Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter Ecclesiastes 3 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Àsìkò wà fún ohun gbogbo, àti ìgbà fún gbogbo nǹkan ní abẹ́ ọ̀run.
2 Ìgbà láti bí àti ìgbà kíkú, ìgbà láti gbìn àti ìgbà láti fàtu.
3 Ìgbà láti pa àti ìgbà láti mú láradá ìgbà láti wó lulẹ̀ àti ìgbà láti kọ́.
4 Ìgbà láti sọkún àti ìgbà láti rín ẹ̀rín ìgbà láti ṣọ̀fọ̀ àti ìgbà láti jó,
5 ìgbà láti tú òkúta ká àti ìgbà láti ṣà wọ́n jọ ìgbà láti súnmọ́ àti ìgbà láti fàsẹ́yìn,
6 ìgbà láti wá kiri àti ìgbà láti ṣàì wá kiri ìgbà láti pamọ́ àti ìgbà láti jù nù,
7 ìgbà láti ya àti ìgbà láti rán ìgbà láti dákẹ́ àti ìgbà láti sọ̀rọ̀,
8 ìgbà láti ní ìfẹ́ àti ìgbà láti kórìíra ìgbà fún ogun àti ìgbà fún àlàáfíà.
9 Kí ni òṣìṣẹ́ jẹ ní èrè nínú wàhálà rẹ̀?
10 Mo ti rí àjàgà tí Ọlọ́run gbé lé ọmọ ènìyàn.
11 Ó ti ṣe ohun gbogbo dáradára ní àsìkò tirẹ̀, ó sì ti fi èrò nípa ayérayé sí ọkàn ọmọ ènìyàn, síbẹ̀, wọn kò le ṣe àwárí ìdí ohun tí Ọlọ́run ti ṣe láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin.
12 Mo mọ̀ wí pé kò sí ohun tí ó dára fún ènìyàn ju pé kí inú wọn dùn kí wọn sì ṣe rere níwọ̀n ìgbà tí wọ́n sì wà láààyè.
13 Wí pé: kí olúkúlùkù le è jẹ, kí wọn sì mu, kí wọn sì rí ìtẹ́lọ́rùn nínú gbogbo iṣẹ́ wọn ẹ̀bùn Ọlọ́run ni èyí jẹ́.
14 Mo mọ̀ wí pé ohun gbogbo tí Ọlọ́run ṣe ni yóò wà títí láé, kò sí ohun tí a lè fi kún un tàbí kí a yọ kúrò nínú rẹ̀. Ọlọ́run ṣe èyí kí ènìyàn le è ní ìbẹ̀rù rẹ̀ ni.
15 Ohun tí ó wà ti wà tẹ́lẹ̀, ohun tí ó ń bọ̀ wá ti wà tẹ́lẹ̀, Ọlọ́run yóò sì mú kí àwọn ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn tún ṣẹlẹ̀.
16 Mo sì tún rí ohun mìíràn ní abẹ́ ọ̀run dípò ìdájọ́, òdodo ni ó wà níbẹ̀ dípò ètò òtítọ́, ẹ̀ṣẹ̀ ni o wà níbẹ̀.
17 Mo wí nínú ọkàn mi, “Ọlọ́run yóò ṣe ìdájọ́ olódodo àti ènìyàn búburú, nítorí pé àsìkò yóò wà fún gbogbo iṣẹ́, àti àsìkò ṣe ìdájọ́ gbogbo ìṣe.”
18 Mo tún rò pé “Ọlọ́run ń dán wa wò láti fihàn wá wí pé bí ẹranko ni ènìyàn rí.
19 Ó ní láti jẹ́ ohun ìrántí pé ìpín ènìyàn rí bí i tẹranko ìpín kan náà ń dúró dè wọ́n. Bí ọ̀kan ti ń kú náà ni èkejì yóò kú. Àwọn méjèèjì ni irú èémí kan náà, ènìyàn kò sàn ju ẹranko lọ, nítorí pé asán ni yíyè jẹ́ fún wọn.
20 Ibìkan náà ni gbogbo wọn ń lọ, wọ́n wá láti inú erùpẹ̀, inú erùpẹ̀ náà ni wọn yóò tún padà sí.
21 Ta ni ó mọ̀ bóyá ẹ̀mí ènìyàn ń lọ sí òkè tí ẹ̀mí ẹranko sì ń lọ sí ìsàlẹ̀ nínú ilẹ̀ ni?”
22 Nígbà náà, ni mo wá rí i wí pé, kò sí ohun tí ó sàn fún ènìyàn ju kí ó gbádùn iṣẹ́ rẹ̀, nítorí pé ìpín tirẹ̀ ni èyí. Tàbí ta ni ó le è mú kí ó rí ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀ kò sí!
Chapter information and study resources

Listen to Ecclesiastes 3 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for Ecclesiastes 3

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about Ecclesiastes 3. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

Ecclesiastes 3 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 4 Early-Church citations.

Hebrew interlinear — Ecclesiastes 3:1–22 (272 words)
1
  1. לַכֹּ֖לlakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. זְמָ֑ןzĕmānzman: an appointed occasionH2165
  3. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לְכָלlĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  5. חֵ֖פֶץḥēpeṣchephets: pleasure; (hence, abstractly) desireH2656
  6. תַּ֥חַתtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  7. הַשָּׁמָֽיִם׃haššāmāyimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
2
  1. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לָלֶ֖דֶתlāledetyalad: to bear young; (causatively) to begetH3205
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לָמ֑וּתlāmûtmuwth: (literally or figuratively) to die; (causatively) to killH4191
  5. עֵ֣תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. לָטַ֔עַתlāṭaʿatnata`: (properly) to strike in, i.e. fix; specifically, to plant (literally or figuratively)H5193
  7. וְעֵ֖תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. לַעֲק֥וֹרlaʿăqôr`aqar: to pluck up (especially by the roots); specifically, to hamstringH6131
  9. נָטֽוּעַ׃nāṭûaʿnata`: (properly) to strike in, i.e. fix; specifically, to plant (literally or figuratively)H5193
3
  1. עֵ֤תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לַהֲרוֹג֙lahărôgharag: to smite with deadly intentH2026
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לִרְפּ֔וֹאlirpôʾrapha': (properly) to mend (by stitching), i.e. (figuratively) to cureH7495
  5. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. לִפְר֖וֹץliprôṣparats: to break out (in many applications, direct and indirect, literal and figurative)H6555
  7. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. לִבְנֽוֹת׃libnôtbanah: to build (literally and figuratively)H1129
4
  1. עֵ֤תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לִבְכּוֹת֙libkôtbakah: to weep; (generally) to bemoanH1058
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לִשְׂח֔וֹקliśḥôqsachaq: to laugh (in pleasure or detraction); (by implication) to playH7832
  5. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. סְפ֖וֹדsĕpôdcaphad: (properly) to tear the hair and beat the breasts (as Orientals do in grief)H5594
  7. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. רְקֽוֹד׃rĕqôdraqad: (properly) to stamp, i.e. to spring about (wildly or for joy)H7540
5
  1. עֵ֚תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לְהַשְׁלִ֣יךְlĕhašlîkshalak: to throw out, down or away (literally or figuratively)H7993
  3. אֲבָנִ֔יםʾăbānîmeben: a stoneH68
  4. וְעֵ֖תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  5. כְּנ֣וֹסkĕnôskanac: to collect; (hence) to enfoldH3664
  6. אֲבָנִ֑יםʾăbānîmeben: a stoneH68
  7. עֵ֣תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. לַחֲב֔וֹקlaḥăbôqchabaq: to clasp (the hands or in embrace)H2263
  9. וְעֵ֖תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  10. לִרְחֹ֥קlirḥōqrachaq: to widen (in any direction), i.e. (intransitively) recede or (transitively) remove (literally or figuratively...H7368
  11. מֵחַבֵּֽק׃mēḥabbēqchabaq: to clasp (the hands or in embrace)H2263
6
  1. עֵ֤תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לְבַקֵּשׁ֙lĕbaqqēšbaqash: to search out (by any method, specifically in worship or prayer)H1245
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לְאַבֵּ֔דlĕʾabbēdabad: (properly) to wander away, i.e. lose oneselfH6
  5. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. לִשְׁמ֖וֹרlišmôrshamar: (properly) to hedge about (as with thorns), i.e. guardH8104
  7. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. לְהַשְׁלִֽיךְ׃lĕhašlîkshalak: to throw out, down or away (literally or figuratively)H7993
7
  1. עֵ֤תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לִקְר֙וֹעַ֙liqrôʿaqara`: to rend, literally or figuratively (revile, paint the eyes, as if enlarging them)H7167
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לִתְפּ֔וֹרlitpôrtaphar: to sewH8609
  5. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. לַחֲשׁ֖וֹתlaḥăšôtchashah: to hush or keep quietH2814
  7. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. לְדַבֵּֽר׃lĕdabbērdabar: perhaps properly, to arrange; but used figuratively (of words), to speakH1696
8
  1. עֵ֤תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  2. לֶֽאֱהֹב֙leʾĕhōbahab: to have affection for (sexually or otherwise)H157
  3. וְעֵ֣תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  4. לִשְׂנֹ֔אliśnōʾsane': to hate (personally)H8130
  5. עֵ֥תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. מִלְחָמָ֖הmilḥāmâmilchamah: a battle (i.e. the engagement); (generally) war (i.e. warfare)H4421
  7. וְעֵ֥תwĕʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  8. שָׁלֽוֹם׃šālômshalowm: safe; (figuratively) well, happy, friendlyH7965
9
  1. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. יִּתְרוֹן֙yitrônyithrown: preeminence, gainH3504
  3. הָֽעוֹשֶׂ֔הhāʿôśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  4. בַּאֲשֶׁ֖רbaʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. ה֥וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  6. עָמֵֽל׃ʿāmēl`amel: toiling; (concretely) a laborerH6001
10
  1. רָאִ֣יתִיrāʾîtîra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  2. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  3. הָֽעִנְיָ֗ןhāʿinyān`inyan: bustle; (generally) employmentH6045
  4. אֲשֶׁ֨רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. נָתַ֧ןnātannathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  6. אֱלֹהִ֛יםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  7. לִבְנֵ֥יlibnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  8. הָאָדָ֖םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  9. לַעֲנ֥וֹתlaʿănôt`anah: to depress literally or figuratively, transitive or intransitive (in various applications, as follows)H6031
11
  1. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  2. הַכֹּ֥לhakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. עָשָׂ֖הʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  4. יָפֶ֣הyāpeyapheh: beautiful (literally or figuratively)H3303
  5. בְעִתּ֑וֹbĕʿittô`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  6. גַּ֤םgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  7. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  8. הָעֹלָם֙hāʿōlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  9. נָתַ֣ןnātannathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  10. בְּלִבָּ֔םbĕlibbāmleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  11. מִבְּלִ֞יmibbĕlîbliy: (properly) failure; nothing or destructionH1097
  12. אֲשֶׁ֧רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  13. לֹאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  14. יִמְצָ֣אyimṣāʾmatsa': (properly) to come forth to, i.e. appear or existH4672
  15. הָאָדָ֗םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  16. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  17. הַֽמַּעֲשֶׂ֛הhammaʿăśema`aseh: an action (good or bad); (generally) a transactionH4639
  18. אֲשֶׁרʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  19. עָשָׂ֥הʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  20. הָאֱלֹהִ֖יםhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  21. מֵרֹ֥אשׁmērōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  22. וְעַדwĕʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  23. סֽוֹף׃sôpcowph: a terminationH5490
12
  1. יָדַ֕עְתִּיyādaʿtîyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  2. כִּ֛יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  3. אֵ֥יןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  4. ט֖וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  5. בָּ֑םbām
  6. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  7. אִםʾimim: (used very widely as demonstrative) lo!; (interrogatively) whether?H518
  8. לִשְׂמ֔וֹחַliśmôaḥsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  9. וְלַעֲשׂ֥וֹתwĕlaʿăśôt`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  10. ט֖וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  11. בְּחַיָּֽיו׃bĕḥayyāywchay: alive; (hence) raw (flesh)H2416
13
  1. וְגַ֤םwĕgamgam: (properly) assemblage; used only adverbially also, even, yea, thoughH1571
  2. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. הָאָדָם֙hāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  4. שֶׁיֹּאכַ֣לšeyyōʾkalakal: to eat (literally or figuratively)H398
  5. וְשָׁתָ֔הwĕšātâshathah: to imbibe (literally or figuratively)H8354
  6. וְרָאָ֥הwĕrāʾâra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  7. ט֖וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  8. בְּכָלbĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  9. עֲמָל֑וֹʿămālô`amal: toil, i.e. wearing effort; (hence) worry, wheth. of body or mindH5999
  10. מַתַּ֥תmattatmattath: a presentH4991
  11. אֱלֹהִ֖יםʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  12. הִֽיא׃hîʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
14
  1. יָדַ֗עְתִּיyādaʿtîyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  2. כִּ֠יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  3. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. אֲשֶׁ֨רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  5. יַעֲשֶׂ֤הyaʿăśe`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  6. הָאֱלֹהִים֙hāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  7. ה֚וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. יִהְיֶ֣הyihyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  9. לְעוֹלָ֔םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  10. עָלָיו֙ʿālāyw`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  11. אֵ֣יןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  12. לְהוֹסִ֔יףlĕhôsîpyacaph: to add or augment (often adverbial, to continue to do a thing)H3254
  13. וּמִמֶּ֖נּוּûmimmennûmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  14. אֵ֣יןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  15. לִגְרֹ֑עַligrōaʿgara`: to scrape off; (by implication) to shave, remove, lessen, withholdH1639
  16. וְהָאֱלֹהִ֣יםwĕhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  17. עָשָׂ֔הʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  18. שֶׁיִּֽרְא֖וּšeyyirĕʾûyare': to fear; morally, to revereH3372
  19. מִלְּפָנָֽיו׃millĕpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
15
  1. מַהmamah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  2. שֶּֽׁהָיָה֙šehāyāhhayah: to exist; to be or becomeH1961
  3. כְּבָ֣רkĕbārkbar: (properly) extent of time, i.e. a great whileH3528
  4. ה֔וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  5. וַאֲשֶׁ֥רwaʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  6. לִהְי֖וֹתlihyôthayah: to exist; to be or becomeH1961
  7. כְּבָ֣רkĕbārkbar: (properly) extent of time, i.e. a great whileH3528
  8. הָיָ֑הhāyâhayah: to exist; to be or becomeH1961
  9. וְהָאֱלֹהִ֖יםwĕhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  10. יְבַקֵּ֥שׁyĕbaqqēšbaqash: to search out (by any method, specifically in worship or prayer)H1245
  11. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  12. נִרְדָּֽף׃nirdāpradaph: to run after (usually with hostile intentH7291
16
  1. וְע֥וֹדwĕʿôd`owd: (properly) iteration or continuance; used only adverbially (with or without preposition), again, repeatedly...H5750
  2. רָאִ֖יתִיrāʾîtîra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  3. תַּ֣חַתtaḥattachath: the bottom (as depressed); only adverbially, below (often with prepositional prefix underneath), in lieu of...H8478
  4. הַשָּׁ֑מֶשׁhaššāmešshemesh: the sun; (by implication) the eastH8121
  5. מְק֤וֹםmĕqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  6. הַמִּשְׁפָּט֙hammišpāṭmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  7. שָׁ֣מָּהšāmmâsham: there (transferring to time) then; often thither, or thenceH8033
  8. הָרֶ֔שַׁעhārešaʿresha`: a wrong (especially moral)H7562
  9. וּמְק֥וֹםûmĕqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  10. הַצֶּ֖דֶקhaṣṣedeqtsedeq: the right (natural, moral or legal); (abstractly) equityH6664
  11. שָׁ֥מָּהšāmmâsham: there (transferring to time) then; often thither, or thenceH8033
  12. הָרָֽשַׁע׃hārāšaʿresha`: a wrong (especially moral)H7562
17
  1. אָמַ֤רְתִּֽיʾāmartîamar: to say (used with great latitude)H559
  2. אֲנִי֙ʾăniyaniy: IH589
  3. בְּלִבִּ֔יbĕlibbîleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  4. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  5. הַצַּדִּיק֙haṣṣaddîqtsaddiyq: justH6662
  6. וְאֶתwĕʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  7. הָ֣רָשָׁ֔עhārāšāʿrasha`: morally wrong; (concretely) an (actively) bad personH7563
  8. יִשְׁפֹּ֖טyišpōṭshaphat: to judge, i.e. pronounce sentence (for or against)H8199
  9. הָאֱלֹהִ֑יםhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  10. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  11. עֵ֣תʿēt`eth: time, especially (adverb with preposition) now, when, etcH6256
  12. לְכָלlĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  13. חֵ֔פֶץḥēpeṣchephets: pleasure; (hence, abstractly) desireH2656
  14. וְעַ֥לwĕʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  15. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  16. הַֽמַּעֲשֶׂ֖הhammaʿăśema`aseh: an action (good or bad); (generally) a transactionH4639
  17. שָֽׁם׃šāmsham: there (transferring to time) then; often thither, or thenceH8033
18
  1. אָמַ֤רְתִּֽיʾāmartîamar: to say (used with great latitude)H559
  2. אֲנִי֙ʾăniyaniy: IH589
  3. בְּלִבִּ֔יbĕlibbîleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  4. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  5. דִּבְרַת֙dibratdibrah: a reason, suit or styleH1700
  6. בְּנֵ֣יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  7. הָאָדָ֔םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  8. לְבָרָ֖םlĕbārāmbarar: to clarify (i.e. brighten), examine, selectH1305
  9. הָאֱלֹהִ֑יםhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  10. וְלִרְא֕וֹתwĕlirʾôtra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  11. שְׁהֶםšĕhemhem: they (only used when emphatic)H1992
  12. בְּהֵמָ֥הbĕhēmâbhemah: (properly) a dumb beast; especially any large quadruped or animal (often collective)H929
  13. הֵ֖מָּהhēmmâhem: they (only used when emphatic)H1992
  14. לָהֶֽם׃lāhemhem: they (only used when emphatic)H1992
19
  1. כִּי֩kiykiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. מִקְרֶ֨הmiqremiqreh: something met with, i.e. an accident or fortuneH4745
  3. בְֽנֵיbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  4. הָאָדָ֜םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  5. וּמִקְרֶ֣הûmiqremiqreh: something met with, i.e. an accident or fortuneH4745
  6. הַבְּהֵמָ֗הhabbĕhēmâbhemah: (properly) a dumb beast; especially any large quadruped or animal (often collective)H929
  7. וּמִקְרֶ֤הûmiqremiqreh: something met with, i.e. an accident or fortuneH4745
  8. אֶחָד֙ʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  9. לָהֶ֔םlāhem
  10. כְּמ֥וֹתkĕmôtmaveth: death (natural or violent); (concretely) the dead, their place or state (hades)H4194
  11. זֶה֙zehzeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  12. כֵּ֣ןkēnken: (properly) set upright; hence (figuratively as adjective) justH3651
  13. מ֣וֹתmôtmaveth: death (natural or violent); (concretely) the dead, their place or state (hades)H4194
  14. זֶ֔הzezeh: the masculine demonstrative pronoun, this or thatH2088
  15. וְר֥וּחַwĕrûaḥruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  16. אֶחָ֖דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  17. לַכֹּ֑לlakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  18. וּמוֹתַ֨רûmôtarmowthar: (literally) gain; (figuratively) superiorityH4195
  19. הָאָדָ֤םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  20. מִןminmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  21. הַבְּהֵמָה֙habbĕhēmāhbhemah: (properly) a dumb beast; especially any large quadruped or animal (often collective)H929
  22. אָ֔יִןʾāyinayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  23. כִּ֥יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  24. הַכֹּ֖לhakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  25. הָֽבֶל׃hābelhebel: emptiness or vanity; (figuratively) something transitory and unsatisfactoryH1892
20
  1. הַכֹּ֥לhakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  2. הוֹלֵ֖ךְhôlēkhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  3. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. מָק֣וֹםmāqômmaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
  5. אֶחָ֑דʾeḥādechad: (properly) united, i.e. one; (as an ordinal) firstH259
  6. הַכֹּל֙hakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  7. הָיָ֣הhāyâhayah: to exist; to be or becomeH1961
  8. מִןminmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  9. הֶֽעָפָ֔רheʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
  10. וְהַכֹּ֖לwĕhakkōlkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  11. שָׁ֥בšābshuwb: to turn back (hence, away) transitively or intransitively, literally or figuratively (not necessarily with the...H7725
  12. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  13. הֶעָפָֽר׃heʿāpār`aphar: dust (as powdered or gray); (hence) clay, earth, mudH6083
21
  1. מִ֣יmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  2. יוֹדֵ֗עַyôdēaʿyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  3. ר֚וּחַrûaḥruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  4. בְּנֵ֣יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  5. הָאָדָ֔םhāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  6. הָעֹלָ֥הhāʿōlâ`alah: to ascend, intransitively (be high) or actively (mount)H5927
  7. הִ֖יאhîʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. לְמָ֑עְלָהlĕmāʿĕlâma`al: (properly) the upper part, used only adverbially with prefix upward, above, overhead, from the top, etcH4605
  9. וְר֙וּחַ֙wĕrûḥaruwach: wind; by resemblance breath, i.e. a sensible (or even violent) exhalationH7307
  10. הַבְּהֵמָ֔הhabbĕhēmâbhemah: (properly) a dumb beast; especially any large quadruped or animal (often collective)H929
  11. הַיֹּרֶ֥דֶתhayyōredetyarad: to descend; (literally) to go downwardsH3381
  12. הִ֖יאhîʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  13. לְמַ֥טָּהlĕmaṭṭâmattah: downward, below or beneath; often adverbially with or without prefixesH4295
  14. לָאָֽרֶץ׃lāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
22
  1. וְרָאִ֗יתִיwĕrāʾîtîra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  2. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  3. אֵ֥יןʾênayin: a non-entity; (generally) used as a negative particleH369
  4. טוֹב֙ṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  5. מֵאֲשֶׁ֨רmēʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  6. יִשְׂמַ֤חyiśmaḥsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  7. הָאָדָם֙hāʾādāmadam: ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.)H120
  8. בְּֽמַעֲשָׂ֔יוbĕmaʿăśāywma`aseh: an action (good or bad); (generally) a transactionH4639
  9. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  10. ה֖וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  11. חֶלְק֑וֹḥelqôcheleq: (properly) smoothness (of the tongue); also an allotmentH2506
  12. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  13. מִ֤יmîmiy: who?; (occasionally, by a peculiar idiom, of things) which?H4310
  14. יְבִיאֶ֙נּוּ֙yĕbîʾennûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  15. לִרְא֔וֹתlirʾôtra'ah: to see, literally or figuratively (in numerous applications, direct and implied, transitive, intransitive and...H7200
  16. בְּמֶ֖הbĕmemah: (properly, interrogative) what? (including how? why? when?)H4100
  17. שֶׁיִּהְיֶ֥הšeyyihyehayah: to exist; to be or becomeH1961
  18. אַחֲרָֽיו׃ʾaḥărāywachar: (properly) the hind part; (generally, as adverb or conjunction) after (in various senses)H310

View the full Hebrew interlinear for Ecclesiastes 3 →

Strong's words in Ecclesiastes 3 (6)
Strong's H6256 — וְעֵ֥ת (wĕʿēt)
`eth (ayth) n-f. 1. time, especially (adverb with preposition) now, when, etc [from H5703] KJV: + after, (al-)ways, X certain, + continually, + evening, long, (due) season, so (long) as, (even-, evening-, noon-)tide, ((meal-)), what) time, when. Root(s): H5703. Appears 31 times in Ecclesiastes 3.
Strong's H3605 — לַכֹּ֖ל (lakkōl)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 13 times in Ecclesiastes 3.
Strong's H120 — הָאָדָ֖ם (hāʾādām)
adam (aw-dawm') n-m. 1. ruddy i.e. a human being (an individual or the species, mankind, etc.) [from H119] KJV: X another, + hypocrite, + common sort, X low, man (mean, of low degree), person. Root(s): H119. Appears 8 times in Ecclesiastes 3.
Strong's H430 — אֱלֹהִ֛ים (ʾĕlōhîm)
elohiym (el-o-heem') n-m. 1. gods in the ordinary sense 2. but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the supreme God 3. occasionally applied by way of deference to magistrates 4. and sometimes as a superlative [plural of H433] KJV: angels, X exceeding, God (gods)(-dess, -ly), X (very) great, judges, X mighty. Root(s): H433. Appears 8 times in Ecclesiastes 3.
Strong's H1961 — יִהְיֶ֣ה (yihye)
hayah (haw-yaw) v. 1. to exist 2. to be or become 3. to come into being, i.e. to happen, to occur (always emphatic, and not a mere copula or auxiliary) [a primitive root] KJV: beacon, X altogether, be. Appears 6 times in Ecclesiastes 3.
Strong's H6213 — הָֽעוֹשֶׂ֔ה (hāʿôśe)
`asah (aw-saw') v. 1. to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows) [a primitive root] KJV: accomplish, advance, appoint, apt, be at, become, bear, bestow, bring forth, bruise, be busy, X certainly, have the charge of, commit, deal (with), deck, + displease, do, (ready) dress(-ed), (put in) execute(-ion), exercise, fashion, + feast, (fight-)ing man, + finish, fit, fly, follow, fulfill, furnish, gather, get, go about, govern, grant, great, + hinder, hold ((a feast)), X indeed, + be industrious, + journey, keep, labour, maintain, make, be meet, observe, be occupied, offer, + officer, pare, bring (come) to pass, perform, pracise, prepare, procure, provide, put, requite, X sacrifice, serve, set, shew, X sin, spend, X surely, take, X thoroughly, trim, X very, + vex, be (warr-)ior, work(-man), yield, use.. Appears 6 times in Ecclesiastes 3.

Browse the full Strong's concordance →

What the Early Church wrote about Ecclesiastes 3 (3 additional)
  • “"A time to speak, when there are hearers who receive the word; but a time to keep silence, when the hearers pervert the word; as Paul says: \"A man that is an heretic, after the first and second admonition, reject.\"”

    — Dionysius of Alexandria (3rd century) on Ecclesiastes 3:7
  • “For Providence cares not only for the useful but also for the seasonable and beautiful.”

    — Dionysius of Alexandria (3rd century) on Ecclesiastes 3:11
  • “For this present time is filled with all things that are most contrary to each other— births and deaths, the growth of plants and their uprooting, cures and killings, the building up and the pulling down of houses, weeping and laughing, mourning and dancing. At this moment a m...”

    — Gregory of Neocaesarea (3rd century) on Ecclesiastes 3:1

Read the full Ante-Nicene Fathers library →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress