Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Isaiah 60 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 “Dìde, tànmọ́lẹ̀, nítorí ìmọ́lẹ̀ rẹ ti dé, ògo Olúwa sì ràdàbò ọ́.
2 Kíyèsi i, òkùnkùn bo ilẹ̀ ayé òkùnkùn biribiri sì wà lórí àwọn ènìyàn, ṣùgbọ́n Olúwa ràn bò ọ́ ògo rẹ̀ sì farahàn lórí i rẹ.
3 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá sí ìmọ́lẹ̀ rẹ, àti àwọn ọba sí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ rẹ.
4 “Gbé ojú rẹ sókè, kí o sì wò. Gbogbo wọn ṣa ara jọ pọ̀, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ rẹ; àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin yóò wá láti ọ̀nà jíjìn, àwọn ọmọ rẹ obìnrin ni a ó tọ́jú ní ẹ̀gbẹ́ rẹ.
5 Nígbà náà ni ìwọ yóò wò tí ojú rẹ yóò máa dán, ọkàn rẹ yó fò, yó sì kún fún ayọ̀; ọrọ̀ inú Òkun ni a ó kò wá sọ́dọ̀ rẹ, sí ọ̀dọ̀ rẹ ni ọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè yóò wá.
6 Ọ̀wọ́ ìbákasẹ yóò bo gbogbo ilẹ̀ rẹ, àwọn ọ̀dọ́ ìbákasẹ Midiani àti Efani. Àti gbogbo wọn láti Ṣeba yóò wá, wọn yóò mú wúrà àti tùràrí lọ́wọ́ tí wọn yóò sì máa kéde ìyìn Olúwa.
7 Gbogbo agbo ẹran ìlú Kedari ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ, àwọn àgbò ti Nebaioti yóò sìn ọ́; wọn yóò jẹ́ ọrẹ ìtẹ́wọ́gbà lórí i pẹpẹ mi, bẹ́ẹ̀ ni n ó sì ṣe tẹmpili ògo mi lọ́ṣọ̀ọ́.
8 “Ta ni àwọn wọ̀nyí tí ń fò lọ bí i kurukuru, gẹ́gẹ́ bí àwọn àdàbà sí ìtẹ́ wọn?
9 Lóòtítọ́ àwọn erékùṣù bojú wò mí; ní ìṣíwájú ni àwọn ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi; mú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ wá láti ọ̀nà jíjìn, pẹ̀lú fàdákà àti wúrà wọn, fún ti ọlá Olúwa Ọlọ́run rẹ, Ẹni Mímọ́ Israẹli, nítorí òun ti fi ohun dídára ṣe ó lọ́ṣọ̀ọ́.
10 “Àwọn àjèjì yóò tún ògiri rẹ mọ àwọn ọba wọn yóò sì sìn ọ́. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ní ìbínú ni mo lù ọ́, ní àánú èmi yóò ṣe inú rere sí ọ.
11 Gbogbo ẹnu-bodè rẹ ni yóò wà ní ṣíṣí sílẹ̀, a kì yóò tì wọ́n ní ọ̀sán àti ní òru, tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn ọkùnrin yóò le è kó ọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè wá tí àwọn ọba wọn yóò ṣáájú ní ọ̀wọ̀ọ̀wọ́ ìṣẹ́gun.
12 Nítorí pé orílẹ̀-èdè tàbí ilẹ̀ ọba tí kì yóò sìn ọ́ ni yóò parun; pátápátá ni yóò sì dahoro.
13 “Ògo Lebanoni yóò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, igi junifa, firi àti sípírẹ́ṣì papọ̀, láti bu ọlá fún ilé ìsìn mi; àti pé èmi yóò sì ṣe ibi ẹsẹ̀ mi lógo.
14 Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àwọn apọ́nilójú rẹ yóò wá foríbalẹ̀ fún ọ; gbogbo àwọn tí ó ti kẹ́gàn rẹ ni wọn yóò tẹríba níwájú rẹ wọn yóò sì pè ọ́ ní ìlú Olúwa, Sioni ti Ẹni Mímọ́ Israẹli.
15 “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a ti kórìíra rẹ, a sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀, láìsí ẹnìkan tí ó ń gba ọ̀dọ̀ rẹ kọjá, Èmi yóò ṣe ọ́ ní ìṣògo ayérayé àti ayọ̀ àtìrandíran.
16 Ìwọ yóò mu wàrà gbogbo orílẹ̀-èdè a ó sì fun ọ́ ni ọmú àwọn ọba. Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé, Èmi Olúwa, èmi ni Olùgbàlà rẹ, Olùdáǹdè rẹ, Alágbára ti Jakọbu.
