẹ̀lú akọ màlúù kọ̀ọ̀kan ni kí wọn ó rú ẹbọ ohun jíjẹ ẹbọ ìdámẹ́ta nínú mẹ́wàá ìyẹ̀fun tí a pòpọ̀ pẹ̀lú òróró; pẹ̀lú àgbò, ni kí wọn ó rú ẹbọ ohun jíjẹ tí í ṣe ìdá méjì nínú mẹ́wàá òsùwọ̀n ìyẹ̀fun tí a pòpọ̀ mọ́ òróró;
13 pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀dọ́-àgùntàn, ni kí ẹ rú ẹbọ ìyẹ̀fun ìyẹ̀fun kíkúnná tí a pò mọ́ òróró. Èyí ni ẹbọ sísun, òórùn dídùn, àti ẹbọ tí a ṣe fún Olúwa pẹ̀lú iná.
14 Kí ẹbọ ohun mímu wọn jẹ́ ààbọ̀ òsùwọ̀n hínì ti ọtí wáìnì, fún akọ màlúù kan, àti ìdámẹ́wàá òsùwọ̀n hínì fún àgbò kan àti ìdámẹ́rin òsùwọ̀n hínì fún ọ̀dọ́-àgùntàn kan. Èyí ni ẹbọ sísun tí wọn ó máa rú ní oṣù kọ̀ọ̀kan nínú ọdún.
15 Yàtọ̀ sí ẹbọ sísun pẹ̀lú ẹbọ ohun mímu, ẹ gbọdọ̀ fi akọ ewúrẹ́ kọ̀ọ̀kan fún Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.
16 “ ‘Ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìn-ín-ní ni ìrékọjá Olúwa gbọdọ̀ wáyé.
17 Ní ọjọ́ kẹ́ẹ̀dógún oṣù yìí ẹ gbọdọ̀ ṣiṣẹ́ àjọ̀dún fún ọjọ́ méje kí ó jẹ àkàrà tí kò ní ìwúkàrà.
18 Ní ọjọ́ kìn-ín-ní kí àpéjọ mímọ́ kí ó wà; ẹ́yin kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.
19 Ẹ rú ẹbọ sísun sí Olúwa, ẹ rú u pẹ̀lú ọ̀dọ́ màlúù méjì akọ, ẹbọ sísun pẹ̀lú iná àgbò kan àti ọ̀dọ́-àgùntàn méje ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan kí wọn kí ó jẹ́ aláìlábùkù.
20 Pẹ̀lú akọ màlúù kọ̀ọ̀kan ni kí ẹ pèsè ẹbọ ohun mímu pẹ̀lú ìdámẹ́ta nínú mẹ́wàá ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi òróró pò; pẹ̀lú àgbò, ìdá méjì nínú mẹ́wàá;
21 pẹ̀lú ọ̀dọ́-àgùntàn kọ̀ọ̀kan ìdákan nínú mẹ́wàá.
22 Pẹ̀lú òbúkọ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣètùtù fún un yín.
23 Ṣe eléyìí ní àfikún sí ẹbọ sísun àràárọ̀.
24 Báyìí ní kí ẹ̀yin rúbọ ní ọjọọjọ́, jálẹ̀ ní ọjọ́ méjèèje, oúnjẹ ẹbọ tí a fi iná ṣe, tí olóòórùn dídùn sí Olúwa; ó rú u pẹ̀lú ẹbọ sísun ìgbà gbogbo, àti ẹbọ ohun mímu.
25 Ní ọjọ́ keje kí ẹ̀yin kí ó ní àpéjọ mímọ́, ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.
26 “ ‘Ní ọjọ́ àkọ́so pẹ̀lú, nígbà tí ẹ̀yin bá mú ẹbọ ohun jíjẹ tuntun wá fún Olúwa lẹ́yìn àsìkò àjọ̀dún, kí ẹ̀yin kí ó ní àpéjọ mímọ́, ẹ̀yin kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ kankan.
27 Kí ẹ mú ẹbọ sísun ẹgbọrọ màlúù méjì, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn méje ọlọ́dún kan gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn fún Olúwa.
28 Pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan akọ màlúù ní kí ẹ rú ẹbọ ohun mímu ìdámẹ́ta pẹ̀lú òsùwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi òróró pò pẹ̀lú àgbò kan.
29 Àti pẹ̀lú ọ̀kọ̀ọ̀kan ọ̀dọ́-àgùntàn méje, kí ó jẹ́ ìdákan nínú mẹ́wàá.
30 Ẹ fi òbúkọ kan ṣe ètùtù fún ara yín.
31 Kí ẹ̀yin kí ó rú wọn pẹ̀lú ẹbọ sísun ìgbà gbogbo, àti ẹbọ ohun mímu yín àti ẹbọ ohun jíjẹ yín. Kí ẹ sì ri dájú pé àwọn ẹranko náà jẹ́ aláìlábùkù.
Chapter information and study resources

Listen to Numbers 28 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Numbers 28

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Numbers 28. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Numbers 28 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 17 cross-references.

Cross-references in Numbers 28 (17)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Numbers 28:1–31 (347 words)
1
  1. וַיְדַבֵּ֥רwaydabbērdabar: perhaps properly, to arrange; but used figuratively (of words), to speakH1696
  2. יְהוָ֖הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. מֹשֶׁ֥הmōšeMosheh: drawing out (of the water), i.e. rescuedH4872
  5. לֵּאמֹֽר׃lēʾmōramar: to say (used with great latitude)H559
2
  1. צַ֚וṣǎwtsavah: (intensively) to constitute, enjoinH6680
  2. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  3. בְּנֵ֣יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  4. יִשְׂרָאֵ֔לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  5. וְאָֽמַרְתָּ֖wĕʾāmartāamar: to say (used with great latitude)H559
  6. אֲלֵהֶ֑םʾălēhemel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  7. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  8. קָרְבָּנִ֨יqorbānîqorban: something brought near the altar, i.e. a sacrificial presentH7133
  9. לַחְמִ֜יlaḥmîlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  10. לְאִשַּׁ֗יlĕʾiššayishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  11. רֵ֚יחַrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  12. נִֽיחֹחִ֔יnîḥōḥînichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  13. תִּשְׁמְר֕וּtišmĕrûshamar: (properly) to hedge about (as with thorns), i.e. guardH8104
  14. לְהַקְרִ֥יבlĕhaqrîbqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  15. לִ֖יlî
  16. בְּמֽוֹעֲדֽוֹ׃bĕmôʿădômow`ed: (properly) an appointment, i.e. a fixed time or seasonH4150
3
  1. וְאָֽמַרְתָּ֣wĕʾāmartāamar: to say (used with great latitude)H559
  2. לָהֶ֔םlāhem
  3. זֶ֚הzezeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  4. הָֽאִשֶּׁ֔הhāʾiššeishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  5. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  6. תַּקְרִ֖יבוּtaqrîbûqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  7. לַֽיהוָ֑הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  8. כְּבָשִׂ֨יםkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  9. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  10. שָׁנָ֧הšānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
  11. תְמִימִ֛םtĕmîmimtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  12. שְׁנַ֥יִםšĕnayimshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  13. לַיּ֖וֹםlayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  14. עֹלָ֥הʿōlâ`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  15. תָמִֽיד׃tāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
4
  1. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  2. הַכֶּ֥בֶשׂhakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  3. אֶחָ֖דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  4. תַּֽעֲשֶׂ֣הtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  5. בַבֹּ֑קֶרbabbōqerboqer: (properly) dawn (as the break of day); (generally) morningH1242
  6. וְאֵת֙wĕʾēteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  7. הַכֶּ֣בֶשׂhakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  8. הַשֵּׁנִ֔יhaššēnîsheniy: (properly) second (the ordinal number); (adverbially) againH8145
  9. תַּֽעֲשֶׂ֖הtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  10. בֵּ֥יןbênbeyn: a distinction; (but used only as a prep) between (repeated before each noun, often with other particles)H996
  11. הָֽעַרְבָּֽיִם׃hāʿarbāyim`ereb: duskH6153
5
  1. וַֽעֲשִׂירִ֧יתwaʿăśîrît`asiyriy: tenth; by abbreviation, tenth month or (feminine) partH6224
  2. הָֽאֵיפָ֛הhāʾêpâeyphah: an ephah or measure for grain; (hence) a measure in generalH374
  3. סֹ֖לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  4. לְמִנְחָ֑הlĕminḥâminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. בְּלוּלָ֛הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  6. בְּשֶׁ֥מֶןbĕšemenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  7. כָּתִ֖יתkātîtkathiyth: beaten, i.e. pure (oil)H3795
  8. רְבִיעִ֥תrĕbîʿitrbiy`iy: fourth; (fractionally) a fourthH7243
  9. הַהִֽין׃hahînhiyn: a hin or liquid measureH1969
6
  1. עֹלַ֖תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  2. תָּמִ֑ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  3. הָֽעֲשֻׂיָה֙hāʿăśuyāh`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  4. בְּהַ֣רbĕharhar: a mountain or range of hills (sometimes used figuratively)H2022
  5. סִינַ֔יsînayCiynay: Sinai, mountain of ArabiaH5514
  6. לְרֵ֣יחַlĕrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  7. נִיחֹ֔חַnîḥōaḥnichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  8. אִשֶּׁ֖הʾiššeishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  9. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
7
  1. וְנִסְכּוֹ֙wĕniskônecek: a libation; also a cast idolH5262
  2. רְבִיעִ֣תrĕbîʿitrbiy`iy: fourth; (fractionally) a fourthH7243
  3. הַהִ֔יןhahînhiyn: a hin or liquid measureH1969
  4. לַכֶּ֖בֶשׂlakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  5. הָֽאֶחָ֑דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  6. בַּקֹּ֗דֶשׁbaqqōdešqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  7. הַסֵּ֛ךְhassēknacak: to pour out, especially a libation, or to cast (metal)H5258
  8. נֶ֥סֶךְneseknecek: a libation; also a cast idolH5262
  9. שֵׁכָ֖רšēkārshekar: an intoxicant, i.e. intensely alcoholic liquorH7941
  10. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
8
  1. וְאֵת֙wĕʾēteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  2. הַכֶּ֣בֶשׂhakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  3. הַשֵּׁנִ֔יhaššēnîsheniy: (properly) second (the ordinal number); (adverbially) againH8145
  4. תַּֽעֲשֶׂ֖הtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  5. בֵּ֣יןbênbeyn: a distinction; (but used only as a prep) between (repeated before each noun, often with other particles)H996
  6. הָֽעַרְבָּ֑יִםhāʿarbāyim`ereb: duskH6153
  7. כְּמִנְחַ֨תkĕminḥatminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  8. הַבֹּ֤קֶרhabbōqerboqer: (properly) dawn (as the break of day); (generally) morningH1242
  9. וּכְנִסְכּוֹ֙ûkĕniskônecek: a libation; also a cast idolH5262
  10. תַּֽעֲשֶׂ֔הtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  11. אִשֵּׁ֛הʾiššēishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  12. רֵ֥יחַrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  13. נִיחֹ֖חַnîḥōaḥnichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  14. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
9
  1. וּבְיוֹם֙ûbĕyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  2. הַשַּׁבָּ֔תhaššabbātshabbath: intermission, i.e (specifically) the SabbathH7676
  3. שְׁנֵֽיšĕnêshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  4. כְבָשִׂ֥יםkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  5. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  6. שָׁנָ֖הšānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
  7. תְּמִימִ֑םtĕmîmimtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  8. וּשְׁנֵ֣יûšĕnêshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  9. עֶשְׂרֹנִ֗יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  10. סֹ֧לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  11. מִנְחָ֛הminḥâminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  12. בְּלוּלָ֥הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  13. בַשֶּׁ֖מֶןbaššemenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  14. וְנִסְכּֽוֹ׃wĕniskônecek: a libation; also a cast idolH5262
10
  1. עֹלַ֥תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  2. שַׁבַּ֖תšabbatshabbath: intermission, i.e (specifically) the SabbathH7676
  3. בְּשַׁבַּתּ֑וֹbĕšabbattôshabbath: intermission, i.e (specifically) the SabbathH7676
  4. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  5. עֹלַ֥תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  6. הַתָּמִ֖ידhattāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  7. וְנִסְכָּֽהּ׃wĕniskāhnecek: a libation; also a cast idolH5262
11
  1. וּבְרָאשֵׁי֙ûbĕrāʾšēyro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  2. חָדְשֵׁיכֶ֔םḥodšêkemchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  3. תַּקְרִ֥יבוּtaqrîbûqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  4. עֹלָ֖הʿōlâ`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  5. לַֽיהוָ֑הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  6. פָּרִ֨יםpārîmpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  7. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  8. בָקָ֤רbāqārbaqar: beef cattle or an animal of the ox family of either gender (as used for plowing)H1241
  9. שְׁנַ֙יִם֙šĕnayimshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  10. וְאַ֣יִלwĕʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  11. אֶחָ֔דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  12. כְּבָשִׂ֧יםkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  13. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  14. שָׁנָ֛הšānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
  15. שִׁבְעָ֖הšibʿâsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  16. תְּמִימִֽם׃tĕmîmimtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
12
  1. וּשְׁלֹשָׁ֣הûšĕlōšâshalowsh: three; occasionally (ordinal) third, or (multipl.) thriceH7969
  2. עֶשְׂרֹנִ֗יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  3. סֹ֤לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  4. מִנְחָה֙minḥāhminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. בְּלוּלָ֣הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  6. בַשֶּׁ֔מֶןbaššemenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  7. לַפָּ֖רlappārpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  8. הָֽאֶחָ֑דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  9. וּשְׁנֵ֣יûšĕnêshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  10. עֶשְׂרֹנִ֗יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  11. סֹ֤לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  12. מִנְחָה֙minḥāhminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  13. בְּלוּלָ֣הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  14. בַשֶּׁ֔מֶןbaššemenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  15. לָאַ֖יִלlāʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  16. הָֽאֶחָֽד׃hāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
13
  1. וְעִשָּׂרֹ֣ןwĕʿiśśārōn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  2. עִשָּׂר֗וֹןʿiśśārôn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  3. סֹ֤לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  4. מִנְחָה֙minḥāhminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. בְּלוּלָ֣הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  6. בַשֶּׁ֔מֶןbaššemenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  7. לַכֶּ֖בֶשׂlakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  8. הָֽאֶחָ֑דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  9. עֹלָה֙ʿōlāh`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  10. רֵ֣יחַrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  11. נִיחֹ֔חַnîḥōaḥnichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  12. אִשֶּׁ֖הʾiššeishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  13. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
14
  1. וְנִסְכֵּיהֶ֗םwĕniskêhemnecek: a libation; also a cast idolH5262
  2. חֲצִ֣יḥăṣîchetsiy: the half or middleH2677
  3. הַהִין֩hahînhiyn: a hin or liquid measureH1969
  4. יִֽהְיֶ֨הyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  5. לַפָּ֜רlappārpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  6. וּשְׁלִישִׁ֧תûšĕlîšitshliyshiy: third; feminine a third (part)H7992
  7. הַהִ֣יןhahînhiyn: a hin or liquid measureH1969
  8. לָאַ֗יִלlāʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  9. וּרְבִיעִ֥תûrĕbîʿitrbiy`iy: fourth; (fractionally) a fourthH7243
  10. הַהִ֛יןhahînhiyn: a hin or liquid measureH1969
  11. לַכֶּ֖בֶשׂlakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  12. יָ֑יִןyāyinyayin: wine (as fermented); (by implication) intoxicationH3196
  13. זֹ֣אתzōtzo'th: this (often used adverb)H2063
  14. עֹלַ֥תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  15. חֹ֙דֶשׁ֙ḥōdešchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  16. בְּחָדְשׁ֔וֹbĕḥodšôchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  17. לְחָדְשֵׁ֖יlĕḥodšêchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  18. הַשָּׁנָֽה׃haššānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
15
  1. וּשְׂעִ֨ירûśĕʿîrsa`iyr: shaggy; as noun, a he-goatH8163
  2. עִזִּ֥יםʿizzîm`ez: a she-goat (as strong), but masculine in plural (which also is used ellipt. for goat's hair)H5795
  3. אֶחָ֛דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  4. לְחַטָּ֖אתlĕḥaṭṭātchatta'ah: an offence (sometimes habitual sinfulness), and its penalty, occasion, sacrifice, or expiationH2403
  5. לַֽיהוָ֑הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  6. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. עֹלַ֧תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  8. הַתָּמִ֛ידhattāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  9. יֵֽעָשֶׂ֖הyēʿāśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  10. וְנִסְכּֽוֹ׃wĕniskônecek: a libation; also a cast idolH5262
16
  1. וּבַחֹ֣דֶשׁûbaḥōdešchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  2. הָֽרִאשׁ֗וֹןhāriʾšônri'shown: first, in place, time or rank (as adjective or noun)H7223
  3. בְּאַרְבָּעָ֥הbĕʾarbāʿâarba`: fourH702
  4. עָשָׂ֛רʿāśār`asar: ten; (only in combination), i.e. -teenH6240
  5. י֖וֹםyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  6. לַחֹ֑דֶשׁlaḥōdešchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  7. פֶּ֖סַחpesaḥpecach: a pretermission, i.e. exemption; used only techically of the Jewish Passover (the festival or the victim)H6453
  8. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
17
  1. וּבַֽחֲמִשָּׁ֨הûbaḥămiššâchamesh: fiveH2568
  2. עָשָׂ֥רʿāśār`asar: ten; (only in combination), i.e. -teenH6240
  3. י֛וֹםyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  4. לַחֹ֥דֶשׁlaḥōdešchodesh: the new moon; (by implication) a monthH2320
  5. הַזֶּ֖הhazzezeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  6. חָ֑גḥāgchag: a festival, or a victim thereforH2282
  7. שִׁבְעַ֣תšibʿatsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  8. יָמִ֔יםyāmîmyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  9. מַצּ֖וֹתmaṣṣôtmatstsah: (properly) sweetness; (concretely) sweet (i.e. not soured or bittered with yeast)H4682
  10. יֵֽאָכֵֽל׃yēʾākēlakal: to eat (literally or figuratively)H398
18
  1. בַּיּ֥וֹםbayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  2. הָֽרִאשׁ֖וֹןhāriʾšônri'shown: first, in place, time or rank (as adjective or noun)H7223
  3. מִקְרָאmiqrāʾmiqra': something called out, i.e. a public meeting (the act, the persons, or the place)H4744
  4. קֹ֑דֶשׁqōdešqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  5. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  6. מְלֶ֥אכֶתmĕleʾketmla'kah: (properly) deputyship, i.e. ministry; (generally) employment (never servile)H4399
  7. עֲבֹדָ֖הʿăbōdâ`abodah: work of any kindH5656
  8. לֹ֥אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  9. תַֽעֲשֽׂוּ׃taʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
19
  1. וְהִקְרַבְתֶּ֨םwĕhiqrabtemqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  2. אִשֶּׁ֤הʾiššeishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  3. עֹלָה֙ʿōlāh`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  4. לַֽיהוָ֔הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  5. פָּרִ֧יםpārîmpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  6. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  7. בָקָ֛רbāqārbaqar: beef cattle or an animal of the ox family of either gender (as used for plowing)H1241
  8. שְׁנַ֖יִםšĕnayimshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  9. וְאַ֣יִלwĕʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  10. אֶחָ֑דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  11. וְשִׁבְעָ֤הwĕšibʿâsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  12. כְבָשִׂים֙kĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  13. בְּנֵ֣יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  14. שָׁנָ֔הšānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
  15. תְּמִימִ֖םtĕmîmimtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  16. יִֽהְי֥וּyihĕyûhayah: to exist; to be or becomeH1961
20
  1. וּמִ֨נְחָתָ֔םûminḥātāmminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  2. סֹ֖לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  3. בְּלוּלָ֣הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  4. בַשָּׁ֑מֶןbaššāmenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  5. שְׁלֹשָׁ֨הšĕlōšâshalowsh: three; occasionally (ordinal) third, or (multipl.) thriceH7969
  6. עֶשְׂרֹנִ֜יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  7. לַפָּ֗רlappārpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  8. וּשְׁנֵ֧יûšĕnêshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  9. עֶשְׂרֹנִ֛יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  10. לָאַ֖יִלlāʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  11. תַּֽעֲשֽׂוּ׃taʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
21
  1. עִשָּׂר֤וֹןʿiśśārôn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  2. עִשָּׂרוֹן֙ʿiśśārôn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  3. תַּֽעֲשֶׂ֔הtaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  4. לַכֶּ֖בֶשׂlakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  5. הָֽאֶחָ֑דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  6. לְשִׁבְעַ֖תlĕšibʿatsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  7. הַכְּבָשִֽׂים׃hakkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
22
  1. וּשְׂעִ֥ירûśĕʿîrsa`iyr: shaggy; as noun, a he-goatH8163
  2. חַטָּ֖אתḥaṭṭātchatta'ah: an offence (sometimes habitual sinfulness), and its penalty, occasion, sacrifice, or expiationH2403
  3. אֶחָ֑דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  4. לְכַפֵּ֖רlĕkappērkaphar: to cover (specifically with bitumen); (figuratively) to expiate or condone, to placate or cancelH3722
  5. עֲלֵיכֶֽם׃ʿălêkem`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
23
  1. מִלְּבַד֙millĕbadbad: (properly) separation; (by implication) a part of the body, branch of a tree, bar for carryingH905
  2. עֹלַ֣תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  3. הַבֹּ֔קֶרhabbōqerboqer: (properly) dawn (as the break of day); (generally) morningH1242
  4. אֲשֶׁ֖רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. לְעֹלַ֣תlĕʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  6. הַתָּמִ֑ידhattāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  7. תַּֽעֲשׂ֖וּtaʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  8. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  9. אֵֽלֶּה׃ʾēlleel-leh: these or thoseH428
24
  1. כָּאֵ֜לֶּהkāʾēlleel-leh: these or thoseH428
  2. תַּֽעֲשׂ֤וּtaʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  3. לַיּוֹם֙layyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  4. שִׁבְעַ֣תšibʿatsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  5. יָמִ֔יםyāmîmyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  6. לֶ֛חֶםleḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  7. אִשֵּׁ֥הʾiššēishshah: (properly) a burnt-offering; but occasionally of any sacrificeH801
  8. רֵֽיחַrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  9. נִיחֹ֖חַnîḥōaḥnichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  10. לַֽיהוָ֑הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  11. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  12. עוֹלַ֧תʿôlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  13. הַתָּמִ֛ידhattāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  14. יֵֽעָשֶׂ֖הyēʿāśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  15. וְנִסְכּֽוֹ׃wĕniskônecek: a libation; also a cast idolH5262
25
  1. וּבַיּוֹם֙ûbayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  2. הַשְּׁבִיעִ֔יhaššĕbîʿîshbiy`iy: seventhH7637
  3. מִקְרָאmiqrāʾmiqra': something called out, i.e. a public meeting (the act, the persons, or the place)H4744
  4. קֹ֖דֶשׁqōdešqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  5. יִֽהְיֶ֣הyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  6. לָכֶ֑םlākem
  7. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  8. מְלֶ֥אכֶתmĕleʾketmla'kah: (properly) deputyship, i.e. ministry; (generally) employment (never servile)H4399
  9. עֲבֹדָ֖הʿăbōdâ`abodah: work of any kindH5656
  10. לֹ֥אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  11. תַֽעֲשֽׂוּ׃taʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
26
  1. וּבְי֣וֹםûbĕyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  2. הַבִּכּוּרִ֗יםhabbikkûrîmbikkuwr: the first-fruits of the cropH1061
  3. בְּהַקְרִ֨יבְכֶ֜םbĕhaqrîbĕkemqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  4. מִנְחָ֤הminḥâminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. חֲדָשָׁה֙ḥădāšāhchadash: newH2319
  6. לַֽיהוָ֔הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  7. בְּשָׁבֻעֹ֖תֵיכֶ֑םbĕšābuʿōtêkemshabuwa`: literal, sevened, i.e. a week (specifically, of years)H7620
  8. מִֽקְרָאmiqĕrāʾmiqra': something called out, i.e. a public meeting (the act, the persons, or the place)H4744
  9. קֹ֙דֶשׁ֙qōdešqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  10. יִֽהְיֶ֣הyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  11. לָכֶ֔םlākem
  12. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  13. מְלֶ֥אכֶתmĕleʾketmla'kah: (properly) deputyship, i.e. ministry; (generally) employment (never servile)H4399
  14. עֲבֹדָ֖הʿăbōdâ`abodah: work of any kindH5656
  15. לֹ֥אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  16. תַֽעֲשֽׂוּ׃taʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
27
  1. וְהִקְרַבְתֶּ֨םwĕhiqrabtemqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  2. עוֹלָ֜הʿôlâ`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  3. לְרֵ֤יחַlĕrêaḥreyach: odor (as if blown)H7381
  4. נִיחֹ֙חַ֙nîḥōḥanichowach: (properly) restful, i.e. pleasant; abstractly, delightH5207
  5. לַֽיהוָ֔הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  6. פָּרִ֧יםpārîmpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  7. בְּנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  8. בָקָ֛רbāqārbaqar: beef cattle or an animal of the ox family of either gender (as used for plowing)H1241
  9. שְׁנַ֖יִםšĕnayimshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  10. אַ֣יִלʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  11. אֶחָ֑דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  12. שִׁבְעָ֥הšibʿâsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  13. כְבָשִׂ֖יםkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  14. בְּנֵ֥יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  15. שָׁנָֽה׃šānâshaneh: a year (as a revolution of time)H8141
28
  1. וּמִנְחָתָ֔םûminḥātāmminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  2. סֹ֖לֶתsōletcoleth: flour (as chipped off)H5560
  3. בְּלוּלָ֣הbĕlûlâbalal: to overflow (specifically with oil.); (by implication) to mixH1101
  4. בַשָּׁ֑מֶןbaššāmenshemen: grease, especially liquid (as from the olive, often perfumed)H8081
  5. שְׁלֹשָׁ֤הšĕlōšâshalowsh: three; occasionally (ordinal) third, or (multipl.) thriceH7969
  6. עֶשְׂרֹנִים֙ʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  7. לַפָּ֣רlappārpar: a bullock (apparently as breaking forth in wild strength, or perhaps as dividing the hoof)H6499
  8. הָֽאֶחָ֔דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  9. שְׁנֵי֙šĕnēyshnayim: two; (as ordinal) twofoldH8147
  10. עֶשְׂרֹנִ֔יםʿeśrōnîm`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  11. לָאַ֖יִלlāʾayilayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  12. הָֽאֶחָֽד׃hāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
29
  1. עִשָּׂרוֹן֙ʿiśśārôn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  2. עִשָּׂר֔וֹןʿiśśārôn`issarown: (fractional) a tenth partH6241
  3. לַכֶּ֖בֶשׂlakkebeśkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
  4. הָֽאֶחָ֑דhāʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  5. לְשִׁבְעַ֖תlĕšibʿatsheba`: a primitive cardinal number; seven (as the sacred full one)H7651
  6. הַכְּבָשִֽׂים׃hakkĕbāśîmkebes: a ram (just old enough to butt)H3532
30
  1. שְׂעִ֥ירśĕʿîrsa`iyr: shaggy; as noun, a he-goatH8163
  2. עִזִּ֖יםʿizzîm`ez: a she-goat (as strong), but masculine in plural (which also is used ellipt. for goat's hair)H5795
  3. אֶחָ֑דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  4. לְכַפֵּ֖רlĕkappērkaphar: to cover (specifically with bitumen); (figuratively) to expiate or condone, to placate or cancelH3722
  5. עֲלֵיכֶֽם׃ʿălêkem`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
31
  1. מִלְּבַ֞דmillĕbadbad: (properly) separation; (by implication) a part of the body, branch of a tree, bar for carryingH905
  2. עֹלַ֧תʿōlat`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  3. הַתָּמִ֛ידhattāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  4. וּמִנְחָת֖וֹûminḥātôminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  5. תַּֽעֲשׂ֑וּtaʿăśû`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  6. תְּמִימִ֥םtĕmîmimtamiym: (literally, figuratively or morally) entireH8549
  7. יִֽהְיוּyihĕyûhayah: to exist; to be or becomeH1961
  8. לָכֶ֖םlākem
  9. וְנִסְכֵּיהֶֽם׃wĕniskêhemnecek: a libation; also a cast idolH5262

View the full Hebrew interlinear for Numbers 28 →

Strong's words in Numbers 28 (6)
Strong's H259 — אֶחָ֖ד (ʾeḥād)
echad (ekh-awd') adj. 1. (properly) united, i.e. one 2. (as an ordinal) first [a numeral from H258] KJV: a, alike, alone, altogether, and, any(-thing), apiece, a certain, (dai-)ly, each (one), + eleven, every, few, first, + highway, a man, once, one, only, other, some, together, Root(s): H258. Appears 15 times in Numbers 28.
Strong's H3532 — כְּבָשִׂ֨ים (kĕbāśîm)
kebes (keh-bes') n-m. 1. a ram (just old enough to butt) [from an unused root meaning to dominate] KJV: lamb, sheep.. Appears 15 times in Numbers 28.
Strong's H6213 — תַּֽעֲשֶׂ֣ה (taʿăśe)
`asah (aw-saw') v. 1. to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows) [a primitive root] KJV: accomplish, advance, appoint, apt, be at, become, bear, bestow, bring forth, bruise, be busy, X certainly, have the charge of, commit, deal (with), deck, + displease, do, (ready) dress(-ed), (put in) execute(-ion), exercise, fashion, + feast, (fight-)ing man, + finish, fit, fly, follow, fulfill, furnish, gather, get, go about, govern, grant, great, + hinder, hold ((a feast)), X indeed, + be industrious, + journey, keep, labour, maintain, make, be meet, observe, be occupied, offer, + officer, pare, bring (come) to pass, perform, pracise, prepare, procure, provide, put, requite, X sacrifice, serve, set, shew, X sin, spend, X surely, take, X thoroughly, trim, X very, + vex, be (warr-)ior, work(-man), yield, use.. Appears 15 times in Numbers 28.
Strong's H5930 — עֹלָ֥ה (ʿōlâ)
`olah (o-law') (or mowlah {o-law'}) n-f. 1. a step or (collectively, stairs, as ascending) 2. usually a holocaust (as going up in smoke) [feminine active participle of H5927] KJV: ascent, burnt offering (sacrifice), go up to. See also H5766. Root(s): H5927 See also: H5766. Appears 14 times in Numbers 28.
Strong's H3068 — יְהוָ֖ה (yĕhwâ)
Yhovah (yeh-ho-vaw') n/p. 1. (the) self-Existent or Eternal 2. Jehovah, Jewish national name of God [from H1961] KJV: Jehovah, the Lord. Root(s): H1961 Compare: H3050, H3069. Appears 13 times in Numbers 28.
Strong's H6241 — עֶשְׂרֹנִ֗ים (ʿeśrōnîm)
`issarown (is-saw-rone') (or oissaron {is-saw-rone'}) n-m. 1. (fractional) a tenth part [from H6235] KJV: tenth deal. Root(s): H6235. Appears 13 times in Numbers 28.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress