Skip to content

A little app tip

Back and forward, in one button

The back arrow at the bottom of the app can take you in either direction.

Tap the arrowGo back
Press and holdGo forward

Hold briefly, then release. Forward is available after you have gone back. You can also use Shift+Enter on a keyboard.

Add your phone number?

Optional. Nothing is sent unless you choose it.

Audio Bible
The Historic Faith

Chapter 1 Chronicles 16 Language Yoruba Bible ID YORDPI Label DPI Catalog Contemporary Bible (Davar Audio) Available audio, text Coverage Old and New Testament

Select Translation

1 Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run, wá sínú àgọ́ ti Dafidi ti pèsè fún un, wọ́n sì gbé ẹbọ sísun àti ọrẹ ìdàpọ̀ kalẹ̀ níwájú Ọlọ́run.
2 Lẹ́yìn tí Dafidi parí ẹbọ sísun àti ọrẹ ìdàpọ̀, ó bùkún àwọn ènìyàn ní orúkọ Olúwa.
3 Nígbà náà ó fún olúkúlùkù ọkùnrin àti obìnrin ọmọ Israẹli ní ìṣù àkàrà kan, àkàrà dídùn ti àkókò kan àti àkàrà dídùn ti èso àjàrà kan.
4 Ó yan díẹ̀ lára àwọn ará Lefi láti máa jọ́sìn níwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa, àti láti ṣe ìrántí àti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa, Ọlọ́run Israẹli.
5 Asafu ni olóyè, àtẹ̀lé rẹ ni Sekariah, Jehieli, Ṣemiramotu, Asieli, Mattitiah, Eliabu, Benaiah, Obedi-Edomu àti Jeieli, àwọn ni yóò lu ohun èlò orin olókùn àti dùùrù haapu. Asafu ni yóò lu símbálì kíkan.
6 Àti Benaiah àti Jahasieli àwọn àlùfáà ni yóò fọn ìpè nígbà gbogbo níwájú àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú ti Ọlọ́run.
7 Ní ọjọ́ náà Dafidi kọ́kọ́ fi lé Asafu àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́ orin Dafidi ti ọpẹ́ sí Olúwa.
8 Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn nínú àwọn ènìyàn fún ohun tí ó ṣe
9 Ẹ kọrin sí i, ẹ kọrin ìyìn, sí i, ẹ sọ ti gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ̀.
10 Ìyìn nínú orúkọ rẹ̀ mímọ́; jẹ kí ọkàn àwọn tí ó yin Olúwa kí ó yọ̀.
11 Ẹ wá Olúwa àti agbára rẹ̀; e wá ojú rẹ̀ nígbà gbogbo.
12 Rántí àwọn ìyanu tí Ó ti ṣe, iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ àti ìdájọ́ tí Ó ti sọ.
13 A! ẹ̀yin ìran ọmọ Israẹli ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn ọmọ Jakọbu, ẹ̀yin tí ó ti yàn.
14 Òun ni Olúwa Ọlọ́run wa; ìdájọ́ rẹ̀ wà ní gbogbo ayé.
15 Ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ láéláé, ọ̀rọ̀ tí ó pàṣẹ, fún ẹgbẹẹgbẹ̀rún ìran,
16 májẹ̀mú tí ó dá pẹ̀lú Abrahamu, ìbúra tí ó ṣe pẹ̀lú fún Isaaki.
17 Ó ṣe ìdánilójú u rẹ̀ fún Jakọbu, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ sí Israẹli, gẹ́gẹ́ bi májẹ̀mú ayérayé:
18 “Sí ọ, ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ Kenaani. Gẹ́gẹ́ bí ààyè tí ìwọ yóò jogún.”
19 Nígbà tí wọn kéré ní iye, wọ́n kéré gidigidi, wọ́n sì jẹ́ àlejò níbẹ̀,
20 wọ́n rìn kiri láti orílẹ̀-èdè sí orílẹ̀-èdè láti ìjọba kan sí èkejì.
21 Kò gba ọkùnrin kankan láyè láti pọ́n wọn lójú; nítorí tiwọn, ó bá àwọn ọba wí.
22 “Má ṣe fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi; má ṣe pa àwọn wòlíì mi lára.”
23 Kọrin sí Olúwa gbogbo ayé; ẹ máa fi ìgbàlà rẹ̀ hàn láti ọjọ́ dé ọjọ́.
24 Kéde ògo à rẹ̀ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, ohun ìyàlẹ́nu tí ó ṣe láàrín gbogbo ènìyàn.
25 Nítorí títóbi ni Olúwa òun sì ni ìyìn yẹ jùlọ; òun ni kí a bẹ̀rù ju gbogbo àwọn Ọlọ́run lọ.
26 Nítorí gbogbo àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè jẹ́ àwọn òrìṣà, ṣùgbọ́n Olúwa dá àwọn ọ̀run.
27 Dídán àti ọláńlá ni ó wà níwájú rẹ̀; agbára àti ayọ̀ ni ó wà ní ibi ibùgbé rẹ̀.
28 Fi fún Olúwa, ẹ̀yin ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ fi ògo àti ipá fún Olúwa.
29 Fún Olúwa ní ìyìn nítorí orúkọ rẹ̀; gbé ọrẹ kí ẹ sì wá síwájú rẹ̀. Sìn Olúwa nínú inú dídùn ìwà mímọ́ rẹ̀.
30 Wárìrì níwájú rẹ̀, gbogbo ayé! Ayé sì fi ìdí múlẹ̀; a kò sì le è ṣí i.
31 Jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó yọ̀, jẹ́ kí ayé kí ó ṣe inú dídùn; lẹ́ kí wọn kí ó sọ láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, pé “Olúwa jẹ ọba!”
32 Jẹ́ kí ọ̀run kí ó tún dún padà, àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀; Jẹ́ kí àwọn pápá kí ó hó fún ayọ̀, àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀!
33 Nígbà náà ni igi igbó yóò kọrin, wọn yóò kọrin fún ayọ̀ níwájú Olúwa, nítorí tí ó wá láti ṣèdájọ́ ayé.
34 Fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ó dára; ìfẹ́ ẹ rẹ̀ dúró títí láé.
35 Ké lóhùn rara, “Gbà wá, Ọlọ́run olùgbàlà a wa; kó wa jọ kí o sì gbà wá kúrò lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, kí àwa kí ó lè fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ, kí àwa kí ó lè yọ̀ nínú ìyìn rẹ̀.”
36 Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Israẹli, láé àti láéláé. Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn ènìyàn wí pé, “Àmín,” wọ́n “Yin Olúwa.”
37 Dafidi fi Asafu àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ níwájú àpótí ẹ̀rí Olúwa láti jíṣẹ́ níbẹ̀ déédé, gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ kọ̀ọ̀kan ṣe gbà.
38 Ó fi Obedi-Edomu àti méjìdínláàádọ́rin ẹlẹgbẹ́ ẹ rẹ̀ láti ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ pẹ̀lú wọn. Obedi-Edomu mọ Jedutuni, àti Hosa pẹ̀lú jẹ́ olùtọ́jú ẹnu-ọ̀nà.
39 Dafidi fi Sadoku àlùfáà àti àwọn àlùfáà ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ níwájú Àgọ́ Olúwa ní ibi gíga ní Gibeoni.
40 Láti gbé pẹpẹ ẹbọ sísun déédé, àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí a kọ sínú òfin Olúwa, tí ó ti fún Israẹli.
41 Pẹ̀lú wọn ni Hemani àti Jedutuni àti ìyókù tí a mú àti yàn nípasẹ̀ orúkọ láti fi ọpẹ́ fún Olúwa, nítorí tí ìfẹ́ rẹ̀ dúró títí láéláé
42 Hemani àti Jedutuni ni wọ́n dúró fún fífọn ìpè àti Kimbali àti fún lílo ohun èlò yòókù fún orin Ọlọ́run. Àwọn ọmọ Jedutuni wà ní ipò dídúró ní ẹnu-ọ̀nà.
43 Nígbà náà gbogbo àwọn ènìyàn kúrò, olúkúlùkù sí ilé rẹ̀: Dafidi yípadà láti súre fún ìdílé rẹ̀.
Chapter information and study resources

Listen to 1 Chronicles 16 with verse-by-verse audio highlighting.

Study tools for 1 Chronicles 16

Cross-references, Hebrew word study, and what the Early Church wrote about 1 Chronicles 16. Tap any section to expand — or right-click any verse for the full interactive study panel.

1 Chronicles 16 study resources: word-by-word Hebrew interlinear with Strong's numbers, 1 Early-Church citation.

Hebrew interlinear — 1 Chronicles 16:1–43 (407 words)
1
  1. וַיָּבִ֙יאוּ֙wayyābîʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  2. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  3. אֲר֣וֹןʾărônarown: a boxH727
  4. הָֽאֱלֹהִ֔יםhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  5. וַיַּצִּ֣יגוּwayyaṣṣîgûyatsag: to place permanentlyH3322
  6. אֹת֔וֹʾōtôeth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  7. בְּת֣וֹךְbĕtôktavek: a bisection; (by implication) the centreH8432
  8. הָאֹ֔הֶלhāʾōhelohel: a tent (as clearly conspicuous from a distance)H168
  9. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  10. נָֽטָהnāṭânatah: to stretch or spread out; (by implication) to bend away (including moral deflection)H5186
  11. ל֖וֹlô
  12. דָּוִ֑ידdāwîdDavid: loving; David, the youngest son of JesseH1732
  13. וַיַּקְרִ֛יבוּwayyaqrîbûqarab: to approach (causatively, bring near) for whatever purposeH7126
  14. עֹל֥וֹתʿōlôt`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  15. וּשְׁלָמִ֖יםûšĕlāmîmshelem: (properly) requital, i.e. a (voluntary) sacrifice in thanksH8002
  16. לִפְנֵ֥יlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  17. הָֽאֱלֹהִֽים׃hāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
2
  1. וַיְכַ֣לwaykalkalah: to end, whether intransitive (to cease, be finished, perish) or transitived (to complete, prepare, consume)H3615
  2. דָּוִ֔ידdāwîdDavid: loving; David, the youngest son of JesseH1732
  3. מֵהַֽעֲל֥וֹתmēhaʿălôt`alah: to ascend, intransitively (be high) or actively (mount)H5927
  4. הָֽעֹלָ֖הhāʿōlâ`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  5. וְהַשְּׁלָמִ֑יםwĕhaššĕlāmîmshelem: (properly) requital, i.e. a (voluntary) sacrifice in thanksH8002
  6. וַיְבָ֥רֶךְwaybārekbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  7. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  8. הָעָ֖םhāʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  9. בְּשֵׁ֥םbĕšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  10. יְהוָֽה׃yĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
3
  1. וַיְחַלֵּק֙wayḥallēqchalaq: to be smooth (figuratively); (by implication) (as smooth stones were used for lots) to apportion or separateH2505
  2. לְכָלlĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. אִ֣ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. יִשְׂרָאֵ֔לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  5. מֵאִ֖ישׁmēʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  6. וְעַדwĕʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  7. אִשָּׁ֑הʾiššâishshah: irregular plural, nashiym {naw-sheem'}; a woman (used in the same wide sense as H0582)H802
  8. לְאִישׁ֙lĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  9. כִּכַּרkikkarkikkar: a circle; (by implication) a circumjacent tract or region, expec. the Ghor or valley of the JordanH3603
  10. לֶ֔חֶםleḥemlechem: food (for man or beast), especially bread, or grain (for making it)H3899
  11. וְאֶשְׁפָּ֖רwĕʾešpāreshpar: a measured portionH829
  12. וַֽאֲשִׁישָֽׁה׃waʾăšîšâashiyshah: something closely pressed together; a cake of raisins or other comfitsH809
4
  1. וַיִּתֵּ֞ןwayyittēnnathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  2. לִפְנֵ֨יlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  3. אֲר֧וֹןʾărônarown: a boxH727
  4. יְהוָ֛הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  5. מִןminmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  6. הַלְוִיִּ֖םhalwiyyimLeviyiy: a Levite or descendant of LeviH3881
  7. מְשָֽׁרְתִ֑יםmĕšārĕtîmsharath: to attend as a menial or worshipper; (figuratively) to contribute toH8334
  8. וּלְהַזְכִּיר֙ûlĕhazkîrzakar: (properly) to mark (so as to be recognized), i.e. to rememberH2142
  9. וּלְהוֹד֣וֹתûlĕhôdôtyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  10. וּלְהַלֵּ֔לûlĕhallēlhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  11. לַֽיהוָ֖הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  12. אֱלֹהֵ֥יʾĕlōhêelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  13. יִשְׂרָאֵֽל׃yiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
5
  1. אָסָ֥ףʾāsāpAcaph: collector; Asaph, the name of three Israelites, and of the family of the firstH623
  2. הָרֹ֖אשׁhārōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  3. וּמִשְׁנֵ֣הוּûmišnēhûmishneh: (properly) a repetition, i.e. a duplicate (copy of a document), or a double (in amount)H4932
  4. זְכַרְיָ֑הzĕkaryâZkaryah: Jah has remembered; Zecarjah, the name of twenty-nine IsraelitesH2148
  5. יְעִיאֵ֡לyĕʿîʾēlY`iy'el: carried away of God; Jeiel, the name of six IsraelitesH3273
  6. וּשְׁמִֽירָמ֡וֹתûšĕmîrāmôtShmiyramowth: name of heights; Shemiramoth, the name of two IsraelitesH8070
  7. וִֽיחִיאֵ֡לwîḥîʾēlYchiy'el: God will live; Jechiel (or Jechavel), the name of eight IsraelitesH3171
  8. וּמַתִּתְיָ֡הûmattityâMattithyah: gift of Jah; Mattithjah, the name of four IsraelitesH4993
  9. וֶֽאֱלִיאָ֡בweʾĕlîʾābEliy'ab: God of (his) father; Eliab, the name of six IsraelitesH446
  10. וּבְנָיָהוּ֩ûbĕnāyāhûBnayah: Jah has built; Benajah, the name of twelve IsraelitesH1141
  11. וְעֹבֵ֨דwĕʿōbēd
  12. אֱדֹ֜םʾĕdōmworker of Edom; Obed-Edom, the name of five IsraelitesH5654
  13. וִֽיעִיאֵ֗לwîʿîʾēlY`iy'el: carried away of God; Jeiel, the name of six IsraelitesH3273
  14. בִּכְלֵ֤יbiklêkliy: something prepared, i.e. any apparatus (as an implement, utensil, dress, vessel or weapon)H3627
  15. נְבָלִים֙nĕbālîmnebel: a skin-bag for liquids (from collapsing when empty)H5035
  16. וּבְכִנֹּר֔וֹתûbĕkinnōrôtkinnowr: a harpH3658
  17. וְאָסָ֖ףwĕʾāsāpAcaph: collector; Asaph, the name of three Israelites, and of the family of the firstH623
  18. בַּֽמְצִלְתַּ֥יִםbamṣiltayimmtseleth: (only dual) double tinklers, i.e. cymbalsH4700
  19. מַשְׁמִֽיעַ׃mašmîaʿshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
6
  1. וּבְנָיָ֥הוּûbĕnāyāhûBnayah: Jah has built; Benajah, the name of twelve IsraelitesH1141
  2. וְיַֽחֲזִיאֵ֖לwĕyaḥăzîʾēlYachaziy'el: beheld of God; Jachaziel, the name of five IsraelitesH3166
  3. הַכֹּֽהֲנִ֑יםhakkōhănîmkohen: (literally) one officiating, a priest; (also, by courtesy) an acting priest (although a layman)H3548
  4. בַּחֲצֹֽצְר֣וֹתbaḥăṣōṣĕrôtchatsotsrah: a trumpet (from its sundered or quavering note)H2689
  5. תָּמִ֔ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  6. לִפְנֵ֖יlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. אֲר֥וֹןʾărônarown: a boxH727
  8. בְּרִיתbĕrîtbriyth: a compact (because made by passing between pieces of flesh)H1285
  9. הָֽאֱלֹהִֽים׃hāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
7
  1. בַּיּ֣וֹםbayyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  2. הַה֗וּאhahûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  3. אָ֣זʾāzaz: at that time or place; (as a conjunction) thereforeH227
  4. נָתַ֤ןnātannathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  5. דָּוִיד֙dāwîdDavid: loving; David, the youngest son of JesseH1732
  6. בָּרֹ֔אשׁbārōšro'sh: the head (as most easily shaken), whether literal or figurative (in many applications, of place, time, rank...H7218
  7. לְהֹד֖וֹתlĕhōdôtyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  8. לַֽיהוָ֑הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  9. בְּיַדbĕyadyad: a hand (the open one (indicating power, means, direction, etc.), in distinction from H3709, the closed one)H3027
  10. אָסָ֖ףʾāsāpAcaph: collector; Asaph, the name of three Israelites, and of the family of the firstH623
  11. וְאֶחָֽיו׃wĕʾeḥāywach: a brother (used in the widest sense of literal relationship and metaphorical affinity or resemblance (like H0001))H251
8
  1. הוֹד֤וּhôdûyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  2. לַֽיהוָה֙layhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. קִרְא֣וּqirʾûqara': to call out to (i.e. properly, address by name, but used in a wide variety of applications)H7121
  4. בִשְׁמ֔וֹbišmôshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  5. הוֹדִ֥יעוּhôdîʿûyada`: to know; (properly) to ascertain by seeingH3045
  6. בָֽעַמִּ֖יםbāʿammîm`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  7. עֲלִֽילֹתָֽיו׃ʿălîlōtāyw`aliylah: an exploit (of God), or a performance (of man, often in a bad sense)H5949
9
  1. שִׁ֤ירוּšîrûshiyr: to singH7891
  2. לוֹ֙lô
  3. זַמְּרוּzammĕrûzamar: (properly) to touch the strings or parts of a musical instrument, i.e. play upon itH2167
  4. ל֔וֹlô
  5. שִׂ֖יחוּśîḥûsiyach: to ponder; (by implication) converse (with oneself, and hence, aloud) or (transitively) utterH7878
  6. בְּכָלbĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  7. נִפְלְאֹתָֽיו׃niplĕʾōtāywpala': (properly, literally or figuratively) perhaps to separate, i.e. distinguishH6381
10
  1. הִֽתְהַלְלוּ֙hitĕhallûhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  2. בְּשֵׁ֣םbĕšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  3. קָדְשׁ֔וֹqodšôqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  4. יִשְׂמַ֕חyiśmaḥsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  5. לֵ֖בlēbleb: the heart; also used (figuratively) very widely for the feelings, the will and even the intellectH3820
  6. מְבַקְשֵׁ֥יmĕbaqšêbaqash: to search out (by any method, specifically in worship or prayer)H1245
  7. יְהוָֽה׃yĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
11
  1. דִּרְשׁ֤וּdiršûdarash: (properly) to tread or frequent; (usually) to follow (for pursuit or search)H1875
  2. יְהוָה֙yĕhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. וְעֻזּ֔וֹwĕʿuzzô`oz: strength in various applications (force, security, majesty, praise)H5797
  4. בַּקְּשׁ֥וּbaqqĕšûbaqash: to search out (by any method, specifically in worship or prayer)H1245
  5. פָנָ֖יוpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  6. תָּמִֽיד׃tāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
12
  1. זִכְר֗וּzikrûzakar: (properly) to mark (so as to be recognized), i.e. to rememberH2142
  2. נִפְלְאֹתָיו֙niplĕʾōtāywpala': (properly, literally or figuratively) perhaps to separate, i.e. distinguishH6381
  3. אֲשֶׁ֣רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  4. עָשָׂ֔הʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
  5. מֹֽפְתָ֖יוmōpĕtāywmowpheth: a miracle; (by implication) a token or omenH4159
  6. וּמִשְׁפְּטֵיûmišpĕṭêmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
  7. פִֽיהוּ׃pîhûpeh: the mouth (as the means of blowing), whether literal or figurative (particularly speech)H6310
13
  1. זֶ֚רַעzeraʿzera`: seed; (figuratively) fruit, plant, sowing-time, posterityH2233
  2. יִשְׂרָאֵ֣לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  3. עַבְדּ֔וֹʿabdô`ebed: a servantH5650
  4. בְּנֵ֥יbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  5. יַֽעֲקֹ֖בyaʿăqōbYa`aqob: heel-catcher (i.e. supplanter); Jaakob, the Israelitish patriarchH3290
  6. בְּחִירָֽיו׃bĕḥîrāywbachiyr: selectH972
14
  1. ה֚וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  2. יְהוָ֣הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. אֱלֹהֵ֔ינוּʾĕlōhênûelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  4. בְּכָלbĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  5. הָאָ֖רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  6. מִשְׁפָּטָֽיו׃mišpāṭāywmishpat: (properly) a verdict (favorable or unfavorable) pronounced judicially, especially a sentence or formal decree...H4941
15
  1. זִכְר֤וּzikrûzakar: (properly) to mark (so as to be recognized), i.e. to rememberH2142
  2. לְעוֹלָם֙lĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  3. בְּרִית֔וֹbĕrîtôbriyth: a compact (because made by passing between pieces of flesh)H1285
  4. דָּבָ֥רdābārdabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  5. צִוָּ֖הṣiwwâtsavah: (intensively) to constitute, enjoinH6680
  6. לְאֶ֥לֶףlĕʾelepeleph: a thousandH505
  7. דּֽוֹר׃dôrdowr: (properly) a revolution of time, i.e. an age or generationH1755
16
  1. אֲשֶׁ֤רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  2. כָּרַת֙kāratkarath: to cut (off, down or asunder); (by implication) to destroy or consumeH3772
  3. אֶתʾeteth: (properly) nearness; (used only as a preposition or an adverb) nearH854
  4. אַבְרָהָ֔םʾabrāhāmAbraham: father of a multitude; Abraham, the later name of AbramH85
  5. וּשְׁבֽוּעָת֖וֹûšĕbûʿātôshbuw`ah: (properly) something sworn, i.e. an oathH7621
  6. לְיִצְחָֽק׃lĕyiṣḥāqYitschaq: laughter (i.e. mockery); Jitschak (or Isaac), son of AbrahamH3327
17
  1. וַיַּֽעֲמִידֶ֤הָwayyaʿămîdehā`amad: to stand, in various relations (literal and figurative, intransitive and transitive)H5975
  2. לְיַֽעֲקֹב֙lĕyaʿăqōbYa`aqob: heel-catcher (i.e. supplanter); Jaakob, the Israelitish patriarchH3290
  3. לְחֹ֔קlĕḥōqchoq: an enactment; (hence) an appointment (of time, space, quantity, labor or usage)H2706
  4. לְיִשְׂרָאֵ֖לlĕyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  5. בְּרִ֥יתbĕrîtbriyth: a compact (because made by passing between pieces of flesh)H1285
  6. עוֹלָֽם׃ʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
18
  1. לֵאמֹ֗רlēʾmōramar: to say (used with great latitude)H559
  2. לְךָ֙lĕkā
  3. אֶתֵּ֣ןʾettēnnathan: to give, used with greatest latitude of application (put, make, etc.)H5414
  4. אֶֽרֶץʾereṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. כְּנָ֔עַןkĕnāʿanKna`an: humiliated; Kenaan, a son a HamH3667
  6. חֶ֖בֶלḥebelchebel: a rope (as twisted), especially a measuring lineH2256
  7. נַֽחֲלַתְכֶֽם׃naḥălatkemnachalah: (properly) something inherited; (abstractly) occupancyH5159
19
  1. בִּהְיֽוֹתְכֶם֙bihyôtĕkemhayah: to exist; to be or becomeH1961
  2. מְתֵ֣יmĕtêmath: (properly) an adult (as of full length); (by implication) a man (only in the plural)H4962
  3. מִסְפָּ֔רmispārmicpar: a number; (definite) arithmetical numberH4557
  4. כִּמְעַ֖טkimʿaṭm`at: a little or few (often adverbial or compar.)H4592
  5. וְגָרִ֥יםwĕgārîmguwr: (properly) to turn aside from the road (for a lodging or any other purpose)H1481
20
  1. וַיִּֽתְהַלְּכוּ֙wayyitĕhallĕkûhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  2. מִגּ֣וֹיmiggôygowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  3. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  4. גּ֔וֹיgôygowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  5. וּמִמַּמְלָכָ֖הûmimmamlākâmamlakah: dominion; (abstractly) the estate (rule)H4467
  6. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  7. עַ֥םʿam`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  8. אַחֵֽר׃ʾaḥēracher: (properly) hinder; (generally) next, other, etcH312
21
  1. לֹֽאlōʾlo': (the simple or absolute negation) not; (by implication) noH3808
  2. הִנִּ֤יחַhinnîaḥyanach: to deposit; (by implication) to allow to stayH3240
  3. לְאִישׁ֙lĕʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  4. לְעָשְׁקָ֔םlĕʿošqām`ashaq: to press upon, i.e. oppress, defraud, violate, overflowH6231
  5. וַיּ֥וֹכַחwayyôkaḥyakach: to be right (i.e. correct); reciprocal, to argueH3198
  6. עֲלֵיהֶ֖םʿălêhem`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  7. מְלָכִֽים׃mĕlākîmmelek: a kingH4428
22
  1. אַֽלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  2. תִּגְּעוּ֙tiggĕʿûnaga`: (properly) to touch, i.e. lay the hand upon (for any purposeH5060
  3. בִּמְשִׁיחָ֔יbimšîḥāymashiyach: anointed; usually a consecrated person (as a king, priest, or saint)H4899
  4. וּבִנְבִיאַ֖יûbinbîʾaynabiy': a prophet; (generally) inspired manH5030
  5. אַלʾalal: (qualified negation) not (used as a deprecative)H408
  6. תָּרֵֽעוּ׃tārēʿûra`a`: (properly) to spoil; (literally) to ruin by breaking to pieces)H7489
23
  1. שִׁ֤ירוּšîrûshiyr: to singH7891
  2. לַֽיהוָה֙layhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. הָאָ֔רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. בַּשְּׂר֥וּbaśśĕrûbasar: (properly) to be fresh; to be full (rosy)H1319
  6. מִיּֽוֹםmiyyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  7. אֶלʾelel: (properly) denoting motion towards, but occasionally used of a quiescent position, i.e. near, with or amongH413
  8. י֖וֹםyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  9. יְשֽׁוּעָתֽוֹ׃yĕšûʿātôyshuw`ah: something saved, i.e. (abstractly) deliveranceH3444
24
  1. סַפְּר֤וּsappĕrûcaphar: (properly) to score with a mark as a tally or recordH5608
  2. בַגּוֹיִם֙baggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  3. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  4. כְּבוֹד֔וֹkĕbôdôkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  5. בְּכָלbĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  6. הָֽעַמִּ֖יםhāʿammîm`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  7. נִפְלְאֹתָֽיו׃niplĕʾōtāywpala': (properly, literally or figuratively) perhaps to separate, i.e. distinguishH6381
25
  1. כִּי֩kiykiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. גָד֨וֹלgādôlgadowl: great (in any sense); (hence) olderH1419
  3. יְהוָ֤הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  4. וּמְהֻלָּל֙ûmĕhullālhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  5. מְאֹ֔דmĕʾōdm`od: (properly) vehemence; (with or without preposition) vehementlyH3966
  6. וְנוֹרָ֥אwĕnôrāʾyare': to fear; morally, to revereH3372
  7. ה֖וּאhûʾhuw': (the third person pronoun singular) he, she, or it (only expressed when emphatic or without a verb)H1931
  8. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  9. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  10. אֱלֹהִֽים׃ʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
26
  1. כִּ֠יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  2. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. אֱלֹהֵ֤יʾĕlōhêelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  4. הָֽעַמִּים֙hāʿammîm`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  5. אֱלִילִ֔יםʾĕlîlîmeliyl: good for nothing, by anal. vain or vanityH457
  6. וַֽיהוָ֖הwayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  7. שָׁמַ֥יִםšāmayimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
  8. עָשָֽׂה׃ʿāśâ`asah: to do or make, in the broadest sense and widest application (as follows)H6213
27
  1. ה֤וֹדhôdhowd: grandeur (i.e. an imposing form and appearance)H1935
  2. וְהָדָר֙wĕhādārhadar: magnificence, i.e. ornament or splendorH1926
  3. לְפָנָ֔יוlĕpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  4. עֹ֥זʿōz`oz: strength in various applications (force, security, majesty, praise)H5797
  5. וְחֶדְוָ֖הwĕḥedwâchedvah: rejoicingH2304
  6. בִּמְקֹמֽוֹ׃bimqōmômaqowm: (properly) a standing, i.e. a spot; but used widely of a locality (general or specific)H4725
28
  1. הָב֤וּhābûyahab: (literally or figuratively) to give; (generally) to putH3051
  2. לַֽיהוָה֙layhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. מִשְׁפְּח֣וֹתmišpĕḥôtmishpachah: a family, i.e. circle of relatives; (figuratively) a class (of persons), a species (of animals) or sort (of...H4940
  4. עַמִּ֔יםʿammîm`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  5. הָב֥וּhābûyahab: (literally or figuratively) to give; (generally) to putH3051
  6. לַֽיהוָ֖הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  7. כָּב֥וֹדkābôdkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  8. וָעֹֽז׃wāʿōz`oz: strength in various applications (force, security, majesty, praise)H5797
29
  1. הָב֥וּhābûyahab: (literally or figuratively) to give; (generally) to putH3051
  2. לַֽיהוָ֖הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. כְּב֣וֹדkĕbôdkabowd: (properly) weight, but only figuratively in a good sense, splendor or copiousnessH3519
  4. שְׁמ֑וֹšĕmôshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  5. שְׂא֤וּśĕʾûnasa': to lift, in a great variety of applications, literal and figurative, absol. and rel. (as follows)H5375
  6. מִנְחָה֙minḥāhminchah: a donation; euphemistically, tributeH4503
  7. וּבֹ֣אוּûbōʾûbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  8. לְפָנָ֔יוlĕpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  9. הִשְׁתַּֽחֲו֥וּhištaḥăwûshachah: to depress, i.e. prostrate (especially reflexive, in homage to royalty or God)H7812
  10. לַֽיהוָ֖הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  11. בְּהַדְרַתbĕhadrathadarah: decorationH1927
  12. קֹֽדֶשׁ׃qōdešqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
30
  1. חִ֤ילוּḥîlûchuwl: (properly) to twist or whirl (in a circular or spiral manner), i.e. (specifically) to dance, to writhe in pain...H2342
  2. מִלְּפָנָיו֙millĕpānāywpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  3. כָּלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  4. הָאָ֔רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. אַףʾapaph: meaning accession (used as an adverb or conjunction)H637
  6. תִּכּ֥וֹןtikkônkuwn: (properly) to be erect (i.e. stand perpendicular)H3559
  7. תֵּבֵ֖לtēbēltebel: the earth (as moist and therefore inhabited)H8398
  8. בַּלbalbal: (properly) a failure; (by implication) nothingH1077
  9. תִּמּֽוֹט׃timmôṭmowt: to waver; (by implication) , to slip, shake, fallH4131
31
  1. יִשְׂמְח֤וּyiśmĕḥûsamach: probably to brighten up, i.e. (figuratively) be (causatively, make) blithe or gleesomeH8055
  2. הַשָּׁמַ֙יִם֙haššāmayimshamayim: the sky (as aloft; the dual perhaps alluding to the visible arch in which the clouds move, as well as to the...H8064
  3. וְתָגֵ֣לwĕtāgēlgiyl: (properly) to spin round (under the influence of any violent emotion), i.e. usually rejoice, or (as cringing) fearH1523
  4. הָאָ֔רֶץhāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
  5. וְיֹֽאמְר֥וּwĕyōʾmĕrûamar: to say (used with great latitude)H559
  6. בַגּוֹיִ֖םbaggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  7. יְהוָ֥הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  8. מָלָֽךְ׃mālākmalak: to reign; (inceptively) to ascend the throneH4427
32
  1. יִרְעַ֤םyirʿamra`am: to tumble, i.e. be violently agitated; specifically, to crash (of thunder)H7481
  2. הַיָּם֙hayyāmyam: a sea (as breaking in noisy surf) or large body of waterH3220
  3. וּמְלוֹא֔וֹûmĕlôʾômlo': fullness (literally or figuratively)H4393
  4. יַֽעֲלֹ֥ץyaʿălōṣ`alats: to jump for joy, i.e. exultH5970
  5. הַשָּׂדֶ֖הhaśśādesadeh: a field (as flat)H7704
  6. וְכָלwĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  7. אֲשֶׁרʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
33
  1. אָ֥זʾāzaz: at that time or place; (as a conjunction) thereforeH227
  2. יְרַנְּנ֖וּyĕrannĕnûranan: (properly) to creak (or emit a stridulous sound), i.e. to shout (usually for joy)H7442
  3. עֲצֵ֣יʿăṣê`ets: a tree (from its firmness); (hence) wood (plural sticks)H6086
  4. הַיָּ֑עַרhayyāʿarya`ar: a copse of bushes; (hence) a forestH3293
  5. מִלִּפְנֵ֣יmillipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  6. יְהוָ֔הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  7. כִּיkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  8. בָ֖אbāʾbow': to go or come (in a wide variety of applications)H935
  9. לִשְׁפּ֥וֹטlišpôṭshaphat: to judge, i.e. pronounce sentence (for or against)H8199
  10. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  11. הָאָֽרֶץ׃hāʾāreṣerets: the earth (at large, or partitively a land)H776
34
  1. הוֹד֤וּhôdûyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  2. לַֽיהוָה֙layhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. כִּ֣יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  4. ט֔וֹבṭôbtowb: good (as an adjective) in the widest senseH2896
  5. כִּ֥יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  6. לְעוֹלָ֖םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  7. חַסְדּֽוֹ׃ḥasdôcheced: kindness; (by implication, towards God) pietyH2617
35
  1. וְאִמְר֕וּwĕʾimrûamar: to say (used with great latitude)H559
  2. הֽוֹשִׁיעֵ֙נוּ֙hôšîʿēnûyasha`: (properly) to be open, wide or free; (by implication) to be safeH3467
  3. אֱלֹהֵ֣יʾĕlōhêelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  4. יִשְׁעֵ֔נוּyišʿēnûyesha`: liberty, deliverance, prosperityH3468
  5. וְקַבְּצֵ֥נוּwĕqabbĕṣēnûqabats: to grasp, i.e. collectH6908
  6. וְהַצִּילֵ֖נוּwĕhaṣṣîlēnûnatsal: to snatch away, whether in a good or a bad senseH5337
  7. מִןminmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  8. הַגּוֹיִ֑םhaggôyimgowy: a foreign nation; (hence) a GentileH1471
  9. לְהֹדוֹת֙lĕhōdôtyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  10. לְשֵׁ֣םlĕšēmshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  11. קָדְשֶׁ֔ךָqodšekāqodesh: a sacred place or thing; (abstract, rarely) sanctityH6944
  12. לְהִשְׁתַּבֵּ֖חַlĕhištabbēaḥshabach: (properly) to address in a loud tone, i.e. (specifically) loudH7623
  13. בִּתְהִלָּתֶֽךָ׃bithillātekāthillah: laudation; (specifically, concretely) a hymnH8416
36
  1. בָּר֤וּךְbārûkbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  2. יְהוָה֙yĕhwāhYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  3. אֱלֹהֵ֣יʾĕlōhêelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  4. יִשְׂרָאֵ֔לyiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
  5. מִןminmin: (properly) a part of; (hence, prepositionally) from or out of (in many senses)H4480
  6. הָֽעוֹלָ֖םhāʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  7. וְעַ֣דwĕʿad`ad: (properly) a (peremptory) terminusH5704
  8. הָֽעֹלָ֑םhāʿōlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  9. וַיֹּֽאמְר֤וּwayyōʾmĕrûamar: to say (used with great latitude)H559
  10. כָלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  11. הָעָם֙hāʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  12. אָמֵ֔ןʾāmēnamen: sure; (abstract) faithfulnessH543
  13. וְהַלֵּ֖לwĕhallēlhalal: to be clear (orig. of sound, but usually of color)H1984
  14. לַֽיהוָֽה׃layhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
37
  1. וַיַּֽעֲזָבwayyaʿăzob`azab: to loosen, i.e. relinquish, permit, etcH5800
  2. שָׁ֗םšāmsham: there (transferring to time) then; often thither, or thenceH8033
  3. לִפְנֵי֙lipnēypaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  4. אֲר֣וֹןʾărônarown: a boxH727
  5. בְּרִיתbĕrîtbriyth: a compact (because made by passing between pieces of flesh)H1285
  6. יְהוָ֔הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  7. לְאָסָ֖ףlĕʾāsāpAcaph: collector; Asaph, the name of three Israelites, and of the family of the firstH623
  8. וּלְאֶחָ֑יוûlĕʾeḥāywach: a brother (used in the widest sense of literal relationship and metaphorical affinity or resemblance (like H0001))H251
  9. לְשָׁרֵ֞תlĕšārētsharath: to attend as a menial or worshipper; (figuratively) to contribute toH8334
  10. לִפְנֵ֧יlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  11. הָֽאָר֛וֹןhāʾārônarown: a boxH727
  12. תָּמִ֖ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  13. לִדְבַרlidbardabar: a word; (by implication) a matter (as spoken of) or thingH1697
  14. י֥וֹםyômyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
  15. בְּיוֹמֽוֹ׃bĕyômôyowm: a day (as the warm hours), whether literal (from sunrise to sunset, or from one sunset to the next), or...H3117
38
  1. וְעֹבֵ֥דwĕʿōbēd
  2. אֱדֹ֛םʾĕdōmworker of Edom; Obed-Edom, the name of five IsraelitesH5654
  3. וַֽאֲחֵיהֶ֖םwaʾăḥêhemach: a brother (used in the widest sense of literal relationship and metaphorical affinity or resemblance (like H0001))H251
  4. שִׁשִּׁ֣יםšiššîmshishshiym: sixtyH8346
  5. וּשְׁמוֹנָ֑הûšĕmônâshmoneh: a cardinal number, eight (as if a surplus above the "perfect" seven)H8083
  6. וְעֹבֵ֨דwĕʿōbēd
  7. אֱדֹ֧םʾĕdōmworker of Edom; Obed-Edom, the name of five IsraelitesH5654
  8. בֶּןbenben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  9. יְדִית֛וּןyĕdîtûnYduwthuwn: laudatory; Jeduthun, an IsraeliteH3038
  10. וְחֹסָ֖הwĕḥōsâChocah: hopeful; Chosah, an IsraeliteH2621
  11. לְשֹֽׁעֲרִֽים׃lĕšōʿărîmshow`er: a janitorH7778
39
  1. וְאֵ֣ת׀wĕʾēteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  2. צָד֣וֹקṣādôqTsadowq: just; Tsadok, the name of eight or nine IsraelitesH6659
  3. הַכֹּהֵ֗ןhakkōhēnkohen: (literally) one officiating, a priest; (also, by courtesy) an acting priest (although a layman)H3548
  4. וְאֶחָיו֙wĕʾeḥāywach: a brother (used in the widest sense of literal relationship and metaphorical affinity or resemblance (like H0001))H251
  5. הַכֹּ֣הֲנִ֔יםhakkōhănîmkohen: (literally) one officiating, a priest; (also, by courtesy) an acting priest (although a layman)H3548
  6. לִפְנֵ֖יlipnêpaniym: the face (as the part that turns); (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc.H6440
  7. מִשְׁכַּ֣ןmiškanmishkan: a residence (including a shepherd's hut, the lair of animals, figuratively, the graveH4908
  8. יְהוָ֑הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  9. בַּבָּמָ֖הbabbāmâbamah: an elevationH1116
  10. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  11. בְּגִבְעֽוֹן׃bĕgibʿônGib`own: hilly; Gibon, a place in IsraelH1391
40
  1. לְֽהַעֲלוֹת֩lĕhaʿălôt`alah: to ascend, intransitively (be high) or actively (mount)H5927
  2. עֹל֨וֹתʿōlôt`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  3. לַֽיהוָ֜הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  4. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  5. מִזְבַּ֧חmizbaḥmizbeach: an altarH4196
  6. הָֽעֹלָ֛הhāʿōlâ`olah: a step or (collectively, stairs, as ascending)H5930
  7. תָּמִ֖ידtāmîdtamiyd: (properly) continuance (as indefinite extension)H8548
  8. לַבֹּ֣קֶרlabbōqerboqer: (properly) dawn (as the break of day); (generally) morningH1242
  9. וְלָעָ֑רֶבwĕlāʿāreb`ereb: duskH6153
  10. וּלְכָלûlĕkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  11. הַכָּתוּב֙hakkātûbkathab: to engrave, carve; (by implication) to write (describe, inscribe, prescribe, subscribe)H3789
  12. בְּתוֹרַ֣תbĕtôrattowrah: a precept or statute, especially the Decalogue or PentateuchH8451
  13. יְהוָ֔הyĕhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  14. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  15. צִוָּ֖הṣiwwâtsavah: (intensively) to constitute, enjoinH6680
  16. עַלʿal`al: above, over, upon, or against (yet always in this last relation with a downward aspect) in a great variety of...H5921
  17. יִשְׂרָאֵֽל׃yiśrāʾēlYisra'el: he will rule as God; Jisrael, a symbolical name of JacobH3478
41
  1. וְעִמָּהֶם֙wĕʿimmāhem`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  2. הֵימָ֣ןhêmānHeyman: faithful; Heman, the name of at least two IsraelitesH1968
  3. וִֽידוּת֔וּןwîdûtûnYduwthuwn: laudatory; Jeduthun, an IsraeliteH3038
  4. וּשְׁאָר֙ûšĕʾārsh'ar: a remainderH7605
  5. הַבְּרוּרִ֔יםhabbĕrûrîmbarar: to clarify (i.e. brighten), examine, selectH1305
  6. אֲשֶׁ֥רʾăšeraher: who, which, what, that; (as adverb) when, where, howH834
  7. נִקְּב֖וּniqqĕbûnaqab: to puncture, literally (to perforate, with more or less violence) or figuratively (to specify, designate, libel)H5344
  8. בְּשֵׁמ֑וֹתbĕšēmôtshem: an appellation, as a mark or memorial of individualityH8034
  9. לְהֹדוֹת֙lĕhōdôtyadah: (literally) to use (i.e. hold out) the handH3034
  10. לַֽיהוָ֔הlayhwâYhovah: (the) self-Existent or Eternal; Jehovah, Jewish national name of GodH3068
  11. כִּ֥יkîkiy: (by implication) very widely used as a relative conjunction or adverb (as below)H3588
  12. לְעוֹלָ֖םlĕʿôlām`owlam: (properly) concealed, i.e. the vanishing pointH5769
  13. חַסְדּֽוֹ׃ḥasdôcheced: kindness; (by implication, towards God) pietyH2617
42
  1. וְעִמָּהֶם֩wĕʿimmāhem`im: adverb or preposition, with (i.e. in conjunction with), in varied applicationsH5973
  2. הֵימָ֨ןhêmānHeyman: faithful; Heman, the name of at least two IsraelitesH1968
  3. וִֽידוּת֜וּןwîdûtûnYduwthuwn: laudatory; Jeduthun, an IsraeliteH3038
  4. חֲצֹֽצְר֤וֹתḥăṣōṣĕrôtchatsotsrah: a trumpet (from its sundered or quavering note)H2689
  5. וּמְצִלְתַּ֙יִם֙ûmĕṣiltayimmtseleth: (only dual) double tinklers, i.e. cymbalsH4700
  6. לְמַשְׁמִיעִ֔יםlĕmašmîʿîmshama`: to hear intelligently (often with implication of attention, obedience, etcH8085
  7. וּכְלֵ֖יûkĕlêkliy: something prepared, i.e. any apparatus (as an implement, utensil, dress, vessel or weapon)H3627
  8. שִׁ֣ירšîrshiyr: a song; abstractly, singingH7892
  9. הָֽאֱלֹהִ֑יםhāʾĕlōhîmelohiym: gods in the ordinary sense; but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the...H430
  10. וּבְנֵ֥יûbĕnêben: a son (as a builder of the family name), in the widest sense (of literal and figurative relationship, including...H1121
  11. יְדוּת֖וּןyĕdûtûnYduwthuwn: laudatory; Jeduthun, an IsraeliteH3038
  12. לַשָּֽׁעַר׃laššāʿarsha`ar: an opening, i.e. door or gateH8179
43
  1. וַיֵּֽלְכ֥וּwayyēlĕkûhalak: a primitive root; to walk (in a great variety of applications, literally and figuratively)H1980
  2. כָלkālkol: (properly) the whole; (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense)H3605
  3. הָעָ֖םhāʿām`am: a people (as a congregated unit); specifically, a tribe (as those of Israel)H5971
  4. אִ֣ישׁʾîšiysh: a man as an individual or a male personH376
  5. לְבֵית֑וֹlĕbêtôbayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004
  6. וַיִּסֹּ֥בwayyissōbcabab: to revolve, surround, or border; used in various applications, literally and figuratively (as follows)H5437
  7. דָּוִ֖ידdāwîdDavid: loving; David, the youngest son of JesseH1732
  8. לְבָרֵ֥ךְlĕbārēkbarak: to kneel; (implication, man toward God) to bless God as an act of adorationH1288
  9. אֶתʾeteth: (properly) self; (generally) used to point out the object of a verb (or preposition) more definitelyH853
  10. בֵּיתֽוֹ׃bêtôbayith: a house (in the greatest variation of applications, especially family, etc.)H1004

View the full Hebrew interlinear for 1 Chronicles 16 →

Strong's words in 1 Chronicles 16 (6)
Strong's H3068 — יְהוָֽה׃ (yĕhwâ)
Yhovah (yeh-ho-vaw') n/p. 1. (the) self-Existent or Eternal 2. Jehovah, Jewish national name of God [from H1961] KJV: Jehovah, the Lord. Root(s): H1961 Compare: H3050, H3069. Appears 25 times in 1 Chronicles 16.
Strong's H3605 — לְכָל (lĕkāl)
kol (kole) (or (Jer. 33) n-m. 1. (properly) the whole 2. (hence) all, any or every (in the singular only, but often in a plural sense) [from H3634] KJV: (in) all (manner, (ye)), altogether, any (manner), enough, every (one, place, thing), howsoever, as many as, (no-)thing, ought, whatsoever, (the) whole, whoso(-ever). Root(s): H3634. Appears 12 times in 1 Chronicles 16.
Strong's H6440 — לִפְנֵ֥י (lipnê)
paniym (paw-neem') (plural (but always as singular) of an unused noun (paneh {paw-neh'}) n-m. 1. the face (as the part that turns) 2. (with prepositional prefix, as a preposition) before, etc. {used in a great variety of applications, literally and figuratively} [from H6437] KJV: + accept, a-(be- )fore(-time), against, anger, X as (long as), at, + battle, + because (of), + beseech, countenance, edge, + employ, endure, + enquire, face, favour, fear of, for, forefront(-part), form(-er time, -ward), from, front, heaviness, X him(-self), + honourable, + impudent, + in, it, look(-eth) (- s), X me, + meet, X more than, mouth, of, off, (of) old (time), X on, open, + out of, over against, the partial, person, + please, presence, propect, was purposed, by reason of, + regard, right forth, + serve, X shewbread, sight, state, straight, + street, X thee, X them(-selves), through (+ - out), till, time(-s) past, (un-)to(-ward), + upon, upside (+ down), with(- in, + -stand), X ye, X you. Root(s): H6437. Appears 11 times in 1 Chronicles 16.
Strong's H430 — הָֽאֱלֹהִ֔ים (hāʾĕlōhîm)
elohiym (el-o-heem') n-m. 1. gods in the ordinary sense 2. but specifically used (in the plural thus, especially with the article) of the supreme God 3. occasionally applied by way of deference to magistrates 4. and sometimes as a superlative [plural of H433] KJV: angels, X exceeding, God (gods)(-dess, -ly), X (very) great, judges, X mighty. Root(s): H433. Appears 10 times in 1 Chronicles 16.
Strong's H5971 — הָעָ֖ם (hāʿām)
`am (am) n-m. 1. a people (as a congregated unit) 2. specifically, a tribe (as those of Israel) 3. hence (collectively) troops or attendants 4. (figuratively) a flock [from H6004] KJV: folk, men, nation, people. Root(s): H6004. Appears 8 times in 1 Chronicles 16.
Strong's H3034 — וּלְהוֹד֣וֹת (ûlĕhôdôt)
yadah (yaw-daw') v. 1. (literally) to use (i.e. hold out) the hand 2. (physically) to throw (a stone, an arrow) at or away 3. (especially) to revere or worship (with extended hands) 4. (intensively) to bemoan (by wringing the hands) [a primitive root; used only as denominative from H3027] KJV: cast (out), (make) confess(-ion), praise, shoot, (give) thank(-ful, -s, -sgiving). Root(s): H3027. Appears 6 times in 1 Chronicles 16.

Browse the full Strong's concordance →

0:00 0:00

Video Bible

Loading video...

Scripture video provided by Faith Comes By Hearing

🌐 Select Language

2883 Bibles in 2502 Languages

Select Translation

Congratulations!

You completed the book of Matthew!

Points Earned +280
28 Chapters
15% NT Progress