17 Dípò idẹ, èmi ó mú wúrà wá fún ọ, dípò fàdákà èmi ó mú irin wá. Dípò igi yóò mú idẹ wá fún ọ, àti irin dípò òkúta. Èmi yóò fi àlàáfíà ṣe àwọn ìjòyè rẹ àti òdodo gẹ́gẹ́ bí alákòóso rẹ.
18 A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́, tàbí ìdahoro àti ìparun nínú agbègbè rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ yóò pe ògiri rẹ ní ìgbàlà àti àwọn ẹnu-bodè rẹ ní ìyìn.
19 Òòrùn kì yóò sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ní ọ̀sán mọ́, tàbí kí ìtànṣán òṣùpá tún ràn sí ọ mọ́, nítorí Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ayérayé, àti Ọlọ́run rẹ yóò jẹ́ ògo rẹ.
20 Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́, àti òṣùpá rẹ kì yóò sì wọ òòkùn mọ́; Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé rẹ, àti àwọn ọjọ́ arò rẹ yóò sì dópin.
21 Lẹ́yìn náà ni gbogbo àwọn ènìyàn rẹ yóò di òdodo àwọn ni yóò sì jogún ilẹ̀ náà títí ayé. Àwọn ni irúgbìn tí mo ti gbìn, iṣẹ́ ọwọ́ mi, láti fi ọláńlá mi hàn.
22 Èyí tí ó kéré jù nínú yín yóò di ẹgbẹ̀rún (1,000) kan, èyí tí ó kéré yóò di orílẹ̀-èdè ńlá. Èmi ni Olúwa; ní àkókò rẹ̀, Èmi yóò ṣe èyí kánkán.”
Chapter information and study resources

Listen to Isaiah 60 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Isaiah 60

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Isaiah 60. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Isaiah 60 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 4 cross-references, 3 Early-Church citations.

Cross-references in Isaiah 60 (4)

See the full cross-reference index →

Hebrew interlinear — Isaiah 60:1–22 (294 words)
1
  1. ק֥וּמִיqûmîquwm: to rise (in various applications, literal, figurative, intensive and causative)H6965
  2. א֖וֹרִיʾôrîowr: to be (causative, make) luminous (literally and metaphorically)H215
  3. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  4. בָ֣אbāʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  5. אוֹרֵ֑ךְʾôrēkowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  6. וּכְב֥וֹדûkĕbôdkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  7. יְהוָ֖הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  8. עָלַ֥יִךְʿālayik`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  9. זָרָֽח׃zārāḥzarach: (properly) to irradiate (or shoot forth beams), i.e. to rise (as the sun)H2224
2
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. הִנֵּ֤הhinnēhinneh: lo!H2009
  3. הַחֹ֙שֶׁךְ֙haḥōšekchoshek: the dark; hence (literally) darknessH2822
  4. יְכַסֶּהyĕkassekacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  5. אֶ֔רֶץʾereṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  6. וַעֲרָפֶ֖לwaʿărāpel`araphel: gloom (as of a lowering sky)H6205
  7. לְאֻמִּ֑יםlĕʾummîmlom: a communityH3816
  8. וְעָלַ֙יִךְ֙wĕʿālayik`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  9. יִזְרַ֣חyizraḥzarach: (properly) to irradiate (or shoot forth beams), i.e. to rise (as the sun)H2224
  10. יְהוָ֔הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  11. וּכְבוֹד֖וֹûkĕbôdôkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  12. עָלַ֥יִךְʿālayik`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  13. יֵרָאֶֽה׃yērāʾera'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
3
  1. וְהָלְכ֥וּwĕholkûhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  2. גוֹיִ֖םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  3. לְאוֹרֵ֑ךְlĕʾôrēkowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  4. וּמְלָכִ֖יםûmĕlākîmmelek: a kingH4428
  5. לְנֹ֥גַהּlĕnōgahnogahh: brilliancy (literally or figuratively)H5051
  6. זַרְחֵֽךְ׃zarḥēkzerach: a rising of lightH2225
4
  1. שְׂאִֽיśĕʾînasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  2. סָבִ֤יבsābîbcabiyb: (as noun) a circle, neighbour, or environsH5439
  3. עֵינַ֙יִךְ֙ʿênayik`ayin: an eye (literally or figuratively); by analogy, a fountain (as the eye of the landscape)H5869
  4. וּרְאִ֔יûrĕʾîra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  5. כֻּלָּ֖םkullāmkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  6. נִקְבְּצ֣וּniqbĕṣûqabats: to grasp, i.e. collectH6908
  7. בָֽאוּbāʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  8. לָ֑ךְlāk
  9. בָּנַ֙יִךְ֙bānayikben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  10. מֵרָח֣וֹקmērāḥôqrachowq: remote, literally or figuratively, of place or timeH7350
  11. יָבֹ֔אוּyābōʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  12. וּבְנֹתַ֖יִךְûbĕnōtayikbath: a daughter (used in the same wide sense as other terms of relationship, literally and figuratively)H1323
  13. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  14. צַ֥דṣadtsad: a side; (figuratively) an adversaryH6654
  15. תֵּאָמַֽנָה׃tēʾāmanâaman: (properly) to build up or support; to foster as a parent or nurseH539
5
  1. אָ֤זʾāzaz: at that time or place; (as a conjunction) thereforeH227
  2. תִּרְאִי֙tirʾiyra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  3. וְנָהַ֔רְתְּwĕnāharĕtnahar: to sparkle, i.e. (figuratively) be cheerfulH5102
  4. וּפָחַ֥דûpāḥadpachad: to be startled (by a sudden alarm); (hence) to fear in generalH6342
  5. וְרָחַ֖בwĕrāḥabrachab: to broaden (intransitive or transitive, literal or figurative)H7337
  6. לְבָבֵ֑ךְlĕbābēklebab: the heart (as the most interior organ); used also like H3820H3824
  7. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  8. יֵהָפֵ֤ךְyēhāpēkhaphak: to turn about or over; (by implication) to change, overturn, return, pervertH2015
  9. עָלַ֙יִךְ֙ʿālayik`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  10. הֲמ֣וֹןhămônhamown: a noise, tumult, crowd; also disquietude, wealthH1995
  11. יָ֔םyāmyam: a sea (as breaking in noisy surf) or large body of waterH3220
  12. חֵ֥ילḥêlchayil: probably a force, whether of men, means or other resourcesH2428
  13. גּוֹיִ֖םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  14. יָבֹ֥אוּyābōʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
6
  1. שִֽׁפְעַ֨תšipĕʿatshiph`ah: copiousnessH8229
  2. גְּמַלִּ֜יםgĕmallîmgamal: a camelH1581
  3. תְּכַסֵּ֗ךְtĕkassēkkacah: (properly) to plump, i.e. fill up hollowsH3680
  4. בִּכְרֵ֤יbikrêbeker: a young camelH1070
  5. מִדְיָן֙midyānMidyan: Midjan, a son of Abraham; also his country and (collectively) his descendantsH4080
  6. וְעֵיפָ֔הwĕʿêpâ`Eyphah: Ephah, the name of a son of Midian, and of the region settled by himH5891
  7. כֻּלָּ֖םkullāmkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  8. מִשְּׁבָ֣אmiššĕbāʾShba': Sheba, the name of three early progenitors of tribes and of an Ethiopian districtH7614
  9. יָבֹ֑אוּyābōʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  10. זָהָ֤בzāhābzahab: gold; (figuratively) golden, something gold-colored (i.e. yellow) such as oil or a clear, sunny skyH2091
  11. וּלְבוֹנָה֙ûlĕbônāhlbownah: frankincense (from its whiteness or perhaps that of its smoke)H3828
  12. יִשָּׂ֔אוּyiśśāʾûnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  13. וּתְהִלֹּ֥תûtĕhillōtthillah: laudation; (specifically, concretely) a hymnH8416
  14. יְהוָ֖הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  15. יְבַשֵּֽׂרוּ׃yĕbaśśērûbasar: (properly) to be fresh; to be full (rosy)H1319
7
  1. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. צֹ֤אןṣōntso'n: a collective name for a flock (of sheep or goats)H6629
  3. קֵדָר֙qēdārQedar: dusky (of the skin or the tent); Kedar, a son of IshmaelH6938
  4. יִקָּ֣בְצוּyiqqābĕṣûqabats: to grasp, i.e. collectH6908
  5. לָ֔ךְlāk
  6. אֵילֵ֥יʾêlêayil: (properly) strength; (hence) anything strongH352
  7. נְבָי֖וֹתnĕbāyôtNbayowth: fruitfulnesses; Nebajoth, a son of Ismael, and the country settled by himH5032
  8. יְשָׁרְת֑וּנֶךְyĕšortûneksharath: to attend as a menial or worshipper; (figuratively) to contribute toH8334
  9. יַעֲל֤וּyaʿălû`alah: to ascend, intransitively (be high) or actively (mount)H5927
  10. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  11. רָצוֹן֙rāṣônratsown: delight (especially as shown)H7522
  12. מִזְבְּחִ֔יmizbĕḥîmizbeach: an altarH4196
  13. וּבֵ֥יתûbêtbayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
  14. תִּפְאַרְתִּ֖יtipʾartîtiph'arah: ornamentH8597
  15. אֲפָאֵֽר׃ʾăpāʾērpa'ar: to gleam, i.e. (causatively) embellish; (figuratively) to boastH6286
8
  1. מִיmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  2. אֵ֖לֶּהʾēlleel-leh: these or thoseH428
  3. כָּעָ֣בkāʿāb`ab: (properly) an envelope, i.e. darkness (or density, 2 Chron. 4H5645
  4. תְּעוּפֶ֑ינָהtĕʿûpênâעוףH5774
  5. וְכַיּוֹנִ֖יםwĕkayyônîmyownah: a dove (apparently from the warmth of their mating)H3123
  6. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  7. אֲרֻבֹּתֵיהֶֽם׃ʾărubbōtêhemarubbah: a latticeH699
9
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. לִ֣י׀lî
  3. אִיִּ֣יםʾiyyîmiy: (properly) a habitable spot (as desirable)H339
  4. יְקַוּ֗וּyĕqawwûqavah: to bind together (perhaps by twisting), i.e. collectH6960
  5. וָאֳנִיּ֤וֹתwāʾŏniyyôtoniyah: a shipH591
  6. תַּרְשִׁישׁ֙taršîšTarshiysh: Tarshish, a place on the Mediterranean; (hence) the ephithet of a merchant vessel (as if for or from that...H8659
  7. בָּרִ֣אשֹׁנָ֔הbāriʾšōnâri'shown: first, in place, time or rank (as adjective or noun)H7223
  8. לְהָבִ֤יאlĕhābîʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  9. בָנַ֙יִךְ֙bānayikben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  10. מֵֽרָח֔וֹקmērāḥôqrachowq: remote, literally or figuratively, of place or timeH7350
  11. כַּסְפָּ֥םkaspāmkeceph: silver (from its pale color); (by implication) moneyH3701
  12. וּזְהָבָ֖םûzĕhābāmzahab: gold; (figuratively) golden, something gold-colored (i.e. yellow) such as oil or a clear, sunny skyH2091
  13. אִתָּ֑םʾittāmeth: (properly) nearness; (used only as a preposition or an adverb) nearH854
  14. לְשֵׁם֙lĕšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  15. יְהוָ֣הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  16. אֱלֹהַ֔יִךְʾĕlōhayikelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  17. וְלִקְד֥וֹשׁwĕliqdôšqadowsh: sacred (ceremonially or morally); (as noun) GodH6918
  18. יִשְׂרָאֵ֖לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  19. כִּ֥יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  20. פֵאֲרָֽךְ׃pēʾărākpa'ar: to gleam, i.e. (causatively) embellish; (figuratively) to boastH6286
10
  1. וּבָנ֤וּûbānûbanah: to build (literally and figuratively)H1129
  2. בְנֵֽיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  3. נֵכָר֙nēkārnekar: foreign, or (concretely) a foreigner, or (abstractly) heathendomH5236
  4. חֹמֹתַ֔יִךְḥōmōtayikchowmah: a wall of protectionH2346
  5. וּמַלְכֵיהֶ֖םûmalkêhemmelek: a kingH4428
  6. יְשָׁרְת֑וּנֶךְyĕšortûneksharath: to attend as a menial or worshipper; (figuratively) to contribute toH8334
  7. כִּ֤יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  8. בְקִצְפִּי֙bĕqiṣpiyqetseph: a splinter (as chipped off); (figuratively) rage or strifeH7110
  9. הִכִּיתִ֔יךְhikkîtîknakah: to strike (lightly or severely, literally or figuratively)H5221
  10. וּבִרְצוֹנִ֖יûbirṣônîratsown: delight (especially as shown)H7522
  11. רִֽחַמְתִּֽיךְ׃riḥamtîkracham: to fondle; (by implication) to loveH7355
11
  1. וּפִתְּח֨וּûpittĕḥûpathach: to open wide (literally or figuratively)H6605
  2. שְׁעָרַ֧יִךְšĕʿārayiksha`ar: an opening, i.e. door or gateH8179
  3. תָּמִ֛ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  4. יוֹמָ֥םyômāmyowmam: dailyH3119
  5. וָלַ֖יְלָהwālaylâlayil: (properly) a twist (away of the light), i.e. nightH3915
  6. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. יִסָּגֵ֑רוּyissāgērûcagar: to shut up; (figuratively) to surrenderH5462
  8. לְהָבִ֤יאlĕhābîʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  9. אֵלַ֙יִךְ֙ʾēlayikel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  10. חֵ֣ילḥêlchayil: probably a force, whether of men, means or other resourcesH2428
  11. גּוֹיִ֔םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  12. וּמַלְכֵיהֶ֖םûmalkêhemmelek: a kingH4428
  13. נְהוּגִֽים׃nĕhûgîmnahag: to drive forth (a person, an animal or chariot), i.e. to lead, carry awayH5090
12
  1. כִּֽיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. הַגּ֧וֹיhaggôygowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  3. וְהַמַּמְלָכָ֛הwĕhammamlākâmamlakah: dominion; (abstractly) the estate (rule)H4467
  4. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  6. יַעַבְד֖וּךְyaʿabdûk`abad: to work (in any sense); (by implication) to serve, tillH5647
  7. יֹאבֵ֑דוּyōʾbēdûabad: (properly) to wander away, i.e. lose oneselfH6
  8. וְהַגּוֹיִ֖םwĕhaggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  9. חָרֹ֥בḥārōbcharab: to parch (through drought) i.e. (by analogy,) to desolate, destroy, killH2717
  10. יֶחֱרָֽבוּ׃yeḥĕrābûcharab: to parch (through drought) i.e. (by analogy,) to desolate, destroy, killH2717
13
  1. כְּב֤וֹדkĕbôdkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  2. הַלְּבָנוֹן֙hallĕbānônLbanown: (the) white mountain (from its snow); Lebanon, a mountain range in IsraelH3844
  3. אֵלַ֣יִךְʾēlayikel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. יָב֔וֹאyābôʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  5. בְּר֛וֹשׁbĕrôšbrowsh: a cypress (?) tree; (hence) a lance or a musical instrument (as made of that wood)H1265
  6. תִּדְהָ֥רtidhārtidhar: enduring; a species of hard-wood or lasting tree (perhaps oak)H8410
  7. וּתְאַשּׁ֖וּרûtĕʾaššûrt'ashshuwr: a species of cedar (from its erectness)H8391
  8. יַחְדָּ֑וyaḥdāwyachad: (properly) a unit, i.e. (adverb) unitedlyH3162
  9. לְפָאֵר֙lĕpāʾērpa'ar: to gleam, i.e. (causatively) embellish; (figuratively) to boastH6286
  10. מְק֣וֹםmĕqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  11. מִקְדָּשִׁ֔יmiqdāšîmiqdash: a consecrated thing or place, especially, a palace, sanctuary (whether of Jehovah or of idols) or asylumH4720
  12. וּמְק֥וֹםûmĕqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  13. רַגְלַ֖יraglayregel: a foot (as used in walking); (by implication) a stepH7272
  14. אֲכַבֵּֽד׃ʾăkabbēdkabad: to be heavy, i.e. in a bad sense (burdensome, severe, dull) or in a good sense (numerous, rich, honorableH3513
14
  1. וְהָלְכ֨וּwĕholkûhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  2. אֵלַ֤יִךְʾēlayikel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  3. שְׁח֙וֹחַ֙šĕḥôḥashachach: to sink or depress (reflexive or causative)H7817
  4. בְּנֵ֣יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  5. מְעַנַּ֔יִךְmĕʿannayik`anah: to depress literally or figuratively, transitive or intransitive (in various applications, as follows)H6031
  6. וְהִֽשְׁתַּחֲו֛וּwĕhišĕttaḥăwûshachah: to depress, i.e. prostrate (especially reflexive, in homage to royalty or God)H7812
  7. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  8. כַּפּ֥וֹתkappôtkaph: the hollow hand or palm (so of the paw of an animal, of the sole, and even of the bowl of a dish or sling, the...H3709
  9. רַגְלַ֖יִךְraglayikregel: a foot (as used in walking); (by implication) a stepH7272
  10. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  11. מְנַֽאֲצָ֑יִךְmĕnaʾăṣāyikna'ats: to scorn; or (Ecclesiastes 12H5006
  12. וְקָ֤רְאוּwĕqārĕʾûqara': to call out to (i.e. properly, address by name, but used in a wide variety of applications)H7121
  13. לָךְ֙lok
  14. עִ֣ירʿîr`iyr: a city (a place guarded by waking or a watch) in the widest sense (even of a mere encampment or post)H5892
  15. יְהוָ֔הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  16. צִיּ֖וֹןṣiyyônTsiyown: Tsijon (as a permanent capital), a mountain of JerusalemH6726
  17. קְד֥וֹשׁqĕdôšqadowsh: sacred (ceremonially or morally); (as noun) GodH6918
  18. יִשְׂרָאֵֽל׃yiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
15
  1. תַּ֧חַתtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  2. הֱיוֹתֵ֛ךְhĕyôtēkhayah: to exist; to be or becomeH1961
  3. עֲזוּבָ֥הʿăzûbâ`azab: to loosen, i.e. relinquish, permit, etcH5800
  4. וּשְׂנוּאָ֖הûśĕnûʾâsane': to hate (personally)H8130
  5. וְאֵ֣יןwĕʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  6. עוֹבֵ֑רʿôbēr`abar: to cross overH5674
  7. וְשַׂמְתִּיךְ֙wĕśamtîksuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  8. לִגְא֣וֹןligʾônga'own: the same as H1346H1347
  9. עוֹלָ֔םʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  10. מְשׂ֖וֹשׂmĕśôśmasows: delight; (concretely) the cause or object of delightH4885
  11. דּ֥וֹרdôrdowr: (properly) a revolution of time, i.e. an age or generationH1755
  12. וָדֽוֹר׃wādôrdowr: (properly) a revolution of time, i.e. an age or generationH1755
16
  1. וְיָנַקְתְּ֙wĕyānaqĕtyanaq: to suck; causatively, to give milkH3243
  2. חֲלֵ֣בḥălēbchalab: milk (as the richness of kine)H2461
  3. גּוֹיִ֔םgôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  4. וְשֹׁ֥דwĕšōdshad: the breast of a woman or animal (as bulging)H7699
  5. מְלָכִ֖יםmĕlākîmmelek: a kingH4428
  6. תִּינָ֑קִיtînāqîyanaq: to suck; causatively, to give milkH3243
  7. וְיָדַ֗עַתְּwĕyādaʿatyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  8. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  9. אֲנִ֤יʾănîaniy: IH589
  10. יְהוָה֙yĕhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  11. מֽוֹשִׁיעֵ֔ךְmôšîʿēkyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  12. וְגֹאֲלֵ֖ךְwĕgōʾălēkga'al: to redeem (according to the Oriental law of kinship)H1350
  13. אֲבִ֥ירʾăbîrabiyr: mighty (spoken of God)H46
  14. יַעֲקֹֽב׃yaʿăqōbYa`aqob: heel-catcher (i.e. supplanter); Jaakob, the Israelitish patriarchH3290
17
  1. תַּ֣חַתtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  2. הַנְּחֹ֜שֶׁתhannĕḥōšetnchosheth: copper; (hence) something made of copper, i.e. a coin, a shackleH5178
  3. אָבִ֣יאʾābîʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  4. זָהָ֗בzāhābzahab: gold; (figuratively) golden, something gold-colored (i.e. yellow) such as oil or a clear, sunny skyH2091
  5. וְתַ֤חַתwĕtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  6. הַבַּרְזֶל֙habbarzelbarzel: iron (as cutting); by extension, an iron implementH1270
  7. אָ֣בִיאʾābîʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  8. כֶ֔סֶףkesepkeceph: silver (from its pale color); (by implication) moneyH3701
  9. וְתַ֤חַתwĕtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  10. הָֽעֵצִים֙hāʿēṣîm`ets: a tree (from its firmness); (hence) wood (plural sticks)H6086
  11. נְחֹ֔שֶׁתnĕḥōšetnchosheth: copper; (hence) something made of copper, i.e. a coin, a shackleH5178
  12. וְתַ֥חַתwĕtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  13. הָאֲבָנִ֖יםhāʾăbānîmeben: a stoneH68
  14. בַּרְזֶ֑לbarzelbarzel: iron (as cutting); by extension, an iron implementH1270
  15. וְשַׂמְתִּ֤יwĕśamtîsuwm: to put (used in a great variety of applications, literal, figurative, inferentially, and elliptically)H7760
  16. פְקֻדָּתֵךְ֙pĕquddātēkpquddah: visitation (in many senses, chiefly official)H6486
  17. שָׁל֔וֹםšālômshalowm: safe; (figuratively) well, happy, friendlyH7965
  18. וְנֹגְשַׂ֖יִךְwĕnōgĕśayiknagas: to drive (an animal, a workman, a debtor, an army)H5065
  19. צְדָקָֽה׃ṣĕdāqâtsdaqah: rightness (abstractly), subjectively (rectitude), objectively (justice), morally (virtue) or figuratively...H6666
18
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יִשָּׁמַ֨עyiššāmaʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  3. ע֤וֹדʿôd`owd: (properly) iteration or continuance; used only adverbially (with or without preposition), again, repeatedly...H5750
  4. חָמָס֙ḥāmāschamac: violence; (by implication) wrongH2555
  5. בְּאַרְצֵ֔ךְbĕʾarṣēkerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  6. שֹׁ֥דšōdshod: violence, ravageH7701
  7. וָשֶׁ֖בֶרwāšebersheber: a fracture, figuratively, ruin; specifically, a solution (of a dream)H7667
  8. בִּגְבוּלָ֑יִךְbigbûlāyikgbuwl: (properly) a cord (as twisted); (by implication) a boundaryH1366
  9. וְקָרָ֤אתwĕqārātqara': to call out to (i.e. properly, address by name, but used in a wide variety of applications)H7121
  10. יְשׁוּעָה֙yĕšûʿāhyshuw`ah: something saved, i.e. (abstractly) deliveranceH3444
  11. חוֹמֹתַ֔יִךְḥômōtayikchowmah: a wall of protectionH2346
  12. וּשְׁעָרַ֖יִךְûšĕʿārayiksha`ar: an opening, i.e. door or gateH8179
  13. תְּהִלָּֽה׃tĕhillâthillah: laudation; (specifically, concretely) a hymnH8416
19
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יִֽהְיֶהyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  3. לָּ֨ךְlāk
  4. ע֤וֹדʿôd`owd: (properly) iteration or continuance; used only adverbially (with or without preposition), again, repeatedly...H5750
  5. הַשֶּׁ֙מֶשׁ֙haššemešshemesh: the sun; (by implication) the eastH8121
  6. לְא֣וֹרlĕʾôrowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  7. יוֹמָ֔םyômāmyowmam: dailyH3119
  8. וּלְנֹ֕גַהּûlĕnōgahnogahh: brilliancy (literally or figuratively)H5051
  9. הַיָּרֵ֖חַhayyārēaḥyareach: the moonH3394
  10. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  11. יָאִ֣ירyāʾîrowr: to be (causative, make) luminous (literally and metaphorically)H215
  12. לָ֑ךְlāk
  13. וְהָיָהwĕhāyâhayah: to exist; to be or becomeH1961
  14. לָ֤ךְlāk
  15. יְהוָה֙yĕhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  16. לְא֣וֹרlĕʾôrowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  17. עוֹלָ֔םʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  18. וֵאלֹהַ֖יִךְwēʾlōhayikelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  19. לְתִפְאַרְתֵּֽךְ׃lĕtipʾartēktiph'arah: ornamentH8597
20
  1. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. יָב֥וֹאyābôʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  3. עוֹד֙ʿôd`owd: (properly) iteration or continuance; used only adverbially (with or without preposition), again, repeatedly...H5750
  4. שִׁמְשֵׁ֔ךְšimšēkshemesh: the sun; (by implication) the eastH8121
  5. וִירֵחֵ֖ךְwîrēḥēkyerach: a lunation, i.e. monthH3391
  6. לֹ֣אlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  7. יֵאָסֵ֑ףyēʾāsēpacaph: to gather for any purpose; (hence) to receive, take awayH622
  8. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  9. יְהוָ֗הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  10. יִֽהְיֶהyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  11. לָּךְ֙lok
  12. לְא֣וֹרlĕʾôrowr: illumination; (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.)H216
  13. עוֹלָ֔םʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  14. וְשָׁלְמ֖וּwĕšolmûshalam: to be safe (in mind, body or estate); (figuratively) to be completedH7999
  15. יְמֵ֥יyĕmêyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  16. אֶבְלֵֽךְ׃ʾeblēkebel: lamentationH60
21
  1. וְעַמֵּךְ֙wĕʿammēk`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  2. כֻּלָּ֣םkullāmkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. צַדִּיקִ֔יםṣaddîqîmtsaddiyq: justH6662
  4. לְעוֹלָ֖םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  5. יִ֣ירְשׁוּyîrĕšûyarash: to occupy (by driving out previous tenants, and possessing in their place)H3423
  6. אָ֑רֶץʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  7. נֵ֧צֶרnēṣernetser: a shoot; (figuratively) a descendantH5342
  8. מַטָּעַ֛וmaṭṭāʿǎwmatta`: something planted, i.e. the place (a garden or vineyard), or the thing (a plant, figuratively or men)H4302
  9. מַעֲשֵׂ֥הmaʿăśēma`aseh: an action (good or bad); (generally) a transactionH4639
  10. יָדַ֖יyādayyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  11. לְהִתְפָּאֵֽר׃lĕhitpāʾērpa'ar: to gleam, i.e. (causatively) embellish; (figuratively) to boastH6286
22
  1. הַקָּטֹן֙haqqāṭōnqatan: abbreviated, i.e. diminutive, literally (in quantity, size or number) or figuratively (in age or importance)H6996
  2. יִֽהְיֶ֣הyihĕyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  3. לָאֶ֔לֶףlāʾelepeleph: a thousandH505
  4. וְהַצָּעִ֖ירwĕhaṣṣāʿîrtsa`iyr: little; (in number) fewH6810
  5. לְג֣וֹיlĕgôygowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  6. עָצ֑וּםʿāṣûm`atsuwm: powerful; (specifically) a pawH6099
  7. אֲנִ֥יʾănîaniy: IH589
  8. יְהוָ֖הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  9. בְּעִתָּ֥הּbĕʿittāh`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  10. אֲחִישֶֽׁנָּה׃ʾăḥîšennâchuwsh: to hurry; (figuratively) to be eager with excitement or enjoymentH2363

View the full Hebrew interlinear for Isaiah 60 →

Strong's words in Isaiah 60 (6)
Strong's H935 — בָ֣א (bāʾ)
bow' (bo) v. 1. to go or come (in a wide variety of applications) [a primitive root] KJV: abide, apply, attain, X be, befall, + besiege, bring (forth, in, into, to pass), call, carry, X certainly, (cause, let, thing for) to come (against, in, out, upon, to pass), depart, X doubtless again, + eat, + employ, (cause to) enter (in, into, -tering, -trance, -try), be fallen, fetch, + follow, get, give, go (down, in, to war), grant, + have, X indeed, (in-)vade, lead, lift (up), mention, pull in, put, resort, run (down), send, set, X (well) stricken (in age), X surely, take (in), way.. Appears 11 times in Isaiah 60.
Strong's H3068 — יְהוָ֖ה (yĕhwâ)
Yhovah (yeh-ho-vaw') n/p. 1. (the) self-Existent or Eternal 2. Jehovah, Jewish national name of God [from H1961] KJV: Jehovah, the Lord. Root(s): H1961 Compare: H3050, H3069. Appears 9 times in Isaiah 60.
Strong's H1471 — גוֹיִ֖ם (gôyim)
gowy (go'-ee) (rarely (shortened) goy {go'-ee}) n-m. 1. a foreign nation 2. (hence) a Gentile 3. (figuratively) a troop of animals, or a flight of locusts [apparently from the same root as H1465 (in the sense of massing)] KJV: Gentile, heathen, nation, people. See also: H1465. Appears 7 times in Isaiah 60.
Strong's H1961 — הֱיוֹתֵ֛ךְ (hĕyôtēk)
hayah (haw-yaw) v. 1. to exist 2. to be or become 3. to come into being, i.e. to happen, to occur (always emphatic, and not a mere copula or auxiliary) [a primitive root] KJV: beacon, X altogether, be. Appears 5 times in Isaiah 60.
Strong's H216 — אוֹרֵ֑ךְ (ʾôrēk)
owr (ore) n-f. 1. illumination 2. (concretely) luminary (in every sense, including lightning, happiness, etc.) [from H215] KJV: bright, clear, + day, light (-ning), morning, sun. Root(s): H215. Appears 5 times in Isaiah 60.
Strong's H3605 — כֻּלָּ֖ם (kullām)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 5 times in Isaiah 60.

Browse the full Strong's concordance →

What the Early Church wrote about Isaiah 60 (2 additional)
  • “[The church] rejoices, receiving the light that never goes down and clothed with the brightness of the Word as with a robe. For with what other more precious or honorable ornament was it becoming that the queen should be adorned, to be led as a bride to the Lord, when she had...”

    — Methodius (4th century) on Isaiah 60:3
  • “And these events can be discovered if one looks, for instance, at when Cyrus and then Darius rebuilt Jerusalem. Also, no less a person than Alexander was impressed by the sacred vestment and turned anger into worship.”

    — Theodore Stratelates (4th century) on Isaiah 60:9

Read the full Ante-Nicene Fathers library →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress